text
stringlengths 23
128
| clean_label
stringclasses 7
values | clean_label_id
int64 0
6
| noisy_label
stringclasses 7
values | noisy_label_id
int64 0
6
|
---|---|---|---|---|
Texas shooting: Ọlapàá ní Seth Ator tó pa ọ̀pọ̀ èèyàn ní Texas ṣẹ̀ṣẹ̀ pàdánù iṣẹ́ rẹ̀ ni | world | 0 | nigeria | 1 |
Open Treasury Portal: APC ní ètò tó ń ṣàmójútó ìnáwó ẹ̀ka ìjọba yóò gbógunti ìwà àjẹbánu | politics | 4 | nigeria | 1 |
2019 Election: Ta ni olùdíje gómìnà l‘Ogun, Kashamu àbí Adebutu? | politics | 4 | politics | 4 |
Ìgbàjọba Seyi Makinde: Hosea Agboọla, Bisi Ilaka wà lára ọmọ ìgbìmọ̀ | politics | 4 | nigeria | 1 |
2019 Election Update: Ìgbìmọ̀ ìgbẹ́jọ́ fún Atiku láyè láti ṣàyẹ̀wò ohun èlò ìdìbò ààrẹ | politics | 4 | politics | 4 |
2019 elections: INEC ní káàdì ìdìbò 15,000 táwọn ọ̀daran jó ní iléeṣẹ́ INEC kò leè dáwọ́ ìdìbò dúró | politics | 4 | politics | 4 |
Naira Marley: Ẹ̀kọ́ rèé fáwọn Marlians tó pa iléẹ̀kọ́ tì, tí wọn ń fa ṣòkòtò sílẹ̀ kiri | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
NIgeria 2019 Election: INEC gba òṣùbà káre lórí àṣeyọrí ìdìbò | politics | 4 | politics | 4 |
Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè: A kan sáárá sí ìpínlẹ̀ Eko fún sísọ èdè Yorùbá di dandan nílé ẹ̀kọ́ | nigeria | 1 | world | 0 |
Iléesẹ́ ológun Nàìjíríà bẹnu àtẹ́ lu ìwádìí Amnesty International | world | 0 | world | 0 |
Poly Ibadan: Lóòtọ́ ni a dáná sún fóònù àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ṣe màgòmágó nínú ìdánwò | nigeria | 1 | world | 0 |
Sleeping at work: Ǹjẹ o yẹ kí èèyàn máa sùn lẹ́nu iṣẹ́? | entertainment | 6 | world | 0 |
Champions league: Lẹ́yìn tó fìdírẹmi ní Spain, Ṣé Liverpool ṣì leè yí ojú ayò padà ní Anfield? | sport | 3 | sport | 3 |
Oyo Algon: Agbẹjọ́rò ìjọba Ọyọ ní Makinde kò tí ì rí ìwé ìpẹ̀jọ́ | politics | 4 | nigeria | 1 |
Headies Award: Orinkórin ni Naira Marley ń kọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Oman ń ṣelédè lẹ́yìn Sultan Qaboos bin Said | world | 0 | world | 0 |
Jesus in Kenya:Ta ni ọkùnrin tí wọ́n ń pè ní ayédèrú Jesu yìí gan an? | africa | 5 | world | 0 |
Iléeṣẹ́ ọmọogun Nàìjíríà ní fídíò tó ti pẹ́ ní fídíò ọmọogun tí kò fẹ́ kojú Boko Haram | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Wòlíì bá obìnrin 300 lò pọ́, ó gba ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n ọ́dún 19 | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
DR Congo Ebola: Òṣìṣẹ́ ìlera méje kú torí ibínú àwọn èèyàn nípa Ebola | health | 2 | health | 2 |
Ẹgbẹ́ agbésùnmọ̀mí IS yọ Al-Barnawi ọmọ olùdásílẹ̀ Boko Haram nípò gẹ́gẹ́ bíi adarí ISWAP | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ibrahim El-Zakzaky: 'Ó ṣeésẹ kí El-Zakzaky máa lọ òkè òkun fún ìtọ́jú mọ́' | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Osun Election 2018 : Ilé ẹjọ́ ní Adeleke kò lẹ́tọ̀ọ́ láti díje dupò gomina | politics | 4 | politics | 4 |
Ìwádìí kan ní Ilééṣẹ́ Facebook leè mọ ìgbà tí àwọn tó wà lójú òpó wọn bá ní ìbálòpọ̀ | world | 0 | nigeria | 1 |
Buhari, Saraki, PDP, Obaseki àti àwọn èèkàn ṣelédè lẹ́yìn Anenih | politics | 4 | politics | 4 |
Ethiopian Airline crash: Àbájáde ìwádìí ọkọ̀ bàálù Ethiopia wẹ awakọ̀ bàálù mọ̀ ọ́ | africa | 5 | africa | 5 |
Cyclone Idai: Ààrẹ Mozambique ní òun rí ọ̀pọ̀ òkú tó lé téńté lórí odò | africa | 5 | nigeria | 1 |
Osinbajo: Àwọn àwòrán bí mó ṣe ń bá Buhari sọ̀rọ̀ ni wọ́n rí bíi pé inú ń bí mi | politics | 4 | politics | 4 |
Genotype test: Ilé aṣòfin kàn án nípá fáwọn tó fẹ́ ṣèyàwó láti ṣàyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀ | health | 2 | health | 2 |
Ex Boko Haram: Àwa ọmọ ẹgbẹ́ Boko Haram kan kìí kírun, à ń mu ìmukúmu, a sì ń ṣe ṣìná | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Lizzy Anjorin: Kò sí òṣèré tíátà lóbìnrin tó ní dúkìá jù mí lọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
PDP: Bí ìjọba Buhari se gbẹ́sẹ̀ lé owó Peter Obi, aya àti ẹ̀bí rẹ̀ kò bójúmu | politics | 4 | politics | 4 |
Olóòtú ìjọba Abiy ni awọn obìnrin kìí hùwà jẹgúdújẹrá tó àwọn ọkùnrin | africa | 5 | africa | 5 |
Election Update 2019: Àwọn ohùn tó yẹ kí ẹ mọ nípa Oloriegbe tó rọ́pò Saraki | politics | 4 | politics | 4 |
Robert Mugabe: Awọn olori orilẹ́èdè àgbáyé ṣèdárò akọni tó lọ | africa | 5 | africa | 5 |
Collapsed Building: Ẹ̀mí kankan kò bọ́ nínú ilé míràn tó wó ládugbó Kakawa l'Eko | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
2019 Elections: Níbo la bá ètò ẹ̀kọ́ dé? | politics | 4 | nigeria | 1 |
Kano Sharia Police: Ènìyàn Kano ọgọ́rin lo ti wà látìmọ́lé nítorí wọn jẹun nínú ààwẹ̀. | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Xenophobia: Àbọ̀ ààrẹ Muhammadu Buhari rèé láti ilẹ̀ South Africa | africa | 5 | africa | 5 |
Presidency: Kí ló dé tí Ààrẹ Buhari tún ń dá àwọn tó fúnrarẹ̀ yọ nípò pàdà | politics | 4 | politics | 4 |
Coronavirus: Àjọ WHO ní àìsàn pàjáwìrì gbogbo àgbaye ló dé yìí | health | 2 | health | 2 |
Ekiti: Lẹ́yìn ààwọ òṣèlú, gómìnà Ekiti méjì fẹ̀rín pàdé ara wọn | nigeria | 1 | politics | 4 |
Àwọn ọmọ Yorùbá wo ni mínísítà ní ìjọba Buhari? | politics | 4 | nigeria | 1 |
Melaye: Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá tún ka ẹ̀ṣùn mẹ́sàn-án mọ́ Dino lọ́rùn | politics | 4 | politics | 4 |
Tani Kingsley Moghalu, ọ̀dọ́ tó fẹ́ jẹ ààrẹ? | politics | 4 | politics | 4 |
Ijora-Wharf bridge: Ìjọba àpapọ̀ ṣí afárá Ijora-Wharf lẹ́yìn àtúnṣe | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Komla Dumor Award 2020: BBC ń wá ìràwọ̀ akọ̀ròyìn tí yóò sọ ìtàn Áfíríkà | africa | 5 | entertainment | 6 |
Oyedepo: Nàíjíríà kò ní pẹ́ bọ́ lọ́wọ́ ọrọ̀ àjé tó mẹ́hẹ, ìfìyàjẹni | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Naira Marley gba àṣẹ onídúró nílé ẹjọ́ pẹ̀lú mílíọ́nù méjì náírà | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Queen's College: Ohùn tó yẹ kí ẹ mọ nípa akọni Efunjoke Coker | entertainment | 6 | world | 0 |
Nigeria Election Update: 'Ilé iṣẹ́ DSS kò mú òṣìṣẹ́ INEC kankan lórí ẹ̀sùn Atiku' | politics | 4 | politics | 4 |
Imo Supreme Court: Fada Mbaka kéde pé ẹ̀mí mímọ́ ti kọ Ihedioha bíi gómìnà Imo | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
MC Oluomo: Àánú ni mo rí gbà láti di alága NURTW Eko | nigeria | 1 | world | 0 |
Oluwo: Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi ni yóò ṣẹlẹ̀ sí ẹni tó bá sọ̀rọ̀ takò mí | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
NLC Kwara-Iṣẹ́ tí èèyàn kò bá tí ṣé, kò yẹ kó gba owó rẹ̀ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Adeboye: Ìkìlọ̀ mẹ́ta tí àgbà ìjọ fi síta nínú ìwàásù f'áwọn Pásítọ̀ ọ̀dọ́ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ìjàmbá Kwara: Isẹ́ ìdárò ń wọlé sọ́dọ̀ ìjọba Kwara | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Muhammadu Buhari: Ààrẹ Nàìjíríà gba Saudi lọ sí ìlú London nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì | world | 0 | politics | 4 |
Àwọn olówó Naijiria 5 tí owó wọn ju owó ìsúnná Naijiria lọ! | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ikoyi Prisons: Iléeṣẹ́ Ọgbà ẹ̀wọ̀n ní kí wọ́dà mẹ́jọ lọ rọ́ọ́kún nílé lórí ikú ẹlẹ́wọ́n márùn ún l'Eko | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
ÌP&ID: Ẹgbẹ́ àgbáríjọpọ̀ ajàfẹ́tọ̀ọ́ fẹ̀hónú hàn l'Abuja lórí ìdájọ́ tó gbẹ́sẹ̀ lé $9.6bn ohun ìní Nàìjíríà | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ìtàn Mánigbàgbé: Adebisi Idikan ni olówó tó kọ́kọ́ ra ọkọ̀ nílẹ̀ Ibadan | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Eid-el Kabir: Aisha Buhari lọ Hajj pẹ̀lú ìyàwó Ààrẹ Niger, Senegal, Gambia | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Yoruba Films: Àwọn òṣèré tíátà Yorùbá ọkùnrin tí ó rẹwà | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ile Asofin Eko: Ọjọ́ Kẹrin oṣù Kejì ni Ambọde yóò yọjú síwájú ilé | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Naira Marley: Ilé ẹjọ́ ní Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Wo àwọn ohun tó yẹ kóo mọ̀ nípa ajọ àwọn gomina Naijiria | politics | 4 | nigeria | 1 |
PDP South West: Ọ̀rọ̀ ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ìjọba tó pòórá kìí ṣe ìṣẹ̀lẹ̀ àfojúfò | politics | 4 | nigeria | 1 |
Asòfin Kenya fẹ́ fi òfin de isó yíyà nínú ọkọ̀ bàlúù | africa | 5 | nigeria | 1 |
Àwọn ọ̀dọ́ ẹ̀yà Hausa kan àtàwọn ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn 'Awawa boys' da ìgboro Eko rú | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ibadan Circular Road- Ilé aṣòfin ní ìṣẹ́ 5.5% ni agbaṣẹ́ṣe ṣe lọ́nà olóbìrípo láti 2017 | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Soapy', àwo orin tuntun Naira Marley tó ń milẹ̀ tìtì | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Tax evasion: Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó pariwo pé 4.8 mílíọ́nù èèyàn ló ń sá fún owó orí sísan | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Taa ni Haleemat Busari tí yóò ṣe igbákejì Jimi Agbaje? | politics | 4 | entertainment | 6 |
NUT ní àìsí àbò ń ṣàkóbá fún àwọn olùkọ́ ní Nàìjíríà | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Meghan and Harry: Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ọmọ ọba tí wọ́n fẹ́ bí | world | 0 | world | 0 |
Iná Ibadan: Àwọn olùgbé inú ilé ń rawọ́ ẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Whatsapp: Àwọn gbéwiri s'àtakò sí Whatsapp, yára ‘Update’ rẹ̀ | world | 0 | nigeria | 1 |
Ogun PDP; Wàhálà tó n wáyé lórí ẹni tí yóò dúpò gómìnà kò tí ì d'ópin | politics | 4 | politics | 4 |
Ọjọ kẹsan an, oṣu kẹfa ọdun 2019 lo yẹ ki saa wọ́n wà sópin | politics | 4 | world | 0 |
Apapa gridlock: Ìjọba àpapọ̀ ní òun kò ní gbà kí wọ́n ba ọrọ̀ ajé ilẹ̀ yìí jẹ́ | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Ekiti: Ìjọba ti iléeṣẹ́ rẹ́díò Fayose pa nipinlẹ Ekiti | politics | 4 | nigeria | 1 |
Bayelsa Attack: Ọ̀gá ọlápàá fọnmú pé kí wọn ṣàwárí àwọn ọ̀daràn tó pa ọlọ́pàá | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Bola Tinubu Colloquium: Tinubu kìlọ̀ fún Buhari lórí ohun tó leè ṣàkóbá fún sáà kejì rẹ̀ | politics | 4 | politics | 4 |
South West Security: Ọlọ́pàá Ogun àti Ọ̀ṣun ni àwọn kò lọ́wọ́ nínú àjọṣepọ̀ ọ̀hún | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Cameroon: Àṣírí èèyàn kan tó dìbò ní ìgbà 89 tú, Ọlọ́pàá gbé e jàǹtò! | africa | 5 | world | 0 |
Russia-Africa summit: Wo àdéhùn méje tí Buhari ṣe pẹ̀lú ilẹ̀ Russia | world | 0 | world | 0 |
Polio: Bàbá kọ abẹ́rẹ́ àjẹsára kí ọmọ rẹ̀ tó ní àìsàn polio! | health | 2 | health | 2 |
Fayoṣe: Gómìnà Fayemi kò nílò ẹjọ́, torí àti ṣe ohun ti ìjọba àná kò leè ṣe ní wọ́n fi dìbò fún un | politics | 4 | politics | 4 |
Surety - Àwọn kan n ṣe onídùró gẹ́gẹ́ bi okòówò | nigeria | 1 | world | 0 |
Rehab Homes: Ọmọdébìnrin kan sọ bí òun ṣe di ẹ̀rọ ìbálòpọ̀ níbùdó aláìgbọràn | nigeria | 1 | world | 0 |
Cosmic Crisp apple: kò le bàjé nínú ẹ̀rọ amóhun tutù fún ọdún kan | entertainment | 6 | world | 0 |
Ìgbìmọ̀ ìgbẹ́jọ́ ìdìbò ààrẹ kọ ẹ̀bẹ̀ ẹgbẹ́ PDP láti yẹ ojú òpó ayélujára INEC wò | politics | 4 | politics | 4 |
Oluwo: Ìgbà mẹ́rin rèé tí ọ̀rọ̀ Oluwo ti Iwo dá awuyewuye sílẹ̀ | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
Oluwo Divorce: Yàtọ̀ sí Olúwó, wo àwọn Ọba alayé tó ti kọ ìyàwó láìpẹ́ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Àwòrán Amosun, Adekunle àti Buhari tó n dá awuyewuye sílẹ̀ | politics | 4 | politics | 4 |
Cultural Burial: Ìdí táwọn ènìyàn South Korea ṣe ń sin èèyàn láàyè! | world | 0 | entertainment | 6 |
Ekiti state: Nítoríi fóònù ìbánisọ̀rọ̀, géńdé méjì kú sínú u kọ̀ǹga l'Ékìtì | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
COZA: Lẹ́yìn ìwadìí PFN ni CAN tó leè sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀sùn tí wọ́n fi kan Fatoyinbo | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Nigeria vs Netherlands: Àtilẹ ló yẹ kí ìjọba ti máa mu ìdàgbàsókè bá eré bọ́ọ̀lù-Onigbinde | sport | 3 | sport | 3 |
Subsets and Splits