ending1
stringlengths 4
149
| ending2
stringlengths 5
156
| startphrase
stringlengths 7
179
| labels
int64 0
1
| split
stringclasses 7
values |
---|---|---|---|---|
Kábíyèsí fi ìyà jẹ Àlàbí
|
Kábíyèsí dá Àlàbí lọ́lá
|
Kábíyèsí fi imú Àlàbí dánrin
| 1 |
yo
|
Kábíyèsí fi ìyà jẹ Àlàbí
|
Kábíyèsí dá Àlàbí lọ́lá
|
Kábíyèsí mórí Àlàbí sre
| 0 |
yo
|
Ènìyàn tí ó máa ń ṣe eléyìí ṣe tọ̀hun ni Adéọlá
|
Ènìyàn tí ó máa ń ṣe ohun ọ̀nà kan ṣoṣo ni Adéọlá
|
Ṣawoṣọ̀gbẹ̀rì ni Àdéọlá
| 1 |
yo
|
Ènìyàn tí ó máa ń ṣe eléyìí ṣe tọ̀hun ni Adéọlá
|
Ènìyàn tí ó máa ń ṣe ohun ọ̀nà kan ṣoṣo ni Adéọlá
|
Awo ìmùlẹ̀ ni Adéọlá
| 0 |
yo
|
Àyìnlá yan Àjàlá jẹ
|
Àyìnlá ṣe òtítọ́ sí Àjàlá
|
Àyìnlá fá Àjàlá lórí
| 1 |
yo
|
Àyìnlá yan Àjàlá jẹ
|
Àyìnlá ṣe òtítọ́ sí Àjàlá
|
Àyì̀nlá dá Àjàlá lọ́lá
| 0 |
yo
|
Gbogbo yín ẹ lọ fi ara balẹ̀
|
Gbogbo yin ẹ lọ ká ọkàn sókè
|
Gbogbo yín ẹ lọ si mẹ̀dọ̀
| 0 |
yo
|
Gbogbo yín ẹ lọ fi ara balẹ̀
|
Gbogbo yin ẹ lọ ká ọkàn sókè
|
Gbogbo yín ẹ lọ káyà sokè
| 1 |
yo
|
Ọ̀gá fìyà jẹ ọmọ iṣẹ́ rẹ
|
Ọ̀gá dá ọmọ iṣẹ́ rẹ̀ lọ́lá
|
Ọ̀gá dá sèríà fún ọmọ iṣẹ́ rẹ̀
| 1 |
yo
|
Ọ̀gá fìyà jẹ ọmọ iṣẹ́ rẹ
|
Ọ̀gá dá ọmọ iṣẹ́ rẹ̀ lọ́lá
|
Ọ̀gá dá sèríà fún ọmọ iṣẹ́ lówó tó pọ̀ àti àgbéga lẹ́nu iṣẹ́
| 0 |
yo
|
Táíwò ti lóyún
|
Táíwò ò tí ì lóyún
|
Táíwò ti di abara méjì
| 0 |
yo
|
Táíwò ti lóyún
|
Táíwò ò tí ì lóyún
|
Táíwò ò tí ì bímọ
| 1 |
yo
|
Adéyẹmí ṣagídí gidigidi
|
Adéyẹmí ṣe pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́
|
Adéyẹmí kágídíborí bíi fáànù Íbò
| 1 |
yo
|
Adéyẹmí ṣagídí gidigidi
|
Adéyẹmí ṣe pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́
|
Adéyẹmí baralẹ̀ bí omi àfòwúrọ̀ pọ̀
| 0 |
yo
|
Ó sálọ
|
Ó dúró
|
Ó fẹsẹ̀ fẹ́ ẹ
| 1 |
yo
|
Ó sálọ
|
Ó dúró
|
Ó gàndí
| 0 |
yo
|
Ó ti run gbogbo dúkìá àwọn òbí rẹ̀
|
Ó ti rà kún gbogbo dúkìá àwọn òbí rẹ̀
|
Ó ti sọ àwọn òbí rẹ̀ di ẹdun arinlẹ̀
| 1 |
yo
|
Ó ti run gbogbo dúkìá àwọn òbí rẹ̀
|
Ó ti rà kún gbogbo dúkìá àwọn òbí rẹ̀
|
O tí sọ àwọn òbí rẹ̀ di onígba aṣọ
| 0 |
yo
|
Kẹ́hìndé lagídí lórí ọ̀rọ̀ náà
|
Kẹ́hìndé fara balẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà
|
Kẹ́hìndé fàáké kórí lórí ọ̀rọ̀ náà
| 1 |
yo
|
Kẹ́hìndé lagídí lórí ọ̀rọ̀ náà
|
Kẹ́hìndé fara balẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà
|
Kẹ́hìndé gbà f'Ọ́lọ́run lórí ọ̀rọ̀ náà
| 0 |
yo
|
Délé sálọ nígbà tí ó gbúròó àwọn Ọlọ́pàá
|
Délé dúró nígbà nígbà tí ó gbúròó àwọn Ọlọ́pàá
|
Délé júba ehoro nígbà tí ó gbùròó àwọn Ọlọ́pàá
| 1 |
yo
|
Délé sálọ nígbà tí ó gbúròó àwọn Ọlọ́pàá
|
Délé dúró nígbà nígbà tí ó gbúròó àwọn Ọlọ́pàá
|
Dé́lé dúró wámú nígbà tí ó gbùròó àwọn Ọlọ́pàá
| 0 |
yo
|
Ó ti rí wàhálà
|
Ó ti rí ìdẹ̀ra
|
Ó ti kan róro nírù
| 1 |
yo
|
Ó ti rí wàhálà
|
Ó ti rí ìdẹ̀ra
|
Ó ti róore lojú olórò
| 0 |
yo
|
Ẹ jẹ́ kí á pa àṣírí ọ̀rọ̀ náà mọ́
|
Ẹ jẹ́ kí á tú pa àṣírí ọ̀rọ̀ náà mọ́
|
Ẹ jẹ́ ká ṣe ọ̀rọ̀ náà ní bòńkẹ́lẹ́
| 0 |
yo
|
Ẹ jẹ́ kí á pa àṣírí ọ̀rọ̀ náà mọ́
|
Ẹ jẹ́ kí á tú pa àṣírí ọ̀rọ̀ náà mọ́
|
Ẹ jẹ́ ká kó ọ̀rọ̀ náà síta
| 1 |
yo
|
Oríre rẹ̀ ti fẹ́ parí
|
Oríre rẹ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀
|
Oríre rẹ̀ ti fẹ́ tẹnu bọpo
| 1 |
yo
|
Oríre rẹ̀ ti fẹ́ parí
|
Oríre rẹ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀
|
Oríre rẹ̀ ti fẹ́ gbìnàyá
| 0 |
yo
|
Ẹ má bínú
|
Ẹ má rọnú
|
Ẹ jẹ̀bùrẹ́ awo olùgbẹ́bẹ̀
| 0 |
yo
|
Ẹ má bínú
|
Ẹ má rọnú
|
Ẹ fàbínú yọ awo olúkòso
| 1 |
yo
|
Bàbá Àlàbí kú fúra rẹ̀
|
Wọ́n pa bàbá Àlàbí
|
Bàbá Àlàbí fọwọ́rọrí kú ni
| 0 |
yo
|
Bàbá Àlàbí kú fúra rẹ̀
|
Wọ́n pa bàbá Àlàbí
|
Bàbá À̀làbí kúkú oró
| 1 |
yo
|
Wọ́n fìyà jẹ Adéyẹmí lójúde Ọba
|
Wọ́n dá Adéyẹmí lọ́lá lójúde Ọba
|
Wọ́n fi imú Adéyẹmí fọn fèrè lójúde Ọba
| 1 |
yo
|
Wọ́n fìyà jẹ Adéyẹmí lójúde Ọba
|
Wọ́n dá Adéyẹmí lọ́lá lójúde Ọba
|
Wọ́n fi ojú Adéyẹmí ríre lójúde Ọba
| 0 |
yo
|
Kí ló dé tí o dúró láìṣe nǹkankan?
|
Kí ló dé tí ò ń ṣiṣẹ́ láìdáwọ́ dúró?
|
Èéṣe tí o káwọ́ rọ̀?
| 1 |
yo
|
Kí ló dé tí o dúró láìṣe nǹkankan?
|
Kí ló dé tí ò ń ṣiṣẹ́ láìdáwọ́ dúró?
|
Eéṣe tí ò ń fẹ̀mí ṣe?
| 0 |
yo
|
Jẹ́ kí ohun burúkú ó padà wá ṣẹlẹ̀ síni
|
Jẹ́ kí ohun rere ó padà wá ṣẹlẹ̀ síni
|
Fogun ẹ̀yìn jàni
| 1 |
yo
|
Jẹ́ kí ohun burúkú ó padà wá ṣẹlẹ̀ síni
|
Jẹ́ kí ohun rere ó padà wá ṣẹlẹ̀ síni
|
Jagun síwájú fún mi
| 0 |
yo
|
Táyé ń lérí ohun tí kò le ṣe ní
|
Táyé ń lérí ohun tó le ṣe ní
|
Táyé ń fẹnu ròfọ́ ni
| 1 |
yo
|
Táyé ń lérí ohun tí kò le ṣe ní
|
Táyé ń lérí ohun tó le ṣe ní
|
Wí bẹ́ẹ̀ ṣe bẹ́ẹ̀ ni Táyé
| 0 |
yo
|
Olófòófó wà ní tòsí
|
Ẹlẹ́nubíbò wà ní tòsí
|
Kókó ń bẹ̀ lẹ́fọ̀ọ́
| 1 |
yo
|
Olófòófó wà ní tòsí
|
Ẹlẹ́nubíbò wà ní tòsí
|
Kò séèrà lójú ọpọ́n
| 0 |
yo
|
Àgbàlagbà tó ń wùwà àgbà ìyà
|
Ọmọdé tó ń wùwà ọmọdé ìṣẹ́
|
Àgbàlagbà tó ń ṣe láńgbáláńgbá
| 1 |
yo
|
Àgbàlagbà tó ń wùwà àgbà ìyà
|
Ọmọdé tó ń wùwà ọmọdé ìṣẹ́
|
Àgbà tí ò jẹ́ kọ́rùn ọmọ ó wọ́
| 0 |
yo
|
Ó ń ṣe àṣedànù
|
Ò ń ṣe àṣejèrè
|
Ó ń pọnmi sí ajádìí apẹ̀rẹ̀
| 1 |
yo
|
Ó ń ṣe àṣedànù
|
Ò ń ṣe àṣejèrè
|
Ó rí kójọ
| 0 |
yo
|
Àwọn ará ìsàlẹ̀ ń bínú lábẹ́lẹ̀
|
Àwọn ará ìsàlẹ̀ ń dunnú
|
Àwọn ará ìṣàlẹ̀ ń fapá jánú
| 1 |
yo
|
Àwọn ará ìsàlẹ̀ ń bínú lábẹ́lẹ̀
|
Àwọn ará ìsàlẹ̀ ń dunnú
|
Àwọn ará òkè ń sòdí wùkẹ̀
| 0 |
yo
|
Ìṣọ̀lá kò lè bá obìnrin lòpọ̀
|
Ìṣọ̀lá lè bá obìnrin lòpọ̀
|
Lákíríboto ni Ìṣọ̀lá
| 1 |
yo
|
Ìṣọ̀lá kò lè bá obìnrin lòpọ̀
|
Ìṣọ̀lá lè bá obìnrin lòpọ̀
|
Agẹṣin èèyàn ni Ìṣọ̀lá
| 0 |
yo
|
Olú sálọ
|
Olú dúró
|
Olú na pápá bora
| 1 |
yo
|
Olú sálọ
|
Olú dúró
|
Olú dúró kalẹ̀
| 0 |
yo
|
Àrèó kò ní ẹ̀sùn kankan lọ́rùn
|
Àrèó ní èsùn púpọ̀ lọ́rùn
|
Àrèó ti wẹ̀ yán kànhìnkàhìn
| 0 |
yo
|
Àrèó kò ní ẹ̀sùn kankan lọ́rùn
|
Àrèó ní èsùn púpọ̀ lọ́rùn
|
Àrèó lẹ́ṣẹ̀ lọ́rùn
| 1 |
yo
|
Gbádébọ̀ fẹ́ràn kí ó máa kọ́kọ́ ṣáájú nínú àwọn nǹkan
|
Gbádébọ̀ fẹ́ràn kí ó máa wà lẹ́yìn nínú àwọn nǹkan
|
Gbádébọ̀ fẹ́ràn kí ó máa ṣàyàngbàǹgbà sí nǹkan
| 1 |
yo
|
Gbádébọ̀ fẹ́ràn kí ó máa kọ́kọ́ ṣáájú nínú àwọn nǹkan
|
Gbádébọ̀ fẹ́ràn kí ó máa wà lẹ́yìn nínú àwọn nǹkan
|
Gbádébọ̀ fẹ́ràn kí ó máa káríbọnú sí nǹkan
| 0 |
yo
|
Ó ti lóyún
|
Ó ti bímọ
|
Ó ti diwọ́disẹ̀ sínú
| 0 |
yo
|
Ó ti lóyún
|
Ó ti bímọ
|
Ó dọyún dẹ̀jẹ̀ dídì sínú
| 1 |
yo
|
Wọ́n ti padà wá ba ohun tí a ṣe tó dára jẹ́
|
Wọ́n ti padà wá tún ohun tí a ṣe tí kò dára ṣe
|
Wọ́n ti gbẹ̀yìn bẹbọ jẹ́
| 1 |
yo
|
Wọ́n ti padà wá ba ohun tí a ṣe tó dára jẹ́
|
Wọ́n ti padà wá tún ohun tí a ṣe tí kò dára ṣe
|
Wọ́n gbẹ̀yìn tẹ́bo rú
| 0 |
yo
|
Àìná ní ahun
|
Àìná máa ń fitọrọ
|
Àìná háwọ́
| 1 |
yo
|
Àìná ní ahun
|
Àìná máa ń fitọrọ
|
Àì̀ná yawọ́
| 0 |
yo
|
A ò ní fa ọ̀rọ̀ náà gùn
|
A ó pẹ́ lórí ọ̀rọ̀ náà
|
A ò ní fọ̀pá pọ̀ọ̀lọ̀pọọlọ pejò
| 0 |
yo
|
A ò ní fa ọ̀rọ̀ náà gùn
|
A ó pẹ́ lórí ọ̀rọ̀ náà
|
A ó wírèégbè ṣúlẹ̀
| 1 |
yo
|
Ọ̀rọ̀ yìí kò nítumọ̀
|
Ọ̀rọ̀ yìí nítumọ̀
|
Omi ẹ̀fọ́ lọ̀rọ̀ yìí
| 1 |
yo
|
Ọ̀rọ̀ yìí kò nítumọ̀
|
Ọ̀rọ̀ yìí nítumọ̀
|
Gòríà obì ni ọ̀rọ̀ yìí
| 0 |
yo
|
Ìyá kú, ọmọ náà sì tún kú
|
Ìyá wà láàyè, ọmọ rẹ̀ náà sì wà láàyè
|
Agbé fọ́, omi sì tún dànù
| 1 |
yo
|
Ìyá kú, ọmọ náà sì tún kú
|
Ìyá wà láàyè, ọmọ rẹ̀ náà sì wà láàyè
|
Tagbè tomi ló ń mí
| 0 |
yo
|
Ṣe ohun ńlá bí ohun kékeré?
|
Ṣe ohun kékeré bí ohun ńlá?
|
Ṣeyán bí ọkà?
| 1 |
yo
|
Ṣe ohun ńlá bí ohun kékeré?
|
Ṣe ohun kékeré bí ohun ńlá?
|
Fìka tótọ́símú remú
| 0 |
yo
|
Iṣẹ́ tí ó rọrùn ni iṣẹ́ yìí
|
Iṣẹ́ tí ó le gan ni iṣẹ́ yìí
|
Iṣẹ́ fẹran jẹ̀kọ ni iṣẹ́ yìí
| 0 |
yo
|
Iṣẹ́ tí ó rọrùn ni iṣẹ́ yìí
|
Iṣẹ́ tí ó le gan ni iṣẹ́ yìí
|
Àpáàrà ni iṣẹ́ yìí
| 1 |
yo
|
Wọ́n ti fìyà jẹ Adéwùmí
|
Wọ́n ti dá Adéwùmí lọ́lá
|
Wọ́n ti ṣọkọ fún Adéwùmí
| 1 |
yo
|
Wọ́n ti fìyà jẹ Adéwùmí
|
Wọ́n ti dá Adéwùmí lọ́lá
|
Wọ́n ti fòrí pa Adéwùmí
| 0 |
yo
|
Ìbùkún máa ń fi nǹkan tọrọ
|
Ìbùkún máa ń tọrọ nǹkan
|
Ìbùkún lawọ́
| 0 |
yo
|
Ìbùkún máa ń fi nǹkan tọrọ
|
Ìbùkún máa ń tọrọ nǹkan
|
Ìbù̀kún háwọ́
| 1 |
yo
|
Àyìnlá ń gbádùn ara rẹ̀ n’Ílọrin
|
Àyìnlá ń jẹ ìyà ní Ìlọrin
|
Àyìnlá ń jayé orí ẹ ní Ìlọrin
| 0 |
yo
|
Àyìnlá ń gbádùn ara rẹ̀ n’Ílọrin
|
Àyìnlá ń jẹ ìyà ní Ìlọrin
|
Àyì̀nlá ń mu gaàrí ní Ìlọrin
| 1 |
yo
|
Sàláwá wùwà àrínfín sí ọ̀gá rẹ̀
|
Sàláwá wùwà àpọ́nlé sí ọ̀gá rẹ̀
|
Sàláwá wo ọ̀gá ẹ̀ lójú
| 1 |
yo
|
Sàláwá wùwà àrínfín sí ọ̀gá rẹ̀
|
Sàláwá wùwà àpọ́nlé sí ọ̀gá rẹ̀
|
Sàláwá gbórí fún ọ̀gá rẹ̀
| 0 |
yo
|
Àwọn ohun tí a ní ti tán
|
Àwọn ohun tí a ní ti pọ̀ síi
|
Àwọn ohun tí a ní ti fìdíjálẹ̀
| 1 |
yo
|
Àwọn ohun tí a ní ti tán
|
Àwọn ohun tí a ní ti pọ̀ síi
|
Àwọn ohun tí a ní ti wà ní ìlọ́po ìlọ́po
| 0 |
yo
|
Rọ́pò kò lè bóbìnrin lòpọ̀
|
Rọ́pọ̀ lè bá obìnrin lòpọ̀
|
Ẹṣin inú ìwé ni Rọ́pò
| 1 |
yo
|
Rọ́pò kò lè bóbìnrin lòpọ̀
|
Rọ́pọ̀ lè bá obìnrin lòpọ̀
|
Ẹsin orí ilẹ̀ ni Rọ́pọ̀, ó lè fàdí ya
| 0 |
yo
|
Àdìó jẹ ìyà
|
Àdìó jẹ ìgbádùn
|
Àdìó fọwọ́ fọ̀nná
| 1 |
yo
|
Àdìó jẹ ìyà
|
Àdìó jẹ ìgbádùn
|
Àdìó fọwọ́ láyin
| 0 |
yo
|
Bímpé ti dé ipò tí a kò ti lè ṣe ìpalára fún un
|
Bímpé ti dé ipò tí a ti lè pa á lára
|
Ọwọ Bímpé ti tẹ ẹ̀kù idà
| 0 |
yo
|
Bímpé ti dé ipò tí a kò ti lè ṣe ìpalára fún un
|
Bímpé ti dé ipò tí a ti lè pa á lára
|
Èèrà abẹ́ bàtà ni Bímpé
| 1 |
yo
|
Àdìsá pàdánù ohun ńlá kan
|
Àdìṣá rí ohun ńlá gbà
|
Òkété bórù mọ́ Àdìsá lọ́wọ́
| 1 |
yo
|
Àdìsá pàdánù ohun ńlá kan
|
Àdìṣá rí ohun ńlá gbà
|
Àdìsá ki Òkété lọ́rùn
| 0 |
yo
|
Ó kú lánàá
|
Ó yè lánàá
|
Ó ta tẹ́ru nípàá lánàá
| 1 |
yo
|
Ó kú lánàá
|
Ó yè lánàá
|
O délé ayé lánàá
| 0 |
yo
|
A ti dárí ji Tọ́pẹ́
|
A ti fìyà jẹ Tọ́pẹ́
|
A ti fàwé ẹ̀ṣẹ̀ Tọ́pé ya
| 0 |
yo
|
A ti dárí ji Tọ́pẹ́
|
A ti fìyà jẹ Tọ́pẹ́
|
A ti ṣíwèé ẹ̀ṣẹ̀ fún Tọ́pẹ́
| 1 |
yo
|
Má fi tipátipá mú mi sọ̀rọ̀
|
Mo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ mú un sọ̀rọ̀
|
Má pọ́ mi nífun ò
| 0 |
yo
|
Má fi tipátipá mú mi sọ̀rọ̀
|
Mo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ mú un sọ̀rọ̀
|
Má fi gògóńgò mií lẹ̀ o
| 1 |
yo
|
Ó ti ṣe àṣìṣe
|
Ó ti ṣe àṣepé
|
Ó ti tasẹ̀ àgẹ̀rẹ̀
| 1 |
yo
|
Ó ti ṣe àṣìṣe
|
Ó ti ṣe àṣepé
|
O kọsẹ̀ báre
| 0 |
yo
|
Ẹ jẹ́ ká fi ipá mú un
|
Ẹ jẹ́ ká fi ẹ̀lẹ̀ mú un
|
Ẹ jẹ́ ká fúnná mọ́ ọn
| 1 |
yo
|
Ẹ jẹ́ ká fi ipá mú un
|
Ẹ jẹ́ ká fi ẹ̀lẹ̀ mú un
|
Ẹ jẹ́ pẹ̀rọ̀ síi
| 0 |
yo
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.