diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Nítorí bí kíkọ̀ tí Ọlọrun kọ̀ wọ́n sílẹ̀ bá mú kí aráyé bá Ọlọrun rẹ́, kí ni yóo ṣẹlẹ̀ nígbà tí Ọlọrun bá gbà wọ́n mọ́ra? Ǹjẹ́ òkú pàápàá kò ní jí dìde?
Nitori bi kiko ti Olorun ko won sile ba mu ki araye ba Olorun re, ki ni yoo sele nigba ti Olorun ba gba won mora? Nje oku paapaa ko ni ji dide?
Ìwọ̀n wúrà tí Sólómónì ń gbà ní ọdún kan sì jẹ́ ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀ta ó lé mẹ́fà talẹ́ńtì wúrà, Láìka èyí tí ó ń gbà lọ́wọ́ àwọn ajẹ́lẹ̀ àti àwọn oníṣòwò, àti ti gbogbo àwọn ọba Árábíà, àti àwọn baálẹ̀ ilẹ̀
Iwon wura ti Solomoni n gba ni odun kan si je otalelegbeta o le mefa talenti wura, Laika eyi ti o n gba lowo awon ajele ati awon onisowo, ati ti gbogbo awon oba Arabia, ati awon baale ile
August 1 , 2008
August 1 , 2008
pẹ̀hìndà, wọn jẹ onígbéraga.
pehinda, won je onigberaga.
Kí ni wọ́n fi ṣe àwọn ohun èlò ìkọrin wọ̀nyẹn ?
Ki ni won fi se awon ohun elo ikorin wonyen ?
Nígbà náà ni Ọlọ́run wí pé, “Mo fi gbogbo ohun ọ̀gbìn tí ń so èso fún un yín bí oúnjẹ àti àwọn igi eléso pẹ̀lú. Gbogbo rẹ̀ yóò jẹ́ oúnjẹ fún un yín.
Nigba naa ni Olorun wi pe, “Mo fi gbogbo ohun ogbin ti n so eso fun un yin bi ounje ati awon igi eleso pelu. Gbogbo re yoo je ounje fun un yin.
3. Njẹ àwọn ẹ̀nìyàn fì rò pé a ô fi
3. Nje awon eniyan fi ro pe a o fi
MO RÁNTÍ pé lágbègbè wa , àwọn tá a jọ bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé náà la jọ parí ẹ̀ .
MO RANTI pe lagbegbe wa , awon ta a jo bere ile iwe naa la jo pari e .
Tabi o kò mọ̀ pé mo lè ké pe Baba mi, kí ó fún mi ní ẹgbaagbeje angẹli nisinsinyii?
Tabi o ko mo pe mo le ke pe Baba mi, ki o fun mi ni egbaagbeje angeli nisinsinyii?
Lẹ́yìn ìgbà yẹn , Dáfídì Ọba ṣètò fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún akọrin láti máa lo àwọn ohun èlò ìkọrin wọn gẹ́gẹ́ bí apá kan ìjọsìn ní tẹ́ńpìlì tí ọmọ rẹ̀ Sólómọ́nì kọ́ . — 1 Kíróníkà 23 : 5 .
Leyin igba yen , Dafidi Oba seto fun egbeegberun akorin lati maa lo awon ohun elo ikorin won gege bi apa kan ijosin ni tenpili ti omo re Solomoni ko . -- 1 Kironika 23 : 5 .
Nígbà tí àwọn ìràwọ̀ òwúrọ̀ jùmọ̀ ń fi ìdùnnú ké jáde , tí gbogbo àwọn ọmọ Ọlọ́run sì bẹ̀rẹ̀ sí hó yèè nínú ìyìn ? ” — Jóòbù 38 : 1 , 4 , 7 .
Nigba ti awon irawo owuro jumo n fi idunnu ke jade , ti gbogbo awon omo Olorun si bere si ho yee ninu iyin ? ” — Joobu 38 : 1 , 4 , 7 .
NISAN 13 ( ó bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn wọ̀ )
NISAN 13 ( o bere nigba ti oorun wo )
N kò ní fojú fo ọ̀rọ̀ yín, n kò ní ṣàánú yín. N óo jẹ yín níyà gẹ́gẹ́ bí ìwà yín, níwọ̀n ìgbà tí ohun ìríra ṣì wà láàrin yín. Ẹ óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi OLUWA, ni mò ń jẹ yín níyà.”
N ko ni foju fo oro yin, n ko ni saanu yin. N oo je yin niya gege bi iwa yin, niwon igba ti ohun irira si wa laarin yin. E oo wa mo nigba naa pe emi OLUWA, ni mo n je yin niya."
Inú wa máa ń dùn láti ran awọn míì lọ́wọ́ , ká sì tún sọ ìrírí wa fún wọn . ”
Inu wa maa n dun lati ran awon mii lowo , ka si tun so iriri wa fun won . "
Ó lè mú kí wọ́n dín ohun tí wọ́n ń ṣe nínú ìjọsìn Ọlọ́run kù . — Héb .
O le mu ki won din ohun ti won n se ninu ijosin Olorun ku . — Heb .
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 19 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 19 ]
31 Wọ́n Gbé Òtítọ́ Pa Mọ́ fún Àádọ́ta Ọdún — Èé Ṣe ?
31 Won Gbe Otito Pa Mo fun Aadota Odun — Ee Se ?
Nígbà tí àwọn ọmọ àwọn wolii tí wọ́n wà ní Jẹriko rí i, wọ́n ní, “Ẹ̀mí Elija ti wà lára Eliṣa!” Wọ́n lọ pàdé rẹ̀, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀,
Nigba ti awon omo awon wolii ti won wa ni Jeriko ri i, won ni, “Emi Elija ti wa lara Elisa!” Won lo pade re, won wole niwaju re,
Mo sì kan àpótí náà pẹ̀lú igi kaṣíà, mo sì gbẹ́ síléètì òkúta méjì náà jáde bí i ti ìṣáájú
Mo si kan apoti naa pelu igi kasia, mo si gbe sileeti okuta meji naa jade bi i ti isaaju
kí gbogbo eniyan lè bu ọlá fún Ọmọ bí wọ́n ti ń bu ọlá fún Baba. Ẹni tí kò bá bu ọlá fún Ọmọ kò bu ọlá fún Baba tí ó rán an wá sí ayé.
ki gbogbo eniyan le bu ola fun Omo bi won ti n bu ola fun Baba. Eni ti ko ba bu ola fun Omo ko bu ola fun Baba ti o ran an wa si aye.
Jésù mọ̀ pé bẹ́nì kan tiẹ̀ fẹ́ ṣe ohun tí ó tọ́ tó sì wù ú gan - an , àìpé ṣì lè ṣàkóbá fún un .
Jesu mo pe beni kan tie fe se ohun ti o to to si wu u gan - an , aipe si le sakoba fun un .
Tí gbòǹgbò igi bá ti fà á mu , kì í jẹ́ kí igi lè gba agbára látinú oòrùn mọ́ , èyí tó nílò fún ìlànà photosynthesis .
Ti gbongbo igi ba ti fa a mu , ki i je ki igi le gba agbara latinu oorun mo , eyi to nilo fun ilana photosynthesis .
Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìrírí yìí tó fún wa nírètí bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ń báni nínú jẹ́ . ” — M .
E seun pupo fun iriri yii to fun wa nireti bo tile je pe o n bani ninu je . ” — M .
ijona-isinkú
ijona-isinku
Kristẹni mìíràn lè sọ pé ẹ̀rí ọkàn òun ò sọ pé kí òun má ṣe irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ níwọ̀n bí kò ti ní ayẹyẹ kankan nínú .
Kristeni miiran le so pe eri okan oun o so pe ki oun ma se iru ise bee niwon bi ko ti ni ayeye kankan ninu .
Fi òróró kún ìwo rẹ , kí o sì lọ .
Fi ororo kun iwo re , ki o si lo .
Bíbélì jẹ́ ká mọ bí ìgbéyàwó wa ṣe lè yọrí sí rere ( Wo ìpínrọ̀ 6 , 7 )
Bibeli je ka mo bi igbeyawo wa se le yori si rere ( Wo ipinro 6 , 7 )
ỌJỌ́ ORÍ : OGÓJÌ ỌDÚN
OJO ORI : OGOJI ODUN
Jáde , ” tó wà nínú ẹ̀dà kọ̀ọ̀kan jẹ́ kí ó yé wa pé “ ìwé ìròyìn yìí ń gbé ìgbẹ́kẹ̀lé ró nínú ìlérí tí Ẹlẹ́dàá ti ṣe nípa ayé tuntun . ”
Jade , " to wa ninu eda kookan je ki o ye wa pe " iwe iroyin yii n gbe igbekele ro ninu ileri ti Eledaa ti se nipa aye tuntun . "
Ohun mẹ́tà wo ló máa ń mú kó ṣòro fáwọn tó tún ìgbéyàwó ṣe láti ṣàṣeyọrí ?
Ohun meta wo lo maa n mu ko soro fawon to tun igbeyawo se lati saseyori ?
Ǹjẹ́ lẹ́yìn èyí, ó mọ odi kan lẹ́yìn ìlú Dafidi, ní ìhà ìwọ̀-oòrùn Gihoni, ní àfonífojì, àní ní àtiwọ ẹnu ibodè ẹja, ó sì yí orí òkè Ofeli ká; ó sì mọ ọ́n ga sókè gidigidi, ó sì fi balógun sínú gbogbo ìlú olódi Juda wọ̀n-ọn-nì.
Nje leyin eyi, o mo odi kan leyin ilu Dafidi, ni iha iwo-oorun Gihoni, ni afonifoji, ani ni atiwo enu ibode eja, o si yi ori oke Ofeli ka; o si mo on ga soke gidigidi, o si fi balogun sinu gbogbo ilu olodi Juda won-on-ni.
Bí ó ti ń sọ báyìí, ìkùùkuu kan wá, ó ṣíji bò wọ́n: ẹ̀rù sì bà wọ́n nígbà tí wọ́n ń wọ inú ìkùùkuu lọ.
Bi o ti n so bayii, ikuukuu kan wa, o siji bo won: eru si ba won nigba ti won n wo inu ikuukuu lo.
Àwọn òṣìṣẹ́ ilẹ̀ Róòmù ló máa ń gba owó ilẹ̀ àti owó orí ẹnì kọ̀ọ̀kan , àmọ́ wọ́n máa ń gbé iṣẹ́ gbígba owó ẹrù tó ń wọlé láti ilẹ̀ òkèèrè àti èyí tó ń lọ sílẹ̀ òkèèrè , àti owó ẹrù tí ó ń gba ibodè ìlú kọjá , fún àwọn agbaṣẹ́ṣe tó bá máa pa owó tó pọ̀ jù lọ sápò ìjọba .
Awon osise ile Roomu lo maa n gba owo ile ati owo ori eni kookan , amo won maa n gbe ise gbigba owo eru to n wole lati ile okeere ati eyi to n lo sile okeere , ati owo eru ti o n gba ibode ilu koja , fun awon agbasese to ba maa pa owo to po ju lo sapo ijoba .
Ẹ jẹ́ kí á tepá mọ́ṣẹ́.
E je ki a tepa mose.
Láìpẹ́ sígbà yẹn , mo fi ìlú ńlá tí mò ń gbé sílẹ̀ , mo sì kó lọ sí ìlú kékeré tí Sandra ti ń ṣe aṣáájú - ọ̀nà . ”
Laipe sigba yen , mo fi ilu nla ti mo n gbe sile , mo si ko lo si ilu kekere ti Sandra ti n se asaaju - ona . ”
Paríparí rẹ̀ ni pé àwa méjèèjì fẹ́ máa bá iṣẹ́ ìsìn alákòókò - kíkún nìṣó .
Paripari re ni pe awa mejeeji fe maa ba ise isin alakooko - kikun niso .
Ìwọ yóò sì ṣe òrùka wúrà méjì fún pẹpẹ náà níṣàlẹ̀ ìgbátí méjèèjì ní òdìkejì ìhà rẹ̀—láti gbá àwọn òpó rẹ̀ mú, láti lè máa fi gbé e.
Iwo yoo si se oruka wura meji fun pepe naa nisale igbati mejeeji ni odikeji iha re--lati gba awon opo re mu, lati le maa fi gbe e.
Wọ́n wá fi òun àti Bíṣọ́ọ̀bù Àgbà ti ìlú Canterbury , tó jẹ́ olórí ìjọ Áńgílíkà mọ́ra wọn , èyí sì padà ṣe Seraphim láǹfààní gan - an .
Won wa fi oun ati Bisoobu Agba ti ilu Canterbury , to je olori ijo Angilika mora won , eyi si pada se Seraphim lanfaani gan - an .
Ó ṣe! Ọjọ́ náà ń bọ̀,ọjọ́ OLUWA dé tán!Ọjọ́ náà yóo dé bí ọjọ́ ìparun láti ọ̀dọ̀ Olodumare.
O se! Ojo naa n bo,ojo OLUWA de tan!Ojo naa yoo de bi ojo iparun lati odo Olodumare.
Níbàámu pẹ̀lú àdúrà yẹn , wo bó ṣe máa ṣàǹfààní tó tí olúkúlùkù yín bá fi ṣe ìpinnu rẹ̀ pé ẹ ó máa ran ara yín lọ́wọ́ àti pé ẹ ò tún “ máa bá a lọ ní fífaradà á fún ara yín lẹ́nì kìíní - kejì , kí ẹ sì máa dárí ji ara yín fàlàlà lẹ́nì kìíní - kejì . ”
Nibaamu pelu adura yen , wo bo se maa sanfaani to ti olukuluku yin ba fi se ipinnu re pe e o maa ran ara yin lowo ati pe e o tun “ maa ba a lo ni fifarada a fun ara yin leni kiini - keji , ki e si maa dari ji ara yin falala leni kiini - keji . ”
Mò ń dúró de ìgbà tí Jèhófà , Olùrànlọ́wọ́ mi , yóò mú gbogbo aburú tó ti ṣẹlẹ̀ kúrò , ìyẹn aburú tó wá látinú ìṣàkóso Sátánì tó kún fún ìnira .
Mo n duro de igba ti Jehofa , Oluranlowo mi , yoo mu gbogbo aburu to ti sele kuro , iyen aburu to wa latinu isakoso Satani to kun fun inira .
Bíbélì pè wọ́n ní “ àwọn ẹ̀bùn [ tí ó jẹ́ ] ènìyàn . ”
Bibeli pe won ni “ awon ebun [ ti o je ] eniyan . ”
70. Àwọn tô ní ìgbàgbọ sí àwọn
70. Awon to ni igbagbo si awon
Bíbélì sọ pé : “ Afọgbọ́nhùwà ni ẹni tí ó ti rí ìyọnu àjálù , tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí fi ara rẹ̀ pa mọ́ . ” — Òwe 22 : 3 .
Bibeli so pe : “ Afogbonhuwa ni eni ti o ti ri iyonu ajalu , ti o si bere si fi ara re pa mo . ” — Owe 22 : 3 .
Ọ̀nà tí ẹ̀sìn náà gbà tàn kálẹ̀ tó sì wà fún ọ̀rúndún bíi mélòó kan ló fi jẹ́ aláìlẹ́gbẹ́ nínú àkọsílẹ̀ ìtàn ìsìn .
Ona ti esin naa gba tan kale to si wa fun orundun bii meloo kan lo fi je alailegbe ninu akosile itan isin .
Ohun táwọn ògbógi ń sọ ni pé dùgbẹ̀dùgbẹ̀ ń fì lókè .
Ohun tawon ogbogi n so ni pe dugbedugbe n fi loke .
Ṣé ó máa ń ṣòro fún ẹ láti gba ìbáwí tí àwọn òbí , olùkọ́ àtàwọn àgbàlagbà míì bá fún ẹ ?
Se o maa n soro fun e lati gba ibawi ti awon obi , oluko atawon agbalagba mii ba fun e ?
Ní àwọn àkókò kan , Ọlọ́run fún orílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì ìgbàanì , tó dìídì yàn ní ọ̀pọ̀ ọ̀rúndún ṣáájú kí ìsìn Kristẹni tó bẹ̀rẹ̀ , láṣẹ pé kí wọ́n kó àwọn ọmọ ogun jọ kí wọ́n sì bá àwọn orílẹ̀ - èdè kan jà .
Ni awon akoko kan , Olorun fun orile - ede Isireli igbaani , to diidi yan ni opo orundun saaju ki isin Kristeni to bere , lase pe ki won ko awon omo ogun jo ki won si ba awon orile - ede kan ja .
nítorí tí Abrahamu gba ohùn mi gbọ́, ó sì pa gbogbo ìkìlọ̀, àṣẹ, ìlànà àti òfin mi mọ́.”
nitori ti Abrahamu gba ohun mi gbo, o si pa gbogbo ikilo, ase, ilana ati ofin mi mo."
bí kò bá sí ìlò
bi ko ba si ilo
Wọn kò sì ti ara wọn .
Won ko si ti ara won .
Wọn yóò sọ wí pé, Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn wa àti ilẹ̀ ìbí wa, kúrò níbi idà àwọn aninilára
Won yoo so wi pe, E dide, e je ki a pada si odo awon eniyan wa ati ile ibi wa, kuro nibi ida awon aninilara
OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ga kan ọ̀run;òtítọ́ rẹ sì kan ojú ọ̀run.
OLUWA, ife re ti ki i ye ga kan orun;otito re si kan oju orun.
Ẹni tí ń rìn déédé bẹ̀rù ,ṣùgbọ́n ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ kò tọ́ kẹ́gàn .
Eni ti n rin deede beru ,sugbon eni ti ona re ko to kegan .
10. Ọjọ tí Òun yòò kò yín jọ fún
10. Ojo ti Oun yoo ko yin jo fun
Àgbà òṣìkà ńgbin ìyà sílẹ̀ de ọmọọ rẹ̀.
Agba osika ngbin iya sile de omoo re.
Báwo ni Bíbélì ṣe lè jẹ́ orísun ìrànwọ́ fáwọn tó ní ìbànújẹ́ ọkàn ?
Bawo ni Bibeli se le je orisun iranwo fawon to ni ibanuje okan ?
Báwo ni Jésù ṣe fi ìrẹ̀lẹ̀ hàn ?
Bawo ni Jesu se fi irele han ?
Àwọn ìyàwó Solomoni.
Awon iyawo Solomoni.
Ṣùgbọ́n ọdún méje mìíràn tí ìyàn yóò mú yóò tẹ̀lé e, nígbà náà ni a ó tilẹ̀ gbàgbé pé ọdún méje tí ọ̀pọ̀ oúnjẹ wà yanturu tilẹ̀ ti wà rí, ìyàn yóò sì run gbogbo ilẹ̀ náà, A kò ní rántí àsìkò ọ̀pọ̀ oúnjẹ yanturu náà mọ́ nítorí pé ìyàn tí yóò tẹ̀lé e yóò pọ̀ púpọ̀
Sugbon odun meje miiran ti iyan yoo mu yoo tele e, nigba naa ni a o tile gbagbe pe odun meje ti opo ounje wa yanturu tile ti wa ri, iyan yoo si run gbogbo ile naa, A ko ni ranti asiko opo ounje yanturu naa mo nitori pe iyan ti yoo tele e yoo po pupo
Ẹnìkan bá sáré, ó ti kinní kan bíi kànìnkànìn bọ inú ọtí kíkan, ó fi sí orí ọ̀pá láti fún un mu, ó ń wí pé, “Ẹ jẹ́ kí á máa wò ó bí Elija yóo wá gbé e sọ̀kalẹ̀!”
Enikan ba sare, o ti kinni kan bii kaninkanin bo inu oti kikan, o fi si ori opa lati fun un mu, o n wi pe, “E je ki a maa wo o bi Elija yoo wa gbe e sokale!”
Sí ìyàlẹ́nu mi , kì í ṣe pé mo ti jáwọ́ nínú tẹ́tẹ́ títa nìkan ni , àmọ́ mo tún ti wá kórìíra rẹ̀ .
Si iyalenu mi , ki i se pe mo ti jawo ninu tete tita nikan ni , amo mo tun ti wa koriira re .
Jésù mà lẹ́mìí ìgbatẹnirò o !
Jesu ma lemii igbateniro o !
Ó dájú pé ẹnì kan ló ṣàkóbá fún wa tí ẹ̀bùn ìwàláàyè tá a ní fi dòbu mọ́ wa lọ́wọ́ .
O daju pe eni kan lo sakoba fun wa ti ebun iwalaaye ta a ni fi dobu mo wa lowo .
Sọ fún un pé, Olúwa Ọlọ́run àwọn Hébérù rán mi sí ọ láti sọ fún ọ pé
So fun un pe, Oluwa Olorun awon Heberu ran mi si o lati so fun o pe
“Mo fi irú àwọn àjàkálẹ̀ àrùn tí ó jà ní Ijipti ba yín jà, mo fi idà pa àwọn ọdọmọkunrin yín lójú ogun; mo kó ẹṣin yín lọ, mo mú kí òórùn àwọn tí wọ́n kú ninu àgọ́ yín wọ̀ yín nímú; sibẹsibẹ ẹ kò pada sọ́dọ̀ mi.
“Mo fi iru awon ajakale arun ti o ja ni Ijipti ba yin ja, mo fi ida pa awon odomokunrin yin loju ogun; mo ko esin yin lo, mo mu ki oorun awon ti won ku ninu ago yin wo yin nimu; sibesibe e ko pada sodo mi.
Abájọ tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù fi sọ nípa rẹ̀ pé : “ Kristi [ ni ] agbára Ọlọ́run . ”
Abajo ti apositeli Poolu fi so nipa re pe : “ Kristi [ ni ] agbara Olorun . ”
Ìwé atúmọ̀ èdè náà , Smith’s Bible Dictionary sọ pé : “ Ìbatisí ní gidi àti ní ṣáńgílítí túmọ̀ sí ìrìbọmi . ”
Iwe atumo ede naa , Smith's Bible Dictionary so pe : " Ibatisi ni gidi ati ni sangiliti tumo si iribomi . "
Síbẹ̀síbẹ̀, aláṣẹ Shehu Shagari ti ẹgbẹ́ òṣèlú National Party of Nigeria (NPN) ló borí nínú ìdìbò yí.
Sibesibe, alase Shehu Shagari ti egbe oselu National Party of Nigeria (NPN) lo bori ninu idibo yi.
Àwọn ọ̀dọ́ kan máa ń ṣípò padà fúngbà díẹ̀ nítorí kí wọ́n lè ṣiṣẹ́ owó tàbí kí wọ́n lè kọ́ èdè kan tó jẹ́ ti ilẹ̀ òkèèrè .
Awon odo kan maa n sipo pada fungba die nitori ki won le sise owo tabi ki won le ko ede kan to je ti ile okeere .
Bí ìròyìn kan bá dà bí ohun tí kò lè ṣẹlẹ̀ , a jẹ́ pé kò lè jóòótọ́ nìyẹn .
Bi iroyin kan ba da bi ohun ti ko le sele , a je pe ko le joooto niyen .
“ Ó JỌ pé ìfẹ́ láti rúbọ jẹ́ ‘ àdámọ́ni ’ gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ láti gbàdúrà ti jẹ́ ; ẹbọ rírú ń fi ohun téèyàn ń rò nípa ara rẹ̀ hàn , nígbà tó jẹ́ pé àdúrà gbígbà ń fi ohun téèyàn ń rò nípa Ọlọ́run hàn , ” òpìtàn Bíbélì nì , Alfred Edersheim , ló kọ ọ̀rọ̀ òkè yìí .
“ O JO pe ife lati rubo je ‘ adamoni ’ gege bi ife lati gbadura ti je ; ebo riru n fi ohun teeyan n ro nipa ara re han , nigba to je pe adura gbigba n fi ohun teeyan n ro nipa Olorun han , ” opitan Bibeli ni , Alfred Edersheim , lo ko oro oke yii .
gbígbéga
gbigbega
Torí náà , Bíbélì ni ohun èlò pàtàkì tó wà nínú oúnjẹ tẹ̀mí wa . — 2 Tím .
Tori naa , Bibeli ni ohun elo pataki to wa ninu ounje temi wa . -- 2 Tim .
Àpẹẹrẹ Rere Kan
Apeere Rere Kan
Torí kí kókó yìí lè yé wa dáadáa , Bíbélì fi bí ọ̀rọ̀ wa ṣe ń rí lára Ọlọ́run wé ìfẹ́ tí abiyamọ máa ń ní sí ọmọ ọwọ́ rẹ̀ .
Tori ki koko yii le ye wa daadaa , Bibeli fi bi oro wa se n ri lara Olorun we ife ti abiyamo maa n ni si omo owo re .
Ìrírí wọn lójú “ ọ̀nà òdodo ” tí wọ́n ti ń rìn látọjọ́ pípẹ́ máa ń mú kí ìjọ túbọ̀ lárinrin ó sì ń jẹ́ kó wu àwọn tó nífẹ̀ẹ́ òtítọ́ láti wá sínú ètò Ọlọ́run . — Òwe 16 : 31 .
Iriri won loju " ona ododo " ti won ti n rin latojo pipe maa n mu ki ijo tubo larinrin o si n je ko wu awon to nifee otito lati wa sinu eto Olorun . -- Owe 16 : 31 .
Dípò tí wàá fi sọ pé : “ Ẹ̀sìn wa ni , àwa la bí ẹ , ohun tá a bá sì sọ fún ẹ lo gbọ́dọ̀ gbà gbọ́ . ”
Dipo ti waa fi so pe : " Esin wa ni , awa la bi e , ohun ta a ba si so fun e lo gbodo gba gbo . "
Ó wá sọ pé : “ Fọkàn rẹ balẹ̀ .
O wa so pe : “ Fokan re bale .
Báwo la ṣe lè fún àwọn Kristẹni bíi tiwa lókun nígbà tí wọ́n bá wà nínú ìpọ́njú ?
Bawo la se le fun awon Kristeni bii tiwa lokun nigba ti won ba wa ninu iponju ?
Máa lo ìdánúṣe .
Maa lo idanuse .
Ẹ̀yin ìyẹn ló wá kan ìdánwò tó ju ìdánwò lọ .
Eyin iyen lo wa kan idanwo to ju idanwo lo .
Tó o bá fẹ́ àlàyé síwájú sí i , ka “ Òtítọ́ Nípa Baba , Ọmọ , àti Ẹ̀mí Mímọ́ ” lójú ìwé 201 sí 204 nínú ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan - an ?
To o ba fe alaye siwaju si i , ka " Otito Nipa Baba , Omo , ati Emi Mimo " loju iwe 201 si 204 ninu iwe Ki Ni Bibeli Fi Koni Gan - an ?
Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ni mo fi ṣe ibi ìsádi mi . ”
Jehofa Oluwa Oba Alase ni mo fi se ibi isadi mi . ”
Jésù sì dáhùn ó wí fún àwọn amòfin àti àwọn Farisí pé, Ǹjẹ́ ó tọ́ láti múni láradá ní ọjọ́ ìsinmi, tàbi kò tọ́
Jesu si dahun o wi fun awon amofin ati awon Farisi pe, Nje o to lati muni larada ni ojo isinmi, tabi ko to
Nítorí náà , Jésù ń sọ pé fún ìgbà díẹ̀ , yóò ṣòro láti mọ ìyàtọ̀ láàárín àwọn Kristẹni tòótọ́ àti àwọn tó jẹ́ ayédèrú .
Nitori naa , Jesu n so pe fun igba die , yoo soro lati mo iyato laaarin awon Kristeni tooto ati awon to je ayederu .
ìwọ kò le gbà ìwà ìkà nítorí kí ni ìwọ ṣe gba àwọn alárékérekè láàyè
iwo ko le gba iwa ika nitori ki ni iwo se gba awon alarekereke laaye
Olùfúnni - ní - ìyè rọ gbogbo ènìyàn láti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ẹ̀jẹ̀ Jésù tí a ta sílẹ̀ .
Olufunni - ni - iye ro gbogbo eniyan lati ni igbekele ninu eje Jesu ti a ta sile .
Tàbí kó jẹ́ pé ayaba tó lẹ́wà gan - an yìí kì í ṣe ẹni tó nítẹríba .
Tabi ko je pe ayaba to lewa gan - an yii ki i se eni to niteriba .
* Kí ló mú kí wọ́n fi ilé àtọ̀nà wọn sílẹ̀ ? Báwo ni nǹkan sì ṣe rí fún wọn ?
* Ki lo mu ki won fi ile atona won sile ? Bawo ni nnkan si se ri fun won ?
Lára ohun tí wọ́n ń lò láti fi hùwà ìrẹ́jẹ nínú ìdánwò ni ẹ̀rọ àfipeni ( pager ) , èyí tí wọ́n máa ń fi gba ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè tó jáde nínú ìdánwò látọ̀dọ̀ ẹnì kan tó wà lọ́nà jíjìn ; ẹ̀rọ ìṣèṣirò tí wọ́n ti ṣe ètò “ àkànṣe ” sínú rẹ̀ ; kámẹ́rà pẹnpẹ tí wọ́n ń fi sábẹ́ aṣọ , èyí tí wọ́n máa ń lò láti fi ìbéèrè ránṣẹ́ sí olùrànlọ́wọ́ kan tó wà níbòmíràn ; ẹ̀rọ ìṣèṣirò tó lè fi ìsọfúnni ránṣẹ́ sí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mìíràn nínú kíláàsì kan náà ; kódà , àwọn ibì kan wà lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì téèyàn ti lè rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè tó máa jáde nínú àwọn ìdánwò iṣẹ́ ilé ẹ̀kọ́ fún sáà ìkẹ́kọ̀ọ́ kan !
Lara ohun ti won n lo lati fi huwa ireje ninu idanwo ni ero afipeni ( pager ) , eyi ti won maa n fi gba idahun si awon ibeere to jade ninu idanwo latodo eni kan to wa lona jijin ; ero isesiro ti won ti se eto “ akanse ” sinu re ; kamera penpe ti won n fi sabe aso , eyi ti won maa n lo lati fi ibeere ranse si oluranlowo kan to wa nibomiran ; ero isesiro to le fi isofunni ranse si awon akekoo miiran ninu kilaasi kan naa ; koda , awon ibi kan wa lori Intaneeti teeyan ti le ri idahun si awon ibeere to maa jade ninu awon idanwo ise ile eko fun saa ikekoo kan !
Ṣùgbọ́n mu mi bí mo ti ń tọ́ agbo ẹran lẹ́yìn, ó sì wí fun mi pé, ‘Lọ sọtẹ́lẹ̀ fun àwọn Israẹli ènìyàn mi.’
Sugbon mu mi bi mo ti n to agbo eran leyin, o si wi fun mi pe, 'Lo sotele fun awon Israeli eniyan mi.'
Àkókò ewu gbáà ni àkókò táwọn ọmọ ogun Jámánì ṣígun ti Netherlands jẹ́ fún mi .
Akoko ewu gbaa ni akoko tawon omo ogun Jamani sigun ti Netherlands je fun mi .
Báwo wá ni nǹkan ṣe ń lọ sí láàárín yín báyìí ?
Bawo wa ni nnkan se n lo si laaarin yin bayii ?
Bóyá ọ̀dọ́ ni ìwọ náà .
Boya odo ni iwo naa .
Jétérì sì kú láìní ọmọ
Jeteri si ku laini omo
Encyclopædia Britannica sọ pé : “ Ńṣe làwọn ìlú máa ń bára wọn díje láti kọ́ kàtídírà tó ga lọ́lá jù . ”
Encyclopaedia Britannica so pe : " Nse lawon ilu maa n bara won dije lati ko katidira to ga lola ju . "
Bí alàgbà kan bá fìwà jọ Ọlọ́run , tó sì sọ̀rọ̀ lọ́nà pẹ̀lẹ́tù , ìyẹn lè mú kí ẹlẹ́ṣẹ̀ náà ronú pìwà dà . — Róòmù 2 : 4 .
Bi alagba kan ba fiwa jo Olorun , to si soro lona peletu , iyen le mu ki elese naa ronu piwa da . -- Roomu 2 : 4 .
Ẹ jẹ́ kí wọ́n bu omi wá kí ẹ fi ṣan ẹsẹ̀, kí ẹ sì sinmi díẹ̀ lábẹ́ igi níhìn-ín.
E je ki won bu omi wa ki e fi san ese, ki e si sinmi die labe igi nihin-in.
Nígbà náà ni Ọlọ́run wí fún Noa pé.
Nigba naa ni Olorun wi fun Noa pe.