diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ìgbàgbọ́ ọ̀hún ni pé “ ohun kan ṣoṣo ló jẹ́ òótọ́ , ohun náà sì ni pé kò sí ohun tó ń jẹ́ òtítọ́ . ”
Igbagbo ohun ni pe “ ohun kan soso lo je ooto , ohun naa si ni pe ko si ohun to n je otito . ”
A ò fẹ́ kí Andrew bẹ̀rẹ̀ sí í kórìíra ìwé kíkà , nítorí náà , a kì í fi ọ̀ràn - an - yàn mú un ju bí agbára rẹ̀ bá ṣe gbé e lọ . ”
A o fe ki Andrew bere si i koriira iwe kika , nitori naa , a ki i fi oran - an - yan mu un ju bi agbara re ba se gbe e lo . "
Kí ẹnikẹ́ni má ṣe jáde kúrò ní àdúgbò rẹ̀ ní ọjọ́ keje . ”
Ki enikeni ma se jade kuro ni adugbo re ni ojo keje . ”
Àmọ́ mi ò lè bẹ̀rẹ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ torí pé ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún [ 16 ] ni mí , mo sì máa pa dà sílé ìwé .
Amo mi o le bere lesekese tori pe omo odun merindinlogun [ 16 ] ni mi , mo si maa pa da sile iwe .
àrúlé kan sôríi ilẹ̀; wọn wí pé
arule kan sorii ile; won wi pe
Ṣùgbọ́n nígbà tí èmi bá bá ọ sọ̀rọ̀, Èmi yóò ṣí ọ lẹ́nu, ìwọ yóò sì sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí Olódùmarè wí.’ Ẹni tó bá fẹ́ kí ó gbọ́, ẹni tó bá fẹ́ kọ̀, kó kọ̀ nítorí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.
Sugbon nigba ti emi ba ba o soro, Emi yoo si o lenu, iwo yoo si so fun won pe, 'Eyi ni ohun ti Olodumare wi.' Eni to ba fe ki o gbo, eni to ba fe ko, ko ko nitori olote ile ni won.
Oúnjẹ Tí Kò Léwu Máa Wà fún Gbogbo Èèyàn
Ounje Ti Ko Lewu Maa Wa fun Gbogbo Eeyan
Àwọn ọba kórìíra ibi ṣíṣe,nítorí nípa òdodo ni a fìdí ìjọba múlẹ̀.
Awon oba koriira ibi sise,nitori nipa ododo ni a fidi ijoba mule.
115. Dájúdájú Àwá ti ṣe ojú rere
115. Dajudaju Awa ti se oju rere
fún àwọn ẹ̀nìyàn rárá.. Ṣùgbọn
fun awon eniyan rara.. Sugbon
Báálì ni òrìṣà tó gba iwájú jù lọ tí àwọn ọmọ Kénáánì ń sìn , Áṣítórétì sì ni wọ́n gbà pé ó jẹ́ ìyàwó rẹ̀ .
Baali ni orisa to gba iwaju ju lo ti awon omo Kenaani n sin , Asitoreti si ni won gba pe o je iyawo re .
Dá mi láre, OLUWA, Ọlọrun mi, gẹ́gẹ́ bí òdodo rẹ;má sì jẹ́ kí wọ́n yọ̀ mí!
Da mi lare, OLUWA, Olorun mi, gege bi ododo re;ma si je ki won yo mi!
Lẹ́yìn oṣù meje wọn yóo yan àwọn kan tí wọn óo la ilẹ̀ náà já, tí wọn óo máa wá òkú tí ó bá kù nílẹ̀, tí wọn óo sì máa sin wọ́n kí wọ́n lè sọ ilẹ̀ náà di mímọ́.
Leyin osu meje won yoo yan awon kan ti won oo la ile naa ja, ti won oo maa wa oku ti o ba ku nile, ti won oo si maa sin won ki won le so ile naa di mimo.
Àgbègbè yìí jẹ́ ibi tó lẹ́wà gan - an , tí àwọn àgbẹ̀ , olùṣọ́ àgùntàn àti àwọn apẹja ti máa ń ṣe iṣẹ́ wọn . Ibi yìí ni Jésù dàgbà sí nínú ìdílé ńlá kan tí kì í ṣe ìdílé olówó . — Mátíù 13 : 55 , 56 .
Agbegbe yii je ibi to lewa gan - an , ti awon agbe , oluso aguntan ati awon apeja ti maa n se ise won . Ibi yii ni Jesu dagba si ninu idile nla kan ti ki i se idile olowo . — Matiu 13 : 55 , 56 .
Nítorí pé wọ́n para pọ̀ di agbo náà tí Jòhánù rí nínú ìran kan , àwọn tí wọ́n ‘ wá sí ìyè , tí wọ́n sì ṣàkóso gẹ́gẹ́ bí ọba pẹ̀lú Kristi fún ẹgbẹ̀rún ọdún . ’
Nitori pe won para po di agbo naa ti Johanu ri ninu iran kan , awon ti won ' wa si iye , ti won si sakoso gege bi oba pelu Kristi fun egberun odun . '
Dáfídì mọ̀ pé Jèhófà nìkan ló lè mú ìdáǹdè tóun nílò lójú méjèèjì wá .
Dafidi mo pe Jehofa nikan lo le mu idande toun nilo loju mejeeji wa .
Ó sì ní ọlá púpọ̀ ju àwọn ọgbọ̀n lọ, ṣùgbọ́n a kò kà á láàrín àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta. Dafidi sì fi sí ìkáwọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́.
O si ni ola pupo ju awon ogbon lo, sugbon a ko ka a laarin awon meteeta. Dafidi si fi si ikawo awon eso.
Àwọn ẹlẹ́wọ̀n mìíràn , tí wọ́n ti dá sílẹ̀ níṣàájú lágọ̀ọ́ tó wà ní ìlú Bor , ti lọ sọ fáwọn èèyàn wa pé gbogbo àwa tí wọ́n kó lọ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n Cservenka làwọn ológun ti pa .
Awon elewon miiran , ti won ti da sile nisaaju lagoo to wa ni ilu Bor , ti lo so fawon eeyan wa pe gbogbo awa ti won ko lo si ogba ewon Cservenka lawon ologun ti pa .
ati nítorí ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ tí ó ti ta sílẹ̀, nítorí tí ó ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní gbogbo ìgboro Jerusalẹmu, OLUWA kò ní dáríjì í.
ati nitori eje alaise ti o ti ta sile, nitori ti o ta eje alaise sile ni gbogbo igboro Jerusalemu, OLUWA ko ni dariji i.
Nínú ìwé kan tí obìnrin oníròyìn kan kọ lẹ́nu àìpẹ́ yìí , ó sọ pé ìbéèré kan tí kò sẹ́ni tó lè dáhùn rẹ̀ .
Ninu iwe kan ti obinrin oniroyin kan ko lenu aipe yii , o so pe ibeere kan ti ko seni to le dahun re .
“ Olúwa , Kí Ló Dé Tó O Fi Dákẹ́ Tó Ò Ń Wòran ? ”
“ Oluwa , Ki Lo De To O Fi Dake To O N Woran ? ”
A dúpẹ́ pé ìjì òjò yẹn ò fi bẹ́ẹ̀ ṣàkóbá fún ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó wà níbẹ̀ .
A dupe pe iji ojo yen o fi bee sakoba fun eka ofiisi wa to wa nibe .
lẹ́ẹ̀kẹ́ta
leeketa
Bó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀ , a yìn ọ́ gan - an .
Bo ba je bee , a yin o gan - an .
Omi láti inú àpáta.
Omi lati inu apata.
Bí a bá gé e lulẹ̀ , àní yóò tún hù . ”
Bi a ba ge e lule , ani yoo tun hu . "
Àmọ́ o , àwọn òbí mi ọ̀wọ́n ló fi ẹsẹ̀ mi lé ọ̀nà àwọn nǹkan tẹ̀mí láti àárọ̀ ọjọ́ .
Amo o , awon obi mi owon lo fi ese mi le ona awon nnkan temi lati aaro ojo .
Gbé igi pátákó tí ó kọ nǹkan sí i sókè ní iwájú wọn,
Gbe igi patako ti o ko nnkan si i soke ni iwaju won,
Ọtí àmujù lè mú kéèyàn dá àwọn ẹ̀ṣẹ̀ míì tó burú jáì .
Oti amuju le mu keeyan da awon ese mii to buru jai .
O lè fojú inú wo bó ṣe máa rí lára Rèbékà tó bá fetí kọ́ ohun tí Élíésérì ń sọ fún àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ !
O le foju inu wo bo se maa ri lara Rebeka to ba feti ko ohun ti Elieseri n so fun awon molebi re !
Èmi ó yọ̀ nípa ṣíṣe wọ́n ní rere, èmi ó sì fi dá wọn lójú nípa gbíngbìn wọ́n sí ilẹ̀ yìí tọkàntọkàn mi
Emi o yo nipa sise won ni rere, emi o si fi da won loju nipa gbingbin won si ile yii tokantokan mi
22 : 1 - 3 , 9 - 12 , 15 - 18 .
22 : 1 - 3 , 9 - 12 , 15 - 18 .
Ẹ̀kọ́ ọ̀mọ̀wé Chelčický gba Gregory ti ìlú Prague lọ́kàn débi pé ó kúrò nínú ẹgbẹ́ Àwọn Ọmọlẹ́yìn Jan Hus .
Eko omowe Chelcicky gba Gregory ti ilu Prague lokan debi pe o kuro ninu egbe Awon Omoleyin Jan Hus .
Wọn kò gbọ́dọ̀ padà wá kó àwọn ìtí ọkà tí wọ́n bá gbàgbé sínú oko .
Won ko gbodo pada wa ko awon iti oka ti won ba gbagbe sinu oko .
Ó ṣòro lati lo ayélujára nitori ai ṣe déédé iná mọ̀nàmọ́ná àti ayélujára, pàtàki bi enia ba jade kúrò ni ilú Èkó, ṣùgbọ́n ó sàn ju ti àtẹ̀hin wá lọ.
O soro lati lo ayelujara nitori ai se deede ina monamona ati ayelujara, pataki bi enia ba jade kuro ni ilu Eko, sugbon o san ju ti atehin wa lo.
jekolíà
jekolia
Tá a ba fi èrò yìí sọ́kàn , a óò lè ka ìjìyà èyíkéyìí tó lè bá wa nínú ètò ìsinsìnyí sí èyí tó jẹ́ fún “ ìgbà díẹ̀ , tí ó sì fúyẹ́ . ”
Ta a ba fi ero yii sokan , a oo le ka ijiya eyikeyii to le ba wa ninu eto isinsinyi si eyi to je fun " igba die , ti o si fuye . "
A kì í rí ewé nílẹ̀ ká fọwọ́ fámí.
A ki i ri ewe nile ka fowo fami.
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó ju mílíọ̀nù méje ààbọ̀ lọ ti wá ‘ rí i ní ti tòótọ́ , ’ a sì fẹ́ràn rẹ̀ gidigidi .
Awa Elerii Jehofa to ju milionu meje aabo lo ti wa ‘ ri i ni ti tooto , ’ a si feran re gidigidi .
Èéṣe tí ìwọ fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mi?Èéṣe tí ara rẹ kò fi lélẹ̀ nínú mi?Fi ìrètí rẹ sínú Ọlọ́run,nítorí èmi yóò sì máa yìn ín, Òun niOlùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.
Eese ti iwo fi n rewesi, iwo okan mi?Eese ti ara re ko fi lele ninu mi?Fi ireti re sinu Olorun,nitori emi yoo si maa yin in, Oun niOlugbala mi ati Olorun mi.
One day Mariví informed me of her desire to dedicate her life to Jehovah and get baptized .
One day Marivi informed me of her desire to dedicate her life to Jehovah and get baptized .
Nítorí orílẹ̀ - èdè yóò dìde sí orílẹ̀ - èdè àti ìjọba sí ìjọba . . .
Nitori orile - ede yoo dide si orile - ede ati ijoba si ijoba . . .
Wọ́n dìídì sọ̀rọ̀ nípa ọjọ́ ọ̀la alárinrin .
Won diidi soro nipa ojo ola alarinrin .
Wọ́n sì wí fún un pé, “Àwa kò rí ìwé gbà láti Judea nítorí rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan nínú àwọn arákùnrin tí ó ti ibẹ̀ wá kò ròyìn, tàbí kí ó sọ̀rọ̀ ibi kan sí ọ.
Won si wi fun un pe, "Awa ko ri iwe gba lati Judea nitori re, bee ni enikan ninu awon arakunrin ti o ti ibe wa ko royin, tabi ki o soro ibi kan si o.
Kí la lè ṣe ká máa bàa kó sínú ìdẹkùn Èṣù ?
Ki la le se ka maa baa ko sinu idekun Esu ?
Bí ọ̀rọ̀ ọ̀pọ̀ adití tá a bá ní kó kàwé ṣe rí gan - an nìyẹn .
Bi oro opo aditi ta a ba ni ko kawe se ri gan - an niyen .
Láìka ohun yòówù tó lè ṣẹlẹ̀ sí , ìgbà gbogbo ló máa ń bójú tó wa . ”
Laika ohun yoowu to le sele si , igba gbogbo lo maa n boju to wa . "
Ìbọ̀rìṣà di ìdẹkùn fún Jèhóáṣì àti Amasááyà , ọmọ rẹ̀ .
Iborisa di idekun fun Jehoasi ati Amasaaya , omo re .
Àmọ́ , àwọn ìyípadà míì ṣì wà tó yẹ kí tọkọtaya ṣe .
Amo , awon iyipada mii si wa to ye ki tokotaya se .
Ó sọ pé : “ Mo nífẹ̀ẹ́ Jèhófà gan - an .
O so pe : “ Mo nifee Jehofa gan - an .
( b ) Àwọn ìbéèrè wo la máa gbé yẹ̀ wò ?
( b ) Awon ibeere wo la maa gbe ye wo ?
Kí nìdí ?
Ki nidi ?
Èyí máa jẹ́ kó o rí i pé Ọlọ́run ti sọ àwọn nǹkan rere tó máa ṣe lọ́jọ́ iwájú fún wa , nígbà tí wàá gbádùn “ ìyè tòótọ́ ” títí láé fáàbàdà .
Eyi maa je ko o ri i pe Olorun ti so awon nnkan rere to maa se lojo iwaju fun wa , nigba ti waa gbadun “ iye tooto ” titi lae faabada .
Ó ṣe pàtàkì ká gbà pé lóòótọ́ ni Sátánì wà , ká sì jẹ́ kí Ọlọ́run ‘ fìdí wa múlẹ̀ gbọn - in gbọn - in , ’ kó sì ‘ sọ wá di alágbára . ’
O se pataki ka gba pe loooto ni Satani wa , ka si je ki Olorun ‘ fidi wa mule gbon - in gbon - in , ’ ko si ‘ so wa di alagbara . ’
Àmọ́ , ìwọ alára lè máa wò ó pé bóyá làwọn ìmọ̀ràn tó wà níbẹ̀ á ṣeé gbára lé .
Amo , iwo alara le maa wo o pe boya lawon imoran to wa nibe a see gbara le .
Ẹ jẹ́ kí a kọ́ àwọn ìlú wọ̀nyí Ó wí fún Júdà, Kí ẹ sì mọ odi yí wọn ká pẹ̀lú àwọn ile ìṣọ́ gíga, àwọn ẹnu ọ̀nà òde, àti àwọn ìpẹ́ẹ̀rẹ̀
E je ki a ko awon ilu wonyi O wi fun Juda, Ki e si mo odi yi won ka pelu awon ile iso giga, awon enu ona ode, ati awon ipeere
Bíbélì mú kó dá wa lójú pé tí èrò yìí bá ń fún àwọn èèyàn rere níṣìírí tó sì tù wọ́n nínú , wọ́n á lè ṣe gbogbo nǹkan tágbára wọn bá gbé .
Bibeli mu ko da wa loju pe ti ero yii ba n fun awon eeyan rere nisiiri to si tu won ninu , won a le se gbogbo nnkan tagbara won ba gbe .
Àwọn ìrírí wọ̀nyí , tó wá láti Mòsáńbíìkì , fi hàn bí Jèhófà ṣe ń san èrè fún ìgbàgbọ́ tó lágbára , tó sì ń gbọ́ àdúrà àtọkànwá .
Awon iriri wonyi , to wa lati Mosanbiiki , fi han bi Jehofa se n san ere fun igbagbo to lagbara , to si n gbo adura atokanwa .
Ọmọ aráyé kò ní pókìkí ẹ̀!!.
Omo araye ko ni pokiki e!!.
Ohun Tó O Lè Ṣe
Ohun To O Le Se
ọ̀wọ́-ogun
owo-ogun
Ṣé o wá bẹ̀rẹ̀ sí í gbéra ga ni , àbí ohun tó gbà ẹ́ lọ́kàn jù ni bó o ṣe máa yanjú ọ̀rọ̀ náà tí wàá sì jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà ? ​ —⁠ Ka Sáàmù 119 : 165 ; Kólósè 3 :⁠ 13 .
Se o wa bere si i gbera ga ni , abi ohun to gba e lokan ju ni bo o se maa yanju oro naa ti waa si je oloooto si Jehofa ? -- Ka Saamu 119 : 165 ; Kolose 3 : 13 .
àìṣedéédéé wa; ní ipò ikú, kí O
aisedeedee wa; ni ipo iku, ki O
àyípadà
ayipada
( Wo àpótí náà “ Ọdún Pàtàkì Kan Nínú Ìtàn . ” )
( Wo apoti naa " Odun Pataki Kan Ninu Itan . " )
Retrieved July 6, 2016.
Retrieved July 6, 2016.
Nínú apá kìíní , Arákùnrin Stephen Lett sọ̀rọ̀ lórí kókó náà “ Ẹ Wà Lójúfò ní Wákàtí Ìkẹyìn Yìí . ”
Ninu apa kiini , Arakunrin Stephen Lett soro lori koko naa “ E Wa Lojufo ni Wakati Ikeyin Yii . ”
Kí ìdáhùn wa lè tọ̀nà , ẹ jẹ́ ká jíròrò àwọn ìbéèrè pàtàkì mẹ́rin .
Ki idahun wa le tona , e je ka jiroro awon ibeere pataki merin .
Àmọ́ , kì í ṣe pé kí wọ́n wá máa lò wọ́n bí ohun èlò ìbálòpọ̀ lásánlàsàn .
Amo , ki i se pe ki won wa maa lo won bi ohun elo ibalopo lasanlasan .
Dafidi sì wí fún un pé, “Má ṣe bẹ̀rù: nítorí pé nítòótọ́ èmi ó ṣe oore fún ọ nítorí Jonatani baba rẹ, èmi ó sì tún fi gbogbo ilé Saulu baba rẹ fún ọ: ìwọ ó sì máa bá mi jẹun nígbà gbogbo ní ibi oúnjẹ mi.”
Dafidi si wi fun un pe, "Ma se beru: nitori pe nitooto emi o se oore fun o nitori Jonatani baba re, emi o si tun fi gbogbo ile Saulu baba re fun o: iwo o si maa ba mi jeun nigba gbogbo ni ibi ounje mi."
Nígbà tó yá , Ẹlẹ́rìí míì tó ń jẹ́ Bill wá ń kọ́ mi ní ẹ̀kọ́ Bíbélì yẹn nìṣó .
Nigba to ya , Elerii mii to n je Bill wa n ko mi ni eko Bibeli yen niso .
Báyĩ sì ni ọdún kejìlélógún ti
Bayi si ni odun kejilelogun ti
“ Ní ti Jèhófà , ojú rẹ̀ ń lọ káàkiri ní gbogbo ilẹ̀ ayé láti fi okun rẹ̀ hàn nítorí àwọn tí ọkàn - àyà wọn pé pérépéré síhà ọ̀dọ̀ rẹ̀ . ”
" Ni ti Jehofa , oju re n lo kaakiri ni gbogbo ile aye lati fi okun re han nitori awon ti okan - aya won pe perepere siha odo re . "
Bó o bá fẹ́ kí ẹnì kan wá ọ wá , jọ̀wọ́ kọ̀wé sínú fọ́ọ̀mù tó wà lójú ewé yìí kó o sì fi ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì tá a kọ síbẹ̀ tàbí sí àdírẹ́sì tó bá yẹ lára èyí tá a tò sójú ewé 5 nínú ìwé ìròyìn yìí .
Bo o ba fe ki eni kan wa o wa , jowo kowe sinu foomu to wa loju ewe yii ko o si fi ranse si adiresi ta a ko sibe tabi si adiresi to ba ye lara eyi ta a to soju ewe 5 ninu iwe iroyin yii .
OLUWA ìwọ yóo fún wa ní alaafia,nítorí pé ìwọ ni o ṣe gbogbo iṣẹ́ wa fún wa.
OLUWA iwo yoo fun wa ni alaafia,nitori pe iwo ni o se gbogbo ise wa fun wa.
O lè ka púpọ̀ sí i nínú ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ “ Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . ” nínú Ìkànnì wa lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì , ìyẹn www.watchtower.org / ype
O le ka pupo si i ninu owo apileko “ Awon Odo Beere Pe . . . ” ninu Ikanni wa lori Intaneeti , iyen www.watchtower.org / ype
Bí àpẹẹrẹ , nígbà tí ère ẹranko náà kọ́kọ́ fara hàn , àwọn oníṣọ́ọ̀ṣì , tó jẹ́ apá pàtàkì nínú Bábílónì Ńlá , ló pọ̀ jù lọ ní ilẹ̀ Yúróòpù àti Amẹ́ríkà .
Bi apeere , nigba ti ere eranko naa koko fara han , awon onisoosi , to je apa pataki ninu Babiloni Nla , lo po ju lo ni ile Yuroopu ati Amerika .
Ẹ̀mí Lọ́ọ̀tì wà nínú ewu .
Emi Looti wa ninu ewu .
Wọ́n tún ṣe àwọn àlàyé kan tó ṣọ̀wọ́n lórí Bíbélì , ìwọ̀nyí ni àkọ́kọ́ irú àlàyé bẹ́ẹ̀ , àwọn ni atọ́kùn àlàyé táwọn èèyàn wá ń ṣe lóde òní lórí ẹsẹ Bíbélì kọ̀ọ̀kan .
Won tun se awon alaye kan to sowon lori Bibeli , iwonyi ni akoko iru alaye bee , awon ni atokun alaye tawon eeyan wa n se lode oni lori ese Bibeli kookan .
Ìwé Òwe sọ pe : “ Ìwọ yóò sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run gan - an . ”
Iwe Owe so pe : " Iwo yoo si ri imo Olorun gan - an . "
ÌTAYỌ WÚNRẸ̀NÈDÈ INÚ EWÌ AṢỌ ÌGBÀ
ITAYO WUNRENEDE INU EWI ASO IGBA
Omijé wá lé ròrò sójú ẹ̀ .
Omije wa le roro soju e .
Tẹ́nì kan bá jẹ́ olódodo , yóò gbọ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ lọ́jọ́ ogbó , tí kò bá jẹ́ olódodo , ńṣe ni yóò kùnà lọ́jọ́ ogbó .
Teni kan ba je olododo , yoo gboregejige lojo ogbo , ti ko ba je olododo , nse ni yoo kuna lojo ogbo .
Ọba a máa ní inú dídùn sí ìránṣẹ́ tí ó gbọ́n ṣùgbọ́n ìbínú rẹ̀ wá sórí ìránṣẹ́ adójútini
Oba a maa ni inu didun si iranse ti o gbon sugbon ibinu re wa sori iranse adojutini
Karl Klein , tó ń sìn gẹ́gẹ́ bíi mẹ́ńbà Ẹgbẹ́ Alákòóso àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà , àti Margaret aya rẹ̀ , bẹ̀ wá wò nígbà ìsinmi wọn lọ́dún mélòó kan sẹ́yìn .
Karl Klein , to n sin gege bii menba Egbe Alakooso awon Elerii Jehofa , ati Margaret aya re , be wa wo nigba isinmi won lodun meloo kan seyin .
Níwọ̀n bó ti jẹ́ pé òun ni “ Ọba ayérayé , ” ó ti wà láti ayérayé , yóò sì máa wà títí láé ni .
Niwon bo ti je pe oun ni “ Oba ayeraye , ” o ti wa lati ayeraye , yoo si maa wa titi lae ni .
Èmi wọ ilé rẹ, ìwọ kò fi omi wẹ ẹṣẹ̀ fún mi
Emi wo ile re, iwo ko fi omi we ese fun mi
Ó pọndandan kí àwọn kan tó jẹ́ ìránṣẹ́ Jèhófà láyé ìgbàanì tún àwọn apá ibì kan nínú ẹ̀mí ìrònú wọn ṣe .
O pondandan ki awon kan to je iranse Jehofa laye igbaani tun awon apa ibi kan ninu emi ironu won se .
Mo sọ pé : “ Mi ò kì í ṣe ọmọlẹ́yìn ẹ̀gbọ́n mi , ọmọlẹ́yìn Jésù Kristi ni mí . ”
Mo so pe : “ Mi o ki i se omoleyin egbon mi , omoleyin Jesu Kristi ni mi . ”
Ẹ̀yin òbí , ẹ máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jèhófà , kẹ́ ẹ máa fún àwọn ọmọ yín níṣìírí , kẹ́ ẹ sì máa gbóríyìn fún wọn tí wọ́n bá ṣe dáadáa .
Eyin obi , e maa te le apeere Jehofa , ke e maa fun awon omo yin nisiiri , ke e si maa gboriyin fun won ti won ba se daadaa .
Èyí sì lè mú kírú ẹni bẹ́ẹ̀ ṣubú nípa tẹ̀mí ní àsẹ̀yìnwá àsẹ̀yìnbọ̀ .
Eyi si le mu kiru eni bee subu nipa temi ni aseyinwa aseyinbo .
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 20 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 20 ]
Pa ohun rere ti a ti fi lé ọ lọ́wọ́ mọ́ nípa Ẹ̀mí Mímọ́ ti ń gbé inú wa
Pa ohun rere ti a ti fi le o lowo mo nipa Emi Mimo ti n gbe inu wa
wọn a sì máa fi (ẹ̀rí) irọ ṣe
won a si maa fi (eri) iro se
( Lọ sí jw.org / yo , kó o wo abẹ́ ÀWỌN ÌTẸ̀JÁDE > ÀWỌN FÍDÍÒ )
( Lo si jw.org / yo , ko o wo abe AWON ITEJADE > AWON FIDIO )
Ẹ̀yin olùfẹ́ ọ̀wọ́n, kì í ṣe òfin tuntun ni mo ń kọ̀wé rẹ̀ sí yín ṣùgbọ́n òfin àtijọ́, èyí tí ẹ̀yin tí gbọ́ ní àtètèkọ́ṣe. Òfin àtijọ́ ni ọ̀rọ̀ náà tí ẹ̀yin tí gbọ́.
Eyin olufe owon, ki i se ofin tuntun ni mo n kowe re si yin sugbon ofin atijo, eyi ti eyin ti gbo ni atetekose. Ofin atijo ni oro naa ti eyin ti gbo.
Ó yẹ fún àfiyèsí pé àwọn pásítọ̀ méjèèjì yìí tí wọ́n jẹ́ Ọmọlẹ́yìn Waldo — ìyẹn Daniele Rivoire àti Giuseppe Banchetti — mọrírì ọ̀nà tí Russell gbà ṣàlàyé Bíbélì .
O ye fun afiyesi pe awon pasito mejeeji yii ti won je Omoleyin Waldo — iyen Daniele Rivoire ati Giuseppe Banchetti — moriri ona ti Russell gba salaye Bibeli .
• Ìgbà wo ló lè ṣòro fún wa láti ṣe ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ , àmọ́ kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká ṣègbọràn ?
* Igba wo lo le soro fun wa lati se ohun ti Iwe Mimo so , amo ki nidi to fi se pataki pe ka segboran ?
Yóò dá, iná sun tẹmpili àwọn òrìṣà Ejibiti, yóò sun tẹmpili àwọn òrìṣà Ejibiti, yóò sì mú wọn lọ ìgbèkùn. Gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn, yóò ró aṣọ rẹ̀ mọ́ra, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò ró Ejibiti òun yóò sì lọ kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà
Yoo da, ina sun tempili awon orisa Ejibiti, yoo sun tempili awon orisa Ejibiti, yoo si mu won lo igbekun. Gege bi oluso-aguntan, yoo ro aso re mora, bee gege ni yoo ro Ejibiti oun yoo si lo kuro nibe ni alaafia
Àwọn ọmọ Sámúẹ́lì kò ronú lórí àkóbá tí ìwà wọ̀bìà àti ìmọtara - ẹni - nìkan wọn máa ṣe fún àwọn èèyàn .
Awon omo Samueli ko ronu lori akoba ti iwa wobia ati imotara - eni - nikan won maa se fun awon eeyan .