raw_text
stringlengths
2
128k
biyi bandele biyi bandele ọjọ́ kẹtàlá oṣù ọ̀wàrà ọdún 1967 ni wọ́n bí i tí ó sì kú ní ọjọ́ kejè oṣù ògún ọdún 2022 òǹkọ̀wé àti òṣeré ọmọ nàìjíríà ni ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ìtàn àròsọ ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú the man who came in from the back of beyond ní ọdún 1991 bákan náà ni ó kọ àwọn eré onísẹ́ kí ó tó wá gbájúmọ́ fíìmù ṣíṣe àkọ́já ewé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí dárí ni half of a yellow sun ní ọdún 2013 tí ó jẹ́ ìwé ìtàn àròsọ chimamanda ngozi adichie ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ yorùbá ni àwọn òbí bandele ìlú kafancha ní kaduna ni wọ́n bí i sí ní ọdún 1967 bàbá rẹ̀ solomon bandele-thomas jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ tí ó ṣe ìpolongo burma ní ogun àgbáyé kejì nígbà tí naijiria ṣì wà lábẹ́ àkóso àwọn bìrìtìkó ọdún méjìdínlógún àkọ́kọ́ ìgbésí ayé ni bándélé lò ni àárín-gbùngbùn àríwá orílẹ̀èdè kí ó tó wá lọ sí ìlú èkó ní ọdún 1987 ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré onísẹ́ ni yunifásítì ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ilé - ifẹ̀ ó kọ ìwé ìtàn àròsọ rẹ̀ àkọ́kọ́ ó gbégbá orókè nínú idije international student playscript ní ọdún 1989 pẹ̀lú iṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n kò tẹ̀ jáde rain kí ó tó gba àmì ẹ̀yẹ british council lagos award ní ọdún 1990 fún àkójọpọ̀ ewì ó lọ sí ìlú london ní ọdún 1990 ní ọmọ ọdún méjìlélógún pẹ̀lú ìwé iṣẹ́ ìtàn srosoyrẹ̀ méjì wọ́n tẹ àwọn ìwé rẹ̀ jáde royal court theatre sì fún ní ní ọdún 1992 ó gba àmì ẹ̀yẹ arts council of great britain writers bu bursar ithenáti tẹ̀síwájú nínú ìwé kíkọ rẹ̀ iṣẹ́ iṣẹ́ kíkọ bándélé kó àkóyawọ́ lórí ìtàn àròsọ tíátà ìròyìn tẹlifíṣàn fíìmù àti rédíò ó siṣẹ́ pẹ̀lú royal court theatre àti iléeṣé royal shakespeare bákan náà ló kọ iṣẹ́ dírámà orí rédíò àti fíìmù fún tẹlifíṣàn lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni rain marching for fausa 1993 resurrections in the season of the longest drought 1994 two horsemen 1994 tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí eré tí ó peregedé jùlọ ní london ní ọdún 1994 death catches the hunter àti me and the boys tí wọ́n tẹ̀ jáde nínú fọ́lọ́mù kìn-ín-ní ọdún 19951995 àti oroonoko aphda behn èyí jẹ́ ìṣe àtúndá ìwé náà adaptation ní ọdún 1997 ó ṣe àṣeyọrí ìwé chinua achebe things fall apart gẹ́gẹ́ bí dírámà àwọn ìtàn brixton bandele ṣe iṣẹ́ àtúndá ìwé ìtàn àròsọ tara rẹ̀ the street sí eré ìtàgé the street ní ọdún 1999 tí wọ́n fi lọ́lẹ̀ ni ọdún 2001 premiered in 2001 tí ó sì jáde nínú fọ́lọ́mù kìn-ín-ní àti eré onísẹ́ rẹ̀ happy birthday mister dekaand was published in tí ó gbé jáde ní 1999 bákan náà ni ó ṣe iṣẹ́ àtúndá lorca yerma ní ọdún volume with 2001 ó siṣẹ́ olùkọ́ òǹkọ̀wé pẹ̀lú iléeṣé tíátà talawa ni odun 1994 sí 1995 bákan náà ló ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀ǹkọ̀tàn eré onísẹ́ pẹ̀lú royal national theatre studio ní ọdún 1996 ọmọ ẹgbẹ́ wilson ni kọ́lẹ́jì churchill yunifásítì cambridge ní 2001 bákan náà ló kópa gẹ́gẹ́ bí royal literary fund resident playwright ni tíátà bush ní ọdún 2002 sí 2003 bandele ti kọ lórí ipa tí iṣẹ́ john osborne - back in anger lórí rẹ̀ tí ó rà ní san-án díẹ̀ díẹ̀ ní ojú irin ní apá àríwá nàìjíríà ikú bandele kú ní ìlú èkó ní ọjọ́ kejè oṣù ògún ọdún 2022 ni ọmọ ọdún mẹ́rinléláàdọ́ta okùnfà ikú rẹ̀ kò tíì di mímọ̀ àkójọpọ̀ ìwé àkójọpọ̀ fíìmù
charles bodunde charles bodunde je olukowe omo ile naijiria
john pepper clark nigerian poet and playwright 19352020 john pepper clark-bekederemo ojoibi april 6 1935 tosi ku ni ọjọ mẹtala óṣu october ọdun 2020 je olukowe omo ile naijiria arakunrin naa ni órukọ rẹ ma njade nigba toba kọ iwè gẹgẹbi jp clark ati john pepper clark igbesi ayè arakunrin naa john ni a bisi kiagbodoilú naigiria fun baba rẹ to jẹ ọmọ ilè ijaw ati iya rẹ to jẹ ọmọ ilẹ urhobo nigba ti arakunrin naa jade lati ilè iwè giga ti ibadan ni ó ṣiṣẹ gẹ̀gẹbi officer ti information ni ministry ti information ati research fellow ni institute ti imọ ẹkọ ilẹ africa ni ilè iwè giga ti ibadan ni ọdun 1982 john ati iyawó rẹ ẹbun odutola professor ati óludari tẹlẹ ri da theatre ti pec repertory silẹ ni ilú eko clark ku si ilè iwosan to wa ni eko ni ọjọ kẹkatala óṣu october ni ọdun 2020 ẹkọ clark lọsi ilè iwè native authority ni okrika ni ijọba ibilẹ ti burutu ilè iwè ti ijọba ni ughelli lẹyin ló tẹsiwaju lọsi ilè iwè giga ti ilú ibadan lati kẹẹkọ lọri imọ ede gẹẹsi arakunrin naa fun aimoyè ọdun lóti jẹ professor ti èèdè gẹẹsi ni ilè iwè giga ti eko to si fẹyinti ni ọdun 1980 clark tigba ipó professor ni ilè iwè giga ti yale ati wesleyan ni ilú united states ami ẹyẹ ati idanilọla clark gba ami ẹyẹ ti national order of merit ti ilẹ naigiria lati ọdọ ilè iwè giga ti howard lóri iwè rẹ the ozidi saga ati akójọpọ ere ati ewi lati ọdun 1958-1988 ni ọjọ kẹfa óṣu december ni ọdun 2011 ni ayẹ ayè professor john pepper clark pẹlú ayẹyẹ to waye ni ikoyi ni ọdun 2015 ni awọn ọdọ ólukọwè ti ilẹ naigiria labẹ akoso wole adedoyin da ẹgbẹ jp clark ti literay lati igbè iṣẹ clark larugẹ
olumbe bassir olumbe bassir je olukowe omo ile naijiria
folasayo dele-ogunrinde folasayo dele-ogunrinde 1968 - 2013 je olùkọ̀wé ati awọn ẹya òṣeré omo ile naijiria
umaru dembo umaru dembo je olukowe omo ile naijiria
philip effiong philip efiong also spelled effiong november 18 1925 november 6 2003 je omo ologun to tifeyinti lati ile-ise ajagun oripapa naijiria ati ikan ninu awon asagun orile-ede biafra alaisimo nigba ogun abẹ́lé nàìjíríà nigba to di igbakeji aare ile biafra si odumegwu ojukwu ati aare ile biafra fun ojo marun leyin ti ojukwu salo efiong ni eni ti o teriba biafra fun naijiria
michael echeruo michael joseph chukwudalu echeruo tí wọ́n bi ni ọjọ kẹrinla oṣù kẹta ọdún 1937 je olukowe ọjọgbọnalariwisi awọn iwe lítíréṣọ̀ ọmọ ìlú umunumo ìjọ́bá ehime-mbano ipínlè imo ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
cyprian ekwensi cyprian ekwensi jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ cyprian odiatu duaka ekwensi jẹ́ ọmọ ilẹ̀ ìgbò tí wọ́n bí sí ìlú minna ìpínlẹ̀ niger ọmọ bíbí ìlú nkwelle ezunaka ní ìjọba ìbílẹ̀ oyi ipinle anambra nàìjíríà bàbá rẹ̀ ni david anadumaka apàlọ́ àti ọdẹ aperin ekwensi lọ sí government college ní ìbàdàn ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ achimota college ní ghana àti iléẹ̀kọ́ ìmọ̀ ajẹmọ́-igbó ìbàdàn leyin náà ló ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ asọ́gbó fún ọdún méjì bákan náà ló lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ṣẹ́ yaba technical institute àti iléẹ̀kọ́ nípa oògùn ní ìlú èkó lagos school of pharmacy àti iléẹ̀kọ́ chelsea nípa oògùn ní yunifásítì ti london ó siṣẹ́ olùkọ́ ní kọ́lẹ́jì igbóbì igbóbì college ẹbí ekwensi fẹ́ eunice anyiwo wọ́n sì bí ọmọ márùn-ún pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọọmọ lára wọn ni cyprian ikechi ekwensi tí wọ́n sọ nù orúkọ bàbá bàbá rẹ̀ àti adrianne tí i ṣe ọmọọmọ tí ó dàgbà jù iṣẹ́ wọ́n yan ekwensi ní olórí ajẹmọ́-àwòmọ́ ní iléeṣé iroyin orílẹ̀èdè nàìjíríà nigerian broadcasting corporation bákan náà ni ẹ̀ka ìròyìn yàn án sípò ni àsìkò ìjọba olómìnira àkọ́kọ́ ó padà di olùdarí ẹ̀ka náà ó fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 1966 ṣáájú ogun abẹ́lé ó kó àwọn ẹbí rẹ̀ padà sí enugu bákan náà ló jẹ́ alága àjọ fún ìpolongo ìlú biafra ekwensi tí kọ ogúnlọ́gọ̀ àwọn ìtàn kéékèèké eré onísẹ́ fún rédíò àti tẹlifíṣàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ìtàn àròsọ pẹ̀lú àwọn ìwé ọmọdé ikú ekwensi di olóògbé ni ọjọ́ kẹrìn oṣù ọ̀wàrà ọdún 2007 ní niger foundation ní ìlú enugu níbi tí ó ti lọ ṣe iṣẹ́ abẹ fún àìsàn tí wọ́n kó sọ di mímọ̀ ẹgbẹ́ àwọn òǹkọ̀wé fẹ́ fún ní àmì ẹ̀yẹ ṣáájú ikú rẹ̀ wọn padà fi ṣe ìyẹ́sí fún un lẹ́yìn ikú rẹ̀ ìtọ́kasí cyprian ekwensi dies at 86 daily trust online 6 november 2007 retrieved 21 november 2007 nigeria today is like a yarn by cyprian ekwensi - the news 1 december 2021 retrieved 6 march 2022 adenekan shola 11 november 2007 prolific writer who chronicled modern life in west africa the new black magazine online retrieved 21 november 2007 gérard albert s 1986 european-language writing in sub-saharan africa john benjamins publishing company p 654 isbn 963-05-3834-2 cyprian ekwensi encyclopedia of world biography thomson gale chuka nnabuife 29 october 2009 authors convention begins in minna nigerian compass retrieved 9 november 2009permanent dead link ekwensi cyprian africana the encyclopedia of the african and african american experience running press 2003 pp 226227 isbn 0-7624-1642-4 gérard p 656 jagua nana's daughter michigan state university press archived from the original on 10 may 2007 retrieved 21 november 2007 ana plans post humous award for ekwensi the tide online rivers state newspaper corporation 11 november 2007 archived from the original on 17 july 2011 retrieved 21 november 2007
buchi emecheta nigerian writer buchi emecheta je olukowe omo ile naijiria ta bini óṣu july ọdun 1944 to si ku ni ọjọ kàrunlèèlogun óṣu january ni ọdun 2017 aràbinrin naa bẹrẹ si ni gbe ilẹ uk lati ọdun 1962 nibi to tin kọ lóri plays itan ati nipa awọn ọmọde ígbèsi àyè àràbinrin naa buchi emecheta ni à bini óṣu july ọdun 1944 si ilú eko fun alice okwuekwuhe emecheta ati jeremy nwabudinke awọn óbi arabinrin naa wa lati umuezeokolo ibusa ni ipinlẹ delta baba olukọwè naa jẹ óṣiṣẹ ti railway ati amọ ikan arabinrin naa wa lara ọmọ ẹgbẹ ti ilè british secretary advisory council race ni ọdun 1979 ni ọdun 1960 arabinrin naa fẹ sylvester onwordi to si bi ọmọ ọkunrin ati óbinrin onwordi lọsi ilè iwè ni ilú london ti emecheta ati awọn ọmọ rẹ si darapọ mọ ni ọdun 1962 larin ọdun mẹfa emecheta bi ọmọ mààrun ọmọ óbinrin mẹta ati ọmọ ọkunrin meji igbèyawó arabinrin naa koro to si kun fun jagidigan eleyi lo mu kuro lọdọ ọkọ rẹ to si awọn ọmọ rẹ dani ẹkọ nitóri ipó tiwọn fi awọn óbinrin sini awujọ aburó buchi ló kọkọ lọsi ilè iwè ṣugbọn lẹyin arọwa fub awọn óbi buchi ni ó to lọsi ilè iwè missionary ti awọn óbinrin lẹyin ọdun kan ni emecheta gba ẹkọ ọfẹ lati lọsi ilè iwè methodist ti awọn óbinrin ni yaba buchi gba bsc lori imọ sociology ni ọdun 1972 ni ilè iwè giga ti london lẹyin naa lo gba phd ni ilè iwè giga naa ni 1991 ami ẹyẹ ati idanilọla arabinrin naa gba idanilọla lóri literature rẹ to si gba ẹbun ti jock campbell ni ọdun 1978 fun iwè rẹ ti akọlè naa jẹ ẹrú óbinrin buchi wa lori magazine ti granta to da lóri awọn ólukọwè ọdọ to darajulọ ti ọdun 1983 buchi gba doctorate ta fi da lọla lori literature lati ọdọ ilè iwè giga ti farleigh dickinson ni ọdun 1992 ni óṣu september ọdun 2004 buchi wa ninu awóran ti a great day in london to da lóri awọn ólúkọwẹ alawọ dudu ati funfun to kopa ninu itẹsiwaju literature ti ilẹ british ni ọdun 2005 buchi ni a da lọlà obe lóri iṣẹ ribi ribi tó ṣè lori literature
olaudah equiano olaudah equianoc 1745 31 march 1797 jẹ́ ọmọ bíbí igbo tí wọ́n kó lẹ́rú nígbà okowò ẹrú igbèsi ayè àràkunrin naa equiano ni a bini essaka eboe ni ilẹ benin ni ọdun 1745 to si kere julọ ninu awọn ọmọ ti baba rẹ bi equiano ni awọn ọga rẹ ninu oko ẹru sọ ni lórukọ lèèmeji oun jẹ michael nigba to wa ninu ọkọ óju ọmi ti awọn ẹru to gbè lọ si ilẹ́ america atipè ẹni to ra lẹru lakọkọ sọ ni jacob mary guerin ati aburó rẹ to jẹ mọlẹbi fun ọgà to ra equiano lẹru kọ ni èdè gẹẹsi ni óṣu december ọdun 1762 pascal ta equiano lẹru fun captain james doran ti charming sally ni gravesend nibi to ti lọ si caribbean lẹyin naa ni montserrat ni islands ti leeward nibi ti wọn ti ta arakunrin naa fun robert king to jẹ olokowo ni caribbean ṣugbon to wa lati ilu philadelphia ni ọjọ keje óṣu april ọdun 1792 equiano fẹ sussanah cullen ni ilè ijọsin ti st andrew ni soham cambridgeshire ti wọn si bi ọmọ óbinrin meji anna maria 1793-1797 ati joanna 1795-1857 ti wọn ṣè iribọ ọmi ni church ti soham iyawó equiano susannah ku ni óṣu february ọdun 1796 ni ọmọ ọdun mẹrin lèèlọgbọn ọmọ óbinrin equiano agba ku ni ọmọ ọdun mẹrin ni ọdun 1797 ti wọn sin si church ti st andrew ni chesterton cambridge joanna vassa tọ jẹ ọmọ óbinrin keji ti equiano bi fẹ henry bromley ni 1821 ti wọn si awọn mejèèji si itẹ ti abney park ni stoke newington london equiano ku ni ọjọ kan lèèlọgbọn óṣu march ni ọdun 1797 ti wọn si sọ nipa iku rẹ ninu iwè iroyin ti ilẹ british ati america wọn si arakunrin naa si whitefield tabernacle ni ọjọ kẹfa óṣu april ọdun 1797 idanilọla óṣèrè lọkunrin ilẹ gambia louis mahoney ṣèrè lóri equiano ninu television ti bbc lori ijagbara ati ominira tita ati rira ẹru ni ọdun 1975 crater to wa ni mercury ni a sọ ni equiano ni ọdun 1976 ni óṣu november ọdun 1996 equiano society ni wọn da silẹ ni ilú london lati fi yẹ arakuneim naa si equiano ni ṣè afihan rẹ ninu ere agbelewó ti amazing grace lati ọdọ ólórin ilẹ senegal youssou n'dour ni ọdun 2006 ni óṣu july equiano ni church ti england yẹ si fun ijagbara ninu óminira tita ati rira ẹru ni ọdun 2008 ere equiano ni awọn ọmọ ilè iwè ti edmund waller mọ si telegraph hill lower park ni new cross ni ilú london ni ọdun 2022 cambridge yẹ equiano si pẹlu sisọ riverside bridge si equiano bridge ni ọdun 2022 ere agbelewó nipa igbesi aye olaudah equiano waye lati ọdọ radio ti bbc
rosemary esehagu rosemary esehagu je olukowe omo ile naijiria
femi euba femi euba je olukowe omo ile naijiria
chielozona eze chielozona eze je olukowe omo ile naijiria
vera ezimora vera ezimora je olukowe omo ile naijiria
macaulay oluseyi akinbami macaulay oluseyi akinbami je olukowe omo ile naijiria
aderinola richardson aderinola richardson je olukowe omo ile naijiria
daniel olorunfemi fagunwa
dan fulani dan fulani je olukowe omo ile naijiria
helon habila helon habila ojoibi 1967 je olukowe omo ile naijiria ti arakunrin naa gba ẹbun ti caine ni ọdun 2001 ígbèsi àyè àrakunrin naa helon habila ni a bini kaltungoipinlẹ gombe ilẹ naigiria ni ọdun 2002 habila lọsi ilú england ni ọdun 2002 ti arakunrin naa di fellow ti akọwè ilẹ africa ni ilè iwè giga ti east anglia ni ọdun 2005 chinua achebe pè habila lati di fellow rẹ akọkọ ni college ti bard lati óṣu july 2013 di óṣu june 2014 habila di fellow ti daad fellow ni berlin germany arakunrin naa ni wọn fi ṣè adajọ ninu ẹbun ti etisalat lori literature ni ọdun 2016 ẹkọ helen kẹẹkọ lóri èdè gẹẹsi ati imọ literature ni ilè iwè giga ti jos lẹyin naa lo ṣiṣẹ ólukọ ni ninu federal polytechnic ti bauchi ami ẹyẹ ati idanilọla ni ọdun 2000 ami ẹyẹ ti ẹgbẹ awọn ólórin ti ilẹ naigiria apapọ ewi ni ọdun 2001 ẹbun ti caine love poems ni ọdun 2003 ẹbun ti commonwealth awọn akọwè ti ilẹ africa waiting for an angel ni ọdun 2007 ẹbun ti emily clark balch the hotel malogo ni ọdun 2008 ami ẹyẹ ti library of virginia literary fun for fiction measuring time ni ọdun 2011 ẹbun ti commonwealth awọn akọwè oil on water ni ọdun 2012 ami ẹyẹ ti iwè orion oil on water ni ọdun 2020 ẹbun ti james tait black memorial travelers
uzodinma iweala uzodinma iweala ojoibi november 5 1982 je olukowe omo ile naijiria
jp clark
nkem nwankwo nkem nwankwo je olukowe omo ile naijiria
flora nwapa florence nwanzuruahu nkiru nwapa je olukowe omo ile naijiria
olu obafemi olu obafemi je olukowe omo ile naijiria
odia ofeimun odia ofeimun je olukowe omo ile naijiria
christopher okigbo christopher ifekandu okigbo 19301967 je olukowe omo ile naijiria
wole oguntokun wole oguntokun jẹ́ ònkọ̀wé adarí eré orí-ìtàgé agbẹjọ́rò àti oníṣẹ́ ìwé ìròyìnìwé ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà
ben okri ben okri obe frsl ojoibi 15 march 1959 je olukowe omo ile naijiria
kole omotosho bankole kole ajibabi omotoso 1943-2023 je olukowe omo ile naijiria
tess onwueme tess onwueme je olukowe omo ile naijiria
osonye tess onwueme
dennis osadebay dennis chukude osadebay june 29 1911—december 26 1994 je asiwaju tele agbegbe nigeria tele arin-apaiwoorun ati olukowe omo ile naijiria
niyi osundare niyi osundare bí ni ọjọ́ kejìlá oṣù ẹ̀rẹnà ọdún 1947 jẹ́ onímọ̀ èdè akéwì onísẹ́ lámèyítọ́ àti eléré onísẹ́ ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ nìyí ọ̀sundare jẹ́ aṣáájú akéwì nílẹ̀ adúláwọ̀ eléré-onísẹ́ onímọ̀ èdè àti onísẹ́ lámèyítọ́ ìlú ìkẹ́rẹ́ èkìtì ní apá ìwọ̀ oòrùn nàìjíríà ni wọ́n ti bí i ni ọjọ́ kejìlá oṣù ẹ̀rẹnà ọdún 1947 òrìṣà tó ò gún ewì rẹ̀ ni ewì alohùn nínú àṣà yorùbá rẹ̀ èyí ló jẹ́ kí ìwọ̀nùbọ̀nú wà nínú iṣẹ́ rẹ̀ àti àṣà ewì àgbáyé yòókù lára wọn ni ilẹ̀ adúláwọ̀ amẹ́ríkà amẹ́ríkà - látìnì éyísà àti yúróòpù ó táko ìdúnmokò mọ́ ọ̀rọ̀ sísọ bákan náà àwọn iṣẹ́ àtinúdá àti àròjinlẹ̀ ni ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ìjàǹgbara òṣèlú òmìnira àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn adúláwọ̀ àti agbègbè ó ti gba ọ́pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ lára wọn ni àmì-ẹ̀yẹ ewì ẹgbẹ́ àwọn òǹkọ̀wé orílẹ̀èdè nàìjíríà association of nigerian authors - ana àmì - ẹyẹ ewì commonwealth àmì ẹ̀yẹ ewì tchicaya u tam'si àti àmì ẹ̀yẹ ewì ana tòun ti iléeṣẹ́ cadbury lẹ́ẹ̀mejì ní ọdún 1991 ọ̀sundare di akéwì adúláwọ̀ onígẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ láti gba àmì ẹ̀yẹ noma bákan náà ló gba àmì ẹ̀yẹ fonlon nichols fún iṣẹ́ takuntakun àti ipa ribiribi rẹ̀ sí ìjàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ní ilẹ̀ áfíríkà ní ọdún 2014 wọ́n gbà á wọlé sí national order of merit tíì ṣe ẹ̀yẹ tó ga jù ní orílẹ̀èdè rẹ̀ fún ìmọ̀ tó tayọ àti ìseyorí àtinúdá ọ̀jọ̀gbọ́n afẹ̀yìntì tí ó tayọ ní ọ̀sundare ní yunifásítì ti ìlú new orleans ebí àti èkó ẹbí àti èkọ́ọ̀sundare gba oyè ẹ̀kọ́ ba nínú èdè gẹ̀ẹ́sì ní yunifásítì ti ìlú ìbàdàn oyè ma ni yunifasiti ìlú leeds and oyè phd ní yunifásítì ìlú canada ó jẹ olórí ẹ̀ka gẹ̀ẹ́sì ní yunifásítì ti ìbàdàn ní ọdún 1993 sí 1997 ó di ọ̀jọ̀gbọ́n èdè gẹ̀ẹ́sì ní yunifásítì new orleans ní ọdún 1997 ọsundare ní ìyàwó àti ọmọ mẹ́ta tí wọ́n ṣì ń gbè ni orílẹ̀èdè nàìjíríà àwọn àmì ẹ̀yẹ first prize western state of nigeria poetry competition 1968 1981 major book prize and letter of commendation bbc poetry competition 1981 honorable mention noma award for publishing in africa 1986 honorable mention noma award for publishing in africa 1989 association of nigerian authors ana poetry prize 1986citation needed joint-winner overall commonwealth poetry prize 1986 kwanza award 1991 noma award for publishing in africa the first anglophone african poet to receive the award 1991 cadbury/ana poetry prize nigeria’s highest poetry prize also won the maiden edition in 1989 1994 fonlon/nichols prize for excellence in literary creativity combined with significant contributions to human rights in africa african literature association ala’s most distinguished award 1998 the spectrum books award to the eye of the earth as “one of nigeria’s best 25 books in the last 25 years” 2004 the tchicaya u tam'si prize for african poetry regarded as africa's highest poetry prize 2008 nigerian national order of merit award nigeria's highest award for academic excellence 2014 àkójọ pò isẹ́ rẹ̀ songs from the marketplace 1983- village voices 1984- the eye of the earth 1986 winner of a commonwealth poetry prize and the poetry prize of the association of nigerian authors- moonsongs 1988- songs of the season 1999- waiting laughters 1990 winner of the noma award- selected poems 1992- midlife 1993- thread in the loom essays on african literature and culture 2002- the word is an egg 2002- the state visit 2002 play- pages from the book of the sun new and selected poems 2002- early birds 2004- two plays 2005- the emerging perspectives on niyi osundare 2003- not my business 2005- tender momentslove poems 2006- city without people the katrina poems 2011- random blues 2011-
helen ovbiagele helen ovbiagele je olukowe omo ile naijiria
sola osofisan sola osofisan je olukowe omo ile naijiria
zulu sofola nwazuluwa onuekwuke zulu sofola je olukowe omo ile naijiria
bode sowande bode sowande je olukowe omo ile naijiria
ken wiwa ken wiwa je olukowe omo ile naijiria ken je omo ken saro-wiwa
molara wood molara wood je olukowe omo ile naijiria
abdullahi sarki mukhtar abdullahi sarki mukhtar je oloselu omo ile naijiria ati gomina ipinle kaduna ati ipinle katsina tele
akojo awon gomina ipinle katsina
àkòjọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ kàtsínà
list of governors of katsina state
àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ kàdúná <onlyinclude>atojo awon alamojuto ati awon gomina ipinle kaduna ipinle kaduna je didasile ni 27 may 1967 bi north central state o si je titunsoloruko ni 17 mar 1976 bi ipinle kaduna </onlyinclude>
list of governors of kaduna state
lawrence onoja lawrence onoja jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà awon ipinle plateau ati katsina tẹ́lẹ̀
john madaki john madaki jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ katsina nígbà kan rí a yàn án sípò ní oṣù kejìlá ọdún 1989 lásìkò ìjọba ológun tí ààrẹ ibrahim babangida saidu barda ló jẹ́ lẹ́yìn rẹ̀ lásìkò ìjọba alágbádá ni oṣù kìíní ọdún 1992
saidu barda saidu barda jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ipinle katsina tẹ́lẹ̀
emmanuel acholonu emmanuel acholonu jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ipinle katsina tẹ́lẹ̀
samaila chama
joseph akaagerger joseph akaagerger jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ipinle katsina tẹ́lẹ̀
list of governors of oyo state
oládayọ̀ pópóọlá ogagun agba oládayọ̀ pópóọlá 26 osu keji 1944 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ológun ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
tunji olurin adetunji idowu olurin ojoibi 3 osu kejila 1944 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
victor omololu olunloyo victor omololu olunloyo tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin ọdún 1935 jẹ́ onímọ̀ mati tí ó di gómìnà ìpínlẹ̀ oyo nàìjíríà ní oṣù kẹ̀wá ọdún 1983 ó di ipò náà mú fún ìgbà díẹ̀ kí ìjọba ológun muhammadu buhari tó gba ìjọba ní oṣù kejìlá ọdún 1983 ó padà darapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú people's democratic party pdp ní ìpínlẹ̀ oyo
rasheed ladoja rasheed ladoja jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
paul tarfa paul tarfa jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
david jemibewon david medaese jemibewon jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
sasaenia oresanya adedeji sasaenia oresanya jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
abdulkareem adisa abdulkareem adisa 1949 - 25 february 2005 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
kolapo ishola kolapo olawuyi ishola jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
adetoye oyetola sode adetoye oyetola sode jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
chinyere ike nwosu chinyere ike nwosu jẹ́ ọmọ ologun omo orilẹ̀-ede nàìjíríà to tifeyinti àti gómìnà awon ipinle abia ati oyo tẹ́lẹ̀
ahmed usman ahmed usman 1951-2021 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
amen edore oyakhire amen edore oyakhire jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
lam adesina lamidi onaolapo adesina 20 january 1939 11 november 2012 jẹ́ oloselu ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀
àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ èkó <ns>0</ns> <revision> <parentid>539272</parentid> <timestamp>2023-09-25t083636z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> <onlyinclude>eyi ni àkójọ awọn alakoso ati awọn gomina ti ipinle eko lagos state was formed in 1967-05-27 from colony province and lagos federal territory </onlyinclude>
list of governors of lagos state
ipinle eko
local government areas in nigeria
mobolaji johnson mobọ́lájí ohofunso johnson jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀
adekunle lawal adekunle shamusideen lawal jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀
ndubuisi kanu ndubuisi kanu 1943-2021 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀
ebitu ukiwe okoh ebitu ukiwe ojoibi 26 osu kewa 1940 jẹ́ ọmọ ologun ilẹ̀ nàìjíríà totifeyinti ati igbakeji aare ile naijiria àti gómìnà tẹ́lẹ̀ fun ìpínlẹ̀ èkó ati ipinle niger
lateef jakande lateef kayode jakande ọjọ́ìbí 23 july 1929-2021 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀ ati alákósó ètò iṣẹ abẹ́lé lábẹ́ ìjọba sani abacha
gbolahan mudasiru gbolahan mudasirueni ti a bi ni 18 october 1945 ti o si fayesile ni 23 september 2003 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀ o jé gomina ipinle èkó laarin osu kinni odun 1984 si osù kejo odun 1986 nígba isejoba ologun muhammadu buhari àti ibrahim babangida
mike akhigbe mike akhigbe jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà ati igbakeji aare ile naijiria àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀
raji rasaki ogagun raji alagbe rasaki ojoibi january 7 1947 jẹ́ ọmọ ologun toti feyinti ara orile-ede nàìjíríà àti gómìnà ipinle eko ondo ati ogun tẹ́lẹ̀
michael otedola michael otedola jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀
buba marwa mohammed buba marwa ojoibi september 9 1953 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà awon ipinle borno ati eko tẹ́lẹ̀
àkójọ àwọn orúkọ àlàjẹ́ ìpínlẹ̀ nàìjíríà tabili isale yi safihan akojo awon oruko alaje awon ipinle naijiria
list of nigerian state nicknames
adamawa state
akwa ibom state university of science and technology 'akwa ibom state university of science and technology ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
abti - american university of nigeria abti - american university of nigeria ni yunifásítì taladani ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ìpínlẹ̀ adámáwá 'yunifásítì ìpínlẹ̀ adámáwá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì ìjọba ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ambrose alli yunifásítì ambrose alli ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ìpínlẹ̀ anámbra yunifásítì ìpínlẹ̀ anámbra ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ìpínlẹ̀ bẹ́núé yunifásítì ìpínlẹ̀ bẹ́núé ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
cross river state university of technology yunifásítì ti ìpínlẹ̀ cross river tí a tún mọ̀ sí unicross jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìjọba tí ó ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga mẹ́rin tí ó tàn káàkiri àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rin ti ìpínlẹ̀ náà ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí cross river university of technology crutech ó tún orúkọ rẹ̀ ní ní oṣù kejì ọdún 2021 nípasẹ̀ àbádòfin tí ó kọjá ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ cross river èyítí gómìnà ìpínlẹ̀ náà benedict ayade fọwọ́sí lẹ́hìn náà ìyípadà ti orúkọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ni láti jẹ́ kí iṣẹ́ fásítì ṣiṣẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti àṣà èyítí ó pèsè àyè láti fúnni ní àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ díẹ̀ síi dípò ìdojúkọ́ lórí àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ìmọ̀-ẹ̀rọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga gba orúkọ abínibí ti ìpínlẹ̀ náà padà ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ cross river uyo ní báyìí yunifásítì ti uyo ìpínlẹ̀ akwa ibom nàìjíríà títí di ọjọ́ kìíní oṣù kẹ́wàá ọdún 1991 nígbà tí ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà da fásítì ti uyo sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ lẹ́hìn ìpínyà ti ìlà akwa ibom láti ìpínlẹ̀ cross river ní ọdún 1987 ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti uyo jogún àwọn ọmọ ilé-ìwé òṣìṣẹ́ àwọn ètò ẹ̀kọ́ àti gbogbo àwọn ohun èlò ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ cross river nígbà náà ti ìṣètò nípasẹ̀ ìpínlẹ̀ cross river ní ọdún 1983
delta state university abraka-nigeria delta state university abraka-nigeria ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ìpínlẹ̀ ẹ̀bọ́nyì yunifásítì ìpínlẹ̀ ẹ̀bọ́nyì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
enugu state university of science and technology enugu state university of science and technology ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì tẹknọ́lọ́jì àpapọ̀ ilú àkúrẹ́ yunifásítì tẹknọ́lọ́jì àpapọ̀ ilú àkúrẹ́ ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni óṣu april ọdun 2023 ọgbẹni charles adẹlẹyẹ to jẹ ọmọ ọdun mẹrin din lọgọta ni a fi jẹ registrar tuntun fun ilè iwè giga naa ti ọgbẹni robert awoyẹmi to jẹ ọmọ ọdun mẹta leelaadọta jẹ alakoso yara ikawe tuntun ta ṣẹṣẹ yan
yunifásítì ìpínlẹ̀ gòmbè yunifásítì ìpínlẹ̀ gòmbè jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ìpínlẹ̀ ímò yunifásítì ìpínlẹ̀ ímò ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifasifi ti ladoke akintola ti imọ-ẹrọ yunifasifi ti ladoke akintola ti imọ-ẹrọ ni yunifásítì to wa ni ilu ogbomọshọ ipinlẹ ọyọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà
yunifásítì ìpínlẹ̀ èkó yunifásítì ìpínlẹ̀ èkó ti a tun mọ si lasu wa ni ojo ilu kan ni ipinle eko nigeria ile-ẹkọ giga ti dasilẹ ni ọdun 1983 nipasẹ ofin ti o fun laaye ni ipinle eko fun ilosiwaju ti ẹkọ ati idasile didara ẹkọ giga gbolohun ọrọ rẹ jẹ fun otitọ ati iṣẹ
federal polytechnic birnin kebbi federal polytechnic birnin kebbi ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
README.md exists but content is empty. Use the Edit dataset card button to edit it.
Downloads last month
37
Edit dataset card