audio
audioduration (s)
2.98
12.5
English
stringlengths
27
137
Yoruba
stringlengths
29
177
Welcome can you tell me whats wrong
Ẹ káàbọ ṣé ẹ lè sọ fún mi ohun tó ń ṣe ẹ
If it happens at all it will be minor like a slight fever or swelling Shall we proceed
Rárá ó bí ó bá tilẹ wa maa ṣẹlẹ papaa yii o jẹ bi awon eewu kékeké bí ara gbi gbóná tàbí oju abi ti a tifun ko wu sẹrẹfẹ Ṣé kí a bẹrẹ si fun labẹrẹ naa
Welcome Can you tell me whats wrong with your stomach
Ẹ káàbọ n jẹ ẹ le sọ ohun ti sí inú yin fun mi
I have stomach pain and I vomit frequently
Mo ní irora ní inú mi ee ibi sì gbe mi ni gbogbo ígbà
Have you eaten recently or is there something you think caused this
Ṣé o ti jẹun lẹnu lọlọ yi ni abi kilẹẹ yin ro to le faa inu runrun yi fun yin
I ate meat that wasnt wellcooked and Ive had diarrhea since then
Mo jẹ ẹran kan ti n kosi jina dáadáa eyin igba yi ni inu mi bẹrẹ si ni rọ lu ra wọn ti mo si bẹrẹ si ni ya gbẹ ti mo si ibii
We will give you medicine for this and recommend that you avoid oily or heavy foods
A fun yin ní oògùn ti o tọ ju àrùn yìí sugbon oo arọ yin ki ẹẹ ma jẹ ounjẹ ti o ni epoo tabi tó wuwo lara yin fun gba di ẹẹ
Welcome how are you feeling
Ẹ káàbọ ṣé ẹ lè sọ un to se yin fun mi
Im fine but I have pain in my body and joints
Ara mi yá ṣùgbọn gbogbo ara loro mi ati gbogbo rikerike ara mi
Have you been drinking enough water or have you been taking your folic acid supplements
Ṣé ẹ mu ọpọlọpọ omi bayi Ṣé ẹ si lo folic acid bo se tọ ati bo si yẹ
Yes but the pain hasnt subsided yet
Bẹẹni ṣùgbọn irora náà kọ kò lọ
I am not feeling well I have body pains and a headache
Ara mi kò yá mo ara gbogbo ara lo ro mi ori fọ na
Continue with the folic acid We will run a test to see if its due to anemia or water retention
ẹ tẹ si wa ju lati ma lo folic acid naa a ṣe àyẹwo fun yin láti mọ bóyá omi arayi ló ti pọ ju nii tabi nkan mi lo fa ara riro fun yin
Do you have a fever or is your body hot
Ṣé o ní iba tàbí ara gbóná ni
Yes my body is very hot and I feel weak
Bẹẹni ara mi gbóná gidigidi ara mi si fu yẹ ara mi wu
It seems you may have malaria We will test your blood to confirm Meanwhile drink plenty of water and take this medicine three times daily
O ma da bi pe e fe ni iba maa ni yẹ A máa ṣe àyẹwọn ẹjẹ yin ati leri aridajú owon ti o se yin sugbon na e gba oògùn yìí ki e ma lo lẹẹmẹta lójó ki esi ma mu opolopo omi pelu rẹẹ
Welcome Has this child received all the necessary vaccinations
Ẹ káàbọ Ṣé ọmọ yìí ti gba gbogbo abẹrẹ rẹ tó yẹ ko gba pe ni
No we havent taken the vaccination for the new infection yet
Rárá a kò tíì gba abẹrẹ fún àrùn àkóràn tuntun yìí to sẹ de
It is important for your child to get the vaccine It will protect their health against severe infections
Ó ma ṣe pàtàkì fún ọmọ yin láti gba abẹrẹ náà yii dáàbò kuro lara kuro lọ dọ àrùn tó ṣòro láti tọju
Does the vaccine have any possible side effects
Ṣé abẹrẹ náà ko ni ewu kankan ti oole jáde leyi ti a ba gba tan
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
43