File size: 34,102 Bytes
9ca02d1
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48
49
50
51
52
53
54
55
56
57
58
59
60
61
62
63
64
65
66
67
68
69
70
71
72
73
74
75
76
77
78
79
80
81
82
83
84
85
86
87
88
89
90
91
92
93
94
95
96
97
98
99
100
101
102
103
104
105
106
107
108
109
110
111
112
113
114
115
116
117
118
119
120
121
122
123
124
125
126
127
128
129
130
131
132
133
134
135
136
137
138
139
140
141
142
143
144
145
146
147
148
149
150
151
152
153
154
155
156
157
158
159
160
161
162
163
164
165
166
167
168
169
170
171
172
173
174
175
176
177
178
179
180
181
182
183
184
185
186
187
188
189
190
191
192
193
194
195
196
197
198
199
200
201
202
203
204
205
206
207
208
209
210
211
212
213
214
215
216
217
218
219
220
221
222
223
224
225
226
227
228
229
230
231
232
233
234
235
236
237
238
239
240
241
242
243
244
245
246
247
248
249
250
251
252
253
254
255
256
257
258
259
260
261
262
263
264
265
266
267
268
269
270
271
272
273
274
275
276
277
278
279
280
281
282
283
284
285
286
287
288
289
290
291
292
293
294
295
296
297
298
299
300
301
302
303
304
305
306
307
308
309
310
311
312
313
314
315
316
317
318
319
320
321
322
323
324
325
326
327
328
329
330
331
332
333
334
335
336
337
338
339
340
341
342
343
344
345
346
347
348
349
350
351
352
353
354
355
356
357
358
359
360
361
362
363
364
365
366
367
368
369
370
371
372
373
374
375
376
377
378
379
380
381
382
383
384
385
386
387
388
389
390
391
392
393
394
395
396
397
398
399
400
401
402
403
404
405
406
407
408
409
410
411
412
413
414
415
416
417
418
419
420
421
422
423
424
425
426
427
428
429
430
431
432
433
434
435
436
437
438
439
440
441
442
443
444
445
446
447
448
449
450
451
452
453
454
455
456
457
458
459
460
461
462
463
464
465
466
467
468
469
470
471
472
473
474
475
476
477
478
479
480
481
482
483
484
485
486
487
488
489
490
491
492
493
494
495
496
497
498
499
500
501
502
503
504
505
506
507
508
509
510
511
512
513
514
515
516
517
518
519
520
521
522
523
524
525
526
527
528
529
530
531
532
533
534
535
536
537
538
539
540
541
542
543
544
545
546
547
548
549
550
551
552
553
554
555
556
557
558
559
560
561
562
563
564
565
566
567
568
569
570
571
572
573
574
575
576
577
578
579
580
581
582
583
584
585
586
587
588
589
590
591
592
593
594
595
596
597
598
599
600
601
602
603
604
605
606
607
608
609
610
611
612
613
614
615
616
617
618
619
620
621
622
623
624
625
626
627
628
629
630
631
632
633
634
635
636
637
638
639
640
641
642
643
644
645
646
647
648
649
650
651
652
653
654
655
656
657
658
659
660
661
662
663
664
10494#0	ọdun wo ni wọn pa funsho william?
10773#0	osu meloo ni oyun ma n lo nínú ikun obinrin ?
10981#0	Ki ni oruko ibilẹ ilu Port Harcourt?
11043#0	ipinlẹ wo ni gbenga Daniel ti jẹ gomina?
11172#0	Ki ni olu-ilu orile-ede Burkina-Faso?
11296#0	Ki ni oluilu Bangladesh?
11435#0	Odun wo ni Nwankwo Kanu da pọ mọ Arsenal?
11775#0	Ki ni orukọ iyawo Babatunde Fasola?
11810#0	Ki ni oluilu orile ede Bulgaria?
12525#0	Ki ni oluilu orile ede Hungari?
12957#0	bawo ni sau Paulo ṣe jinna tó sí Rio De Janeiro?
12971#0	Ki ni orukọ ọmọ anọbi Idris ninu Kurani?
13297#0	ọmọ orílé ede wo ni Bill Gates ?
13307#0	orile-ede meloo ni o wa ni Europe?
13310#0	kini oluilu orile-ede Paraguai?
13342#0	Kí ni oluilu orile-ede El Salvador?
13361#0	Ta ni o da ile iṣẹ Innoson silẹ?
13541#0	Awon odun wo ni won ma n se ni orile-ede Bhutan?
13590#0	Orisi kemika wo lo wa?
13690#0	Ki no won ma n fi kemika iodine ṣe?
13760#0	iru awon eja wo ni eeyan le ri ninu odo?
13883#0	Orile ede wo ni Cape Town wa ?
13915#0	kí ni oluilu ipinle Akwa-Ibom?
14163#0	eya mélòó lo wa ni orile-ede Naijiria?
14498#0	Iṣẹ wo ni Sunday Igboho n ṣe?
14515#0	Ede meloo ni won so ni orile-ede Benin?
14681#0	Ibaṣepọ wo lo wa laarin awọn Giriki aye ijọun ati awọn ara Egypt?
14745#0	Orile-ede wo lo ni NASA?
14767#0	ọdún wo ni wọn dá NASA silẹ?
14783#0	Odun wo ni wọn pari ogun agbaye ikeji?
14787#0	Odo wo lo gun ju ni orile-ede Liberia?
14810#0	ọdún wo ni ọkọ ofurufu kọkọ tẹ'do sí Naijiria?
14826#0	ogagun wo lo ṣe aṣáájú àwọn ologun Biafra ni odun 1967?
14874#0	Orile ede wo ni ilu Boston wa?
14970#0	awọn nkan wo lo lè fa ijamba ọkọ ofurufu?
15062#0	Ki ni oluilu ipinle akwa ibom?
15084#0	Ki ni oluilu orile ede Tonga?
15086#0	Orile ede meloo lo wa ni NATO?
15099#0	Orile ede wo ni ilu Alexandria wa?
15101#0	Ki lo pa Alan Turing?
15121#0	Iwe wo ni Immanuel Kant kọ?
15197#0	Iwe wo ni Ibn Battuta kọkọ kọ?
15241#0	Onimo mathematiki wo lo gbe Algebra jade?
15252#0	awọn ẹbun wo ni Roald Engelbregt gba ?
15256#0	Ibasepo wo lo wa laarin ede  Latini ati ede geesi?
15265#0	Ta ni oba orile ede Bahrain?
15309#0	ara ìlú wo ni mama to bi Muritala muhammed?
15317#0	ki ni iye eeyan ti o wa ni abule Aliyu Amba ni Ethiopia?
15325#0	ẹgbẹ agbaboolu wo ni Kelechi Iheanacho wa pẹlu?
15335#0	Orile ede wo ni wọn bí Kamaru Usman sí?
15349#0	iru sistemu ìjọba wo ni wọn lo ni fransi?
15367#0	ẹgbẹ olóṣèlú wo ni David Mark wa pẹlu?
15374#0	Egbe oselu wo ni Nicolas Sarkozy wa  pẹlu?
15444#0	mosalasi wo lo tobi  julo ni orile-ede Algeria?
15498#0	Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Albania?
15511#0	Omo orile ede wo ni Kevin Durant?
15517#0	ọdún wo ni Hubert Ogunde da ilé iṣẹ tíátà rẹ silẹ?
15596#0	Omo orile ede wo ni Cheikh Diop?
15629#0	ọdun wo ni wọn kọkọ ṣe komputa?
15734#0	ilé iṣẹ radiio wo ni Tolu Oniru n ba ṣiṣẹ?
15777#0	Ṣe orile-ede Bhutan wa ni Asia?
15783#0	Ṣe orukọ Potugiisi ni Silva?
15787#0	Ki ni oluilu Burkina Faso?
15805#0	ọdun wo ni orile ede Kongo gba ominira?
15807#0	ipo wo ni Adolphe Muzito je labe ijoba Joseph Kabila?
15808#0	Ilu wo ni won bi Rafael Nadal si?
15809#0	ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede kroatia?
15810#0	ile iṣẹ oniroyin wo ni Toke Makinwa wa pẹlu?
15819#0	Awọn orile-ede wo lo sunmo Djibouti?
15822#0	Awọn Orile-ede wo lo wa ni Soviet union?
15833#0	Kini iyatọ laarin awọn ara Ethiopia ati Eritrea?
15847#0	Osu wo ni odun keresimesi bọ si?
15868#0	Ilu wo ni agabọọlu Pepe n gba bọọlu fun?
15882#0	obinrin alawọ dudu wo lo kọkọ yege idije Miss World?
15884#0	ọdun wo ni agbani darego yege idije Miss World?
15892#0	Iṣẹ wo ni ọkọ Omotola Jalade n ṣe?
15898#0	Ki ni wọn n pe ni Eurasia?
15909#0	Ede wo ni won sọ ni orile-ede Ireland?
15919#0	Eeyan meloo lo n ṣe ẹsin kristeni ni orile-ede Jordan?
15922#0	Kí ni ìtúmò Karim ni ede lárúbáwá?
15954#0	Awọn ede wo ni wọn sọ ni Kuwait yatọ si Larubawa?
15970#0	Ara ilu wo ni Hans-Adam?
15974#0	ọdun wo ni a ma n ṣe ni oṣu December?
16001#0	kí ni olu-ilu orile-ede norway?
16005#0	Orile-ede wo lo fẹ ju lo ni Europe?
16007#0	Ipinle wo ni Ilu Gbongan wa?
16009#0	Ta ni Aarẹ ikẹta orile-ede United States of America?
16019#0	Kilọọbu wo ni agbabọọlu Robert Lwandowski n gba bọọlu fun?
16238#0	orile ede wo ni Ilu Madrid wa?
16281#0	Ta ni iyawo Bill Clinton?
16288#0	Awọn orile-ede wo ni wọn ti n sọ ede faranse ni Afirika?
16297#0	Èdè wo ni àwọn ará orile ede Nepal n sọ?
16299#0	Ọmọ orílé èdè wo ni akọrin Peter Tosh?
16312#0	Ki ni orukọ iyawo Muhammad Ali?
16365#0	Ẹgbẹ wo ni agbaboolu ti a mọ sí Roberto Carlos bá gbá bọọlu gbẹhin kí ó tó fẹ̀hinti?
16373#0	Omo orile-ede wo ni onimo mathematiki Carl Friedrich?
16376#0	kí ni iye eniyan to wa ni orile ede switsalandi?
16382#0	Odun wo ni won bere ogun orile-ede Siria?
16391#0	ta ni ààrẹ akọkọ orílé èdè Togo?
16407#0	Odun wo ni Sultan Muhammadu Maccido ku?
16426#0	ara ìlú wo ni oludasile Google ti a mọ sí Sergei brin?
16427#0	Odun wo ni won bi onisowo Efunroye Tinubu?
16479#0	Ta ni ààrẹ orile-ede Ethiopia?
16656#0	awon apa ijoba meloo lo wa?
16664#0	Ilu wo lo tobi julo ni ipinle Anambra?
16727#0	Odun wo ni Samuel Peter ba Vladmir Klitschko ja?
16770#0	Ki ni oruko bibi  alawada Frank Donga?
16781#0	Ki ni oluilu ipinle Ondo?
16798#0	Odun wo ni Ekiti ati Ondo ya sọtọ?
16801#0	Awon ẹya wo lo wa ni ilu Ẹlẹmẹ?
16861#0	ilu wo lo tobi julọ ni ipinlẹ rivers?
16956#0	Tani Philip Efiong ja fun ni Ogun Biafra?
17021#0	Omo ilu wo ni Ngozi Nwosu?
17024#0	Ipo oselu wo ni Lamidi Adesina di mu gege bi oloselu ?
17206#0	Omo ipinle wo ni Lateef Adedimeji?
17214#0	Gomina meloo lo wa ni orile-ede Naijiria?
17238#0	Bawo ni oju ojo se ma n ri ni ipinle Enugu?
17258#0	Tani gomina ipinle Ekiti?
17287#0	ṣe wọn ni epo ni ipinlẹ rivers?
17323#0	ilu wo lo tóbi jù lọ ní ipinlẹ ebonyi?
17325#0	Ki ni kapitaali ipinle Ebonyi?
17372#0	kí ni orúkọ ọba sultan ilu sókótó?
17476#0	Ọdun wo ni awọn ologun gba ijọba ni Naijiria?
17478#0	Ṣe papa ọkọ ofurufu wa ni Ipinle Enugu?
17485#0	Se Ile Ibo ni ipinle Enugu wa?
17518#0	Ede wo ni awon ara Imo n sọ?
17534#0	Lábé ìjọba aare Naijiria wo ni àwọn òṣìṣẹ́ ti ṣe àtakò occupy Nigeria?
17539#0	kí ni olú ìlú ipinlẹ Rivers ?
17558#0	Awon ile iwe wo lo wa ni agbegbe orumba?
17559#0	Ki ni olu-ilu ipinle Anambra?
17589#0	Ta ni ọba wọn ni Ilẹ Sokoto?
17600#0	Ta ni Sultan Sokoto ni odun 2003?
17612#0	Ọdun melo ni Shehu Shagari lo lori Aleefa?
17644#0	Ta ni gomina ipinle Sokoto?
17658#0	Ki ni itumo Enugu ni ede Igbo?
17695#0	Ta lo kọkọ jẹ Sultan ipinlẹ Sokoto?
17758#0	Awon esin wo lo gbajumọ ni orile-ede jemani?
17820#0	Ipo wo ni agbabọọlu Thomas Muller n gba fun Bayern Munich?
18094#0	Ta ni obinrin to kọkọ gba ebun nobel?
18226#0	Ilu wo lo tobi ju lọ ni ipinlẹ Ogun?
18307#0	Ipinle wo ni Yunifasiti Olabisi Onabanjo wa?
18308#0	Odun wo ni Oladipo Diya je gomina ipinle Ogun l'asiko ijoba ologun?
18321#0	ati orile-ede wo ni pasta ti wa ?
18356#0	Awon eranko wo lo wa ni Australia?
18357#0	Awon orile-ede wo ni o wa ni Melanesia?
18397#0	Odun wo ni Fidel Castro kuro lori aleefa?
18519#0	Orile ede wo ni odo Amazon wa?
18548#0	Orile-ede wo ni ilu Houston wa?
18560#0	Ta ni Aare orile-ede Amẹrika?
18574#0	orile ede wo ni awọn elesin onigbagbo pọ si ju lọ?
18581#0	Orile ede wo ni Ras Al Khaimah wa?
18607#0	Ki ni olu ilu ipinle cross river?
18640#0	Ta ni ààrẹ Orile ede Tajikistan?
18642#0	kí ni oluilu orile ede Peru?
18665#0	Iru owo wo ni won na ni orile-ede Morocco?
18667#0	Odun wo ni orile ede Mozambique gba ominira?
18668#0	ọdun wo ni  orile-ede Mozambique gba ominira?
18705#0	awon ipinle wo ni won yọ jáde lati ipinle gongola?
18809#0	Iru ounjẹ wo ni wọn ma n jẹ ni ipinle Akwa Ibom?
18839#0	Awon eya meloo lo wa ni orile-ede Nigeria?
18859#0	Ilu wo ni won bi Serena Williams si?
18964#0	ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Ibrahim Shekarau wa pẹlu?
19044#0	Ọdun wo ni wọn kọkọ ṣe iwari epo ni ipinlẹ Bayelsa?
19071#0	Ki ni oluilu ipinle kebbi?
19115#0	Ki ni oluilu ipinlẹ Niger?
19133#0	Odun wo ni Musilliu Haruna Ishola kọ soyoyo?
19232#0	Iyawo meloo ni Solomon fẹ ninu bibeli?
19245#0	Odun wo ni Aminu Tambuwal di gomina Sokoto?
19270#0	Ibaṣepọ wo lo wa laarin awọn Taliban ati Pakistan?
19408#0	Lati igba wo ni won ti n jagun ni orile-ede South Sudan?
19535#0	Ki ni oruko aare orile-ede Italy?
19661#0	Omo odun meloo ni Mike Tyson nigba to kọkọ gba oye heavyweight?
19971#0	Orile-ede wo ni ilu Dar es Salaam wa?
19976#0	Omo ilu wo ni Hassan Minhaj?
19977#0	Ise wo ni Benjamin Franklin ṣe?
20007#0	Ki ni awọn kan ti eeyan le ṣe ni Zanzibar fun isinmi?
20022#0	ede meloo ni won so ni orile-ede tanzania?
20041#0	Awon orile ede wo lo yika Tanzania?
20221#0	orile-ede wo ni a mo gẹgẹ bii Giant of Africa?
20240#0	Egbe agbaboolu wo ni agbaboolu Fernando Torres koko gba boolu fun?
20252#0	Kí ni iye èèyàn dúdú ti ó wà ní orílé èdè Brazil?
20255#0	nọmba wo ni a le pe ti a ba wa ninu ìṣòro?
20338#0	Odun wo ni won bi onimo sayensi Thomas Edison?
20440#0	Se Tibet sunmo orile-ede China?
20453#0	Ki ni asia orile-ede Morocco?
20467#0	Kí ni àwọ àsìá Orile ede Pakistan ?
20523#0	Ede meloo ni wọn so ni orile-ede Pakistan
20573#0	Kí ni orúkọ ilé ìjọsìn David Oyedepo?
20581#0	Awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni ọdun 1920?
20647#0	Ibaṣepọ wo lo wa laarin Michael Jackson ati Janet Jackson ?
20685#0	ile iwe eko giga wo ni Donald Trump ti jade?
20692#0	Akowe wo lo kọ iwe Arrow of God?
20772#0	Odun wo ni Ogun Agbekọya bẹrẹ?
20782#0	Kí ni oluilu ipinle Jigawa?
20982#0	ìyàwó mélòó ni osama bin Laden fẹ́?
21005#0	ọdún wo ni orile-ede Senegal gba ominira?
21115#0	Kí ni oluilu orile-ede Macedonia?
21197#0	Ki ni oluilu orile ede Albania?
21425#0	èdè wo ni àwọn ará Papua n sọ?
21498#0	Erekusu wo lo tobi ju lọ ni agbaye?
21520#0	Nibo ni ipinlẹ Enugu ni awọn oyinbo ti kọkọ ri eedu?
21578#0	Olukowe wo lo kọ iwe Jagua Nana?
21580#0	Ọdún wo ni ẹlẹsẹ Samuel Peter ba Klitschko ja?
21582#0	Ọdún mélòó ni Ike Ibeabuchi lo lẹ́wọ̀n?
21583#0	Ilu wo ni won bi Jaja Wachuku si?
21666#0	Ọmọ ipinle wo ni Uche Jombo?
21904#0	Odun wo ni orile ede Colombia gba ominira?
21915#0	Odun wo ni Ronald Reagan jẹ gomina California?
22000#0	Eya meloo lo wa ni orile-ede Uganda?
22034#0	Yunifasiti wo ni Bill Gates ti kàwé ?
22043#0	Ki ni Iṣẹ igbakeji aarẹ?
22066#0	kí ni orúkọ ọkọ Maria sharapova?
22133#0	Esin wo lo gbajumo ju lo ni orile-ede Ireland?
22144#0	Ki ni oluilu orile ede Uganda?
22218#0	Awọn orile-ede wo lo sunmọ Italy?
2230#0	Odun wo ni akọwe Adebayo Faleti bere si sise pelu WNTV?
22470#0	Awon orisi jeometri wo lo wa?
22498#0	Ta ni olori ẹgbẹ al-kaida?
22501#0	Orile ede wo ni ilu Boston wa?
22521#0	owo korensi wo wọn n ná ní orílé èdè Pakistan?
22522#0	Awon ipinle wo lo tobi julo ni orile-ede Amerika?
22525#0	Odun wo ni won bi oṣere Samuel Jackson?
22532#0	Oke wo lo ga ju ni orile-ede Australia?
22553#0	Ta ni o n je Edward Blyden?
22562#0	Se orile-ede Griisi dara?
22595#0	Ilu wo ni George Washington ṣe Aarẹ fun?
22654#0	Olorin wo lo ni okiki ju ni orile-ede Griisi?
22677#0	Orile ede wo ni ilu Athens wa?
22802#0	Ta ni o gba ẹbun Nobel fun litireṣọ ti ọdun 2016?
22860#0	esin wo ni John Maxwell n ṣe?
2291#0	ta ni Onkowe to ko iwe "The art of war'?
22917#0	Ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Jemani?
22955#0	Aarẹ wo ni Afrika lo fi'ra ẹ jẹ Field Marshall
23142#0	Ki ni olu-ilu orile-ede Argentina?
23186#0	Orile ede wo ni agbaboolu Roberto Carlos gba bóòlù fún?
23245#0	Awon eya wo lo tobi ju lọ ni orile-ede sierra leone?
23551#0	ọdún wo ni Carl Pauling gba ẹbun Nobel?
23562#0	Omo orile ede wo ni Karl Marx?
23567#0	elo ni wọn san fún àwọn tí wọn bá gba ẹbun Nobel ?
23599#0	Bawo ni orile-ede Kanada ṣe tobi to?
23647#0	Kí ni oluilu orile-ede Switzerland?
23706#0	Ilu wo ni won bi Maurice Bishop si?
23712#0	ilu wo ni won bi Joseph Stalin si?
23732#0	Ara ilu wo ni ẹlẹṣe felix trinidad?
23845#0	Ta ni eni to kọkọ lọ si space?
24197#0	Ki ni orukọ bibi Akọrin Afrika Bambaata?
24311#0	èdè wo ni wọn sọ ni orile-ede thailand?
24335#0	ta ni Alakoso ilu dubai ?
24910#0	Awọn ọunje wo lo da fun ilera ati alaafia?
25182#0	Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré Taiwo Hassan ?
25231#0	Awọn òpìtàn wo lo kọ nípa ìtàn Nàìjíríà?
25394#0	Awọn ẹya  meloo lo wa ni orile-ede kongo?
2567#0	Ede wo ni won so ni orile-ede Afghanistan?
25674#0	ọdún wo ni asiwaju Bola Tinubu kọkọ jẹ gomina ipinle Eko?
2571#0	elo ni wọn ta oruka ti ìgbéyàwó?
25763#0	ọdún wo ni Keshi di mọnija ẹgbẹ agbaboolu Naijiria?
25952#0	orile-ede wo ni agbaboolu Pele gba bọọlu fún?
25953#0	awon ere idaraya wo lo gbajumo ni orile-ede Naijiria?
2598#0	ṣe ede larubawa ni wọn n sọ ni orile-ede Algeria?
26004#0	Odun wo ni Augusto Pinochet fi aye silẹ?
26090#0	Aare Amerika wo lo da eru kiko duro?
26145#0	Ẹgbẹ olóṣèlú wo lo tóbi jù lọ ní orile ede Kroatíà?
26186#0	awọn orile ede wo ni àwọn komunisti pọ sí jù?
26190#0	Ara Ilu wo ni Rosa Luuxemburg?
26237#0	ọdún wo ni orile-ede Nàìjíríà di republiki?
26342#0	ki ni itumo keynesian economics?
26401#0	Ọdún wo ni Joseph Stalin fi ayé silẹ?
26468#0	Ilu wo ni won bi Alfred Hitchrock si?
26876#0	kí ni ìjọba Buhari ti ṣe fún ìdàgbàsókè orile-ede Naijiria?
27059#0	Ilu wo ni wọn bi Wilson Oruma si?
27063#0	Fiimu wo ni Chadwick Boseman kọ́kọ́ ṣe?
27067#0	Iwadi wo ni Sir George Thomson gbe jade?
2709#0	Odun wo ni DO Fagunwa kọ iwe Ogboju Ode?
27113#0	ibaṣepọ wo lo wa laarin Tinubu ati Fashola?
27120#0	ṣe lootọ ni wipe omi agbara lo gbe Metusela lọ?
27373#0	Ilu wo ni won bi Adam Smith si?
2741#0	Awọn onisayensi wo ni wọn wa lati orile-ede Armenia?
2749#0	Ki ni oluilu Andorra?
27746#0	Ipinle wo ni Phillip Edward Island wa ni Canada ?
27753#0	Odun wo ni Mohammad Abdus Salam gba  ẹbun nobel?
27782#0	Ki ni oruko eni to kọkọ gba ebun nobel fun kemistri?
27802#0	kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti jack Dorsey da silẹ
27804#0	Ki ni oruko bibi olorin Roy Chicago?
27815#0	Ara ilu wo ni ẹlẹṣẹ Vitaly Klitschko?
28166#0	egbe oṣelu wo ni Barack Obama wa pẹlu?
28209#0	Ara ilu wo ni Ralph Lauren?
28404#0	ede wo ni won so ni orile-ede virgin islands
2853#0	Nibo ni Afirika ni Madagascar wa?
28626#0	Oṣu wo ni ọdun Easter bọ si?
28630#0	Ojo melo lo wa ninu oṣu Februrari?
28770#0	Ki ni anfani ogẹdẹ jijẹ?
2901#0	Ta ni eniyan akọkọ ninu bibeli?
29099#0	Awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni Ọdún 1975?
2925#0	awọn èdè wo ló ṣòro láti kọ́ jù?
29322#0	Awon iwe wo ni Henry James ko?
29343#0	Ise wo ni Ludwig Van Beethoven ṣe?
29350#0	Iwadi wo ni otto warburg ṣe to fi gba ebun nobel?
29601#0	Onimọ sayensi wo lo gbe alaye evolution jade?
29796#0	ọdun wo ni Bill Gates da ile-iṣe Microsoft silẹ?
2988#0	Orile ede wo ni won ti n so ede Bijago?
30023#0	Ile-ise wo ni Ezra Olubi da sile?
30046#0	ki ni iye eeyan alawodudu to wa ni orile-ede Argentina?
30054#0	Esin wo ni awọn Tuareg n ṣe?
30081#0	Olorin wo lo kọ orin "African Queen"?
30203#0	Ta ni o gba Ebun Nobel Fisiiksi odun 1999?
30205#0	Awon awari ati iwadi wo ni onimosayensi Albert Einstein gbe jade?
30208#0	ọdún wo ni Dominique Pire gba Ebun Nobel?
30242#0	Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Morocco?
30365#0	Ọdun wo ni oṣere Jeff Bridges ṣe sinima "The Fisher King" ?
30366#0	Kí ni orúkọ inagijẹ onisowo orin Sean Combs ?
30369#0	Awọn ẹbun wo ni Jack Nicholson ti gba fún eré ṣíṣe?
30374#0	ọdún wo ni robert De niro bẹrẹ sí ṣe òṣèré?
30416#0	àwọn òṣèré wo lo ṣe fiimu "The avengers" ?
30459#0	Odun wo ni Josehine Baker fi aiye silẹ?
30516#0	Iwadi wo Baron de montesquieu gbe jade?
30579#0	Egbe agbaboolu wo ni Luis Figo ba gba gbehin ki o to fehinti?
30703#0	Ibaṣepo wo lo wa laarin Pakistan ati India?
31085#0	Tani Baba Jccob ninu Bibeli?
31331#0	Pilaneeti wo lo tobi ju ̀lọ?
3171#0	Ki ni olu ilu orile-ede Cameroon?
3178#0	Awon orile-ede wo ni won ti n so Yoruba yato si Naijiria?
32899#0	Iwe wo ni Umberto Eco kọkọ kọ?
32946#0	Ojise olorun meloo ni o wa ninu kurani?
32958#0	Ọdun wo ni wọn pari Ogun Biafra?
3327#0	iru kalẹnda wo ni àwọn ará Ethiopia n lo?
33282#0	Ki ni itumọ Homo Sapien?
3346#0	Ki ni iyatọ laarin "odd nomba" ati "even nomba"?
33463#0	ṣẹ alawọ dudu ni baba to bi Lewis Hamilton?
33519#0	Orile ede wo ni won bi Karl Marx si?
33566#0	Ta ni eni to koko gba ebun Nobel fun kemistri?
33568#0	Ile-ise iroyin wo ni Benjamin Franklin ba ṣiṣẹ gege bi akọwe?
3360#0	Ki lo de ti Imọ mathematiki ṣe le pupọ?
33626#0	Egbe agbaboolu alapere wo ni Kareem Abdul Jabbar gba fún?
33682#0	Eeyan meloo ni King Leopold pa ni orile-ede Congo?
33692#0	Ilu wo ni won bi onkowe Wiliam Shakespeare si?
33857#0	Omo orile ede wo ni Maria Sharapova?
33953#0	Awon awari sayensi wo ni John von Neumann gbe jade?
33976#0	Odun wo ni Joseph Stalin s'alaisi?
33997#0	ọdun wo ni wọn da orile-ede Amerika silẹ?
34094#0	Obinrin wo lo kọkọ jẹ adajọ ni orile-ede Naijiria?
34105#0	ipò wo ni Teslim Elias jẹ ni International court of justice?
34135#0	egbe agbaboolu afesegba wo ni Joachim low n gbe lọ si World Cup?
34138#0	Ki ni o fa iku Giordano Bruno?
34140#0	Omo orile-ede wo ni akowe Walter rodney?
34150#0	awọn àṣà wo ni a mọ yoruba fún?
3487#0	kí ni nọmba ọlọpa ti a le pe ta ba wa ninu ọrọ òjìji?
35524#0	Awon orile-ede wo ni Afrika ni awon somali wa?
35534#0	Odun meloo ni Freddie Ljumberg lo ni Arsenal?
35546#0	Ise wo ni Whoopi Goldberg n se?
35579#0	Ọdún wo ni Ronald Reagan jẹ ààrẹ Orile-ede Amẹrika?
35617#0	Ilu wo ni wọn bi Colin Powell si?
35909#0	ile ise rekoodu wo ni Barbra Joan wa pẹlu?
35915#0	Odun wo ni Diane Keaton bere si se fiimu?
35926#0	Awọn oṣere wo lo ṣe sinima "Black Panther" ?
35927#0	Ta ni ọkọ Laura Ikeji?
36817#0	Odun wo ni Bola Tinubu di Seneto?
36873#0	Iru orin wo ni Segun Adewale n kọ?
36877#0	Ta ni onilu Àlàmú Tatalo?
36889#0	iru orin wo ni Majek Fashek kọ?
36893#0	Ilu wo ni wọn bí Kelechi Iheanacho sí ?
36898#0	ile iṣẹ wo ni Peter Thiel da silẹ?
36940#0	Agbegbe wo ni Senator Abaribe n ṣe aṣoju fún?
37099#0	Ki ni Nnamdi Kanu n ja fun?
37133#0	Ki ni idi ti Suka Dimka ṣe fẹ pa Murtala?
37145#0	ọmọ mélòó ni òṣèré samuel jackson ni ?
37162#0	Ki ni orukọ owo ti wọn na ni orile ede Spain?
37171#0	Ki ni oluilu orile-ede spain?
37182#0	Awon ilu wo lo tobi ju lọ ni Spain?
37197#0	orile ede wo ni ilu San Francisco wa?
37202#0	Awọn oloṣelu wo lo gba ominira fun orile-ede Ghana?
37245#0	ọdún wo ni orile-ede venezuela gba ominira?
37271#0	Ilu wo ni won bi Crristobal Hurtado si?
37276#0	Awon nkan ilẹ adayeba wo ni won ni ni orile-ede Venezuela?
37479#0	Odun wo ni oṣere Moses Olaiya fi aiye silẹ?
37591#0	orile-ede wo ni arturo Vidal n gba bọọlu fún ?
37653#0	ọdun wo ni George washington ṣ'alaisi?
37671#0	Odun wo ni George Bush di Aare orile-ede Amerika?
37697#0	Ilu wo ni won bi Alexander the Great si?
37738#0	ọdún wo ni Colin Powell fi ayé silẹ?
37773#0	Iwari wo ni Albert Einstein gbe jade?
37854#0	awọn òṣèré wo lo ṣe fiimu "black panther" ?
37991#0	ọdún wo ni ẹlẹsẹ ti a mo si oscar De la hoya ba Floyd Mayweather ja?
38035#0	Kini oluilu orile-ede Paraguay?
38050#0	ṣe awọn eeyan alawọ dudu wa ni orile-ede Trinidad?
38051#0	Ki ni koodu orile-ede Trinidad?
38162#0	Agbegbe ijjọba Ibilẹ wo ni Desmond Elliot n ṣe aṣoju fun?
38221#0	Ki ni oluilu orile-ede Belarusi?
38541#0	Oloselu wo lo ba MKO abiola dije ni ibo odun 1993?
38694#0	ipinlẹ wo ni wọn pe ni bendel tẹlẹ?
42261#0	Planeti meloo lo wa?
4410#0	Iru aso wo ni awon Yoruba ma n wọ?
44432#0	Ọdun wo ni ẹlẹṣẹ Buster Douglas ba Mike Tyson ja?
47009#0	Odun wo ni awon onimosayensi se awari 141 Lumen?
48503#0	ọdun wo ni Thutmose jẹ Farao ni ilu Egypt?
51063#0	bá wo ni àwọn Yorùbá ṣe má ń ṣe ọsẹ dúdú?
5126#0	Ki ni orukọ ọọni Ile Ifẹ?
5223#0	Ọdún wo ni Adesoji Aderemi jẹ Ọọni Ile Ifẹ?
53626#0	orisa wo ni orisa ibeji?
53718#0	Odun wo ni Chang Myon je Minisita orile-ede Korea
53740#0	Kí ni oluilu orile-ede Kenya?
53823#0	Iwadi wo ni Dan Shechtman se ti o fi gba ebun Nobel?
53830#0	Odun wo ni Bruce Lee se fiimu "Enter the dragon" ?
53881#0	Ilu wo ni won sin Octave Mirbeau si?
53890#0	ẹgbẹ oloṣelu wo ni Corey Booker wa pẹlu?
5392#0	Odun wo ni Olagunsoye Oyinlola di gomina Osun?
53994#0	Ta ni aare Egypti ni ọdun 2010?
54187#0	Kí ni orúkọ inagijẹ Andre Young ?
54188#0	Ki ni orukọ akọrin Curtis Jackson?
54270#0	Iṣẹ wo ni Rosa Parks ṣe?
54280#0	awọn Orile ede wo ni wọn ti n sọ Swahili?
54282#0	Kontinenti wo ni orile-ede Komoro wa?
54445#0	akọwe wo lo kọ iwe Harry potter?
5452#0	Orile-ede wo ni Ásíà ni a ti le ri amọtẹkun?
54886#0	ẹkọ wo ni a le mu lo lati aye Jésù kristi?
55034#0	Ta ni o pa Martin Luther King?
55084#0	Ta ni ẹni to da ile iṣẹ Space X silẹ?
55585#0	Awon oloselu wo lo wa lati ipinle Jigawa?
55834#0	Odun wo ni Nelson Mandela kuro ni ẹwọn?
55868#0	Ede meloo ni won n so ni Ghana?
55988#0	Iwadi wo ni Isaac Newton gbe jade?
58427#0	ki ni idi ti ede igala fi jo ede Yoruba?
58461#0	Ounjẹ wo ni awọn South Afrika fẹran ju lọ?
58469#0	Ede wo lo l'okiki ju lọ ni Afrika?
58528#0	Iṣẹ wo ni Margaret Etim n ṣe?
58529#0	Ta ni Aarẹ orile-ede Russia?
58543#0	Ta ni ààrẹ orile-ede Saina?
58608#0	Odun wo ni Sam Amuka Pemu da ile iṣẹ iroyin Vanguard silẹ?
58616#0	ọjọ wo ni idije olympiki to n bọ ma bọ sí?
58639#0	ilu wo lo kere jù lọ ní orílé-ede fransi?
58653#0	Akorin wo lo kọ "Billie Jean" ?
58689#0	Odun wo ni wọn bi Elon Musk?
58694#0	ki ni oruko ilé iṣẹ ti Andy Rubin da silẹ?
58699#0	Ilu wo ni a bi agba  oṣere Robin Williams si?
58921#0	awọn ẹranko wo lo wa ni ipinlẹ Florida?
58949#0	Awon orile ede wo ni Afrika ni won n sọ ede French?
59044#0	Odun wo ni jelena jankovic fehinti?
59086#0	Awọn akewi  wo ni wọn wa lati orile-ede Romania?
59095#0	orile-ede wo ni ilu Fort Murray wa?
59165#0	ẹya mélòó lo wa ni orile-ede Kroatíà?
59166#0	awọn orilẹ-ede wo lo sunmọ Australia?
59178#0	Ki lo fa ogun ti Russia ati Ukraine?
59204#0	ilu wo ni won bi Tommy Haas si?
59313#0	Odun wo ni Sloane Stephens yege US open?
59530#0	Odun wo ni Gloria Macapagal di aare orile ede Fillipines?
59623#0	Awon iwadi wo ni onimo sayensi Stephen Hawking gbe jade?
59694#0	Ki ni itumo elimenti ni imo sayensi?
59736#0	awọn wo ló dá ẹgbẹ ọmọ oduduwa sí lẹ̀?
59753#0	iru metali wo ni aluminiomu?
59787#0	Orisi elimenti wo lo wa ?
59878#0	oríṣi atomu wo ló wà?
59915#0	ọdun wo Saddam Hussein ṣe alaisi?
59947#0	Ati orile ede  wo ni Reggae ti wa?
60024#0	ilu wo ni wọn bí onkọwe Franz Fanon sí?
60031#0	Iru orin wo ni John Lennon kọ?
60037#0	ìwé wo lo ṣe pàtàkì jù lọ laarin gbogbo iwe ti Walter Rodney kọ?
60042#0	Awon orile ede wo lo sunmo Rọṣia?
60106#0	Ki ni orukọ inagije Charles Olumọ?
60131#0	Ise wo ni Jackie Aina n ṣe?
60184#0	Ilu wo ni wọn bi Serena Williams si?
60316#0	Egbe oloselu wo ni Doug Ford wa pẹlu?
60324#0	òṣèré wo lo ṣe fiimu Jẹnifa?
60349#0	ẹgbẹ agbaboolu alapere wo ni Kobe Bryant gba bọọlu fún gbẹhin?
60417#0	Ki ni oju ọjọ ni Ilu Florence?
60477#0	Egbe agbaboolu wo ni Ambrose Vanzekin n gba bọọlu fun?
60493#0	Onkowe wo lo kọ Harry Potter?
60527#0	Abala OPC wo ni Frederick Fasheun da silẹ?
60529#0	Odun wo ni agbaboolu Ji Sung Park fehinti?
60571#0	Odun wo ni won bi onimo sayensi Isaac Newton?
60709#0	Omi adagun meloo lo wa ni ipinlẹ Minnesota?
60756#0	Ilu wo ni won bi Nicki Minaj si?
60761#0	Odun wo ni Christopher Colombus se iwadi Amerika?
60767#0	ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ redio Lagos silẹ?
60777#0	ọmọ ìlú wo ni Linda Ejiofor?
60828#0	Ara ilu wo ni olusare Noah Lyles?
60879#0	Ọdún wo ni ẹlẹsẹ James Toney bá Samuel Peters jà?
60893#0	ọmọ meloo ni  Serena Williams bi?
60980#0	Yunifasiti wo ni Akọwe Wọle Ṣoyinka ti kawe?
61045#0	àwọn akọrin wo lo wa lati orile-ede Korea?
61165#0	Ki ni orukọ iyawo ti Efrem Zimbalist kọkọ fẹ?
61169#0	Ọmọ mélòó ni Eve bi fún Adam ?
61172#0	Ki ni inagijẹ Dwayne Carter ?
61180#0	òṣèré wo lo ṣe fiimu True Lies?
61239#0	agbaboolu wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede bulgaria?
61243#0	Ki ni awọ asia orile ede Naijiria?
61249#0	Ọdún wo ni wọn bí òṣèré Sofia Vergara?
61257#0	iru owo wo ni wọn ná ní Bulgaria?
61344#0	Kí ni ìtúmò Safari ni ede Swahili?
61412#0	Odun wo ni Telifisan kọkọ de Naijiria?
61423#0	ọdun wo ni wọn bi aarẹ Muhammadu Buhari?
61442#0	Awon ile iwe ẹkọ giga wo lo wa ni Santiago?
61517#0	ogun wo ni èèyàn lè lo fún àrùn malaria?
61676#0	Ta ni o da iwe iroyin El Marino silẹ?
61771#0	kí ni a mọ ilu Salamanca fun?
61775#0	kí ni o ma n fa àrùn onígbáméjì?
61798#0	ki ni o ma n fa arun ti a mo si atọsi?
61829#0	ki ni o ma n fa arun Onchocerciasis?
61835#0	Odun wo ni Cassius Clay yi oruko si Muhammed Ali?
61876#0	Erekusu wo ni Wakiki wa?
61880#0	erekusu wo lo tobi ju lo ni agbaye?
61882#0	Orile ede wo ni Tenerife wa?
61928#0	oríṣi mọ́tò wo ló wà?
61930#0	orisi ẹfọri wo lo wa?
61950#0	Orile ede wo ni ilu Hachinohe wa?
61975#0	Ki ni idi ti won se n pe Chile ni orile-ede awon Akewi?
62011#0	Bawo ni Moscow se jinna to si Saint Petersburg?
62015#0	kí ni o ma n fa arun ọpọlọ?
62016#0	Oogun wo ni eeyan le lo lati fi pa kokoro?
62130#0	Ki ni orukọ iyawo Will Smith?
62168#0	Iye eniyan meloo lo wa ni orile-ede Scotland?
62175#0	kí ni o ma n fa arun ọpọlọ?
62183#0	Egbe agbaboolu afesegba wo ni Paolo maldini gba boolu fun?
62192#0	Ẹbun fiimu mélòó ni Stephen Spielberg ti gba ?
62194#0	Awọn akọwe ni wọn wa lati Vienna?
62218#0	kí ni ìdí tí alangba ṣe ma n mi'ri?
62227#0	Ki ni idi ti alangba ṣe ma n mi ori?
62229#0	awon eya wo ni won ma n je Edikan Ikong?
62231#0	Iru alangba wo ni Geico?
62257#0	ki ni itumo enzyme?
62295#0	idile wo ni Awujalẹ Sikiru Adetona ti wá?
62300#0	ọdun wo ni wọn da ẹgbẹ PDP silẹ?
62388#0	Ki lo pa elere idaraya ti a mọ si Florence Joyner?
62397#0	Iru awon alangba wo lo wa ni Afrika?
62424#0	Awọn iṣoro wo lo wa gẹgẹ bi obinrin ni Naijiria?
62444#0	Odun wo ni Lateef Adedimeji bẹrẹ si ṣe fiimu?
62453#0	Awon aami wo lo ma n han wipe obinrin ti ni oyun?
62461#0	Awọn ounjẹ wo lo ni protein ninu ju?
62465#0	Ilu wo ni wọn bí akọrin Tyler the creator sí?
62569#0	Ere wo ni oṣere Jackie Chan kọkọ ṣe?
6536#0	Iru orin wo ni akọrin Wizkid n ko?
65712#0	Ilu wo ni wọn bi ẹlẹṣẹ Roy Jones si?
65763#0	kí ni oluilu orile-ede Gambia ?
65767#0	ẹya wo lo tóbi jù lọ ní orile ede Liberia?
65784#0	Awo meloo ni Sikiru Ayinde Barrister ṣe ki o to ku?
65791#0	ilu wo ni wọn ti n ṣe awọn ẹṣọ Calvin Klein?
65821#0	Kí ni oluilu orile-ede Bẹljiọm?
65842#0	ọdún wo ni akorin Victor Olaiya ṣ'alaisi
65851#0	Awọn oniṣowo wo lo gbajumọ laiye ijọun ni ilu Ibadan?
66015#0	Ki ni oruko iyawo rotimi akeredolu?
66019#0	Ki ni oluilu orile-ede Israeli?
66023#0	kí ni orúkọ ile-iṣẹ ti Richard Branson da silẹ?
66100#0	Ki ni oruko ile-ise tI Sean Combs da sile?
66110#0	Ipo wo ni Bamanga Tukur jẹ labẹ ijọba Sani Abacha?
66113#0	Ipinle wo ni Aliyu Wamakko ti jẹ gomina?
66120#0	Ipò Ajagun wo lo tobi ju lọ ní Naijiria?
66342#0	ounje wo ni awon Hausa fẹran ju lọ?
66435#0	Awo meloo ni olorin Adewale ayuba ti ṣe?
66437#0	ọmọ ilu wo ni Lawrence Anini?
66443#0	Elo ni ijọba n san fun awọn agbofinro?
66445#0	Ara Ilu wo ni Bimbo Akintola?
66562#0	Orile-ede wo ni agbabọọlu Gabriel Jesus n gba bọọlu fun?
66876#0	Awon tira wo ni Sheik Adam Al Ilory kọ?
66945#0	ọdún wo ni wọn pa Tafawa Balewa?
66987#0	ile iṣẹ wo ni Femi Otedola da silẹ?
67007#0	bawo ni moremi ṣe tú àṣírí àwọn ará Igbo?
67036#0	Alaafin Oyo wo ni a mo si Orompotoniyun?
67047#0	Goolu meloo ni Muda Lawal gba wole fun Naijiria?
67317#0	Ta ni ẹni to kọ fiimu Ovy's voice?
67362#0	Odun wo ni 9ice gbe awo Gongo Aso jade?
67416#0	Ati ibo ni Aṣọ Ofi ti wa?
67527#0	Yunifasiti wo ni Funsho Williams ti kàwé?
67557#0	ile-ise wo ni Tara Fela-Durotoye da silẹ?
67562#0	Ọdún wo ni Wahab Folawiyo fi aiyé silẹ?
67610#0	Ki ni oluilu orile-ede Kenya?
67616#0	ọjọ wo ni Valentine bọ si?
67649#0	Odun wo ni won da OGBC silẹ?
67675#0	Awọn orile ede wo ni wọn ti n sọ Urdu?
67686#0	Awon irin ise wo ni akorin Prince lo?
67688#0	ọdún wo ni akọrin Fatai Rolling Dollar ṣ'àláìsí?
67760#0	Ilu wo ni won bi Immanuella Samueli si?
67764#0	Ọdún wo ni Chioma Ajunwa gba ẹbun ni ìdíje òlímpíkì?
67775#0	Ki lo pa Samuel Okwaraji?
67786#0	Odun wo ni Gbenga Daniel je gomina ipinlẹ Ogun?
67886#0	Ta ni ọba awọn ogu ni Badagry?
67907#0	Ki ni oruko iyawo Odunlade Adekola?
67942#0	Ipò wo ni Surajudeen Ajibola jẹ ni ipinlẹ Ọsun ?
67949#0	Ọdún wo ni Haruna Ìṣọ̀lá fi aiyé silẹ?
67956#0	yunifasiti wo ni gomina Dapo Abiodun ti kàwé?
67961#0	Odun wo ni olorin tupac shakur s'alaisi?
67991#0	ipo wo ni Robert Adeyinka je ni Western Region
68015#0	kí ni orúkọ ìyàwó Yemi Osinbajo?
68024#0	Ta ni Akran ilu Badagry?
68035#0	ilé iṣẹ wo ni Tony Elumelu da silẹ?
68047#0	Ọdún wo ni George Weah di ààrẹ orile ede Liberia?
68053#0	ọdún wo ni Bukky Wright bẹrẹ sí ṣe eré itage?
68058#0	Ta ni Baba Kunle Afolayan?
68059#0	ibaṣepọ wo lo wa laarin Gabriel ati Kunle Afolayan?
68234#0	Odun wo ni won da ile ifowoppamo Wema silẹ?
68240#0	Awon ile-ise wo ni Mark Zuckerberg da sile?
68242#0	Àwọn Gómìnà wo lo da ẹgbẹ amọtẹkun silẹ?
68250#0	awọn wo lo ko samuel crowther l'ẹ́rú?
68301#0	Kí ni èèyàn lè fi ata ṣọ̀mbọ̀ sè?
68376#0	Ipinle wo ni Samuel Ortom ti je gomina?
68427#0	kí ni  olúìlú ìpínlẹ̀ Abia?
68435#0	Orile ede wo ni ilu Phoenix wa ?
68532#0	ta ni aṣoju agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Badagry?
68664#0	Ki ni o fa iku Tolulope Arotile?
68728#0	nibo ni abule faransé wa ni Badagry?
68737#0	Ki ni awon aami wipe eeyan ti ni ni arun Coronavirus?
68841#0	Ta ni oludari NCDC?
68861#0	Ọjọ meloo lo wa ninu oṣu Februrari?
68882#0	Odun wo ni Kemi Adetiba gbe fiimu King of Boys jade?
69261#0	Ile iroyin wo ni Aisha Falode ba ṣiṣẹ?
69404#0	Ki ni orukọ abisọ alakitiyan Malik El Shabazz?
69661#0	Ki ni orukọ abisọ Burna Boy?
69674#0	Ki ni a n pe ni pythagoras theorem ni Matimatiki?
69736#0	ati ilu wo ni COVID 19 ti kọkọ bẹrẹ?
69944#0	Ile-ise wo ni Bode Akindele da silẹ?
70088#0	olorin wo lo ko "African Queen" ?
70147#0	Fiimu wo ni Rahama Sadau ṣe pẹlu Ali Nuhu?
70174#0	ere mélòó ni òṣèré eniola ajao ti ṣe?
70219#0	Iṣẹ wo ni Sandra Ezekwesili ń ṣe?
70228#0	Awo meloo ni akọrin Tunde Nightingale ṣe ki o to fi aiye silẹ?
70236#0	Odun wo ni Mike Bamiloye da Mount Zion sile?
70240#0	Ki ni oluilu orile ede Morocco?
70265#0	Oye wo ni fi Gani Adams jẹ?
70287#0	ere wo ni Bukky Ajayi kọkọ gbe jade?
70355#0	Ara ìlú wo ni Ààfáà Muyideen Bello?
70363#0	Ta ni ọkọ Thelma Okoduwa?
70419#0	Ipinle wo ni Yunifasiti Ahmadu Bello wa?
70433#0	Ise wo ni Margaret Etim n ṣe?
70450#0	Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré tí a mọ sí Taiwo Hassan?
70460#0	Ile-iwe ko giga ẹwo ni Yvonne Orji ti ka'we?
70493#0	Ipo wo ni won fi Kemi Adeosun si labe ijoba Muhammadu Buhari
70503#0	Ilu wo ni won bi Agnes Osazuwa si?
70557#0	Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Burkina?
70571#0	Omo ilu wo ni Mercy Johnson?
70576#0	Ipinle wo ni Ibrahim Shekarau ti jẹ gomina?
70598#0	ọdún wo ni Ogun àdùbí bẹrẹ?
70614#0	Odun wo ni Chioma Ajunwa yege ni idije olympiiki?
70629#0	Fiimu meloo ni Ini Ikpe ti ṣe?
70633#0	ọdún wo ni akọwe Frances Welsing fi aiyé silẹ?
70656#0	Orile ede wo ni Marina Niava to wa?
70693#0	Ọdún wo ni Leopold Senghor di ààrẹ orile-ede Senegal?
70713#0	Ta ni ọkọ Flora Shaw ki o to fi aiye silẹ?
70729#0	Ta ni o se oludari fiimu Mionga ki Obo?
70783#0	ọdún wo ni wọn bí Anọbi Muhammad?
70864#0	ipinle wo ni ilu Igboho wa?
70918#0	Ki ni orukọ inagije Temilade Openiyi?
70933#0	Ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Adeniran Ogunsanya bá ṣe?
70964#0	Odun wo ni Akiwunmi Ambode jẹ gomina ipinlẹ Eko?
70974#0	Ta ni o da ile iṣẹ Mainframe silẹ?
70993#0	ipò ìjọba wo ni Femi Adesina wa labẹ ijoba Aare Buhari?
70994#0	Orile ede wo lo yege idije World Cup ti 2006?
71068#0	Awọn nkan wo ni wọn fi n ṣe Baba Ghanoush?
71092#0	Awo wo ni Temi Dee kọkọ gbé jade?
71178#0	Ipinle wo ni Ayodele Fayọse ti ṣe gomina?
71200#0	Ọdún wo ni Ezra Olubi da ilé iṣẹ Paystack silẹ?
71202#0	Iṣẹ wo ni Tiwalola Olanubi n ṣe?
71220#0	yunifasiti wo ni denrele ti kàwé?
71252#0	ki ni anfani ere idaraya?
71280#0	Ta ni ọkọ Naa Ashorkor?
71282#0	Ọdún wo ni ọgbẹni Rauf Aregbesola jẹ gomina ipinlẹ Ọsun?
71307#0	ọdún wo ni Michael Jackson gbe awo Thriller jáde?
71352#0	konsonanti mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá?
71424#0	Odun wo ni Oluwaseun Osewa da Nairaland silẹ?
71511#0	oṣu wo ni odun 1999 ni Olusegun Obasanajo di Aarẹ orile ede Naijiria?
71529#0	Odun wo ni Vivica Fox bẹrẹ si ṣe ere itage?
71554#0	Odun wo ni Facebook ra Whatsapp?
71569#0	Odun wo ni arun coronavirus bẹrẹ?
7183#0	orile ede wo ni odo mississipi wa?
7208#0	Ọjọ mélòó ló wà nínú oṣù Dìsẹ́mbà?
7523#0	Kí ni orúkọ abisọ Kwame Ture?
8837#0	ẹgbẹ oloṣelu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?