nomiracl / data /yoruba /topics /test.relevant.tsv
nthakur's picture
added initial training data and script
9ca02d1
raw
history blame
34.1 kB
10494#0 ọdun wo ni wọn pa funsho william?
10773#0 osu meloo ni oyun ma n lo nínú ikun obinrin ?
10981#0 Ki ni oruko ibilẹ ilu Port Harcourt?
11043#0 ipinlẹ wo ni gbenga Daniel ti jẹ gomina?
11172#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Burkina-Faso?
11296#0 Ki ni oluilu Bangladesh?
11435#0 Odun wo ni Nwankwo Kanu da pọ mọ Arsenal?
11775#0 Ki ni orukọ iyawo Babatunde Fasola?
11810#0 Ki ni oluilu orile ede Bulgaria?
12525#0 Ki ni oluilu orile ede Hungari?
12957#0 bawo ni sau Paulo ṣe jinna tó sí Rio De Janeiro?
12971#0 Ki ni orukọ ọmọ anọbi Idris ninu Kurani?
13297#0 ọmọ orílé ede wo ni Bill Gates ?
13307#0 orile-ede meloo ni o wa ni Europe?
13310#0 kini oluilu orile-ede Paraguai?
13342#0 Kí ni oluilu orile-ede El Salvador?
13361#0 Ta ni o da ile iṣẹ Innoson silẹ?
13541#0 Awon odun wo ni won ma n se ni orile-ede Bhutan?
13590#0 Orisi kemika wo lo wa?
13690#0 Ki no won ma n fi kemika iodine ṣe?
13760#0 iru awon eja wo ni eeyan le ri ninu odo?
13883#0 Orile ede wo ni Cape Town wa ?
13915#0 kí ni oluilu ipinle Akwa-Ibom?
14163#0 eya mélòó lo wa ni orile-ede Naijiria?
14498#0 Iṣẹ wo ni Sunday Igboho n ṣe?
14515#0 Ede meloo ni won so ni orile-ede Benin?
14681#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin awọn Giriki aye ijọun ati awọn ara Egypt?
14745#0 Orile-ede wo lo ni NASA?
14767#0 ọdún wo ni wọn dá NASA silẹ?
14783#0 Odun wo ni wọn pari ogun agbaye ikeji?
14787#0 Odo wo lo gun ju ni orile-ede Liberia?
14810#0 ọdún wo ni ọkọ ofurufu kọkọ tẹ'do sí Naijiria?
14826#0 ogagun wo lo ṣe aṣáájú àwọn ologun Biafra ni odun 1967?
14874#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa?
14970#0 awọn nkan wo lo lè fa ijamba ọkọ ofurufu?
15062#0 Ki ni oluilu ipinle akwa ibom?
15084#0 Ki ni oluilu orile ede Tonga?
15086#0 Orile ede meloo lo wa ni NATO?
15099#0 Orile ede wo ni ilu Alexandria wa?
15101#0 Ki lo pa Alan Turing?
15121#0 Iwe wo ni Immanuel Kant kọ?
15197#0 Iwe wo ni Ibn Battuta kọkọ kọ?
15241#0 Onimo mathematiki wo lo gbe Algebra jade?
15252#0 awọn ẹbun wo ni Roald Engelbregt gba ?
15256#0 Ibasepo wo lo wa laarin ede Latini ati ede geesi?
15265#0 Ta ni oba orile ede Bahrain?
15309#0 ara ìlú wo ni mama to bi Muritala muhammed?
15317#0 ki ni iye eeyan ti o wa ni abule Aliyu Amba ni Ethiopia?
15325#0 ẹgbẹ agbaboolu wo ni Kelechi Iheanacho wa pẹlu?
15335#0 Orile ede wo ni wọn bí Kamaru Usman sí?
15349#0 iru sistemu ìjọba wo ni wọn lo ni fransi?
15367#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni David Mark wa pẹlu?
15374#0 Egbe oselu wo ni Nicolas Sarkozy wa pẹlu?
15444#0 mosalasi wo lo tobi julo ni orile-ede Algeria?
15498#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Albania?
15511#0 Omo orile ede wo ni Kevin Durant?
15517#0 ọdún wo ni Hubert Ogunde da ilé iṣẹ tíátà rẹ silẹ?
15596#0 Omo orile ede wo ni Cheikh Diop?
15629#0 ọdun wo ni wọn kọkọ ṣe komputa?
15734#0 ilé iṣẹ radiio wo ni Tolu Oniru n ba ṣiṣẹ?
15777#0 Ṣe orile-ede Bhutan wa ni Asia?
15783#0 Ṣe orukọ Potugiisi ni Silva?
15787#0 Ki ni oluilu Burkina Faso?
15805#0 ọdun wo ni orile ede Kongo gba ominira?
15807#0 ipo wo ni Adolphe Muzito je labe ijoba Joseph Kabila?
15808#0 Ilu wo ni won bi Rafael Nadal si?
15809#0 ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede kroatia?
15810#0 ile iṣẹ oniroyin wo ni Toke Makinwa wa pẹlu?
15819#0 Awọn orile-ede wo lo sunmo Djibouti?
15822#0 Awọn Orile-ede wo lo wa ni Soviet union?
15833#0 Kini iyatọ laarin awọn ara Ethiopia ati Eritrea?
15847#0 Osu wo ni odun keresimesi bọ si?
15868#0 Ilu wo ni agabọọlu Pepe n gba bọọlu fun?
15882#0 obinrin alawọ dudu wo lo kọkọ yege idije Miss World?
15884#0 ọdun wo ni agbani darego yege idije Miss World?
15892#0 Iṣẹ wo ni ọkọ Omotola Jalade n ṣe?
15898#0 Ki ni wọn n pe ni Eurasia?
15909#0 Ede wo ni won sọ ni orile-ede Ireland?
15919#0 Eeyan meloo lo n ṣe ẹsin kristeni ni orile-ede Jordan?
15922#0 Kí ni ìtúmò Karim ni ede lárúbáwá?
15954#0 Awọn ede wo ni wọn sọ ni Kuwait yatọ si Larubawa?
15970#0 Ara ilu wo ni Hans-Adam?
15974#0 ọdun wo ni a ma n ṣe ni oṣu December?
16001#0 kí ni olu-ilu orile-ede norway?
16005#0 Orile-ede wo lo fẹ ju lo ni Europe?
16007#0 Ipinle wo ni Ilu Gbongan wa?
16009#0 Ta ni Aarẹ ikẹta orile-ede United States of America?
16019#0 Kilọọbu wo ni agbabọọlu Robert Lwandowski n gba bọọlu fun?
16238#0 orile ede wo ni Ilu Madrid wa?
16281#0 Ta ni iyawo Bill Clinton?
16288#0 Awọn orile-ede wo ni wọn ti n sọ ede faranse ni Afirika?
16297#0 Èdè wo ni àwọn ará orile ede Nepal n sọ?
16299#0 Ọmọ orílé èdè wo ni akọrin Peter Tosh?
16312#0 Ki ni orukọ iyawo Muhammad Ali?
16365#0 Ẹgbẹ wo ni agbaboolu ti a mọ sí Roberto Carlos bá gbá bọọlu gbẹhin kí ó tó fẹ̀hinti?
16373#0 Omo orile-ede wo ni onimo mathematiki Carl Friedrich?
16376#0 kí ni iye eniyan to wa ni orile ede switsalandi?
16382#0 Odun wo ni won bere ogun orile-ede Siria?
16391#0 ta ni ààrẹ akọkọ orílé èdè Togo?
16407#0 Odun wo ni Sultan Muhammadu Maccido ku?
16426#0 ara ìlú wo ni oludasile Google ti a mọ sí Sergei brin?
16427#0 Odun wo ni won bi onisowo Efunroye Tinubu?
16479#0 Ta ni ààrẹ orile-ede Ethiopia?
16656#0 awon apa ijoba meloo lo wa?
16664#0 Ilu wo lo tobi julo ni ipinle Anambra?
16727#0 Odun wo ni Samuel Peter ba Vladmir Klitschko ja?
16770#0 Ki ni oruko bibi alawada Frank Donga?
16781#0 Ki ni oluilu ipinle Ondo?
16798#0 Odun wo ni Ekiti ati Ondo ya sọtọ?
16801#0 Awon ẹya wo lo wa ni ilu Ẹlẹmẹ?
16861#0 ilu wo lo tobi julọ ni ipinlẹ rivers?
16956#0 Tani Philip Efiong ja fun ni Ogun Biafra?
17021#0 Omo ilu wo ni Ngozi Nwosu?
17024#0 Ipo oselu wo ni Lamidi Adesina di mu gege bi oloselu ?
17206#0 Omo ipinle wo ni Lateef Adedimeji?
17214#0 Gomina meloo lo wa ni orile-ede Naijiria?
17238#0 Bawo ni oju ojo se ma n ri ni ipinle Enugu?
17258#0 Tani gomina ipinle Ekiti?
17287#0 ṣe wọn ni epo ni ipinlẹ rivers?
17323#0 ilu wo lo tóbi jù lọ ní ipinlẹ ebonyi?
17325#0 Ki ni kapitaali ipinle Ebonyi?
17372#0 kí ni orúkọ ọba sultan ilu sókótó?
17476#0 Ọdun wo ni awọn ologun gba ijọba ni Naijiria?
17478#0 Ṣe papa ọkọ ofurufu wa ni Ipinle Enugu?
17485#0 Se Ile Ibo ni ipinle Enugu wa?
17518#0 Ede wo ni awon ara Imo n sọ?
17534#0 Lábé ìjọba aare Naijiria wo ni àwọn òṣìṣẹ́ ti ṣe àtakò occupy Nigeria?
17539#0 kí ni olú ìlú ipinlẹ Rivers ?
17558#0 Awon ile iwe wo lo wa ni agbegbe orumba?
17559#0 Ki ni olu-ilu ipinle Anambra?
17589#0 Ta ni ọba wọn ni Ilẹ Sokoto?
17600#0 Ta ni Sultan Sokoto ni odun 2003?
17612#0 Ọdun melo ni Shehu Shagari lo lori Aleefa?
17644#0 Ta ni gomina ipinle Sokoto?
17658#0 Ki ni itumo Enugu ni ede Igbo?
17695#0 Ta lo kọkọ jẹ Sultan ipinlẹ Sokoto?
17758#0 Awon esin wo lo gbajumọ ni orile-ede jemani?
17820#0 Ipo wo ni agbabọọlu Thomas Muller n gba fun Bayern Munich?
18094#0 Ta ni obinrin to kọkọ gba ebun nobel?
18226#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni ipinlẹ Ogun?
18307#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Olabisi Onabanjo wa?
18308#0 Odun wo ni Oladipo Diya je gomina ipinle Ogun l'asiko ijoba ologun?
18321#0 ati orile-ede wo ni pasta ti wa ?
18356#0 Awon eranko wo lo wa ni Australia?
18357#0 Awon orile-ede wo ni o wa ni Melanesia?
18397#0 Odun wo ni Fidel Castro kuro lori aleefa?
18519#0 Orile ede wo ni odo Amazon wa?
18548#0 Orile-ede wo ni ilu Houston wa?
18560#0 Ta ni Aare orile-ede Amẹrika?
18574#0 orile ede wo ni awọn elesin onigbagbo pọ si ju lọ?
18581#0 Orile ede wo ni Ras Al Khaimah wa?
18607#0 Ki ni olu ilu ipinle cross river?
18640#0 Ta ni ààrẹ Orile ede Tajikistan?
18642#0 kí ni oluilu orile ede Peru?
18665#0 Iru owo wo ni won na ni orile-ede Morocco?
18667#0 Odun wo ni orile ede Mozambique gba ominira?
18668#0 ọdun wo ni orile-ede Mozambique gba ominira?
18705#0 awon ipinle wo ni won yọ jáde lati ipinle gongola?
18809#0 Iru ounjẹ wo ni wọn ma n jẹ ni ipinle Akwa Ibom?
18839#0 Awon eya meloo lo wa ni orile-ede Nigeria?
18859#0 Ilu wo ni won bi Serena Williams si?
18964#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Ibrahim Shekarau wa pẹlu?
19044#0 Ọdun wo ni wọn kọkọ ṣe iwari epo ni ipinlẹ Bayelsa?
19071#0 Ki ni oluilu ipinle kebbi?
19115#0 Ki ni oluilu ipinlẹ Niger?
19133#0 Odun wo ni Musilliu Haruna Ishola kọ soyoyo?
19232#0 Iyawo meloo ni Solomon fẹ ninu bibeli?
19245#0 Odun wo ni Aminu Tambuwal di gomina Sokoto?
19270#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin awọn Taliban ati Pakistan?
19408#0 Lati igba wo ni won ti n jagun ni orile-ede South Sudan?
19535#0 Ki ni oruko aare orile-ede Italy?
19661#0 Omo odun meloo ni Mike Tyson nigba to kọkọ gba oye heavyweight?
19971#0 Orile-ede wo ni ilu Dar es Salaam wa?
19976#0 Omo ilu wo ni Hassan Minhaj?
19977#0 Ise wo ni Benjamin Franklin ṣe?
20007#0 Ki ni awọn kan ti eeyan le ṣe ni Zanzibar fun isinmi?
20022#0 ede meloo ni won so ni orile-ede tanzania?
20041#0 Awon orile ede wo lo yika Tanzania?
20221#0 orile-ede wo ni a mo gẹgẹ bii Giant of Africa?
20240#0 Egbe agbaboolu wo ni agbaboolu Fernando Torres koko gba boolu fun?
20252#0 Kí ni iye èèyàn dúdú ti ó wà ní orílé èdè Brazil?
20255#0 nọmba wo ni a le pe ti a ba wa ninu ìṣòro?
20338#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Thomas Edison?
20440#0 Se Tibet sunmo orile-ede China?
20453#0 Ki ni asia orile-ede Morocco?
20467#0 Kí ni àwọ àsìá Orile ede Pakistan ?
20523#0 Ede meloo ni wọn so ni orile-ede Pakistan
20573#0 Kí ni orúkọ ilé ìjọsìn David Oyedepo?
20581#0 Awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni ọdun 1920?
20647#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin Michael Jackson ati Janet Jackson ?
20685#0 ile iwe eko giga wo ni Donald Trump ti jade?
20692#0 Akowe wo lo kọ iwe Arrow of God?
20772#0 Odun wo ni Ogun Agbekọya bẹrẹ?
20782#0 Kí ni oluilu ipinle Jigawa?
20982#0 ìyàwó mélòó ni osama bin Laden fẹ́?
21005#0 ọdún wo ni orile-ede Senegal gba ominira?
21115#0 Kí ni oluilu orile-ede Macedonia?
21197#0 Ki ni oluilu orile ede Albania?
21425#0 èdè wo ni àwọn ará Papua n sọ?
21498#0 Erekusu wo lo tobi ju lọ ni agbaye?
21520#0 Nibo ni ipinlẹ Enugu ni awọn oyinbo ti kọkọ ri eedu?
21578#0 Olukowe wo lo kọ iwe Jagua Nana?
21580#0 Ọdún wo ni ẹlẹsẹ Samuel Peter ba Klitschko ja?
21582#0 Ọdún mélòó ni Ike Ibeabuchi lo lẹ́wọ̀n?
21583#0 Ilu wo ni won bi Jaja Wachuku si?
21666#0 Ọmọ ipinle wo ni Uche Jombo?
21904#0 Odun wo ni orile ede Colombia gba ominira?
21915#0 Odun wo ni Ronald Reagan jẹ gomina California?
22000#0 Eya meloo lo wa ni orile-ede Uganda?
22034#0 Yunifasiti wo ni Bill Gates ti kàwé ?
22043#0 Ki ni Iṣẹ igbakeji aarẹ?
22066#0 kí ni orúkọ ọkọ Maria sharapova?
22133#0 Esin wo lo gbajumo ju lo ni orile-ede Ireland?
22144#0 Ki ni oluilu orile ede Uganda?
22218#0 Awọn orile-ede wo lo sunmọ Italy?
2230#0 Odun wo ni akọwe Adebayo Faleti bere si sise pelu WNTV?
22470#0 Awon orisi jeometri wo lo wa?
22498#0 Ta ni olori ẹgbẹ al-kaida?
22501#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa?
22521#0 owo korensi wo wọn n ná ní orílé èdè Pakistan?
22522#0 Awon ipinle wo lo tobi julo ni orile-ede Amerika?
22525#0 Odun wo ni won bi oṣere Samuel Jackson?
22532#0 Oke wo lo ga ju ni orile-ede Australia?
22553#0 Ta ni o n je Edward Blyden?
22562#0 Se orile-ede Griisi dara?
22595#0 Ilu wo ni George Washington ṣe Aarẹ fun?
22654#0 Olorin wo lo ni okiki ju ni orile-ede Griisi?
22677#0 Orile ede wo ni ilu Athens wa?
22802#0 Ta ni o gba ẹbun Nobel fun litireṣọ ti ọdun 2016?
22860#0 esin wo ni John Maxwell n ṣe?
2291#0 ta ni Onkowe to ko iwe "The art of war'?
22917#0 Ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Jemani?
22955#0 Aarẹ wo ni Afrika lo fi'ra ẹ jẹ Field Marshall
23142#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Argentina?
23186#0 Orile ede wo ni agbaboolu Roberto Carlos gba bóòlù fún?
23245#0 Awon eya wo lo tobi ju lọ ni orile-ede sierra leone?
23551#0 ọdún wo ni Carl Pauling gba ẹbun Nobel?
23562#0 Omo orile ede wo ni Karl Marx?
23567#0 elo ni wọn san fún àwọn tí wọn bá gba ẹbun Nobel ?
23599#0 Bawo ni orile-ede Kanada ṣe tobi to?
23647#0 Kí ni oluilu orile-ede Switzerland?
23706#0 Ilu wo ni won bi Maurice Bishop si?
23712#0 ilu wo ni won bi Joseph Stalin si?
23732#0 Ara ilu wo ni ẹlẹṣe felix trinidad?
23845#0 Ta ni eni to kọkọ lọ si space?
24197#0 Ki ni orukọ bibi Akọrin Afrika Bambaata?
24311#0 èdè wo ni wọn sọ ni orile-ede thailand?
24335#0 ta ni Alakoso ilu dubai ?
24910#0 Awọn ọunje wo lo da fun ilera ati alaafia?
25182#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré Taiwo Hassan ?
25231#0 Awọn òpìtàn wo lo kọ nípa ìtàn Nàìjíríà?
25394#0 Awọn ẹya meloo lo wa ni orile-ede kongo?
2567#0 Ede wo ni won so ni orile-ede Afghanistan?
25674#0 ọdún wo ni asiwaju Bola Tinubu kọkọ jẹ gomina ipinle Eko?
2571#0 elo ni wọn ta oruka ti ìgbéyàwó?
25763#0 ọdún wo ni Keshi di mọnija ẹgbẹ agbaboolu Naijiria?
25952#0 orile-ede wo ni agbaboolu Pele gba bọọlu fún?
25953#0 awon ere idaraya wo lo gbajumo ni orile-ede Naijiria?
2598#0 ṣe ede larubawa ni wọn n sọ ni orile-ede Algeria?
26004#0 Odun wo ni Augusto Pinochet fi aye silẹ?
26090#0 Aare Amerika wo lo da eru kiko duro?
26145#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo lo tóbi jù lọ ní orile ede Kroatíà?
26186#0 awọn orile ede wo ni àwọn komunisti pọ sí jù?
26190#0 Ara Ilu wo ni Rosa Luuxemburg?
26237#0 ọdún wo ni orile-ede Nàìjíríà di republiki?
26342#0 ki ni itumo keynesian economics?
26401#0 Ọdún wo ni Joseph Stalin fi ayé silẹ?
26468#0 Ilu wo ni won bi Alfred Hitchrock si?
26876#0 kí ni ìjọba Buhari ti ṣe fún ìdàgbàsókè orile-ede Naijiria?
27059#0 Ilu wo ni wọn bi Wilson Oruma si?
27063#0 Fiimu wo ni Chadwick Boseman kọ́kọ́ ṣe?
27067#0 Iwadi wo ni Sir George Thomson gbe jade?
2709#0 Odun wo ni DO Fagunwa kọ iwe Ogboju Ode?
27113#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Tinubu ati Fashola?
27120#0 ṣe lootọ ni wipe omi agbara lo gbe Metusela lọ?
27373#0 Ilu wo ni won bi Adam Smith si?
2741#0 Awọn onisayensi wo ni wọn wa lati orile-ede Armenia?
2749#0 Ki ni oluilu Andorra?
27746#0 Ipinle wo ni Phillip Edward Island wa ni Canada ?
27753#0 Odun wo ni Mohammad Abdus Salam gba ẹbun nobel?
27782#0 Ki ni oruko eni to kọkọ gba ebun nobel fun kemistri?
27802#0 kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti jack Dorsey da silẹ
27804#0 Ki ni oruko bibi olorin Roy Chicago?
27815#0 Ara ilu wo ni ẹlẹṣẹ Vitaly Klitschko?
28166#0 egbe oṣelu wo ni Barack Obama wa pẹlu?
28209#0 Ara ilu wo ni Ralph Lauren?
28404#0 ede wo ni won so ni orile-ede virgin islands
2853#0 Nibo ni Afirika ni Madagascar wa?
28626#0 Oṣu wo ni ọdun Easter bọ si?
28630#0 Ojo melo lo wa ninu oṣu Februrari?
28770#0 Ki ni anfani ogẹdẹ jijẹ?
2901#0 Ta ni eniyan akọkọ ninu bibeli?
29099#0 Awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni Ọdún 1975?
2925#0 awọn èdè wo ló ṣòro láti kọ́ jù?
29322#0 Awon iwe wo ni Henry James ko?
29343#0 Ise wo ni Ludwig Van Beethoven ṣe?
29350#0 Iwadi wo ni otto warburg ṣe to fi gba ebun nobel?
29601#0 Onimọ sayensi wo lo gbe alaye evolution jade?
29796#0 ọdun wo ni Bill Gates da ile-iṣe Microsoft silẹ?
2988#0 Orile ede wo ni won ti n so ede Bijago?
30023#0 Ile-ise wo ni Ezra Olubi da sile?
30046#0 ki ni iye eeyan alawodudu to wa ni orile-ede Argentina?
30054#0 Esin wo ni awọn Tuareg n ṣe?
30081#0 Olorin wo lo kọ orin "African Queen"?
30203#0 Ta ni o gba Ebun Nobel Fisiiksi odun 1999?
30205#0 Awon awari ati iwadi wo ni onimosayensi Albert Einstein gbe jade?
30208#0 ọdún wo ni Dominique Pire gba Ebun Nobel?
30242#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Morocco?
30365#0 Ọdun wo ni oṣere Jeff Bridges ṣe sinima "The Fisher King" ?
30366#0 Kí ni orúkọ inagijẹ onisowo orin Sean Combs ?
30369#0 Awọn ẹbun wo ni Jack Nicholson ti gba fún eré ṣíṣe?
30374#0 ọdún wo ni robert De niro bẹrẹ sí ṣe òṣèré?
30416#0 àwọn òṣèré wo lo ṣe fiimu "The avengers" ?
30459#0 Odun wo ni Josehine Baker fi aiye silẹ?
30516#0 Iwadi wo Baron de montesquieu gbe jade?
30579#0 Egbe agbaboolu wo ni Luis Figo ba gba gbehin ki o to fehinti?
30703#0 Ibaṣepo wo lo wa laarin Pakistan ati India?
31085#0 Tani Baba Jccob ninu Bibeli?
31331#0 Pilaneeti wo lo tobi ju ̀lọ?
3171#0 Ki ni olu ilu orile-ede Cameroon?
3178#0 Awon orile-ede wo ni won ti n so Yoruba yato si Naijiria?
32899#0 Iwe wo ni Umberto Eco kọkọ kọ?
32946#0 Ojise olorun meloo ni o wa ninu kurani?
32958#0 Ọdun wo ni wọn pari Ogun Biafra?
3327#0 iru kalẹnda wo ni àwọn ará Ethiopia n lo?
33282#0 Ki ni itumọ Homo Sapien?
3346#0 Ki ni iyatọ laarin "odd nomba" ati "even nomba"?
33463#0 ṣẹ alawọ dudu ni baba to bi Lewis Hamilton?
33519#0 Orile ede wo ni won bi Karl Marx si?
33566#0 Ta ni eni to koko gba ebun Nobel fun kemistri?
33568#0 Ile-ise iroyin wo ni Benjamin Franklin ba ṣiṣẹ gege bi akọwe?
3360#0 Ki lo de ti Imọ mathematiki ṣe le pupọ?
33626#0 Egbe agbaboolu alapere wo ni Kareem Abdul Jabbar gba fún?
33682#0 Eeyan meloo ni King Leopold pa ni orile-ede Congo?
33692#0 Ilu wo ni won bi onkowe Wiliam Shakespeare si?
33857#0 Omo orile ede wo ni Maria Sharapova?
33953#0 Awon awari sayensi wo ni John von Neumann gbe jade?
33976#0 Odun wo ni Joseph Stalin s'alaisi?
33997#0 ọdun wo ni wọn da orile-ede Amerika silẹ?
34094#0 Obinrin wo lo kọkọ jẹ adajọ ni orile-ede Naijiria?
34105#0 ipò wo ni Teslim Elias jẹ ni International court of justice?
34135#0 egbe agbaboolu afesegba wo ni Joachim low n gbe lọ si World Cup?
34138#0 Ki ni o fa iku Giordano Bruno?
34140#0 Omo orile-ede wo ni akowe Walter rodney?
34150#0 awọn àṣà wo ni a mọ yoruba fún?
3487#0 kí ni nọmba ọlọpa ti a le pe ta ba wa ninu ọrọ òjìji?
35524#0 Awon orile-ede wo ni Afrika ni awon somali wa?
35534#0 Odun meloo ni Freddie Ljumberg lo ni Arsenal?
35546#0 Ise wo ni Whoopi Goldberg n se?
35579#0 Ọdún wo ni Ronald Reagan jẹ ààrẹ Orile-ede Amẹrika?
35617#0 Ilu wo ni wọn bi Colin Powell si?
35909#0 ile ise rekoodu wo ni Barbra Joan wa pẹlu?
35915#0 Odun wo ni Diane Keaton bere si se fiimu?
35926#0 Awọn oṣere wo lo ṣe sinima "Black Panther" ?
35927#0 Ta ni ọkọ Laura Ikeji?
36817#0 Odun wo ni Bola Tinubu di Seneto?
36873#0 Iru orin wo ni Segun Adewale n kọ?
36877#0 Ta ni onilu Àlàmú Tatalo?
36889#0 iru orin wo ni Majek Fashek kọ?
36893#0 Ilu wo ni wọn bí Kelechi Iheanacho sí ?
36898#0 ile iṣẹ wo ni Peter Thiel da silẹ?
36940#0 Agbegbe wo ni Senator Abaribe n ṣe aṣoju fún?
37099#0 Ki ni Nnamdi Kanu n ja fun?
37133#0 Ki ni idi ti Suka Dimka ṣe fẹ pa Murtala?
37145#0 ọmọ mélòó ni òṣèré samuel jackson ni ?
37162#0 Ki ni orukọ owo ti wọn na ni orile ede Spain?
37171#0 Ki ni oluilu orile-ede spain?
37182#0 Awon ilu wo lo tobi ju lọ ni Spain?
37197#0 orile ede wo ni ilu San Francisco wa?
37202#0 Awọn oloṣelu wo lo gba ominira fun orile-ede Ghana?
37245#0 ọdún wo ni orile-ede venezuela gba ominira?
37271#0 Ilu wo ni won bi Crristobal Hurtado si?
37276#0 Awon nkan ilẹ adayeba wo ni won ni ni orile-ede Venezuela?
37479#0 Odun wo ni oṣere Moses Olaiya fi aiye silẹ?
37591#0 orile-ede wo ni arturo Vidal n gba bọọlu fún ?
37653#0 ọdun wo ni George washington ṣ'alaisi?
37671#0 Odun wo ni George Bush di Aare orile-ede Amerika?
37697#0 Ilu wo ni won bi Alexander the Great si?
37738#0 ọdún wo ni Colin Powell fi ayé silẹ?
37773#0 Iwari wo ni Albert Einstein gbe jade?
37854#0 awọn òṣèré wo lo ṣe fiimu "black panther" ?
37991#0 ọdún wo ni ẹlẹsẹ ti a mo si oscar De la hoya ba Floyd Mayweather ja?
38035#0 Kini oluilu orile-ede Paraguay?
38050#0 ṣe awọn eeyan alawọ dudu wa ni orile-ede Trinidad?
38051#0 Ki ni koodu orile-ede Trinidad?
38162#0 Agbegbe ijjọba Ibilẹ wo ni Desmond Elliot n ṣe aṣoju fun?
38221#0 Ki ni oluilu orile-ede Belarusi?
38541#0 Oloselu wo lo ba MKO abiola dije ni ibo odun 1993?
38694#0 ipinlẹ wo ni wọn pe ni bendel tẹlẹ?
42261#0 Planeti meloo lo wa?
4410#0 Iru aso wo ni awon Yoruba ma n wọ?
44432#0 Ọdun wo ni ẹlẹṣẹ Buster Douglas ba Mike Tyson ja?
47009#0 Odun wo ni awon onimosayensi se awari 141 Lumen?
48503#0 ọdun wo ni Thutmose jẹ Farao ni ilu Egypt?
51063#0 bá wo ni àwọn Yorùbá ṣe má ń ṣe ọsẹ dúdú?
5126#0 Ki ni orukọ ọọni Ile Ifẹ?
5223#0 Ọdún wo ni Adesoji Aderemi jẹ Ọọni Ile Ifẹ?
53626#0 orisa wo ni orisa ibeji?
53718#0 Odun wo ni Chang Myon je Minisita orile-ede Korea
53740#0 Kí ni oluilu orile-ede Kenya?
53823#0 Iwadi wo ni Dan Shechtman se ti o fi gba ebun Nobel?
53830#0 Odun wo ni Bruce Lee se fiimu "Enter the dragon" ?
53881#0 Ilu wo ni won sin Octave Mirbeau si?
53890#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Corey Booker wa pẹlu?
5392#0 Odun wo ni Olagunsoye Oyinlola di gomina Osun?
53994#0 Ta ni aare Egypti ni ọdun 2010?
54187#0 Kí ni orúkọ inagijẹ Andre Young ?
54188#0 Ki ni orukọ akọrin Curtis Jackson?
54270#0 Iṣẹ wo ni Rosa Parks ṣe?
54280#0 awọn Orile ede wo ni wọn ti n sọ Swahili?
54282#0 Kontinenti wo ni orile-ede Komoro wa?
54445#0 akọwe wo lo kọ iwe Harry potter?
5452#0 Orile-ede wo ni Ásíà ni a ti le ri amọtẹkun?
54886#0 ẹkọ wo ni a le mu lo lati aye Jésù kristi?
55034#0 Ta ni o pa Martin Luther King?
55084#0 Ta ni ẹni to da ile iṣẹ Space X silẹ?
55585#0 Awon oloselu wo lo wa lati ipinle Jigawa?
55834#0 Odun wo ni Nelson Mandela kuro ni ẹwọn?
55868#0 Ede meloo ni won n so ni Ghana?
55988#0 Iwadi wo ni Isaac Newton gbe jade?
58427#0 ki ni idi ti ede igala fi jo ede Yoruba?
58461#0 Ounjẹ wo ni awọn South Afrika fẹran ju lọ?
58469#0 Ede wo lo l'okiki ju lọ ni Afrika?
58528#0 Iṣẹ wo ni Margaret Etim n ṣe?
58529#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Russia?
58543#0 Ta ni ààrẹ orile-ede Saina?
58608#0 Odun wo ni Sam Amuka Pemu da ile iṣẹ iroyin Vanguard silẹ?
58616#0 ọjọ wo ni idije olympiki to n bọ ma bọ sí?
58639#0 ilu wo lo kere jù lọ ní orílé-ede fransi?
58653#0 Akorin wo lo kọ "Billie Jean" ?
58689#0 Odun wo ni wọn bi Elon Musk?
58694#0 ki ni oruko ilé iṣẹ ti Andy Rubin da silẹ?
58699#0 Ilu wo ni a bi agba oṣere Robin Williams si?
58921#0 awọn ẹranko wo lo wa ni ipinlẹ Florida?
58949#0 Awon orile ede wo ni Afrika ni won n sọ ede French?
59044#0 Odun wo ni jelena jankovic fehinti?
59086#0 Awọn akewi wo ni wọn wa lati orile-ede Romania?
59095#0 orile-ede wo ni ilu Fort Murray wa?
59165#0 ẹya mélòó lo wa ni orile-ede Kroatíà?
59166#0 awọn orilẹ-ede wo lo sunmọ Australia?
59178#0 Ki lo fa ogun ti Russia ati Ukraine?
59204#0 ilu wo ni won bi Tommy Haas si?
59313#0 Odun wo ni Sloane Stephens yege US open?
59530#0 Odun wo ni Gloria Macapagal di aare orile ede Fillipines?
59623#0 Awon iwadi wo ni onimo sayensi Stephen Hawking gbe jade?
59694#0 Ki ni itumo elimenti ni imo sayensi?
59736#0 awọn wo ló dá ẹgbẹ ọmọ oduduwa sí lẹ̀?
59753#0 iru metali wo ni aluminiomu?
59787#0 Orisi elimenti wo lo wa ?
59878#0 oríṣi atomu wo ló wà?
59915#0 ọdun wo Saddam Hussein ṣe alaisi?
59947#0 Ati orile ede wo ni Reggae ti wa?
60024#0 ilu wo ni wọn bí onkọwe Franz Fanon sí?
60031#0 Iru orin wo ni John Lennon kọ?
60037#0 ìwé wo lo ṣe pàtàkì jù lọ laarin gbogbo iwe ti Walter Rodney kọ?
60042#0 Awon orile ede wo lo sunmo Rọṣia?
60106#0 Ki ni orukọ inagije Charles Olumọ?
60131#0 Ise wo ni Jackie Aina n ṣe?
60184#0 Ilu wo ni wọn bi Serena Williams si?
60316#0 Egbe oloselu wo ni Doug Ford wa pẹlu?
60324#0 òṣèré wo lo ṣe fiimu Jẹnifa?
60349#0 ẹgbẹ agbaboolu alapere wo ni Kobe Bryant gba bọọlu fún gbẹhin?
60417#0 Ki ni oju ọjọ ni Ilu Florence?
60477#0 Egbe agbaboolu wo ni Ambrose Vanzekin n gba bọọlu fun?
60493#0 Onkowe wo lo kọ Harry Potter?
60527#0 Abala OPC wo ni Frederick Fasheun da silẹ?
60529#0 Odun wo ni agbaboolu Ji Sung Park fehinti?
60571#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Isaac Newton?
60709#0 Omi adagun meloo lo wa ni ipinlẹ Minnesota?
60756#0 Ilu wo ni won bi Nicki Minaj si?
60761#0 Odun wo ni Christopher Colombus se iwadi Amerika?
60767#0 ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ redio Lagos silẹ?
60777#0 ọmọ ìlú wo ni Linda Ejiofor?
60828#0 Ara ilu wo ni olusare Noah Lyles?
60879#0 Ọdún wo ni ẹlẹsẹ James Toney bá Samuel Peters jà?
60893#0 ọmọ meloo ni Serena Williams bi?
60980#0 Yunifasiti wo ni Akọwe Wọle Ṣoyinka ti kawe?
61045#0 àwọn akọrin wo lo wa lati orile-ede Korea?
61165#0 Ki ni orukọ iyawo ti Efrem Zimbalist kọkọ fẹ?
61169#0 Ọmọ mélòó ni Eve bi fún Adam ?
61172#0 Ki ni inagijẹ Dwayne Carter ?
61180#0 òṣèré wo lo ṣe fiimu True Lies?
61239#0 agbaboolu wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede bulgaria?
61243#0 Ki ni awọ asia orile ede Naijiria?
61249#0 Ọdún wo ni wọn bí òṣèré Sofia Vergara?
61257#0 iru owo wo ni wọn ná ní Bulgaria?
61344#0 Kí ni ìtúmò Safari ni ede Swahili?
61412#0 Odun wo ni Telifisan kọkọ de Naijiria?
61423#0 ọdun wo ni wọn bi aarẹ Muhammadu Buhari?
61442#0 Awon ile iwe ẹkọ giga wo lo wa ni Santiago?
61517#0 ogun wo ni èèyàn lè lo fún àrùn malaria?
61676#0 Ta ni o da iwe iroyin El Marino silẹ?
61771#0 kí ni a mọ ilu Salamanca fun?
61775#0 kí ni o ma n fa àrùn onígbáméjì?
61798#0 ki ni o ma n fa arun ti a mo si atọsi?
61829#0 ki ni o ma n fa arun Onchocerciasis?
61835#0 Odun wo ni Cassius Clay yi oruko si Muhammed Ali?
61876#0 Erekusu wo ni Wakiki wa?
61880#0 erekusu wo lo tobi ju lo ni agbaye?
61882#0 Orile ede wo ni Tenerife wa?
61928#0 oríṣi mọ́tò wo ló wà?
61930#0 orisi ẹfọri wo lo wa?
61950#0 Orile ede wo ni ilu Hachinohe wa?
61975#0 Ki ni idi ti won se n pe Chile ni orile-ede awon Akewi?
62011#0 Bawo ni Moscow se jinna to si Saint Petersburg?
62015#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ?
62016#0 Oogun wo ni eeyan le lo lati fi pa kokoro?
62130#0 Ki ni orukọ iyawo Will Smith?
62168#0 Iye eniyan meloo lo wa ni orile-ede Scotland?
62175#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ?
62183#0 Egbe agbaboolu afesegba wo ni Paolo maldini gba boolu fun?
62192#0 Ẹbun fiimu mélòó ni Stephen Spielberg ti gba ?
62194#0 Awọn akọwe ni wọn wa lati Vienna?
62218#0 kí ni ìdí tí alangba ṣe ma n mi'ri?
62227#0 Ki ni idi ti alangba ṣe ma n mi ori?
62229#0 awon eya wo ni won ma n je Edikan Ikong?
62231#0 Iru alangba wo ni Geico?
62257#0 ki ni itumo enzyme?
62295#0 idile wo ni Awujalẹ Sikiru Adetona ti wá?
62300#0 ọdun wo ni wọn da ẹgbẹ PDP silẹ?
62388#0 Ki lo pa elere idaraya ti a mọ si Florence Joyner?
62397#0 Iru awon alangba wo lo wa ni Afrika?
62424#0 Awọn iṣoro wo lo wa gẹgẹ bi obinrin ni Naijiria?
62444#0 Odun wo ni Lateef Adedimeji bẹrẹ si ṣe fiimu?
62453#0 Awon aami wo lo ma n han wipe obinrin ti ni oyun?
62461#0 Awọn ounjẹ wo lo ni protein ninu ju?
62465#0 Ilu wo ni wọn bí akọrin Tyler the creator sí?
62569#0 Ere wo ni oṣere Jackie Chan kọkọ ṣe?
6536#0 Iru orin wo ni akọrin Wizkid n ko?
65712#0 Ilu wo ni wọn bi ẹlẹṣẹ Roy Jones si?
65763#0 kí ni oluilu orile-ede Gambia ?
65767#0 ẹya wo lo tóbi jù lọ ní orile ede Liberia?
65784#0 Awo meloo ni Sikiru Ayinde Barrister ṣe ki o to ku?
65791#0 ilu wo ni wọn ti n ṣe awọn ẹṣọ Calvin Klein?
65821#0 Kí ni oluilu orile-ede Bẹljiọm?
65842#0 ọdún wo ni akorin Victor Olaiya ṣ'alaisi
65851#0 Awọn oniṣowo wo lo gbajumọ laiye ijọun ni ilu Ibadan?
66015#0 Ki ni oruko iyawo rotimi akeredolu?
66019#0 Ki ni oluilu orile-ede Israeli?
66023#0 kí ni orúkọ ile-iṣẹ ti Richard Branson da silẹ?
66100#0 Ki ni oruko ile-ise tI Sean Combs da sile?
66110#0 Ipo wo ni Bamanga Tukur jẹ labẹ ijọba Sani Abacha?
66113#0 Ipinle wo ni Aliyu Wamakko ti jẹ gomina?
66120#0 Ipò Ajagun wo lo tobi ju lọ ní Naijiria?
66342#0 ounje wo ni awon Hausa fẹran ju lọ?
66435#0 Awo meloo ni olorin Adewale ayuba ti ṣe?
66437#0 ọmọ ilu wo ni Lawrence Anini?
66443#0 Elo ni ijọba n san fun awọn agbofinro?
66445#0 Ara Ilu wo ni Bimbo Akintola?
66562#0 Orile-ede wo ni agbabọọlu Gabriel Jesus n gba bọọlu fun?
66876#0 Awon tira wo ni Sheik Adam Al Ilory kọ?
66945#0 ọdún wo ni wọn pa Tafawa Balewa?
66987#0 ile iṣẹ wo ni Femi Otedola da silẹ?
67007#0 bawo ni moremi ṣe tú àṣírí àwọn ará Igbo?
67036#0 Alaafin Oyo wo ni a mo si Orompotoniyun?
67047#0 Goolu meloo ni Muda Lawal gba wole fun Naijiria?
67317#0 Ta ni ẹni to kọ fiimu Ovy's voice?
67362#0 Odun wo ni 9ice gbe awo Gongo Aso jade?
67416#0 Ati ibo ni Aṣọ Ofi ti wa?
67527#0 Yunifasiti wo ni Funsho Williams ti kàwé?
67557#0 ile-ise wo ni Tara Fela-Durotoye da silẹ?
67562#0 Ọdún wo ni Wahab Folawiyo fi aiyé silẹ?
67610#0 Ki ni oluilu orile-ede Kenya?
67616#0 ọjọ wo ni Valentine bọ si?
67649#0 Odun wo ni won da OGBC silẹ?
67675#0 Awọn orile ede wo ni wọn ti n sọ Urdu?
67686#0 Awon irin ise wo ni akorin Prince lo?
67688#0 ọdún wo ni akọrin Fatai Rolling Dollar ṣ'àláìsí?
67760#0 Ilu wo ni won bi Immanuella Samueli si?
67764#0 Ọdún wo ni Chioma Ajunwa gba ẹbun ni ìdíje òlímpíkì?
67775#0 Ki lo pa Samuel Okwaraji?
67786#0 Odun wo ni Gbenga Daniel je gomina ipinlẹ Ogun?
67886#0 Ta ni ọba awọn ogu ni Badagry?
67907#0 Ki ni oruko iyawo Odunlade Adekola?
67942#0 Ipò wo ni Surajudeen Ajibola jẹ ni ipinlẹ Ọsun ?
67949#0 Ọdún wo ni Haruna Ìṣọ̀lá fi aiyé silẹ?
67956#0 yunifasiti wo ni gomina Dapo Abiodun ti kàwé?
67961#0 Odun wo ni olorin tupac shakur s'alaisi?
67991#0 ipo wo ni Robert Adeyinka je ni Western Region
68015#0 kí ni orúkọ ìyàwó Yemi Osinbajo?
68024#0 Ta ni Akran ilu Badagry?
68035#0 ilé iṣẹ wo ni Tony Elumelu da silẹ?
68047#0 Ọdún wo ni George Weah di ààrẹ orile ede Liberia?
68053#0 ọdún wo ni Bukky Wright bẹrẹ sí ṣe eré itage?
68058#0 Ta ni Baba Kunle Afolayan?
68059#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Gabriel ati Kunle Afolayan?
68234#0 Odun wo ni won da ile ifowoppamo Wema silẹ?
68240#0 Awon ile-ise wo ni Mark Zuckerberg da sile?
68242#0 Àwọn Gómìnà wo lo da ẹgbẹ amọtẹkun silẹ?
68250#0 awọn wo lo ko samuel crowther l'ẹ́rú?
68301#0 Kí ni èèyàn lè fi ata ṣọ̀mbọ̀ sè?
68376#0 Ipinle wo ni Samuel Ortom ti je gomina?
68427#0 kí ni olúìlú ìpínlẹ̀ Abia?
68435#0 Orile ede wo ni ilu Phoenix wa ?
68532#0 ta ni aṣoju agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Badagry?
68664#0 Ki ni o fa iku Tolulope Arotile?
68728#0 nibo ni abule faransé wa ni Badagry?
68737#0 Ki ni awon aami wipe eeyan ti ni ni arun Coronavirus?
68841#0 Ta ni oludari NCDC?
68861#0 Ọjọ meloo lo wa ninu oṣu Februrari?
68882#0 Odun wo ni Kemi Adetiba gbe fiimu King of Boys jade?
69261#0 Ile iroyin wo ni Aisha Falode ba ṣiṣẹ?
69404#0 Ki ni orukọ abisọ alakitiyan Malik El Shabazz?
69661#0 Ki ni orukọ abisọ Burna Boy?
69674#0 Ki ni a n pe ni pythagoras theorem ni Matimatiki?
69736#0 ati ilu wo ni COVID 19 ti kọkọ bẹrẹ?
69944#0 Ile-ise wo ni Bode Akindele da silẹ?
70088#0 olorin wo lo ko "African Queen" ?
70147#0 Fiimu wo ni Rahama Sadau ṣe pẹlu Ali Nuhu?
70174#0 ere mélòó ni òṣèré eniola ajao ti ṣe?
70219#0 Iṣẹ wo ni Sandra Ezekwesili ń ṣe?
70228#0 Awo meloo ni akọrin Tunde Nightingale ṣe ki o to fi aiye silẹ?
70236#0 Odun wo ni Mike Bamiloye da Mount Zion sile?
70240#0 Ki ni oluilu orile ede Morocco?
70265#0 Oye wo ni fi Gani Adams jẹ?
70287#0 ere wo ni Bukky Ajayi kọkọ gbe jade?
70355#0 Ara ìlú wo ni Ààfáà Muyideen Bello?
70363#0 Ta ni ọkọ Thelma Okoduwa?
70419#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Ahmadu Bello wa?
70433#0 Ise wo ni Margaret Etim n ṣe?
70450#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré tí a mọ sí Taiwo Hassan?
70460#0 Ile-iwe ko giga ẹwo ni Yvonne Orji ti ka'we?
70493#0 Ipo wo ni won fi Kemi Adeosun si labe ijoba Muhammadu Buhari
70503#0 Ilu wo ni won bi Agnes Osazuwa si?
70557#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Burkina?
70571#0 Omo ilu wo ni Mercy Johnson?
70576#0 Ipinle wo ni Ibrahim Shekarau ti jẹ gomina?
70598#0 ọdún wo ni Ogun àdùbí bẹrẹ?
70614#0 Odun wo ni Chioma Ajunwa yege ni idije olympiiki?
70629#0 Fiimu meloo ni Ini Ikpe ti ṣe?
70633#0 ọdún wo ni akọwe Frances Welsing fi aiyé silẹ?
70656#0 Orile ede wo ni Marina Niava to wa?
70693#0 Ọdún wo ni Leopold Senghor di ààrẹ orile-ede Senegal?
70713#0 Ta ni ọkọ Flora Shaw ki o to fi aiye silẹ?
70729#0 Ta ni o se oludari fiimu Mionga ki Obo?
70783#0 ọdún wo ni wọn bí Anọbi Muhammad?
70864#0 ipinle wo ni ilu Igboho wa?
70918#0 Ki ni orukọ inagije Temilade Openiyi?
70933#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Adeniran Ogunsanya bá ṣe?
70964#0 Odun wo ni Akiwunmi Ambode jẹ gomina ipinlẹ Eko?
70974#0 Ta ni o da ile iṣẹ Mainframe silẹ?
70993#0 ipò ìjọba wo ni Femi Adesina wa labẹ ijoba Aare Buhari?
70994#0 Orile ede wo lo yege idije World Cup ti 2006?
71068#0 Awọn nkan wo ni wọn fi n ṣe Baba Ghanoush?
71092#0 Awo wo ni Temi Dee kọkọ gbé jade?
71178#0 Ipinle wo ni Ayodele Fayọse ti ṣe gomina?
71200#0 Ọdún wo ni Ezra Olubi da ilé iṣẹ Paystack silẹ?
71202#0 Iṣẹ wo ni Tiwalola Olanubi n ṣe?
71220#0 yunifasiti wo ni denrele ti kàwé?
71252#0 ki ni anfani ere idaraya?
71280#0 Ta ni ọkọ Naa Ashorkor?
71282#0 Ọdún wo ni ọgbẹni Rauf Aregbesola jẹ gomina ipinlẹ Ọsun?
71307#0 ọdún wo ni Michael Jackson gbe awo Thriller jáde?
71352#0 konsonanti mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá?
71424#0 Odun wo ni Oluwaseun Osewa da Nairaland silẹ?
71511#0 oṣu wo ni odun 1999 ni Olusegun Obasanajo di Aarẹ orile ede Naijiria?
71529#0 Odun wo ni Vivica Fox bẹrẹ si ṣe ere itage?
71554#0 Odun wo ni Facebook ra Whatsapp?
71569#0 Odun wo ni arun coronavirus bẹrẹ?
7183#0 orile ede wo ni odo mississipi wa?
7208#0 Ọjọ mélòó ló wà nínú oṣù Dìsẹ́mbà?
7523#0 Kí ni orúkọ abisọ Kwame Ture?
8837#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?