diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Nítorí èyí , àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà jákèjádò ayé yóò pàdé pọ̀ lálẹ́ ọjọ́ pàtàkì yìí láti ṣe Ìṣe Ìrántí náà bí Jésù ṣe ní ká máa ṣe é .
Nitori eyi , awa Elerii Jehofa jakejado aye yoo pade po lale ojo pataki yii lati se Ise Iranti naa bi Jesu se ni ka maa se e .
Nígbà tó wà lórí ilẹ̀ ayé , ó ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ pàápàá àwọn òtòṣì .
Nigba to wa lori ile aye , o ran awon eeyan lowo paapaa awon otosi .
A gbọ́ ohùn àgàn láti ibi gíga,ẹkún àti ẹ̀bẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli,nítorí wọ́n ti yí ọ̀nà wọn po,wọ́n sì ti gbàgbé Ọlọ́run wọn.
A gbo ohun agan lati ibi giga,ekun ati ebe awon omo Israeli,nitori won ti yi ona won po,won si ti gbagbe Olorun won.
Láìsí àní - àní , Kristẹni aya ní láti ronú nípa àwọn ẹlòmíràn — ìyẹn ipa tó máa ní lórí wọn .
Laisi ani - ani , Kristeni aya ni lati ronu nipa awon elomiran -- iyen ipa to maa ni lori won .
Ẹnì kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú lè pinnu ọ̀nà tó dára jù lọ tí wọ́n á máa gbà lo ìrọ̀lẹ́ tó ṣí sílẹ̀ náà .
Eni kookan pelu le pinnu ona to dara ju lo ti won a maa gba lo irole to si sile naa .
nígbà náà, ẹ fẹ ẹ̀yí tí ô tẹ yín lọrùn
nigba naa, e fe eyi ti o te yin lorun
Nípa ìwà wọn , wọ́n ti èrò náà lẹ́yìn pé ìgbésí ayé ẹ̀dá èèyàn á lójú láìfi ti Jèhófà ṣe , kí ẹ̀dá ẹ̀mí kan tó jẹ́ ọlọ̀tẹ̀ sì máa darí wọn .
Nipa iwa won , won ti ero naa leyin pe igbesi aye eda eeyan a loju laifi ti Jehofa se , ki eda emi kan to je olote si maa dari won .
A máa ń tètè jẹ́ kí àwọn aláṣẹ mọ̀ .
A maa n tete je ki awon alase mo .
Àwọn kan lára àwọn olùkọ́ àtàwọn ọ̀mọ̀wé tó ń bójú tó ọ̀ràn ẹ̀kọ́ gbà pé ó yẹ káwọn dín àwọn ọjọ́ táwọn yà sọ́tọ̀ fáwọn àṣà Kérésìmesì kù tàbí káwọn má tiẹ̀ tẹ̀ lé àṣà náà mọ́ .
Awon kan lara awon oluko atawon omowe to n boju to oran eko gba pe o ye kawon din awon ojo tawon ya soto fawon asa Keresimesi ku tabi kawon ma tie te le asa naa mo .
Ìdí nìyẹn tí Jésù fi gba àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ nímọ̀ràn pé kí wọ́n “ jẹ́ oníṣọ̀ọ́ra gẹ́gẹ́ bí ejò , ” kí wọ́n sì jẹ́ “ ọlọ́rùn - mímọ́ gẹ́gẹ́ bí àdàbà . ”
Idi niyen ti Jesu fi gba awon omoleyin re nimoran pe ki won “ je onisoora gege bi ejo , ” ki won si je “ olorun - mimo gege bi adaba . ”
A dúpẹ́ pé a lè dá àwọn ìwà àrékérekè yìí mọ̀ nítorí pé a ti kọ àwọn ọgbọ́n tí Èṣù ń lò sílẹ̀ nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run .
A dupe pe a le da awon iwa arekereke yii mo nitori pe a ti ko awon ogbon ti Esu n lo sile ninu Oro Olorun .
Jésù ti fi ìlànà lélẹ̀ fún gbogbo àwọn tó bá fẹ́ di ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ .
Jesu ti fi ilana lele fun gbogbo awon to ba fe di omo eyin re .
Jèhófà rọ àwọn Júù láti fi ọkàn wọn sí iṣẹ́ títún tẹ́ńpìlì kọ́ láti ọjọ́ yẹn lọ , kì í ṣe pé kí wọ́n máa ronú nípa bí wọ́n ṣe pa iṣẹ́ náà tì tẹ́lẹ̀ .
Jehofa ro awon Juu lati fi okan won si ise titun tenpili ko lati ojo yen lo , ki i se pe ki won maa ronu nipa bi won se pa ise naa ti tele .
Bẹ́ẹ̀ ní Jeroboamu kò sì tún ní agbára mọ́ ní ọjọ́ Abijah. sì lù ú ó sì kú.
Bee ni Jeroboamu ko si tun ni agbara mo ni ojo Abijah. si lu u o si ku.
Àmọ́ , fúngbà díẹ̀ nìyẹn ṣá o .
Amo , fungba die niyen sa o .
Kí wọn má ba à mu ọtí yó kí wọn sì gbàgbé ohun tí òfin wíkí wọn sì fi ẹ̀tọ́ àwọn tí ara ń ni dù wọ́n
Ki won ma ba a mu oti yo ki won si gbagbe ohun ti ofin wiki won si fi eto awon ti ara n ni du won
Àkọsílẹ̀ náà sọ pé nígbà tí wọ́n dé sí Pẹ́gà , “ Jòhánù fi wọ́n sílẹ̀ , ó sì padà sí Jerúsálẹ́mù . ”
Akosile naa so pe nigba ti won de si Pega , “ Johanu fi won sile , o si pada si Jerusalemu . ”
Bákan náà ni wàá tún nílò àwọn òdòdó , ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ , o sì tún lè nílò ibi tí wàá ti kó àwọn èèyàn lẹ́nu jọ , onífọ́tò , àwọn olórin àtàwọn nǹkan mìíràn .
Bakan naa ni waa tun nilo awon ododo , oko ayokele , o si tun le nilo ibi ti waa ti ko awon eeyan lenu jo , onifoto , awon olorin atawon nnkan miiran .
ÌDÁ 11
IDA 11
Jesu dáhùn pé, “Mo fẹ́ kí o mọ̀ dájúdájú pé, ẹnikẹ́ni tí a kò bá fi omi ati Ẹ̀mí bí, kò lè wọ ìjọba Ọlọrun.
Jesu dahun pe, "Mo fe ki o mo dajudaju pe, enikeni ti a ko ba fi omi ati Emi bi, ko le wo ijoba Olorun.
( b ) Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù ?
( b ) Bawo la se le te le apeere Jesu ?
Bí àpẹẹrẹ , ronú nípa ojú tí Jésù fi wo kùdìẹ̀ - kudiẹ àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ , pàápàá jù lọ lórí ọ̀rọ̀ ta lọ̀gá tí wọ́n máa ń fà láàárín ara wọn .
Bi apeere , ronu nipa oju ti Jesu fi wo kudie - kudie awon apositeli re , paapaa ju lo lori oro ta loga ti won maa n fa laaarin ara won .
Àwọn Ìnira Ìgbà Ogun Mú Mi Gbára Dì fún Bá A Ṣeé Gbé Ìgbésí Ayé 12
Awon Inira Igba Ogun Mu Mi Gbara Di fun Ba A See Gbe Igbesi Aye 12
ní ti òdodo tí ó wà nínú òfin, mo jẹ́ aláìlẹ́gàn
ni ti ododo ti o wa ninu ofin, mo je alailegan
Èmi wí tèmi, àmọ́ ẹnu ọlọ́rọ̀ lọ̀rọ̀ ti ń dùn. Ẹ fetí sí ètò Yorùbá Gbòde níbi tí olóòtú Ṣọla Yusuf ti gba amòye onímọ̀ nípa Ebola, tí wọ́n sì làwá lọ́yẹ̀ dáadáa.
Emi wi temi, amo enu oloro loro ti n dun. E feti si eto Yoruba Gbode nibi ti olootu Sola Yusuf ti gba amoye onimo nipa Ebola, ti won si lawa loye daadaa.
nípa àwọn arákùnrin wọn nígbà tí
nipa awon arakunrin won nigba ti
“ Àgọ́ Àwọn Adúróṣánṣán Yóò Gbilẹ̀ ” , 11 / 15
“ Ago Awon Adurosansan Yoo Gbile ” , 11 / 15
Nínú ọ̀rọ̀ àkọ́sọ inú ìwé ìléwọ́ kan tí Almeida ṣe lọ́dún 1668 , Ohun tó sọ nínú rẹ̀ fáwọn tó máa ka ìwé náà ni pé : “ Mo nírètí . . . láìpẹ́ láti fi odindi Bíbélì ní èdè tiyín gangan dá a yín lọ́lá , èyí tá á jẹ́ ẹ̀bùn tó tóbi jù lọ àti ohun ìṣúra ṣíṣeyebíye jù lọ tí ẹnikẹ́ni kò tíì fún un yín rí . ”
Ninu oro akoso inu iwe ilewo kan ti Almeida se lodun 1668 , Ohun to so ninu re fawon to maa ka iwe naa ni pe : " Mo nireti . . . laipe lati fi odindi Bibeli ni ede tiyin gangan da a yin lola , eyi ta a je ebun to tobi ju lo ati ohun isura siseyebiye ju lo ti enikeni ko tii fun un yin ri . "
Bí àpẹẹrẹ , ìlú ńlá lè dà bí ibi tó máa ṣẹnuure , tó máa jẹ́ kéèyàn ronú pé òun máa ní àsìkò ìgbádùn , owó oṣù tó pọ̀ rẹpẹtẹ , àti ibùgbé tó dára .
Bi apeere , ilu nla le da bi ibi to maa senuure , to maa je keeyan ronu pe oun maa ni asiko igbadun , owo osu to po repete , ati ibugbe to dara .
Ǹjẹ́ kì í ṣe irú ẹ̀mí yẹn ló yẹ ká ní nígbà tá a bá fẹ́ ṣèrànwọ́ fáwọn àgùntàn tó ti ṣáko lọ kúrò nínú agbo Ọlọ́run ?
Nje ki i se iru emi yen lo ye ka ni nigba ta a ba fe seranwo fawon aguntan to ti sako lo kuro ninu agbo Olorun ?
Jẹrìí, ẹ̀yin náà sì ti mò pé àwa kò
Jerii, eyin naa si ti mo pe awa ko
Yálà a ní ìrètí láti gbé ní ọ̀run tàbí a ní ìrètí láti máa gbé nínú Párádísè lórí ilẹ̀ ayé , ẹ jẹ́ ká pinnu láti jẹ́ olóòótọ́ lẹ́nu iṣẹ́ wíwàásù àti sísọni dọmọ ẹ̀yìn tí Ọlọ́run gbé lé wa lọ́wọ́ .
Yala a ni ireti lati gbe ni orun tabi a ni ireti lati maa gbe ninu Paradise lori ile aye , e je ka pinnu lati je oloooto lenu ise wiwaasu ati sisoni domo eyin ti Olorun gbe le wa lowo .
Iṣẹ́ arìnrìn - àjò yìí la ṣe fún ohun tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [ 25 ] ní orílẹ̀ - èdè Brazil .
Ise arinrin - ajo yii la se fun ohun to feree to odun meeedogbon [ 25 ] ni orile - ede Brazil .
Wọn béèrè, ó sì mú ẹyẹ àparò wá,ó sì fi oúnjẹ ọ̀run tẹ́ wọn lọ́rùn.
Won beere, o si mu eye aparo wa,o si fi ounje orun te won lorun.
Anne , tó jẹ́ ìyá ọlọ́mọ méjì , sọ pé : “ Gbogbo ìgbà la máa ń rí i dájú pé ilé wa jẹ́ ibì kan táwọn ọmọ ti lè gbádùn ara wọn dáadáa .
Anne , to je iya olomo meji , so pe : “ Gbogbo igba la maa n ri i daju pe ile wa je ibi kan tawon omo ti le gbadun ara won daadaa .
Kí nìdí táwọn èèyàn Jèhófà fi ń dojú kọ ọ̀pọ̀ ìpọ́njú ?
Ki nidi tawon eeyan Jehofa fi n doju ko opo iponju ?
Gbogbo wọn ló gbọ́dọ̀ kú káwọn míì sì rọ́pò wọn .
Gbogbo won lo gbodo ku kawon mii si ropo won .
Ìwádìí kan táa ṣe lọ́dọ̀ àwọn ọ̀dọ́ tó jẹ́ mẹ́ńbà ìdílé Bẹ́tẹ́lì lẹ́nu àìpẹ́ yìí fi hàn pé ìpín mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n nínú ọgọ́rùn - ún lára wọn ló jẹ́ pé àwọn Kristẹni alábòójútó ló gbà wọ́n níyànjú láti fi iṣẹ́ ìsìn Bẹ́tẹ́lì ṣe góńgó wọn .
Iwadii kan taa se lodo awon odo to je menba idile Beteli lenu aipe yii fi han pe ipin merinlelogbon ninu ogorun - un lara won lo je pe awon Kristeni alaboojuto lo gba won niyanju lati fi ise isin Beteli se gongo won .
lọdọ Musa) o sì tún gbogun (tì i).
lodo Musa) o si tun gbogun (ti i).
o tẹ́ tán ni mo sọ fún ọ
o te tan ni mo so fun o
Gbogbo ìgbésí ayé rẹ̀ ló sì fi gbájú mọ́ iṣẹ́ yìí . Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ìjọ Kátólíìkì ta kò ó , tí àwọn tí wọ́n ń bá a ṣiṣẹ́ kò ka iṣẹ́ náà sí , tó tún rí ìṣòro tó dà bíi pé kò ní dópin lọ́dọ̀ àwọn tó ń yẹ ìwé rẹ̀ wò , àti àìlera tirẹ̀ fúnra rẹ̀ , síbẹ̀ ìfaradà rẹ̀ lérè .
Gbogbo igbesi aye re lo si fi gbaju mo ise yii . Bo tile je pe Ijo Katoliiki ta ko o , ti awon ti won n ba a sise ko ka ise naa si , to tun ri isoro to da bii pe ko ni dopin lodo awon to n ye iwe re wo , ati ailera tire funra re , sibe ifarada re lere .
Àwọn ọmọ kìnnìún a máa ṣe aláìní ebi a sì máa pa wọ́n;ṣùgbọ́n àwọn tí ó wá kì yóò ṣe aláìní ohun tí ó dára.
Awon omo kinniun a maa se alaini ebi a si maa pa won;sugbon awon ti o wa ki yoo se alaini ohun ti o dara.
ìkólọ
ikolo
Kí ó lè ru ìfẹ́ olùkọ́ àtàwọn ọmọ kíláàsì rẹ̀ sókè , ó gba àṣẹ láti kó àwọn ìtẹ̀jáde mélòó kan táa gbé ka Bíbélì sí ibi ìkówèésí .
Ki o le ru ife oluko atawon omo kilaasi re soke , o gba ase lati ko awon itejade meloo kan taa gbe ka Bibeli si ibi ikoweesi .
( b ) Báwo làwọn arákùnrin tí ń mú ipò iwájú ṣe fi ìfẹ́ bá ẹnì kan tó fẹ̀sùn èké kan àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lò ?
( b ) Bawo lawon arakunrin ti n mu ipo iwaju se fi ife ba eni kan to fesun eke kan awa Elerii Jehofa lo ?
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 8 ]
[ Awon aworan to wa ni oju iwe 8 ]
wá, àní ìwé ìràntí àwọn ènìyàn nã tí nwọ́n rí egungun nwọn; a sì fín in sórí àwo irin àìpò.
wa, ani iwe iranti awon eniyan na ti nwon ri egungun nwon; a si fin in sori awo irin aipo.
Kíyẹn lè ṣeé ṣe , o bẹ̀rẹ̀ sí í fi àwọn nǹkan kan du ara rẹ kí àwọn ohun ìní díẹ̀ lè tẹ́ ọ lọ́rùn .
Kiyen le see se , o bere si i fi awon nnkan kan du ara re ki awon ohun ini die le te o lorun .
Láti January ọdún 1957 ni Jèhófà tún ti ń ràn mí lọ́wọ́ lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ .
Lati January odun 1957 ni Jehofa tun ti n ran mi lowo lona to sara oto .
Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run ?
Se Jesu Ni Olorun ?
Ọ̀kan nínú márùn - ún wọn ló mu ún ní oṣù kan ṣáájú .
Okan ninu marun - un won lo mu un ni osu kan saaju .
Kàkà bẹ́ẹ̀ , mímú tí wọ́n mú idà lọ́wọ́ lálẹ́ ọjọ́ tí Júdásì da Jésù mú kó ṣeé ṣe fún Jésù láti kọ́ wọn ní ẹ̀kọ́ pàtàkì kan .
Kaka bee , mimu ti won mu ida lowo lale ojo ti Judasi da Jesu mu ko see se fun Jesu lati ko won ni eko pataki kan .
Ńṣe lèmi àti ìdílé mi jìjọ ń lọ sípàdé àti òde ẹ̀rí .
Nse lemi ati idile mi jijo n lo sipade ati ode eri .
Báwo ló ṣe máa ń wù ẹ́ tó pé kó o wà nípàdé , kí lo sì ti pinnu pé wàá ṣe ?
Bawo lo se maa n wu e to pe ko o wa nipade , ki lo si ti pinnu pe waa se ?
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọ̀rúndún tí ẹrẹ̀ ti ń wọ́ lọ sínú rẹ̀ , ojú ibi tó wà ò ṣeé dá mọ̀ mọ́ nítorí pé ó ti dí pátápátá .
Leyin opo orundun ti ere ti n wo lo sinu re , oju ibi to wa o see da mo mo nitori pe o ti di patapata .
ìsàkóso ètò ìjọba ààrẹ apaṣẹ
isakoso eto ijoba aare apase
Ọlọ́run wá jẹ́ kí Pétérù mọ ohun tí Ananíà ṣe yìí .
Olorun wa je ki Peteru mo ohun ti Anania se yii .
ìyà wò nítorí pé ẹ ṣàìgbàgbọ.'
iya wo nitori pe e saigbagbo.'
Mo fi ọ̀pá kẹ́sẹ́ màlúù ṣá ẹgbẹ̀ta àwọn Filísínì balẹ̀ .
Mo fi opa kese maluu sa egbeta awon Filisini bale .
Ohun tí ó ti rí tí ó sì ti gbọ́ èyí náà sì ni òun ń jẹ́rìí rẹ̀; kò sì sí ẹni tí ó gba ẹ̀rí rẹ̀.
Ohun ti o ti ri ti o si ti gbo eyi naa si ni oun n jerii re; ko si si eni ti o gba eri re.
Ó sì ti tó nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta [ 3,000 ] ọdún báyìí tí wọ́n ti ń wa ojúlówó àwọn nǹkan àmúṣọrọ̀ jáde níbi tá à ń wí yìí .
O si ti to nnkan bi egberun meta [ 3,000 ] odun bayii ti won ti n wa ojulowo awon nnkan amusoro jade nibi ta a n wi yii .
O Lè Jẹ́ Amẹ̀tọ́mọ̀wà Bí Kò Bá Tiẹ̀ Rọrùn , Jan .
O Le Je Ametomowa Bi Ko Ba Tie Rorun , Jan .
A ṣègbéyàwó lọ́dún 1989 .
A segbeyawo lodun 1989 .
Ó dí ojú òṣùpá,ó sì fi ìkùukùu bò ó.
O di oju osupa,o si fi ikuukuu bo o.
Kí ló máa ń tù wá nínú tá a bá wà nínú ìpọ́njú ?
Ki lo maa n tu wa ninu ta a ba wa ninu iponju ?
Ó tún gbàfiyèsí pé àwọn ańgẹ́lì pàápàá fi ìfẹ́ tó jinlẹ̀ hàn sí ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ nípa Irú Ọmọ náà tí Ọlọ́run ṣèlérí àti ìjọ àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró . — Ka 1 Pétérù 1 : 10 - 12 .
O tun gbafiyesi pe awon angeli paapaa fi ife to jinle han si ohun ti Iwe Mimo so nipa Iru Omo naa ti Olorun seleri ati ijo awon Kristeni eni ami ororo . — Ka 1 Peteru 1 : 10 - 12 .
PERESINI, a ti pín ìjọba rẹ, a sì ti fún àwọn ará Mede ati àwọn ará Pasia.”
PERESINI, a ti pin ijoba re, a si ti fun awon ara Mede ati awon ara Pasia."
Ìràpadà yìí ló mú kó ṣeé ṣe fún gbogbo èèyàn tó bá jẹ́ olóòótọ́ láti ní ìyè àìnípẹ̀kun .
Irapada yii lo mu ko see se fun gbogbo eeyan to ba je oloooto lati ni iye ainipekun .
Ẹ mọ̀ pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti àyà yín pé, kò sí ohun kan tí ó kùnà nínú àwọn ìlérí rere gbogbo tí Olúwa Ọlọ́run yín fi fún un yín
E mo pelu gbogbo okan yin ati aya yin pe, ko si ohun kan ti o kuna ninu awon ileri rere gbogbo ti Oluwa Olorun yin fi fun un yin
Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni máa la ogun Amágẹ́dọ́nì já ?
Nje enikeni maa la ogun Amagedoni ja ?
Àwọn ìwé yìí á ràn yín lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ yín àti nínú ìdílé yín . ”
Awon iwe yii a ran yin lowo lenu ise yin ati ninu idile yin . ”
ní agbára láti ràn wọn lỌwọ-
ni agbara lati ran won lOwo-
Ẹwà tún pọ̀ gan - an lórí àwọn òkè .
Ewa tun po gan - an lori awon oke .
Èyí kọ́ wa pé káwa náà tó ṣe ìpinnu èyíkéyìí tó kan ìjọsìn wa sí Ọlọ́run , ó yẹ ká kọ́kọ́ gbàdúrà sí Jèhófà pé kó tọ́ wa sọ́nà .
Eyi ko wa pe kawa naa to se ipinnu eyikeyii to kan ijosin wa si Olorun , o ye ka koko gbadura si Jehofa pe ko to wa sona .
Jesu bá wo ọ̀tún, ó wo òsì, ó wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Yóo ṣòro pupọ fún àwọn ọlọ́rọ̀ láti wọ ìjọba Ọlọrun!”
Jesu ba wo otun, o wo osi, o wi fun awon omo-eyin re pe, “Yoo soro pupo fun awon oloro lati wo ijoba Olorun!”
Wọ́n mú kí ipa tí Jésù kó túbọ̀ ṣe kedere , wọ́n ṣàlàyé ìdí tó fi wá sáyé , ìdí tó fi kú àti ohun tó ń ṣe ní báyìí .
Won mu ki ipa ti Jesu ko tubo se kedere , won salaye idi to fi wa saye , idi to fi ku ati ohun to n se ni bayii .
Ẹ máa dúpẹ́ nígbà gbogbo fún ohun gbogbo lọ́wọ́ Ọlọ́run, àní Baba, ní orúkọ Jesu Kristi Olúwa wá.
E maa dupe nigba gbogbo fun ohun gbogbo lowo Olorun, ani Baba, ni oruko Jesu Kristi Oluwa wa.
9, Ẹnikẹni tô bá sì ṣe iṣẹ búburú
9, Enikeni to ba si se ise buburu
Angẹli karun-un wá fun kàkàkí rẹ̀, mo bá rí ìràwọ̀ kan tí ó ti ojú ọ̀run já bọ́ sí orí ilẹ̀ ayé. A fún ìràwọ̀ yìí ní kọ́kọ́rọ́ kànga tí ó jìn tóbẹ́ẹ̀ tí eniyan kò lè dé ìsàlẹ̀ rẹ̀.
Angeli karun-un wa fun kakaki re, mo ba ri irawo kan ti o ti oju orun ja bo si ori ile aye. A fun irawo yii ni kokoro kanga ti o jin tobee ti eniyan ko le de isale re.
“Ìwọ, Ọlọ́run mi, ti fihan ìránṣẹ́ rẹ pé, ìwọ yóò kọ́ ilé fún un. Bẹ́ẹ̀ ni ìránṣẹ́ rẹ ti ní ìgboyà láti gbàdúrà sí ọ.
"Iwo, Olorun mi, ti fihan iranse re pe, iwo yoo ko ile fun un. Bee ni iranse re ti ni igboya lati gbadura si o.
Ohun pàtàkì tí Ọlọ́run béèrè nípa fífi ẹran rúbọ fi hàn pé ẹbọ Jésù máa jẹ́ èyí tí kò lábààwọ́n àti èyí tí kò léèérí àti pé ohun tí Jèhófà kà sí ohun tó dára jù lọ tó sì ṣe pàtàkì jù lọ ló máa fi rúbọ kó bàa lè ra aráyé pa dà . — 1 Pét .
Ohun pataki ti Olorun beere nipa fifi eran rubo fi han pe ebo Jesu maa je eyi ti ko labaawon ati eyi ti ko leeeri ati pe ohun ti Jehofa ka si ohun to dara ju lo to si se pataki ju lo lo maa fi rubo ko baa le ra araye pa da . — 1 Pet .
Á sì máa ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọ́n lè la ìparun tó ń bọ̀ sórí ayé búburú yìí já , kí wọ́n sì wọ inú ayé tuntun tí Ọlọ́run ṣèlérí . — Ka 2 Pétérù 3 : 7 , 13 ; Ìṣípayá 7 : 17 .
A si maa ran won lowo ki won le la iparun to n bo sori aye buburu yii ja , ki won si wo inu aye tuntun ti Olorun seleri . -- Ka 2 Peteru 3 : 7 , 13 ; Isipaya 7 : 17 .
ẹrigẹtẹsi
erigetesi
Ìyà kì í jẹni rere níjẹ ìwòsí
Iya ki i jeni rere nije iwosi
Èyí bẹ̀rẹ̀ sí í ṣẹlẹ̀ ní ọgọ́rùn - ún ọdún mélòó kan ṣáájú àkókò òpin .
Eyi bere si i sele ni ogorun - un odun meloo kan saaju akoko opin .
Fi èyí wé ipò tó lè dojú kọ ẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Kristẹni ọ̀dọ́ kan .
Fi eyi we ipo to le doju ko e gege bii Kristeni odo kan .
Ó máa ń jókòó sábẹ́ igi ọ̀pẹ , á sì máa ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn bí Jèhófà bá ṣe darí rẹ̀ .
O maa n jokoo sabe igi ope , a si maa se idajo awon eeyan bi Jehofa ba se dari re .
Obìnrin kan tí kò lọ́kọ tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jenny * tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà dúpẹ́ pé òun kọbi ara sí àwọn ìránnilétí Jèhófà .
Obinrin kan ti ko loko toruko re n je Jenny * to je okan lara awon Elerii Jehofa dupe pe oun kobi ara si awon irannileti Jehofa .
Ká ní o ní ilé kan tó jojú ní gbèsè , tó o sì ní káwọn èèyàn máa gbé ibẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ .
Ka ni o ni ile kan to joju ni gbese , to o si ni kawon eeyan maa gbe ibe lofee .
òrùngbẹ́
orungbe
Èrò àwọn míì tó wà ní àpéjọ náà jọ ti arákùnrin yìí .
Ero awon mii to wa ni apejo naa jo ti arakunrin yii .
A kì í fẹ́ sọ fún ara wa pé , ‘ Ó dùn mí pé mi ò lè bá yín lọ . ’ ” — Joan , láti orílẹ̀ - èdè Ọsirélíà .
A ki i fe so fun ara wa pe , ' O dun mi pe mi o le ba yin lo . ' " -- Joan , lati orile - ede Osirelia .
Ojú Ìwòye Bíbélì
Oju Iwoye Bibeli
Ká wá sọ pé o ti fìgbà kan rí sọ fún un pé kò ní ṣeé ṣe ńkọ́ ?
Ka wa so pe o ti figba kan ri so fun un pe ko ni see se nko ?
( Ka Dáníẹ́lì 3 : 16 - 18 . )
( Ka Danieli 3 : 16 - 18 . )
Ó ṣe, ikú o ṣèyí tán!
O se, iku o seyi tan!
ronú jinljẹ̀.
ronu jinlje.
Nígbà tó sì jẹ́ pé ìfọkànsìn tí a yà sọ́tọ̀ gedegbe ni Jèhófà ń fẹ́ , ó di dandan kí n fi àwọn ọlọ́run mìíràn tí mò ń sìn tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ .
Nigba to si je pe ifokansin ti a ya soto gedegbe ni Jehofa n fe , o di dandan ki n fi awon olorun miiran ti mo n sin tele sile .
Wọ́n sọ pé dókítà náà jẹ́ “ onínúure àti ẹni tó lẹ́mìí ìbánikẹ́dùn . ”
Won so pe dokita naa je " oninuure ati eni to lemii ibanikedun . "
29. 'Bi ìwọ bá na ọwọ rẹ si mi
29. 'Bi iwo ba na owo re si mi