_id
stringlengths 17
21
| url
stringlengths 32
377
| title
stringlengths 2
120
| text
stringlengths 100
2.76k
|
---|---|---|---|
20231101.yo_2242_25 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Ẹran mẹ́ta ni wọ́n bá ní ilé àwọn olè wọ̀nyí nítorí pé wọ́n ti jí méjì tẹ́lẹ̀. Nítorí pé Ọ̀sanyìnnínbí jẹ́ ọ̀gá fún àwọn olè wọ̀nyí, wọ́n mú un lọ sí Àgọ́ ọlọ́pàá tí ó wà ní Morèmi ní ilé-Ifè. |
20231101.yo_2242_26 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | 6. Nígbà ti Ọlọ́fìn-íntótó gbọ́ pé wọ́n mú Ọ̀sanyìnnínbí sí àgọ́ ọlọ́pàá Morèmi, òun àti Ilésanmí lọ́ sí ibẹ̀. Aago mẹ́fà sí mẹ́jọ ni ọ̀gá ọlọ́pàá máa ń rí ènìyàn ṣùgbọ́n ó gbà láti rí Akin àti Ilésanmí lẹ́yìn ìgbà tí ó ti rí káàdì Akin. |
20231101.yo_2242_27 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Pópóọlá ni orúkọ ọ̀gá ọlọ́pàá yìí. Ọ̀rẹ́ Akin Olófìn-íntótó, ọmọ Olúṣínà ni. Àbéòkúta ni Pópóọlá wà tẹ̀lẹ̀ kí wọ́n tí wá gbé e wá sí Morèmi ní Ifẹ̀ níbi tí ó ti jẹ́ ọ̀gá àwọn ọlọ́pàá ibẹ̀. Ó ti tó ọdún mẹ́ta tí ó ti rí Akìn mọ. Pópóọlá bèèrè Túndé Atọ̀pinpin lọ́wọ́ Akin. |
20231101.yo_2242_28 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n tí wọ́n ti ṣè àlàyé pé ọ̀rọ́ Ọ̀sanyìnnínbí tí wọ́n mú ni ó gbé àwọn wa ni wọ́n ṣe àlàye pé tí ó bá jẹ́ pé òun ni ó jí owó Orímóògùnjẹ́, yóò ti ná tó ẹgbẹ̀jọ náírà (N1,600.00) nínú owó náà. Ẹran ti Ọ̀sanyìnnínbí jí gbé ni ó jẹ́ kí wọ́n ní àǹfààní láti yẹ ilé rẹ̀ wo. |
20231101.yo_2242_29 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Pópóọlá sọ pé, ‘Ẹni tí ó pe tóró, Á ṣẹnu tọ́ńtọ́..’ Ó yẹ kí á ṣe àkíyèsí pé Àlàó ni oríkì Pópóọlá. Eléyìí yàtò sí Àlàó tí ó tójú àwọn Olófìn-íntótó tí a ti ṣe àkíyèsí rẹ̀ ṣáájú. |
20231101.yo_2242_30 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Nígbà tí wọ́n ló yẹ ilé Ọ̀sanyìnnínbí wò, owó tí wọ́n bá ní ibẹ̀ jẹ́ ọgọ́sàn-án náírà (N180.00) Níní orí yìí, a ó rí òwe, ‘Àfàgò kẹ́yin àparò…’ Ohun tí ó fa òwe yìí ni ẹran tí Ọ̀sanyìnnínbí jí gbé àti ẹ̀wọ̀n tí wọ́n ní yóò lọ tí ìyàwó rẹ̀ yóò sì ti bímọ kí ó tó dé. Àpatán òwe yìí ni, ‘Afàgò kẹ́yin àparò, ohun ojú ń wá lojú ń rí. |
20231101.yo_2242_31 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | 7. Akin Olúṣínà àti Ilésanmí lọ sí ilé Ọ̀sanyìnnínbí. Nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀, òògùn ni Ọ̀sanyìnnínbí wá ṣe. Orí yìí ni a ti mọ ìdí tí Ọ̀sanyìnnínbí fi fẹ́ràn Orímóògùnjẹ́. Ìdí tí ó fi fẹ́ràn rẹ̀ nip é nígbà tí Ọ̀sanyìnnínbí ń ṣe òkú ìyá rẹ̀, ó fún un ní ọgọ́rùn-ún náírà (N100.00) níbi tí kò ti sí ẹni tí ó tún fún un ju náírà márùn-ún lọ. |
20231101.yo_2242_32 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Ọ̀sanyìnnínbí sọ pé Orímóògùnjẹ́ kì í finú tan Àlàó yìí Àwọn ohun tí ó tún yẹ kí á ṣe àkíyèsí ní orí yìí ni ìwọ̀nyí: |
20231101.yo_2242_33 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Àkànbí, àbúrò Aríyìíbí, tí Ọ̀sanyìnnínbí nígbà tí ó ń ṣàìṣàn ní ó dúró fún Ọ̀sanyìnnínbí ní àgọ́ ọlọ́pàá (Ìyẹn ni pé Àkàbí tí Ọ̀sanyìnnínbí wòsàn ni ó dúró fún òun náà) |
20231101.yo_2242_34 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Ní ọjọ́ tí àwọn Ọ̀fíntótó wá sí ilé Ọ̀sanyìnnínbí, nǹkan bí agogo mókànlá ni ó wọlé àwọn Òfíntótó sì dé ilé rẹ̀ ní aago méjì kọjá ìṣẹ́jú mẹ́wàá. |
20231101.yo_2242_35 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Nígbà tí Akin Olúṣínà àti Ilésanmí dé ọ̀dọ̀ Ọ̀sanyìnnínbí tí ó rò pé oògùn ni wọ́n wá ṣe ní ọ̀dọ̀ òun, àwọn ẹbọ tí ó kà fún wọn ni ìyá ewúrẹ́ kan, ẹgbẹ̀rún náírà ìgò epo kan, iṣu mẹ́ta àti ìgàn aṣọfunfun kan. |
20231101.yo_2242_36 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Akin Olúsínà mu ẹmu ní ilé Ọ̀sanyìnnínbí Ajéwọlé ni ó ra kòkó lówọ́ Ọ̀sanyìnnínbí. Ẹgbẹ̀fà náírà (N200.00) ni ó gbà ní owó kòkó náà. |
20231101.yo_2242_37 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Láti lè mọ iye tí Ọ̀sanyìnnínbí gbà fún kòkó tí ó tà fún Ajéwọlé, ọgbọ́n ni wọ́n fi tan Ọ̀sanyìnnínbí. Wọ́n sọ fún un pé ẹnì kan ń rọbí àti pé yóò nílò oníṣèẹ̀gùn. |
20231101.yo_2242_38 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Bándélé jẹ́ ọmọ odún mẹ́jọ. Ọmọ Àṣàkẹ́ ni Jayéjayé kan ni Àṣàkẹ́ máa ń wọ àdìrẹ tàbí borokéèdì ó sì máa ń wọ súwẹ́ta nígbà òtútù. |
20231101.yo_2242_39 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Fawọlé: Ó wà lára àwọn ẹni tí ó wá wo Orímóògùnjẹ́ nígbà tí ara rè kò yá. Nígbà tí Akin Olúsínà ṣe ìwádìí nípa rẹ̀, èsì tí ó rí gbọ́ ni ìwọ̀nyí: |
20231101.yo_2242_40 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Nípa aṣọ tí ó wọ̀ ní ọjọ́ tí ó wá sí ọ̀dọ̀ Orímóògùnjẹ́, ẹni kan sọ pé aṣọ sáfẹ́ẹ̀tì pẹ̀lú aṣọ òfì ni ó wọ̀. Ẹni kan sọ pé sán-ányán ni aṣọ tí ó wọ̀ níwọ̀n ìgbà tí ó ti jẹ́ pé àwọn ọmọ́dé kìí tètè gbàgbé nǹkan, Akin Olúṣínà ní kí awọ́n bèèrè ìbéèrè nípá Fáwọlé lọ́wọ̀ Fólúkẹ́ àti Bándélé. |
20231101.yo_2242_41 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Folúkẹ́ ní ojoojúmọ́ ni Ọ̀sányìnnínbí máa ń wá sọ́dọ̀ Orímóògùnjẹ́ nígbà tí Orímóògùnjẹ́ ń sàìsàn ó sì máa ń dúró di ìgbà tí wọ́n bá ń pèrun alẹ́ kí ó tó kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ̀. Folúkẹ́ ní òun rí nǹkan kan bí ológbò ní àpò rẹ̀ ni ọjọ́ kan. |
20231101.yo_2242_42 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Àlàó kò gbọ́ nípa ẹni tí ó ń fi kọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò nítorí pé ó lọ sí ibì òkú ìyá Báyọ̀ ní ọjọ́ náà. |
20231101.yo_2242_43 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Ìyá Bándélé ni ẹni tí ó fi kọ́kọ́rọ́ dan séèfù wò náà Orímóògùnjẹ́ kò sọ ọ̀rọ̀ eni tí ó fi kọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò yìí fún Àlàó. Yéwándé náà kò sọ fún un. |
20231101.yo_2242_44 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | 9. Igba náírà (N200.00) ni wọ́n bá ní ilé Àṣàkẹ́, ìyẹn ìyá Bándélé nígbà tí àwọn Akin Ọlọ́fìn-íntótó yẹ ilé rẹ̀ wò. Ẹni tí ó fi kọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ lókè ni Àṣàkẹ́ ìyá Bándélé. folúkẹ́ ni ó sọ fún ìyá rẹ̀ pé Àṣàké ń fi kọ́kọ́rọ́ dán séèfù wò. Àṣàkẹ́ máa ń kanra mọ́ ọmọdé. Aṣọ òfì ni Yéwándé wọ̀ nígbà tó wọ́n ń ṣe ìwádìí yìí torí òtútù. Ọjọ́ kejì ọjà Ajágbénulékè ni Àṣàkẹ́ rí kọ́kọ́rọ́ tí ó fi dán séèfù wò nínú yàrá rẹ̀. Àlàá, Àkin àti Ilésanmí fi kọ́kọ́rọ́ náà dán séèfù wò, kò sí i. |
20231101.yo_2242_45 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Lẹ́yìn ìwádìí ti ọjọ́ yìí, Akin Ọlọ́fìn-íntótó àti ilésanmí padà sí Ìbàdàn. Ní ibi tí Akin ti dá mọ́lò dúró nígbà tí o fẹ́ ẹran ìgbẹ́ ni bàbá alágbẹ̀dẹ kan ti sọ fún ọmọ kan pé kí ó wò ọkọ̀ náà. Kọ́lá ni orúkọ ọmọ yìí. Orí yìí ní wọ́n ti wá mọ orúkọ ọmọge tí Akin Olúṣínà ra ọtí fún nígbà tí wọ́n ń lọ sí Ifẹ̀ tí a ti mẹ́nu bà ṣáájú. Orúkọ ọmọge yìí ni fìlísíà Olówólàgbà. A ó rí i ní iwájú pé filísíà Olówólàgbà yìí ni orúkọ mìíràn fún ìyàwo Orímóògùnjẹ́ tí ó jí owó Orímóògùnjé gbé. |
20231101.yo_2242_46 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Akin àti Ilésanmí wá filísíà yìí lọ sí pètéèsì aláwò pupa rúsúsúsú. Kọ́lá ni ó ràn wọ́n lọ́wọ́ láti mọ ilé yìí. Akin àti Ilésanmí sun ọ̀dọ Fìlísíà mọ́jú. Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n rí Pópóọlá. Ó gbé wọn dé màpó. |
20231101.yo_2242_47 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | 10. Akin lọ gbowó ní bàǹkì. Òun àti Ilésanmí ni wọ́n jọ lọ. Ní báǹkì, wọ́n pàdé Kọ́lá. Ẹnu rẹ̀ ni wọ́n ti gbọ́ pé Bínpé àbúrò fìlísíà fẹ́ ṣe ìgbéyàwó ní Gbọ̀ngán. Pópóọlá gbé Akin, Ilésanmí àti Kọ́lá. Ní ọ̀nà, ní ibi tí alágbẹ̀dẹ́ ti fi Kọ́lá sí ọkọ̀ ní ìjelòó, wọ́n rí àwọn méjì tí wọ́n ń jà Ògúndélé ni orúkọ alágbẹ̀dẹ yìi. Òun ni ó ń bá Jìnádù jà. Wọ́n gbá Adénlé tí ó fẹ́ là là wọ́n ní ẹ̀sẹ̀ nínú. Pópóọlá tí ó jẹ́ ọlọ́pàá ni ó pàṣẹ pé kí wọn dá ọwọ́ ìjà dúró tí wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀. |
20231101.yo_2242_48 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Ohun tí ó fa ìjà tí Ògúndélé àti Jinádù ń jà ni pé Ògúndélé tí ó jé alágbẹ̀dẹ rọ kọ́kọ́rọ́ kan fún jìnádù ní múrí mẹ́ta (#60), Jìnádù san Múrí kan (#20) níbẹ̀ ó ku múrí méjì (#40). Ògúndélé bínú nítorí pé Jìnádù kò tètè san múrí méjì tí ó kì. Jìnádù bínú nítorí pé ó sọ pé Ògúndélé sin òun ní owó ní àárí àwùjọ. Jìnádù sọ pé Ògúndélé fi òrùkọ ẹ̀rẹ na òun. Nígbà tí Kọ́là sọ̀ kalẹ̀ tí ó ń lọ, ó gbàgbé àpò rẹ̀ ṣùgbọ́n wọ́n dá a padà fún un. |
20231101.yo_2242_49 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Nígbà tí Ain àti Ilésanmí ti Ìbàdàn tí wọ́n ti ń bọ̀ dé Ilé-Ifẹ̀, wọ́n lọ sí ilé fáwọlé Nígbà tí Orímóògùnjẹ́ ń ṣàìsàn lọ́wọ́ tí fọláṣadé 9tí àwa tún mọ̀ sí fìlísíà) wá sí Ifẹ̀, ó lò tó ọjọ́ mẹ́ta dípò méjì tí ó máa ń lò tẹ́lẹ̀. Ìpàdé ọmọlẹ́bí tí wọ́n fẹ́ ṣe gan-an ni ó tèlè mú un padà. Yàtọ̀ sí ìgbà tí ìnáwó pàjáwùrù bá wà ọjọ́ karùn-ún kànùn-ún ni Orímóògùnjẹ́ máa ń mú owó nínú séèfù rẹ̀ nígbà tí ó wà láyé. |
20231101.yo_2242_50 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ tẹ́lẹ̀, Yéwándé máa ń bá Orímóògùnjẹ́ mú owó nínú séèfù rẹ̀ ṣùgbọ́n ó tó oṣù kan sí ìgbà tí Orímóògùnjẹ́ tó kú tí ó ti rán an mú owó nínú rẹ̀ gbèyìn. Ọjọ́ ọjà ni ọjọ́ tí Orímóògùnjẹ́ máa ń mú owó nínú séèfù rẹ̀ máa ń bọ́ sí. Ọjọ́ kẹ́rin tí Orímóògùnjẹ́ mú owó kẹ́yìn nínú séèfù rẹ̀ ni ó kú. Ìyẹn ni pé ọjà dọ̀la ni ó kú Orímóògùnjẹ́ máa ń fún àwọn ìyàwó rẹ̀ ní owó-ìná tí ó bá ti mówó. Níbi tí wọ́n ti ń ṣe ìwadìí yìí, Akin Olúṣínà ń fi ataare jobì. Túndé Atọ̀pinpin ní kí àwọn yẹ yàrá Fọláṣadé wò. |
20231101.yo_2242_51 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | 11. Ìsòrí kọkànlá yìí ni ó ti hàn gbangba pé Fọláṣadé, ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó Orímóògùn ni ó jí owó rẹ̀ gbé. Ó ní ìdí tí òun fi jí owó náà gbé nip é òun kò bímọ fún Orímóògùnjẹ́ òun kò sì fẹ́ kì tòun ó gbé sílé rẹ̀ nítorí pé ọmọ tì obìnrin bá bí fún ọkọ ni wọ́n fi máa ń pín ogún ọkọ náà ní ilẹ̀ Yorùbá. Fọláṣadé ni ó yí orúkọ padà tí ó di fìlísíà. Òun náà ni ó lọ rọ kọ́kọ́rọ́ lọ́dọ̀ bàbá àgbẹ̀dẹ tí Àṣàkẹ́ fi dán séèfù wò. |
20231101.yo_2242_52 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Akin Olúṣínà: Òun ni wọ́n máa ń pè ní Akin Ọlófìn-íntótó, ọmọ Olúṣínà. Òun ni ó ṣe ìwádìí owó tí ó sọnù. Àròsọ ni ó ti wọkọ̀ lọ sí Ifẹ̀ láti lọ ṣe ìwádìí owó náà. Fìlà rẹ̀ sí bọ́ sílẹ̀ nínú mọ́tò tí ó wọ̀. Dírẹ́bà ọkọ̀ yìí kò mọ ọkọ̀ wà dáadáa. Akin Olúṣíná fẹ́ràn ẹran ìgbẹ́. Ó máa ń mutí. Ó máa ń jobì tó fi ataa sínú rẹ̀. Ó ní túbọ̀mu ó sì máa ń fi ọwọ́ pa á. Ó ṣe wàhálà púpọ̀ kí ó tó mọ̀ pé Fọláṣadé tí ó tún ń jẹ́ filísíà nì ó jí owó Orímóògùnjẹ́ kó. |
20231101.yo_2242_53 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Foláṣádé: Òun ni ó jí owó Orímóògùnjẹ́ kó. Kò bímọ fún Orímóògùnjẹ́. Ìdí nì yí tí ó fi jí owó rẹ̀ gbé. Ó ní kí ti òun má bàa jẹ́ òfo nílé Orímóògùnjẹ́ ni ó jẹ́ kí òun jí owó rẹ̀ gbé. Fọláṣadé náà ni ó yí orúkọ padà sí fìlísíà Olówálàgbà. Orúkọ yìí ni ó si fi lọ fi owó pamọ́ sí báǹkì. Gbòngán ni ó ń gbé ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bíi fìlísíà, ó ní ilé sí Ibadan. |
20231101.yo_2242_54 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Gẹ́gẹ́ bíi fìlísíà, Ọ̀gá ni ó jẹ́ fún Kọ́lá Òwú ara súwẹ́tà rẹ̀ tí ó já bọ́ síbi séèfù wà lára ohun tí ó ran Akin Olúṣínà lọ́wọ́ láti rí i mú. Ìwé ìfowópamọ́ rẹ̀ tí Akin Olúṣínà rí lọ́wọ́ Kọ́lá náà tún wà lára ohun tí ó ran Akin Olúṣínà lọ́wọ́. |
20231101.yo_2242_55 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Fọláṣadé wà lára àwọn tí wọ́n bí séèfù lójú rẹ̀ ní ilé Orímóògùnjẹ́ tí wọn kò bá nǹkan kan níbẹ̀. Kò sì jẹ́wọ́ pé òun ni òun kó owó tí ó wà níbẹ̀. Ó máa ń ti Gbọ̀ngán wá sí Ifẹ̀. Òun ni ìyàwó àfẹ́kẹ́yìn foún Orímóògùnjẹ́. Tí ó bá wá láti Gbọ̀ngán, ó máa ń lò tó ọjọ́ márùn-ún ní Ifẹ̀ tàbí ọ̀sẹ̀ kan. Ilé oúnjẹ ni Akin àti Ilésanmí ti kọ́kọ́ pàdé rẹ̀. Lẹ́yìn tí ó jiyán tán ní ilé olóúnjẹ yìí, ó mu ìgò otí kan àti àbọ̀ nínú ọtí tí Akin Olúṣínà rà. |
20231101.yo_2242_56 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Àkàngbé Ọrímóògùnjẹ́: Òun ni wọ́n jí owó rẹ̀ gbé tí Akin Olúṣínà wá ṣe ìwádìí rẹ̀. Àìsàn tí ó ṣe é tí ó fi kú kò ju ọjọ́ mẹ́wàá lọ. Abẹ́ ìrọ̀rí rẹ̀ ni kọ́kọ́rọ́ ojú ńlá séèfù rẹ̀ máa ń wà. Inú séèfù yìí nì ó máa ń kó owó sí. Kìí yọ àwọn kọ́kọ́rọ́ ojú kékeré séèfù yìí. Tí wọ́n bá ti ilèkùn yàrá rẹ̀, wọ́n máa ń fi kọ́kọrọ́ há orí àtérígbà níbi tí ẹnikẹ́ni ti lè mú un. Orúkọ múràn tí ó ń jẹ́ ni Bándélé. Ogóje náírà (#140), péré ni wọ́n bá nígbà tí ó kú tán. Kí ó tó kú ó ti ra ilẹ̀ tí yóò fi kọ́lè. Ajíṣafínní ni ó bá a dá sí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ tí ó rà náà. Owó Òṣúnlékè ni ó ti rà á. Ẹgbàáta náírà (#6,000) ni ó ra ilẹ̀ náà. |
20231101.yo_2242_57 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Dúró: Dúró ni àkọ́bí ọmọ Àkàngbé Orímóògùnjẹ́. Ilé-ẹ̀kọ́ girama ni ó wà. Ọdún kan ni ó kù kí ó jáde. Òun ni ó kọ ìwé sí Akin Olúṣínà pé kí ó wá bá òun wádìí owó bàbá òun tí wọn kò rí mọ́. Àdùnní ni orúkọ ìyá rẹ̀ òun nìkan ni ó sì bí fún bàbá rẹ̀. Àdùnní yìí tí kú ní ọdún mẹ́ta ṣáájú bàbá rẹ̀. Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún (17) nì Dúró. Àbúrò mẹ́rin ni ó ní. Àwọn náà ni Àdùkẹ́, Ọmọ́wùmí, Oládípò àti Bándélé. |
20231101.yo_2242_58 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Àdùnní: Àdùnní ni ìyàwó tí Orímóògùnjẹ́ kọ́kọ́ fẹ́. Ó kú ní ọdún mẹ́ta sáájú ọkọ rẹ̀. Òun ni ó bí Dúró fún Orímóògùnjẹ́. Ẹ̀gbọ́n ni ó jẹ́ fún Ilésanmí. Ọmọ ìlú kan náà nì òun àti Akin Olúṣínà. |
20231101.yo_2242_59 | https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9 | Kọ́lá Akínlàdé | Kola Akinlade (1976), Owo Eje. Ibadan, Nigeria: Onibonoje Press and Book Industries (Nig. Ltd). Oju-iwe = 116 |
20231101.yo_2251_0 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | Iṣẹ́ yìí dá lórí àyẹ̀wò fonọ́lọ́jì ẹ̀ka-èdè Ìṣẹ̀-Èkìtì, èyí tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ka-èdè tí à ń sọ ní ìpínlẹ̀ Èkìtì. Láti ṣe àgbékalẹ̀ iṣẹ́ yìí, tíọ́rì onídàrọ́ ni a lò. |
20231101.yo_2251_1 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | Ìpín mẹ́rin ni a pín iṣẹ́ yìí sí. Ní orí kìn-ín-ní ni a ti sọ ìtàn orírun Ìṣẹ̀-Èkìtì. A sọ èrèdí iṣẹ́ yìí, ọgbọ́n ìwádìí tí a lò àti àyẹ̀wò iṣẹ́ tí ó wà nílẹ̀. Bákan náà, a sọ tíọ́rì tí a lò fún iṣẹ́ yìí. |
20231101.yo_2251_2 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | Ní orí kejì ni a ti ṣe àlàyé lórí àwọn ìró inú ẹ̀ka-èdè ìṣẹ̀-èdè Ìṣẹ̀-Èkìtì. Bíi ìró kónsónáǹtì, ìró fáwẹ́lì, ìró ohùn, iṣẹ́ ohùn, sílébù àti oríṣiríṣi. sílébù tí a lè rí nínú ẹ̀ka-èdè Ìṣẹ̀-Èkìtì. |
20231101.yo_2251_3 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | Ní orí kẹ́ta àpilẹ̀ko yìí ni a ti ṣàyẹ̀wo nípa ìgbésẹ̣̀ fonọ́lọ́jì tí ó wà nínú ẹ̀ka-èdè Ìṣẹ̀-Èkìtì. A wo ìpàrójẹ, àrànmọ́ àti àǹkóò fáwẹ́lì. |
20231101.yo_2251_4 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | Ní orí kẹ́rin iṣẹ́ yìí ni a ti gbìyànjú láti wo àwọn ìyàtọ̀ àti ìjọra tí ó wà láàrin fonọ́lọ́ji ẹ̀ka-èdè Ìsè-Èkìtì àti ti olórí ẹ̀ka-èdè Yorùbá. |
20231101.yo_2251_5 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | Àgbálọgbábọ̀ iṣẹ́ yìí dá lé àwọn tuntun tí ó jáde nínú ìwádìí ti a ṣe a si tọ́ka sí àwọn ibi tí a lérò pé iṣẹ́ kù sí. |
20231101.yo_2251_6 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8C%E1%B9%A3%E1%BA%B9%CC%80-%C3%88k%C3%ACt%C3%AC | Ìṣẹ̀-Èkìtì | M.G. Fátóyè, (2003), Àyèwò Fónolojì Ẹ̀ka Èdè Ìsè Èkìtì.’, Àpilẹ̀kọ fún Oyè Ẹ́meè, DALL, OAU, Ifẹ̀, Nigeria. |
20231101.yo_2276_0 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | A kò le sọ pàtó ọdún tàbí àkókò tí wọn tẹ ìlú Àkúrẹ́ dó, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí Arífálò (1991) ṣe wòye, ó ní Àkúrẹ́ fẹ́rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí ó pẹ́ tí wọn ti tẹ̀dó ni ilẹ̀ Yorùbá |
20231101.yo_2276_1 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Ìtàn sọ fún wa pé, Aga, ẹni tí a tún wá mọ orúkọ rọ̀ bí Alákùnrẹ́ ni ó kọ́kọ́ tẹ ìlú Àkúrẹ́ dó. Orúkọ̀ bàbá rẹ̀ ni ìyàngèdè. Ìtàn sọ fún wa pé, Ẹ̀pé, ní ẹ̀bá ìlú Òǹdó ni ó kọ́kọ́ fi ṣe ibùgbé lẹ́yìn tí wọn kúrò ní Ilé-Ifẹ̀. Alákùnrẹ́ tẹ̀ síwájú láti dá ibùgbé tirẹ̀ ní. Ní àsìkò yìí, ohun ọ̀ṣọ́ ọwọ́ rẹ̀ tí á ń pè ní ‘Àkún’ gé. Ó pe ibẹ̀ ní ‘Àkún rẹ́’ nítorí ìtumọ̀ ‘gé’ ni ‘rẹ́’ ní èdè Àkúrẹ́. Eléyìí ni ó wá di ‘Àkúrẹ́’ títí dòní yìí. Alákùnrẹ́ sì jókòó gẹ́gẹ́ bí olórí ìlú. A kì í pè é ní ọba ní àsìkò yẹn bí kò ṣe ‘Ọmọlójù’. Ó lo ipò rẹ̀ bí olórí ìlú àti ọmọ Odùduwà ní ìlú Àkúrẹ́. |
20231101.yo_2276_2 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Ní àsìkò yìí ni àwọn ọmọ Odùduwà ń jẹ ọba káàkiri ilẹ̀ Yorùbá. A gbọ́ pé, Àjàpadá Aṣọdẹ́bọ̀yèdé tí o jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ Odùduwà kúrò ní ìlú Òṣú, ó sì dúró sí ìlú kan tí wọn ń pè ní ‘Òyè’nítòsí Ẹ̀fọ̀n-Alààyè. Rògbòdìyàn, Ìṣòro, ogun àti àìfọkànbalẹ̀ kọ lu ìgbé – ayé Àjàpadá pẹ̀lú ara ìlú ‘Òyè’ náà. Ó wá di dandan fún Àjàpadá láti kúrò ní ìlú ‘Òyè’fún ààbò. Òun àti àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ dórí kọ ilẹ̀ àìmọ̀rí fún ibùgbé. |
20231101.yo_2276_3 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Àjàpadá gbáradì, ó kó àwọn ènìyàn rẹ̀, ó sì ṣe gẹ́gẹ́ bí akíkanjú àti ògbójú ọdẹ. wọ́n rìn títí tí wọn fi dé igbó Àkúrẹ́, ibí ni wọ́n ti bá wọn pa erin. Erin tí Àjàpadá pa fún àwọn ará ìlú Àkúrẹ́ fún àwọn ará ìlú ní ìwúrí àti ìbẹ̀rù, nítorí pé, ọdẹ tí ó bá pa erin jẹ́ ọdẹ abàmì àti akíkanjú ọdẹ. Àwọn ará ìlú Àkúrẹ́ wá gba Àjàpadà gẹ́gẹ́ bí akíkanjú ọdẹ tí yóò lè ní agbára láti gba ará ìlú rẹ̀ ní ọjọ́ mìíràn tí ogun tàbí ọ̀tẹ̀ bá dé. Àwọn ará ìlú Àkúrẹ́ fún Àjàpadá ní orúkọ ‘Aṣọdẹbóyèdé’. |
20231101.yo_2276_4 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Àjàpadá tí à ń pè ní Aṣọdẹbóyèdé wá ní iyì gidi tí àwọn ará ìlú sì fẹ́ràn rẹ gan-an. Àwọn ará ìlú wá gbé Àjàpadá ga ju Alákùnrẹ́ tí o kọ́kọ́ dé ìlú Àkúrẹ́ lọ. Alákùnrẹ́ náà ṣàkíyèsí pé, àwọn ará ìlú fẹ́ràn Àjàpadá ju òun lọ, ó wa dàbí ẹni pé wọ́n rí ‘ọkọ́ tuntun gbé àlòkù èṣí dànù’. Alákùnrẹ́ wá já ọwọ́ rẹ̀ nínú irọ́kẹ̀kẹ̀ àti akitiyan láti jẹ́ ọba fún ìlú Àkúrẹ́ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òun gan-an ni ẹni kìíní tí ó kọ́kọ́ tẹ ìlú Àkúrẹ́ dó. Itàn sọ fún wa pé Alákùnrẹ́ fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ kúrò fún Àjàpadá Aṣọdẹbóyèdé. |
20231101.yo_2276_5 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Àjàpadá Aṣọdẹbóyèdé wá jẹ́ ọba ìlú Àkúrẹ́ kìíní, gbogbo ayé gbọ́, ọ̀run sì mọ̀. Iwádìí fi hàn wá pé, Àjàpadá yìí jẹ́ ọmọ Ẹkùn, Ẹkùn sì jẹ́ ọmọ Òdùduwà1. Òdùduwà tí ó jẹ́ bàba Ẹkùn ni ó tọ́jú Àjàpadá dàgbà nítorí Ẹkùn tètè kú. Àjàpadé jẹ́ ọmọ rere, ó sì fẹ́ràn láti máa ṣeré káàkiri ààfin Òdùduwà, àwọn ènìyàn a sì máa pè é ní ‘Àjàpadá Ọmọ Ẹkùn. A gbọ́ pé Odùduwà fún Àjàpadá ní ẹ̀wù oògùn kan tí wọn ń pè ní ‘Ẹ̀wù Ogele’ tí Òduduwà fúnra rẹ̀ fi ń ṣe ọdẹ, nígbà tí Àjàpadá pinnu láti dá ibùgbé tirẹ̀ ní. |
20231101.yo_2276_6 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Wo: T. A. Ládélé a.y. Àkòjọpọ̀ Iwádìí Ìjìnlẹ̀ Àsà Yorùbá. Ibadan’, Macmillan Nigeria Publishers Ltd. 1986, o.i. 1-2. |
20231101.yo_2276_7 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Ohun méjì ni ó mú kí Òdùduwà ṣe èyí, èkínní ni ìwà akíkanjú tí Àjàpadá fi hàn nígbà tí o fi ‘Àjà’1 kékeré pa eku ẹdá nínú ilé àìlujú nígbà èwè rẹ. Èkejì ni ìfẹ́ tí Òdùduwà ní sí Ẹkùn tí ó jẹ́ bàbá fún Àjàpadá. Ẹkùn sì tètè kú, ‘Ọmọ́rẹ̀mílẹ́kún’ ni Àjàpadá jẹ́ sí Odùduwà. |
20231101.yo_2276_8 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Ẹ̀bùn ẹ̀wù yìí nìkan kò tẹ́ Àjàpadá lọ́rùn, ó bẹ Odùduwà fún àwọn ohun ọrọ̀ míràn, èyí wá jẹ́ kí Òdùduwà tún rob í baba Àjàpadá ti jẹ́, ó sì wọ ilé lọ, nígbà tí o máa jáde, ó jáde pẹ̀lú ẹwà iwà mímọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ó gbé adé kan lọ́wọ́, ó súre fún Àjàpadá, ó sì sọ fún Àjàpadá pé, ‘mo fi adé yìí jì ọ́’ Mo fi adé jì ọ́, ni ó wá di ‘Déjì’tí o jẹ́ orúkọ oyè ọba ìlú Àkúrẹ́, gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Òdùduwà fi adé jì2. Adé yìí jẹ ìtọ́kasí pé ọmọ ọba ni Àjàpadá. |
20231101.yo_2276_9 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | 1. Ohun èlò ọdẹ ti wọn fi irin ṣe ni o ń jẹ́ ‘Àjà’. Ibi náà ni orúkọ Àjàpadá tí ṣúyọ tí o túmọ̀ sí ‘A fi ajà pá ẹdá (Àjàpadá) |
20231101.yo_2276_10 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Àjàpadá ọmọ Ẹkùn Aṣọdẹbóyèdé, Déjì kìíní ní ìlú Àkúrẹ́ jẹ́ akínkanjú ògbójú ọdẹ ni gbogbo ìgbésì ayé rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ Weir (1934)1 ogójì ọba ni ó ti jẹ ní ìlú Àkúrẹ́ láti ìgbà tí ìtàn ti bẹ̀rẹ̀. Ọba mẹrìn sì ti jẹ lẹ́yìn àkókò tí Weir ṣe ìwádìí tirẹ̀. Àpapọ̀ ọba tí ó ti jẹ ní Àkúrẹ́ jẹ́ mẹ́rìnlélógójì2. À rí igbọ́ pé obìnrin méjì ni ó wà nínú wọn.3 Obìnrin kìínì ni Èyé – Aró ti ó jẹ ọba ní ọdún 1393 títí di ọdún 1419 A.D. Ohun tí o fà á tí oyè fi kan obìnrin yìí nip é, òun nìkan ni ifá rẹ fọ rere láàrin àwọn tí wọn dárúkọ fún ifá rẹ fọ rere láàrin àwọn tí wọn dárúkọ fún Ifá. Àwọn Àkúrẹ́ sì fẹ́ tẹ̀ lé ohun tí Ifá sọ nítorí pé wọn ti fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọba jẹ tí wọn kò pẹ lórí oyè. Ifá sọ pé obìnrin yìí yóò pẹ́ lórí oyè àti pé àsìkò rẹ̀ yóò tuba tùṣẹ. Obìnrin kejì tí ó jẹ ọba ní Èyémọhin, ó wà lórí oyè ni ọdún 1705 títí di ọdún 1735. A gbọ́ pé nígbà tí wọn tún dá ifá ní àsìkò yìí, ifá kò mú ọmọkùnrin ọmọ-ọba kọọkan, bí kò ṣe ọmọ-ọba-bìnrin yìí. Eléyìí ni ó mú kí àwọn ará Àkúrẹ́ fi ọmọ-ọba-bìnrin yìí jẹ ọba. |
20231101.yo_2276_11 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | 1. Wo: N.A. C. Weir 1934 Akurẹ District Intelligence Report. Filo 41, 30014 Nigerian National Archives Ìbàdàn. |
20231101.yo_2276_12 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Ọba Adéṣidá Afúnbíowó ni a gbọ́ pé, ó pẹ́ láyé jù gẹ́gẹ́ bí ọba ìlú Àkúrẹ́. Ó lo bí ọgọ́ta ọdún láyé (1897 -1957.) |
20231101.yo_2276_13 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Èròngbà iṣẹ́ yìí ni láti ṣe ìwádìí sí ohun tí àwọn ará Àkúrẹ́ máa ń lo orin fún ní àwùjọ wọn. Ó jẹ́ ọ̀nà láti ṣẹ̀dámọ̀ àwọn orin àwùjọ Àkúrẹ́, láti ṣàlàyé ìṣẹ̀ṣe àwọn orin wọn àti láti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn kókó tí orin máa ń dá lé. |
20231101.yo_2276_14 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Ìlò orin ní àwùjọ Àkúrẹ́ tí iṣẹ́ ìwádìí yìí dá lé ni èròngbà láti sí ọ̀nà titun sílẹ̀ fún àtúpalẹ̀ lítíréṣọ̀ lọ́nà láti mú kí àwọn orin wọ̀nyí yé ni dáradára. Ó tún jẹ́ ọ̀nà láti ṣí ọ̀nà titun sílẹ̀ fún ìwádìí lórí lítíréṣọ̀ alohùn pàápàá ti àwùjọ Àkúrẹ́ tí ó jẹ́ pé iṣẹ́ ìwádìí kò ì tí pọ̀ lórí rẹ̀. |
20231101.yo_2276_15 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | À ṣe àkójọ-èdè-fáyẹ̀wò láti ọdọ̀ àwọn ọ̀kọrin. Apohùn ìṣẹ̀nbáyé àti àwọn abínà-ìmọ̀. A ṣe àdàkọ àwọn orin tí a gbà jọ, a sì ṣe àgbéyẹwò àwọn iṣẹ́ tí wọn ti wà nílẹ̀ lórí orin ní àwọn agbègbè mìíràn. A ka àwọn ìwá tí ọwọ́ wa tẹ̀ ní agbègbè náà, a sì rí ọ̀kọ́ tó wúlò fún wa lórí orí ọ̀rọ̀ tí iṣẹ́ wa yìí dá lé. |
20231101.yo_2276_16 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Iṣẹ́ ìwádìí yìí fi hàn pé àkọ́jinlẹ̀ orin nípa síṣe àtúpalẹ̀ kókó ohun tí à ń lo orin fún pọn dandan kí a tó le ní òye iṣẹ́ ọnà àti Ìtumọ̀ orin ní àpapọ̀. |
20231101.yo_2276_17 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81 | Àkúrẹ́ | Iṣẹ́ yìí tún fi hàn pé ẹ̀sìn ní o máa ń bí àwọn orin ẹ̀sìn ní àwùjọ Àkúrẹ́ àti pé àṣà àti ìṣe àwùjọ ni ó máa ń ṣe okùnfà fún àwọn orin aláìjọmẹ́sìn. |
20231101.yo_2277_0 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Ìtàn tí n ó sọ nípa bí eégún ̣ṣe délé ayé yìí, mo gbọ́ ọ láti ẹnu baba babaà mi ni kí ó tó di pé wọ́n jẹ́ ìpè Olódùmarà ní nǹkan bí ọdún mẹ́wàá sẹ́hìn. Ìdí pàtàkì tí ó jẹ́ kí n fi ara mọ́ ìtàn náà ni pé ó fi ara jọ ìtàn tí mo kà lórí nǹkan kan náà ìwé Òmọ̀wé J.A. Adédèjì1. Ìdí mìíràn tí ó jẹ́ kí n fi ara ḿọ́ ìtàn náà yàtọ̀ sí òmíràn nip é ẹnu àwọn tí mo ṣe ìwadìí lọ́wọ́ wọn kò kò lóŕi ọ̀rọ̀ náà. Ó dà bí ẹni pé olúkálukú ni ó fẹ́ fi bu iyi kún ìlú tirẹ̀ pé ní ìĺú tòun ni awo Iségún ti bẹ̀rẹ̀. Ògbẹ́ni Táyélolú Ṣáṣálọlá tí ó ń gbé ni ìlú Oǹd́ó tilẹ̀ sọ f́ún mi pé ní ìlú Ọ̀fà ni Eégun ti ṣẹ̀. Nígbà tí mo sì fi ọ̀rọ̀ wá a lénu wò, mo rí i pé ọmọ Ọ̀fà ni baba rẹ̀. Ọmọ Iwékọṣẹ́ tún sọ fún mí pé ó dá òun lójú pé ní ìlú Òkè-igbó lẹ́bàá Oǹd́ó ni Eégún ti kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀. |
20231101.yo_2277_1 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Nínú Ìdàrúdàpọ̀ yìí ni mo wá rò ó pé bí ènìyàn bá fẹ́ẹ́ mọ òtítọ́ tí ó wà nídìí ọ̀rọ̀ náà, àfi bí ènìyàn bá tọ Ifá lọ nítorí pé If́a kò ní í gbè sẹ́hìn ẹnìkẹ́ni. Orísìí ìtàn méjì ni mo sì wá rí ńinú Ifá. Ṣùgbọ́n ìtàn kéjì ni mo fi ara mọ́. Ìdí tí mo sì ṣe fi ara mọ́ ọn náà nip é ó jọ ìtàn tí mo ti gbọ́ lẹ́nu baba babaà mi. Èyí nìkan kọ́: mo fi ara mọ́ |
20231101.yo_2277_2 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | 1. Adédèjì J.A. The Alárìnjó Theatre: The Study of a Yorúbà theatrical Art form its Origin to the Present Times. Ph.D. Thesis (University of Ibadan), 1969, pp. 20-90. |
20231101.yo_2277_3 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Ìtàn àkọ́kọ́ yìí wà nínú Odù Èjì ogbè, Ẹsẹ̀ Èkejì. Ìbéjì ni wọ́n fi Eẹgún bí. Ọ̀kán kú èkejì sì wà láàyè. Èyí tí ó wà láàyè si wá ́n sunkún ṣá. Wọ́n wá dọ́gbọ́n, wọ́n dáṣọ̣ Eégún. Wọ́n mú èyí tí ó wà ẹnìkan lórí. Ẹni tí ó gbé Eégún náà ń pe ẹni tí ó wà láàyè pé: |
20231101.yo_2277_4 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Ìtàn ke jì wà nínú ìwé Ọ̀mọ́wé J.A. Adédèjì tí mo ti tọ́ka sí tẹ́lẹ̀. Ńińu Odù Ọ̀wọ́nrínsẹ̀ ni ó wà. Ìtàn náà lọ báyìí: |
20231101.yo_2277_5 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Nígbà TÌ Ọ̀wọ́nrín tí ọ́ ń gbé ní Ìsányín dolóògbé, àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta - Arúkú, Arùḱu àti Aròḱu-rọja-má-tà kò ní owó lọ́wọ́ lati fi ṣe òkú bàbáa wọn. Ìrònú ọ̀ràn náà pọ̀ dé bi pé èyí Arúkú tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún gbogbo wọn fi ìlú sílẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èyí àtẹ̀lé rẹ̀, Arùkú, mú ìmọ̀ràn wá pé kí àwọn ó ta òkú náà1. Èyí àbúrò wọn, Aròkú-rọja-má-tà, bá kiri òkú náà lọ. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó ti kiri fún ìgbà díẹ̀ tí kò ti rí ẹni ra òkú náà ni ó ti sú u, ó sì wọ́ òkú náà jùnù sínú igbó; ó bá tirẹ̀ lọ. Lẹ́hìn ìgbà díẹ̀, èyí ẹ̀gbọ́n di baálé ilé, ó sì gba ipò bàbá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ológbìín. Gẹ́gẹ́ bí ipò rẹ̀ òun ni ó sì wá di Ológbo2. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé abuké ni, Aláàfin fún un ní ìyàwó kan, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ìyá Mòsè. Ṣùgbọ́n fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọd́un, Mòsè kò gbọ́ mokòó |
20231101.yo_2277_6 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | rárá; ó kàn ń fọwọ́ osùn nu ògiri gbígbẹ ni. Èyí ni ó mú kí ọkọ rẹ̀ Ológbìín tọ Ọ̀rúnmìlà lọ. Nígbà tí ó débà tí ó débẹ̀, ó ńi “emi ló dé tí ìyàwó òun fi rọ́mọ lẹ́hìn adìẹ tó bú púrú sẹ́kún?” Ọ̀rúnmìlà sì sọ fún un pé àfi tí ó bá lè ṣe ẹ̀yẹ ìkẹhìn fún baba rẹ̀ tí ó ti kú kí ìyàwó rẹ̀ ó tó lè bímọ. |
20231101.yo_2277_7 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Ní àkókò yìí, Ìyá Mòsè ti lọ́ sọ́dọ̀ Amúsan láti lọ ṣe ìwádìí ohun tí ó fa sábàbí. Bí Ìyá Mòsè ti ń bọ̀ láti odò Asà níjọ̀ kan ni elégbèdè kan jáde sí i láti inu igbó tí ó sì bá a lòpọ̀. Bẹ́ẹ̀ ni Ìyá Mosè ṣe bẹ́ẹ̀ lóyún. Mòsè kò sì lè jẹ́wọ̀ bí ó ṣe lóyún fún ọkọ rẹ̀. Ó sì fọ̀n ọ́n ó di ọ̀dọ̀ Ọlọ́pọndà tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n Ìyá Mòsè. Níbẹ̀ ni ó ti bí ìjímèrè. Ìtìjú a máa pa gbajúmọ̀. Nígbà tíìtìjú pọ̀ fún Mòsè, ó tún fọn ọ́n, ó di ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀. Bí ó sì ti ń lọ lọ́nà ni ó ju ìjímèrè sínú igbó. Ṣé ọkọ rẹ̀ kò kúkú mọ nǹ̀̀kan tí ó bí. Nígbà tí ó dijọ̀ keje ni Ato tí ó jẹ́ ìyàwó Ògògó tí ó jẹ́ ọmọ Ìgbórí rí ìjímèrè igbó. Ní àkókò tí a ń wí yìí. Ológbìín ti gbọ́ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀. Ó ti lọ sí ọ̀dọ̀ Ọ̀rúnmìlà, Ifá sì ti sọ fún un pé sùúrù lẹbọ. Ifá ní kí Ológbìín máa tọ́jú abàmì ọmọ náà, ṣùgbọ́n kí ó tún ṣe ẹ̀yẹ ìkọhìn fún baba rẹ̀ nìpa lílọ sí igbó níbi tí wọ́n ti rí abàmì ọmọ náà láti lọ ya eégún baba rẹ̀. Àwọn ohun tí Ifá pa láṣẹ ètùtù náà ni ẹgbẹ̀rin àkàrà, ẹgbẹ̀rin ẹ̀kọ, ẹgbẹ̀rin pàsán àti ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ẹmu. Igbó tí wọn ti ṣe ètùtù náà ni a mọ̀ sí igbó ìgbàlẹ̀ di òní olónìí. |
20231101.yo_2277_8 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Aláràn-án òfí tí ó jẹ́ ìyekan Ológbìín ni ó gbé aṣọ òdòdó tí baba Ológbìín tí ó ti kú ń lò nígbà ayé rẹ̀ bora, tí ó sì tún gbé abàmì ọmọ náà pọ̀n sẹ́hìn, tí ó sì ń jó bọ̀ wá sí àárín ìlú láti inú igbó náà pẹ̀lú ìlù àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lẹ́hìn rẹ̀. Ológbìín ti fi lọ̀ tẹ́lẹ̀ pé òun yóò ṣe ẹ̀yẹ ìkẹhìn fún baba òun tí ó ti kú nítorí náà nígbà tí wọ́n rí Aláràn-án Òrí nínú aṣọ òdòdó, wọ́n ṣe bí Ológbìín tí ó ti kú ni, pàápàá tí abàmì ọmọ tí ó pọ̀n dà bí iké ẹ̀hìn rẹ̀. Àwọn ènìyàn ń sún mọ́ ọn láti wò ó dáadáa ṣùgbọ́n pàṣán tí wọ́n fi ń nà wọ́n kò jẹ́ kí wọn sì wọ ilé baba Ológbìín tí ó ti kú lọ. Bí àwọn ènìyàn ti ń wò ó ni wọ́n wí pé: |
20231101.yo_2277_9 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Báyìí ni àrá ọ̀run náà ṣe ṣe káàkiri ìlú tí ó sì ń súre fún àwọn ènìyàn. Nígbà tí ó sì ṣe ó wọ káà lọ. Wọ́n sì pe Ato kí ó máa tọ́jú abàmì ọmọ náà. Wọ́n sì ń pe abàmì ọmọ náà níOlúgbẹ̀rẹ́ Àgan. Nínú káà yìí ni Ògògó tí ó jẹ́ ọkọ Ato, ti ń wo ọmọ náà nígbàkúùgbà. Àwọn ènìyàn inú ilé a sì máa pe Ògògó ní Alàgbọ̀ọ́-wá1. Alágbọ̀ọ́-wá yìí ni ó sì di Alágbàá (baba Maríwo) títí di òní olónìí. Odù Òwọ́nrínsẹ̀ náà nìyí: |
20231101.yo_2277_10 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Bí a bá sì tún wo oríkì eégún, ọ̀rọ̀ nípa bí eégún ṣe kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ yóò túbọ̀ tún yé wa sí i. Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀, oríkì ni ọ̀rọ̀ tí ó júwe ìwà, ìṣe2 àti Ìtàn ìbí àwọn òrìṣà, ènìyàn àti àwọn nǹkan mìíràn. Oríkì Egúngún náà lọ báyìí: |
20231101.yo_2277_11 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | 1. Adédèjì, J.A. The Alárinjó Theatre. The Study of a Yorùbá theatrical Art from its Origin to the Present Times. Ph.D. Thesis (University of Ibadan 1969). Pp. 60-88. |
20231101.yo_2277_12 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Theatrical Art from its Origin to the Present Times.) Ph.D. Thesis (University of Ibadan 1969). Pp. 60.88. |
20231101.yo_2277_13 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Ṣùgbọ́n láyé òde òní ń kọ́? Báwo ni a ṣe ń ‘ṣẹ́’ eégún? Ó ṣòroó sọ pàtó pé kò níí sí ìyàtọ̀ díẹ̀ láti ìlú dé ìlú lórí ọ̀rọ̀ bí a ṣe ń ‘ṣẹ́’ eégún. Ṣùgbọ́n bí ìyàtọ̀ kàn tilẹ̀ wà náà, kò pọ̀ rárá. Mo léèrò wí pé àwọn obìnrin kò ní í mọ ìdí abájọ. Obìn in a sì máa mọ awo, ṣùgbọ́n bí wọ́n bá tilẹ̀ mọ ọ́n, wọn kò gbọdọ̀ wí. Àgbàlagbà Ọ̀jẹ̀ nikan ni wọ́n ń ‘sẹ́’ eégún rẹ̀ bí ó bá kú. Bí a bá ti fẹ́ ‘ṣẹ́’ eégún ẹni tí ó ti kù yìí, a ó wá pàsán1 mẹ́ta, a ó wá aṣọ fúnfún tí ó tóbi, a ó tún wá ẹni tí kò sé kò yẹ̀ gíga ẹni tí a fẹ́ ‘ṣẹ́’ eégún rẹ̀ náà. Ìtàn sọ fún mi pé láyé àtìjọ́, tí wọ́n bá pe òkú Òjẹ̀ nígbà tí wọn kò bá tíì sin ín, pé ó maa ń dáhùn tí yóò sì bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀. Ṣùgbọ́n eke ti dáyé, aáṣà ti dÁpòmù, nǹkan ò rí bí í ti í rí mọ́ nítorí pé a kò lè ṣe é bí a ti í ṣe é tẹ́lẹ̀. |
20231101.yo_2277_14 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Bí àwọn èròjà tí a kà sílẹ̀ wọ̀nyí bá ti dé ọwọ́ àwọn àgbà Òjẹ̀, a ó mú ọkùnrin tí kò sé kò yẹ̀ gíga òkú Òjẹ̀ náà lọ sínú igbó ìgbàlẹ̀. Àwọn àgbà Ọ̀jẹ̀ nìkan ni wọ́n lè mọ ẹni náà. Lẹ́hìn èyí, àwọn Òjẹ̀ yókù àti àwọn ènìyàn yóò máa lu ìlù eégún ní ibi tí wọn ti pa pẹrẹu lẹ́bàá igbó ìgbàlẹ̀ náà. Ọ̀wẹ́wẹ́2 ni ìlù tí a ń wí yìí. Tí wọ́n bá ti ń lu ìlù báyìí, àgbà Ọ̀jẹ̀ kan yóò máa mú ọ̀kọ̀ọ̀kan nínú pàṣán yẹn, yóò |
20231101.yo_2277_15 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | 1. Òpá àtòrì tí a fi irin gbígbóná ṣe ọnà sí lára tí àwọn tí ó máa ń tẹ̀lé eégún lọ sóde fi ń na ènìyàn. |
20231101.yo_2277_16 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Sì máa fin a ilẹ̀ lẹ́ẹ́mẹ́ta mẹ́ta. Bí ó bá ti ń ṣe bẹ́ẹ̀ ni yóò máa pe orúkọ ẹni tí ó ti kú náà tí a sì fẹ́ ‘sẹ́’ eégún rẹ̀ yìí. Nígbà tí ó bá ti fi pàṣán kẹta na ilẹ̀ lẹ́ẹ́kẹ́ta tí ó sì tún pe orúkọ ẹni tí ó ti kú náà, ẹni tí ó ti wà nínú igbó ìgbàlẹ̀ yóò dáùn, yóò sì máa bọ̀ pẹ̀lú aṣọ fúnfún báláú lọ́rí rẹ̀. Àwọn ènìyàn yóò sì máa yọ̀ pé baba àwọn dáhùn, pé kò tilẹ̀ kú rárá. |
20231101.yo_2277_17 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Bí babá bá ti jáde báyìí ni àwọn ènìyàn yóò máa béèrè oríṣìíríṣìí nǹkan lọ́wọ́ rẹ̀, tí baba náà yóò sì máa dá wọn lóhùn. Nígbà tí ó bá ti jó dáadáa fún ìgbà díẹ̀, yóò súre fún àwọn ènìyàn kí ó tó padà bá inú igbó ìgbàlẹ̀ lọ. Bí eégún ṣe ń jáde lóde òní nìyí ní ìlú Oǹdó. |
20231101.yo_2277_18 | https://yo.wikipedia.org/wiki/E%C3%A9g%C3%BAn | Eégún | Gẹ́gẹ́ bí yóò ti hàn níwájú, kì í ṣe èdè tí àwọn ará Oǹdó ń fọ̀ lẹ́nu ni wọ́n fi ń kógbèérè: èdè Ọ̀yọ́ ni wọ́n ń lò. Èyí jẹ́ ìtọ́kasí kan láti fi hàn pé láti Ọ̀yọ́ ni eégún ti kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ kí ó tó tàn ká gbogbo ilẹ̀ Yorùbá. Ní ayé àtijọ́, nígbà tí ogun àti ọ̀tẹ̀ pọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni ogún kó láti ìlú kan dé òmíràn. Àwọn mìíràn lè ṣe àtìpó níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ kí wọn ó sì padà sílé nígbà tí wọn bá ti ra ara. Àwọn mìíràn a tilẹ̀ kúkú jókòó sí ìlú náà wọn a sì fẹ́ Ìyàwó níbẹ̀. Bẹ́ẹ̀ àṣà kò ṣeé fi sílẹ̀ bọ̀rọ̀. Àwọn ènìyàn wọ̀nyí kò gbàgbé ẹ̀sìn wọn bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ń gbé e |
20231101.yo_2281_0 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Rárà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ewì àbáláyè ni ilẹ́ ẹ̀ Yorùbá. Gẹ́gẹ́ bí mo tí ṣe ṣe àlàyé nínú ọ̀rọ̀ àkọ́sọ, agbègbè Ìbàdàn àti Ọ̀yọ́ ni irú ewì báyìí tí wọ́pọ̀. Òun ni ọ̀kan nínú àwọn ewì `tí a máa ń fi ń yin ẹnikẹ́ni tí a bá ń sun ún fún yálà ní ìgbà tí ó bá ń ṣe ìnáwó tàbí àríyá kan. Bí ó ti jẹ́ ohun tí a fí ń yin ènìyàn náà ni ó tún jẹ́ ohun tí a lè fi pe àkíyèsí ènìyàn sí ìwà àléébù tí ó ń hù. Bákan náà, rárà jẹ́ ọ̀nà kan tí a fi máa ń ṣe àpọ́nlé ènìyàn ju bí ó tí yẹ lọ, nígbà tí a bá sọ pé ó ṣe ohun tí ó dà bí ẹni pé ó ju agbára rẹ̀ lọ. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orúkọ ni a máa ń bá pàdé nínú un rárà ó sì dà bí ẹni pé àwọn orúkọ wọ̀nyí jẹ́ orúkọ àwọn ẹni àtijọ́ tí ó jẹ́ bí i baba ńlá ènìyàn tí ó ṣẹni sílẹ̀. |
20231101.yo_2281_1 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Nítorí pé ọ̀rọ̀ iyìn àti ẹ̀pọ́n la máa ń bá pàdé nínú un rárà, èyí máa ń mú inú àwọn ènìyàn tí ó bá ń gbọ́ rárà náà dùn, orí a sì máa wu. Ní ààrin orí wíwú àti yíyá báyìí ni àwọn ènìyàn tí à ń sun rárà fún yíò tí máa fún àwọn asunrárà náà ní ẹ̀bùn tí wọn bá rò pé ó tọ́ sí wọn. |
20231101.yo_2281_2 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Rárà sísun báyìí pé oriṣI méjì tàbí mẹ́ta ni agbègbè ibi tí wọn ti ń suún. OríṣI kan ni àwọn èyí tí obìnrin-ilé máa ń sun. tí àwọn obìnrin ilé wọ̀nyí kò ń ṣe gbogbo ìgbà. Ìgbà tí ọmọ-ilé kan ọkùnrin tàbí ọmọ-osu, tàbí ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó ilé bá ń ṣe ìnáwó ni wọn tóó sun ti wọn. OríṣI kejì nit i àwọn ọkùnrin tí ó máa ń lu ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀. Àwọn ẹni kẹta ni àwọn ọkùnrin tí kò ń lú sí tiwọn. |
20231101.yo_2281_3 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Jákèjádò ilẹ̀ ẹ Yorùbá, ó ní ìgbà tí a máa ń sába ń kéwì. Gẹ́gẹ́ bí mo ti sọ nínú ọ̀rọ̀ àkọ́sọ àti bí òwe àwọn Yorùbá tí ó sọ wí pé “Ẹ̀ṣẹ́ kì í ṣẹ́ lásán”, bákan náà ni fún rárà, a kì í déédé sun rárà láìjẹ́ pé ó ni nǹkankan pàtàkì tí à ń ṣe. |
20231101.yo_2281_4 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Gẹ́gẹ́ bí a ti rí i àti bí a ṣe gbọ́ láti ẹnu àwọn asunrárà tí a wádìí lọ́dọ̀ ọ wọ́n, àwọn àsìkò tí a máa ń sun rárà jẹ àsìkò ti a bá ń ṣe àríyá tàbí àjọyọ̀. Gẹ́gẹ́ bí àwọn asunrárà Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́ tí wo, ó jẹ́ ìwá àti ìṣe wọn láti máa lọ̀ ọ́ sun rárà fún Aláafìn ní àǹfin rẹ̀. Lẹ́hìn ti ààfin sísun fún yìí, wọn a tún máa sún tẹ̀lé ọba yìí bí ó bá ńlọ sí ìdálẹ̀ kan. Wọ́n ń ṣe èyí kí àwọn ẹni tí ọba náà kọjá ni ìlú u wọn lè mọ́ ẹni tí ń kọjá lọ. |
20231101.yo_2281_5 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Ní ìlú Ọ̀yọ́ àti Ìbàdàn, ó dà bí ẹni pé a ya ọjọ́ kan sọ́tọ̀ fún rárà sísun yìí. Ọjọ́ yìí ní à ń pè ní ọjọ́ ọ Jímọ́ọ̀ Ọlóyin. Ọjọ́ yìí máa ń pé ní ọjọ kọkàndílọ́gbọ̀n sí ara wọn. Ọjọ́ yìí ni á gbọ́ pé ó ṣe pàtàkì nínú ìkà oṣù àwọn Yorùbá. Ọjọ́ yìí ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé wá sí ààrin ìlú láti oko tí wọ́n ń gbé yálà láti wá ṣo ìpàdé e mọ̀lẹ́bí tàbí láti wá ṣe ohun pàtàkì míràn. Ní ọjọ́ yìí, àwọn ènìyàn máa ń pọ̀ nínú ìlú jú bí ó ṣe máa ń wà tẹ́lẹ̀ lọ. |
20231101.yo_2281_6 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Ní Ọ̀yọ́ ní ọjọ́ Jímọ́ọ̀ Olóyin yìí, àwọn asunrárà náà yíò máa káàkiri ilé awọn Ọ̀yọ́ Mèsì àti àwọn ìjoyé ìlú yókù. Lẹ́hìn ti èyí wọn ó padà sí àafin láti wá jókòó sí ojú aganjú. Níhìín ni wọn yíò tí máa sun rárà kí gbogbo àwọn àlejò tí ó bá ń lọ kí Aláàfin. Wọ́n ń ṣe èyí láti lè rí ẹ̀bùn gbà lọ́wọ́ àwọn àlejò náà; àti láti lè jẹ́ kí Aláàfin mọ irú àlejò tí ń bò. |
20231101.yo_2281_7 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Bákan náà a gbọ́ pé ní ayé àtijọ́ ní ìgbà tí ogun wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá, àwọn jagunjagun máa ń ní asunrárà tí í máa sun rárà tẹ̀ lé wọn bí wọn bá ńlọ sí ogun1. Mo rò pé wọ́n ń ṣe èyí láti lé fún àwọn jagunjagun náà ní ìṣírí. Bákan náà wọ́n a tún máa sọ fún wọn bí ó ti ṣe yẹ kí wọ́n ṣe lójú ogun. |
20231101.yo_2281_8 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Lẹ́hìn ti kí a sún rárà fún àwọn ọba, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà tí a tún ń sun rárà jẹ́ àwọn àsìkò ìnáwó tàbí àríyá. Ni ìgbà tí ènìyàn bá ń ṣe Ìgbéyàwó àwọn onírárà a máa sun rárà fún onínàwó náà. Fún àpẹẹrẹ ni ibi ìyàwó tí àwọn obìnrin bá ń sun rárà fún ẹni tí ń gbé Ìyàwó náà wọn ó máa wí báyìí: |
20231101.yo_2281_9 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Ìgbà tí a tún máa ń sun rárà ni ibi ìnáwó ìsọmọ lórúkọ. Irú ìsọmọlórúkọ yìí gbọ́dọ̀ jẹ́ èyí tí a ṣe tìlù tìfọn. Bákan náà bí a bá ń sin òkú àgbàlagbà ó lè jẹ́ ìyá, bàbá, tàbí ẹ̀gbọ́n ẹni. Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ibi tí a bá gbé ń ṣe nǹkan tí ó lè mú ìdùnnú lọwọ, yálà ilé ṣíṣí ní tàbí ìwuyè ni a ti i máa ń rí àwọn asunrárà. |
20231101.yo_2281_10 | https://yo.wikipedia.org/wiki/R%C3%A1r%C3%A0 | Rárà | Ní ayé ìsin yìí a tún máa ń rí àwọn asunrárà nì ìgbà tí àwọn ènìyàn bá ń ṣe ọdún. Nínú ọdún iléyá ti àwọn mùsùlùmí tàbí ọdún un kérésìmesì tí àwọn onígbàgbọ́, àwọn onírárà a máa káàkiri ilé àwọn ẹlẹ́sìn wọ̀nyi, láti kí wọn kú ọdún nípa rárà sisun. Àwọn ọlọ́dún wọǹyí yìò sì máa fún àwọn asunrárà náà lẹ́bùn. Àwọn asunrárà ọkùnrin tí ó máa ń fi rárà ṣe iṣẹ́ ṣe ni wọ́n máa ń ya ilé kiri láti sun rárà. |
20231101.yo_2284_0 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Eré àpíìrì jẹ́ ohun tí ó ní orin, ìlù àti ijó nínú. Gẹ́gẹ́ bí ìwádìí, erée pelebe ni ó di àpíìrì níwọ̀n ìrínwó ọdún sẹ́hìn. Ìjerò-Èkìtì ni eré àpíìrì yìí ti bẹ̀rẹ̀. Ìtàn fi yé wa pé wọn mọ̀ ọ́n fúnra wọn ni, kì í ṣe wí pé wọ́n mú un wá láti Ilé-Ifẹ̀ tí ó jẹ́ orírun Yorùbá. Eré yìí bẹ̀rẹ̀ ní àkókó tí àwọn ará Ìjerò mú Alákeji jọba dípò ẹ̀gbọ́n rẹ̀ tí ó jẹ́ ọba. Ìtàn fi yé wa pé nígbà tí ogun àti ọ̀tẹ̀ yí ìlú Ìjerò ká, ẹ̀gbọ́n Alákeji tí ó jẹ́ ọba wá gbéra láti lọ wá ọ̀nà tí wọn yíò fi ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá tí ó yí wọn ká. Nígbà tí àwọn ará ìlú kò tètè rí i, wọ́n gbèrò láti fi àbúrò rẹ̀ Alákeji jọba. Nígbà tí ẹ̀gbọ́n Alájeji wá padà, ó rí i pé wọ́n ti mú àbúrò òun jọba. Ó ka gbogbo ètùtù tí wọ́n ní kí ará ìlú ṣe láti lè ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá tí ó yí wọn káàkiri. Ìtàn yìí náà ni ó fi yé wa pé kò torí èyí bínú kúrò ní ìlú. Ó sọ fún àwọn ará ìlú pé kí wọn máa ṣe eégún fún òun lákòókò ọdún Ògún fún ìrántí òun, kí wọn sì máa ṣeré àpíìrì tí egúngún yìí bá jáde. Lẹ́hìn èyí ni eré àpíìrì ti bẹ́rẹ̀ ní ìlú Ìjerò-Èkìtì. |
20231101.yo_2284_1 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Àwọn alápìíìrì tí ó ti dolóògbèé ni Ọ̀gbẹ́ni Àṣàkẹ́ Ìwénifá, Ajórùbú, Àjàlá, Olóyè Ọsọ́lọ̀ Òkunlọlá, Afọlábí Ọ̀jẹ̀gẹ̀lé. Àwọn eléré àpíìrì tí ó tì ń ṣeré ní Ìjerò báyìí ni Èyéọwá Ọmọyẹyè, S.O. Fómilúsì tí ó sọ ìtàn bí eré àpíìrì ṣe bẹ̀rẹ̀ ní Ìjerò-Èkìtì. Gẹ́gẹ́ bí mo ti fẹnu bà á ní ọ̀rọ̀ àkọ́sọ, ìbágbé pọ̀ àwọn èèyàn ni ó mú eré àpíìrì tàn kálẹ̀ ní Ìwọ̀ Oòrùn Èkìtì. |
20231101.yo_2284_2 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Èèyàn méjọ sí mẹ́wàá ni ó sábà máa ń ṣeré àpíìrì, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ènìyàn mẹ́rin péré ni í máa ń lu ìlù. Ohùn méjì pàtàkì ni a ń bá pàdé nínú eré àpíìrì. Èkíní ni ohùn pàtàkì ni a ń bá pàdé nínú eré àpíìrì. Èkíní ni ohùn alámọ̀, tó sábà máa ń jáde lẹ́nu nígbà tí eléré àpíìrì bá fẹ́ salámọ̀. Èyìí fẹ́ jọ ohùn arò. Ohùn orin ni èkejì tí a máa ń bá pàdé nínú eré àpíìrì. |
20231101.yo_2284_3 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Lítíréṣọ̀ aláfohùnpè ni eré àpíìrì. Eré yìí sábà máa ń ní olórí tí yíò máa dá orin, tí àwọn yòókù yíò máa gbè ti ìlù bá ń lọ lọ́wọ́. Ẹni tí ń lé orin yìí lè ṣe ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo tàbí ènìyàn méjì lápapọ̀ láti lè fi ohùn dárà nínú orin lílé. Nígbà míràn, ó lè ṣe ẹni tí ń dá orin náà ni yíò máa salámọ̀ láàrin eré, ó sì tún lè jẹ́ ènìyàn méjì yàtọ̀ sí àwọn tí ń dárin. Kíkọ́ ni mímọ̀ ni ọ̀rọ̀ eré yìí. Ẹni tí kò kọ́ ìlù eré àpíìrì tàbí orin rẹ̀ kò lè mọ̀ ọ́n. Àwọn eléré àpíìrì máa ń ronú láti lè mú kí wọn mú oríṣìíríṣìí ìrírí wọn lò nínú orin wọn. Èyí fi ìdàgbàsókè ti ń dé bá eré àpìírì hàn. Ní àtijọ́ ọdún Ògún ni eré àpíìrì wà fún, ṣùgbọ́n níwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé yíyí ni ayé ń yi, àwọn òṣèré náà wá ń báyé yí nípa pé kí wọn ṣẹ̀dá orin àpíìrì fún onírúurú àṣeyẹ tí a ó mẹ́nu bà níwáju. Eré àpíìrì kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìmọ̀ àti òye tí ó fi ọgbọ́n, ìrònú, àkíyèsí, èrò, èèwò àti ìgbàgbọ́ àwa Yorùbá hàn. |
20231101.yo_2284_4 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Àwọn ohun tí ó ya eré àpíìrì sọ́tọ̀ sí eré ìbílẹ̀ míràn ni, irúfẹ́ ìlù tí a ń lò fún eré yìí, ọ̀nà tí a ń gbà kọ orin àpíìrì àti bí ìlù tí a ń lò ṣe ń dún létí. Nǹkan mìíràn tí ó tún ya eré yìí sọ́tọ̀ sí òmíràn nip é agbègbè Ìwọ̀ Oòrùn Èkìtì nìkan ni a ti ń ṣe irú eré yìí ní gbogbo ilẹ̀ káàárọ̀-oò-jíire. |
20231101.yo_2284_5 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Àwọn ohun tí a ń lò bí ìlù nínú eré àpíìrì láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ wá ni agbè tí ajé wà lára rẹ̀. Agbè àti ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ jẹ́ ohun èlò ìlù lílù àti ijó jíjó tí a dá sílẹ̀ ní àkókò Ẹ́mpáyà Bìní. Àwọn Ẹ̀gùn àti Pópó ni ó dá a sílẹ̀ ní àkókò ọba Oníṣílè. Agogo náà tún jẹ́ ọ̀kan nínú ohun èlò eré àpíìrì. Àwọn agbè tàbí ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ wọ̀nyí máa ń tóbi jura wọn, kí dídún wọn bàá lè yàtọ̀ síra. Orúkọ tí a ń pe ajé tàbí agbè wọ̀nyí ní Ìwọ̀ Oòrùn Èkìtì ni, Èyé ajé tàbí Èyé ùlù, kugú, ọ̀pẹẹẹrẹ àti agogo. Bí àwọn agbè wọ̀nyí ṣe tóbi sí ni a ṣe fún wọn lórúkọ. Wọn máa ń lo ìrùkẹ̀rẹ̀ láti jó ijó àpíìrì. Ìdàgbàsókè tí ń dé bá ohun èlò eré àpíìrì. Ní Ìwọ̀ Oòrùn Èkìtì gẹ́gẹ́ bí ìwádìí ṣe fi hàn. Àwọn Yorùbá ló ń pà á lówe pé, ‘báyé bá ń yí ká báyé yí, bígbà bá ń yí ká bá ìgbà yí, ìgbà laṣọ, ìgbà lẹ̀wù, ìgbà sì ni òdèré ikókò nílè Ìlọrin.’ Nísìsíìyí, arábìnrin Adépèjì Afọlábí tí ó jẹ́ eléré àpíìrì ní Ìdó-Èkìtì ti mú ìlù Bẹ̀mbẹ́ àti àkúbà mọ́ agbè àti agogo tí a ń lò tẹ́lẹ̀ nínú eré àpíìrì. |
20231101.yo_2284_6 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Àwọn olùgbọ́ kó ipa pàtàkì nínú eré àpíìrì tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú Lítíréṣọ̀ aláfohùnpè. Àwọn olùgbọ́ máa ń gbe orin pẹ̀lú àwọn òṣèré. Wọn a máa jó, wọn a sì máa pa àtẹ́wọ́ tí erá bá ti wọ̀ wọ́n lára. Irú ìtẹ́wẹ́gbà báyìí sì máa ń mú kí ọ̀sèré túbọ̀ ṣe eré tí ó dára lójú agbo. |
20231101.yo_2284_7 | https://yo.wikipedia.org/wiki/Apiiri | Apiiri | Gẹ́gẹ́ bí àlàyé tí mo ṣe ṣáájú, ọ̀nà tí àwọn alápíììrì ń gbà ṣe eré wọn ni kí olórí eré máa lé orin fún àwọn elégbè tí yíò máa gbe orin tí ó bá dá. Olórí lè kọ́kọ́ kọrin kí alámọ̀ tẹ̀lé e tàbí kí ó kọ́kọ́ salámọ̀ kí ó tó kọrin. Kò sí bátànì kan pàtó tí alápìíìrì gbọ́dọ̀ tẹ̀lé nínú eré nítorí pé bí ó bá ṣe wuni ni a ṣe ń ṣèmọ̀le ẹni Ní àpẹẹrẹ ìsàlẹ̀ yìí, alámọ̀ ni eléré àpíìrì yìí fi bẹ̀rẹ̀ erée rẹ̀. Ẹ jẹ́ ká wò ó. |
20231101.yo_2286_0 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0 | Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà | Oríṣìíríṣìí ìtàn àtẹnudẹ́nu ni a ti gbọ́ nípa ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà, ọ̀rọ̀ òkèèrè sì nìyí, bí kò bá lé yóò dín. |
20231101.yo_2286_1 | https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0 | Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà | Ọ̀kan nínú àwọn ìtàn náà sọ pé: Ọwà Iléṣà kìíní Ajíbógun àti Ọba Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà kìíni, Agírgírì jẹ́ tẹ̀gbọ́n tábúrò. Ọba Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ni ẹ̀gbọ́n tí Ọwá sì jẹ́ àbúrò. Bákan náà, tẹ̀gbọ́n tàbúrò ni ìyá tí ó bí wọn. Láti ọmọomún ni ìyá Ajíbógun Ọwá Iléṣà ti kú Ìyá Agígírì tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n ìyá rẹ̀ ló wò ó dàgbà, ọmún rẹ̀ ló sì mún dàgbà. Nípa bẹ́ẹ̀ Ọwá Ajíbógun àti Agígírì jọ dàgbà pọ̀. Èyí ló mú kí wọn di kòrí-kòsùn ara wọn láti kékeré wá, wọn kí í sì í yara wọn bí ó ti wú kí ó rí. |
Subsets and Splits