diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ẹ̀yin Ọkọ , Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìfẹ́ Kristi , 5 / 15
Eyin Oko , E Te Le Apeere Ife Kristi , 5 / 15
Bẹ́ẹ̀ ni , “ ìdùnnú Jèhófà ni odi agbára [ wa ] . ”
Bee ni , “ idunnu Jehofa ni odi agbara [ wa ] . ”
Wọ́n wo ọkunrin tí wọ́n mú lára dá tí ó dúró lọ́dọ̀ wọn, wọn kò sì mọ ohun tí wọn yóo sọ.
Won wo okunrin ti won mu lara da ti o duro lodo won, won ko si mo ohun ti won yoo so.
Nígbà tí a wọ ọkọ̀ láti Tiroasi, a lọ tààrà sí Samotirake. Ní ọjọ́ keji a gúnlẹ̀ ní Neapoli.
Nigba ti a wo oko lati Tiroasi, a lo taara si Samotirake. Ni ojo keji a gunle ni Neapoli.
Àwa náà lè ṣe bíi tiẹ̀ .
Awa naa le se bii tie .
darú
daru
Ènìyàn kì yóò wà láàyè nípa àkàrà nìkan
Eniyan ki yoo wa laaye nipa akara nikan
Nígbà yẹn , ó bá Jèhófà ṣiṣẹ́ láti dá àwọn áńgẹ́lì , ayé àti ọ̀run àtàwa èèyàn nígbẹ̀yìngbẹ́yín .
Nigba yen , o ba Jehofa sise lati da awon angeli , aye ati orun atawa eeyan nigbeyingbeyin .
Ọlọ́run máa tó mú ayé tẹ́rù ò ti ní bani mọ́ wá
Olorun maa to mu aye teru o ti ni bani mo wa
tí wọ́n ti tẹ̀ láti ohun tó lé lógún ọdún sẹ́yìn , bẹ́ẹ̀ nìwọ náà ṣe lè rí “ ẹ̀kún àpò ọgbọ́n ” nínú àwọn ìwé ìròyìn tọ́jọ́ wọn ti pẹ́ yìí .
ti won ti te lati ohun to le logun odun seyin , bee niwo naa se le ri " ekun apo ogbon " ninu awon iwe iroyin tojo won ti pe yii .
Àmọ́ , Ìwé Mímọ́ tún jẹ́ ká mọ̀ pé : “ Kò sí ohun tí ó sàn ju pé kí ènìyàn máa yọ̀ nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ . ”
Amo , Iwe Mimo tun je ka mo pe : " Ko si ohun ti o san ju pe ki eniyan maa yo ninu awon ise re . "
ọbára
obara
Lọ́wọ́ kan wẹ́rẹ́ báyìí ni wọ́n ń rí àwọn ìsọfúnni tí wọ́n bá ń wá lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì .
Lowo kan were bayii ni won n ri awon isofunni ti won ba n wa lori Intaneeti .
Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣe bá ara yín wí, kí á má baà da yín lẹ́jọ́. Onídàájọ́ ti dúró lẹ́nu ọ̀nà.
Eyin ara, e ma se ba ara yin wi, ki a ma baa da yin lejo. Onidaajo ti duro lenu ona.
Dípò ìyẹn , ńṣe ni wọ́n máa ń gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n máa sin Jèhófà nítorí ìfẹ́ tí wọ́n ní sí òun àti Jésù àtàwọn ọmọnìkejì wọn . — Mátíù 22 : 37 - 39 .
Dipo iyen , nse ni won maa n gba won niyanju pe ki won maa sin Jehofa nitori ife ti won ni si oun ati Jesu atawon omonikeji won . -- Matiu 22 : 37 - 39 .
Bí àwọ̀n ńlá kan ṣe máa ń kó “ ẹja onírúurú ” jọ rẹpẹtẹ , bẹ́ẹ̀ náà ni iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa ń fa ọ̀kẹ́ àìmọye onírúurú èèyàn mọ́ra .
Bi awon nla kan se maa n ko “ eja oniruuru ” jo repete , bee naa ni ise iwaasu ihin rere Ijoba Olorun se maa n fa oke aimoye oniruuru eeyan mora .
Ọ̀kan lára àpẹẹrẹ tá a rí nínú Bíbélì nípa bí wọ́n ṣe máa ń lo Úrímù àti Túmímù ni ìgbà tí Dáfídì ní kí Ábíátárì mú éfódì tó ṣeé ṣe kó jẹ́ ti àlùfáà àgbà wá , inú ẹ̀ sì ni Úrímù àti Túmímù máa ń wà .
Okan lara apeere ta a ri ninu Bibeli nipa bi won se maa n lo Urimu ati Tumimu ni igba ti Dafidi ni ki Abiatari mu efodi to see se ko je ti alufaa agba wa , inu e si ni Urimu ati Tumimu maa n wa .
Ńṣe lowó máa ń kúnnu rẹ̀ fọ́fọ́ lójoojúmọ́ .
Nse lowo maa n kunnu re fofo lojoojumo .
Ó gba pé ká ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àṣekára ká bàa lè máa ṣẹ̀tìlẹ́yìn fún àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ Ìjọba Ọlọ́run .
O gba pe ka se opo ise asekara ka baa le maa setileyin fun awon nnkan to je mo Ijoba Olorun .
Eyi ni ó jẹ́ ki Yorùbá ma ki ẹni ti ó bá ntọ ọmọ lọ́wọ́ pé Ẹ kú ọwọ lómi nítorí ọwọ́ ki kúrò ni omi aṣọ fí fọ̀
Eyi ni o je ki Yoruba ma ki eni ti o ba nto omo lowo pe E ku owo lomi nitori owo ki kuro ni omi aso fi fo
BÍ ÀKÓKÒ tí a ó ṣe Ìrántí Ikú Kristi ti ń sún mọ́lé , ó yẹ kí àwa èèyàn Ọlọ́run tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù pé ká “ tẹjú mọ́ Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa , Jésù . ”
BI AKOKO ti a o se Iranti Iku Kristi ti n sun mole , o ye ki awa eeyan Olorun te le imoran apositeli Poolu pe ka " teju mo Olori Asoju ati Alasepe igbagbo wa , Jesu . "
tí a dá yanrí nínú àwọn ẹrúsìn Rẹ."
ti a da yanri ninu awon erusin Re."
Ó sì wí fún un pé, (Ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ yìí ni “rán”). Nítorí náà ó gba ọ̀nà rẹ̀ lọ, ó wẹ̀, ó sì dé, ó ń ríran.
O si wi fun un pe, (Itumo oro yii ni "ran"). Nitori naa o gba ona re lo, o we, o si de, o n riran.
Sadoku, alufaa, wà láàrin wọn, àwọn ọmọ Lefi sì wà pẹlu rẹ̀, wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí lọ́wọ́. Wọ́n gbé e kalẹ̀ títí tí gbogbo àwọn eniyan náà fi jáde kúrò ní ìlú. Abiatari, alufaa náà wà láàrin wọn.
Sadoku, alufaa, wa laarin won, awon omo Lefi si wa pelu re, won gbe apoti eri lowo. Won gbe e kale titi ti gbogbo awon eniyan naa fi jade kuro ni ilu. Abiatari, alufaa naa wa laarin won.
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 16 ]
[ Awon aworan to wa ni oju iwe 16 ]
A mọ̀ pé àwọn òbí tó mọṣẹ́ wọn níṣẹ́ kì í fọ̀rọ̀ àwọn ọmọ wọn ṣeré wọn kì í sì í fìyà jẹ wọ́n .
A mo pe awon obi to mose won nise ki i foro awon omo won sere won ki i si i fiya je won .
Èyí ni ọ̀rọ̀ tí sọ wí pé:“Ẹ fi ayọ̀ kọrin sí Jakọbu;ẹ hó sí olórí àwọn orílẹ̀-èdè gbogbo.Jẹ́ kí wọ́n gbọ́ ìyìn rẹ kí o sì wí pé,‘, gba àwọn ènìyàn rẹ là;àwọn tí ó ṣẹ́kù ní Israẹli.’
Eyi ni oro ti so wi pe:"E fi ayo korin si Jakobu;e ho si olori awon orile-ede gbogbo.Je ki won gbo iyin re ki o si wi pe,', gba awon eniyan re la;awon ti o seku ni Israeli.'
Inú kíláàsì ńkọ́ ?
Inu kilaasi nko ?
116. 'Ṣé ẹ ha rò pé A dá yín láìní
116. 'Se e ha ro pe A da yin laini
Ipa Tí Ẹ̀ṣẹ̀ Ń Ní Lórí Wa
Ipa Ti Ese N Ni Lori Wa
Kí ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ṣe nígbà tó di àgbàlagbà ?
Ki ni apositeli Poolu se nigba to di agbalagba ?
Bó o bá fẹ́ láti rí ẹ̀dà kan ìwé pẹlẹbẹ yìí gbà , jọ̀wọ́ kàn sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò rẹ .
Bo o ba fe lati ri eda kan iwe pelebe yii gba , jowo kan si awon Elerii Jehofa to wa laduugbo re .
Ara wọn ni àwọn tíí máa tọ ojúlé kiri, tí wọn máa ń ki àwọn aṣiwèrè obinrin mọ́lẹ̀, àwọn obinrin tí ìwà ẹ̀ṣẹ̀ ti wọ̀ lẹ́wù, tí wọn ń ṣe oríṣìíríṣìí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́.
Ara won ni awon tii maa to ojule kiri, ti won maa n ki awon asiwere obinrin mole, awon obinrin ti iwa ese ti wo lewu, ti won n se orisiirisii ifekufee.
56. Mímu gbùn-ún-gbùn-ún bí
56. Mimu gbun-un-gbun-un bi
Èyí ti fún ìgbàgbọ́ wa lókùn gan - an . ” Lọ́dún 2014 , a ṣe àkànṣe àpéjọ kan ní Myanmar .
Eyi ti fun igbagbo wa lokun gan - an . " Lodun 2014 , a se akanse apejo kan ni Myanmar .
Ọlọ́run fi agbára ńlá rẹ̀ hàn , ó sì “ ṣẹ́gun àwọn ará Etiópíà níwájú Ásà ” torí pé ọkàn rẹ̀ pé “ pérépéré pẹ̀lú Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ rẹ̀ . ” ​ —⁠ 2 Kíró .
Olorun fi agbara nla re han , o si “ segun awon ara Etiopia niwaju Asa ” tori pe okan re pe “ perepere pelu Jehofa ni gbogbo ojo re . ” ​ —⁠ 2 Kiro .
Ó ní òun ò gbà pé Ọlọ́run wà .
O ni oun o gba pe Olorun wa .
Wàyí ò, ó já sí pé kì í ṣe èmi alára ni mò ń hùwà bẹ́ẹ̀, bíkòṣe ẹ̀ṣẹ̀ tí ń gbé inú mi.
Wayi o, o ja si pe ki i se emi alara ni mo n huwa bee, bikose ese ti n gbe inu mi.
Nínú àwọn sáàmù tí Ọlọ́run mí sí , ìgbà míì wà tí Dáfídì ṣàkọsílẹ̀ bí inú rẹ̀ ṣe bà jẹ́ tó .
Ninu awon saamu ti Olorun mi si , igba mii wa ti Dafidi sakosile bi inu re se ba je to .
Nígbà ìjíròrò yẹn , mo dábàá pé ká sọ̀rọ̀ nípa Mẹ́talọ́kan nìkan .
Nigba ijiroro yen , mo dabaa pe ka soro nipa Metalokan nikan .
Láti inú ayé ni àwọn yìí ti wá; nítorí náà, wọ́n ń sọ nǹkan ti ayé, àwọn aráyé sì ń gbọ́ tiwọn.
Lati inu aye ni awon yii ti wa; nitori naa, won n so nnkan ti aye, awon araye si n gbo tiwon.
Kò gbọ́dọ̀ fọwọ́ yẹpẹrẹ mú irú ọ̀ràn bẹ́ẹ̀ rárá .
Ko gbodo fowo yepere mu iru oran bee rara .
Bí àpẹẹrẹ , àwọn ìwé tí wọ́n máa ń kó lọ yìí ló mú kí ará abúlé kan tọ́nà rẹ̀ jìn gan - an ní Central African Republic nítòsí orílẹ̀ - èdè Sudan lè máa ka Bíbélì lédè rẹ̀ .
Bi apeere , awon iwe ti won maa n ko lo yii lo mu ki ara abule kan tona re jin gan - an ni Central African Republic nitosi orile - ede Sudan le maa ka Bibeli lede re .
A ó sọ pé : ‘ Ṣé o ò jáde ni ?
A o so pe : ' Se o o jade ni ?
Kò tiẹ̀ kábàámọ̀ ohun tó ṣe rárá nígbà tí Jèhófà bi í pé : “ Ibo ni Ébẹ́lì arákùnrin rẹ wà ? ”
Ko tie kabaamo ohun to se rara nigba ti Jehofa bi i pe : “ Ibo ni Ebeli arakunrin re wa ? ”
elẹ́kẹjì
elekeji
Bí àpẹẹrẹ , tá a bá fẹ́ ṣàlàyé pé Ọlọ́run ju Jésù lọ , a lè lo àbá yìí .
Bi apeere , ta a ba fe salaye pe Olorun ju Jesu lo , a le lo aba yii .
JÓSẸ́FÙ — APÁ KÌÍNÍ
JOSEFU — APA KIINI
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì gba orílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà láyè láti di alágbára , síbẹ̀ àwọn ọmọ ogun ojú omi ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ló ṣì ń dáàbò bò ó .
Bo tile je pe ile Geesi gba orile - ede Amerika laye lati di alagbara , sibe awon omo ogun oju omi ile Geesi lo si n daabo bo o .
Ísírẹ́lì Kò Yípadà Sí Ọlọ́run
Isireli Ko Yipada Si Olorun
Kò sí ẹni tí ó le è ríran rí ẹlòmíràn tàbí kí ó kúrò ní ibi tí ó wà fún ọjọ̀ mẹ́ta
Ko si eni ti o le e riran ri elomiran tabi ki o kuro ni ibi ti o wa fun ojo meta
Ẹ fi ojú sọ́nà fún àlàyé lori àwọn ọ̀nà ti enia lè lò lati tètè fi idi kalẹ̀ ni àjò
E fi oju sona fun alaye lori awon ona ti enia le lo lati tete fi idi kale ni ajo
gìrìgìrì
girigiri
Kí nìdí tí Ọlọ́run kò fi tẹ́wọ́ gba àwọn ẹbọ bẹ́ẹ̀ ?
Ki nidi ti Olorun ko fi tewo gba awon ebo bee ?
Ewu ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́ tó wà lóde yìí gba pé kí òbí fi ọgbọ́n kọ́ ọmọ .
Ewu egbekegbe to wa lode yii gba pe ki obi fi ogbon ko omo .
Bọ̀wọ̀ Fáwọn Aláṣẹ
Bowo Fawon Alase
Èyí fa ìṣòro ńlá fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí wọ́n ti pinnu láti wà ní àìdásí - tọ̀tún - tòsì nínú ìforígbárí náà .
Eyi fa isoro nla fun awon Elerii Jehofa ti won ti pinnu lati wa ni aidasi - totun - tosi ninu iforigbari naa .
Ọgbọ́n wo ni màá ta sí i ?
Ogbon wo ni maa ta si i ?
( a ) Kí nìdí tí Jésù fi kìlọ̀ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé ayé yóò kórìíra wọn ?
( a ) Ki nidi ti Jesu fi kilo fun awon omo eyin re pe aye yoo koriira won ?
Kí làwọn oníṣọ́ọ̀ṣì ń ṣe nípa ọ̀ràn yìí ?
Ki lawon onisoosi n se nipa oran yii ?
Inú mi dùn gan - an pé wọ́n pé mí sí kíláàsì Kẹtàlélọ́gbọ̀n ti ilé ẹ̀kọ́ Gílíádì .
Inu mi dun gan - an pe won pe mi si kilaasi Ketalelogbon ti ile eko Giliadi .
Ẹni tó bá ń fàwọn ìmọ̀ràn inú Ìwé Mímọ́ ṣèwà hù á máa fún irú àwọn aláṣẹ bẹ́ẹ̀ ní ọlá tó yẹ wọ́n .
Eni to ba n fawon imoran inu Iwe Mimo sewa hu a maa fun iru awon alase bee ni ola to ye won .
hágígì
hagigi
èmi ó sì kọ orúkọ Ọlọ́run mi sí i lára, àti orúkọ ìlú Ọlọ́run mi, tí i ṣe Jerúsálémù tuntun, tí ó ń ti ọrun sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run mi wá
emi o si ko oruko Olorun mi si i lara, ati oruko ilu Olorun mi, ti i se Jerusalemu tuntun, ti o n ti orun sokale lati odo Olorun mi wa
Pa èmi iranṣẹ rẹ mọ́ kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ àmọ̀-ọ́n-mọ̀-dá;má jẹ́ kí wọ́n jọba lórí mi.Nígbà náà ni ara mi yóo mọ́,n kò sì ní jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.
Pa emi iranse re mo kuro ninu ese amo-on-mo-da;ma je ki won joba lori mi.Nigba naa ni ara mi yoo mo,n ko si ni jebi ese nla.
Kíkọ̀ táwọn Kristẹni àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ kọ̀ láti jagun mú kí nǹkan nira fún wọn .
Kiko tawon Kristeni akokobere ko lati jagun mu ki nnkan nira fun won .
ti ṣìnà, bẹ̀ ni, wọn kò sì le rí
ti sina, be ni, won ko si le ri
Nítorí náà wọn yóò dàbí ìkùùkuu òwúrọ̀,bí ìrì òwúrọ̀ kùtùkùtù tó máa ń parẹ́,bí i èèpo ìyẹ̀fun tí afẹ́fẹ́ gbé láti ibi ìpakàbí èéfín tó rú jáde gba ojú fèrèsé.
Nitori naa won yoo dabi ikuukuu owuro,bi iri owuro kutukutu to maa n pare,bi i eepo iyefun ti afefe gbe lati ibi ipakabi eefin to ru jade gba oju ferese.
Kí la lè fi àdúrà àtọkànwá tó ò ń gbà wé ?
Ki la le fi adura atokanwa to o n gba we ?
Ọ̀pọ̀ nǹkan làwọn òbí lè ṣe láti ran àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ kí wọ́n lè fẹ́ láti ní àjọṣe tó dára pẹ̀lú Ọlọ́run .
Opo nnkan lawon obi le se lati ran awon omo won lowo ki won le fe lati ni ajose to dara pelu Olorun .
18. 'Kí ni ohun tí n bẹ ní ọwọ
18. 'Ki ni ohun ti n be ni owo
Nítorí náà , aago mẹ́fà àárọ̀ la ti gbọ́dọ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ka lè bá àwọn èèyàn nílé .
Nitori naa , aago mefa aaro la ti gbodo bere si i waasu ka le ba awon eeyan nile .
nítorí náà, ojú ara mi tì mí,fún ohun tí mo ti sọ,mo sì ronupiwada ninu erùpẹ̀ ati eérú.”
nitori naa, oju ara mi ti mi,fun ohun ti mo ti so,mo si ronupiwada ninu erupe ati eeru."
Nígbà tí Harry tó ti dẹni ọdún mẹ́tàdínláàádọ́rùn - ún [ 87 ] ń ṣàlàyé ohun tó sún un láti ṣe ohun tó ṣe yẹn , ó ní , “ Mo fẹ́ lo ìyókù ìgbésí ayé mi lọ́nà tó bọ́gbọ́n mu , kí n sì rí i pé mo wúlò gan - an nínú iṣẹ́ ìsìn Jèhófà níbi tágbára mi bá gbé e dé . ”
Nigba ti Harry to ti deni odun metadinlaaadorun - un [ 87 ] n salaye ohun to sun un lati se ohun to se yen , o ni , “ Mo fe lo iyoku igbesi aye mi lona to bogbon mu , ki n si ri i pe mo wulo gan - an ninu ise isin Jehofa nibi tagbara mi ba gbe e de . ”
Kí ni gbogbo èèyàn ní , kí ló sì máa ń ṣe ?
Ki ni gbogbo eeyan ni , ki lo si maa n se ?
Àmọ́ , ó ṣì ku ànímọ́ kan , tó jẹ́ pé téèyàn ò bá ní in , gbogbo ànímọ́ yòókù kò ní níyì , kódà wọ́n tiẹ̀ lè máà wúlò .
Amo , o si ku animo kan , to je pe teeyan o ba ni in , gbogbo animo yooku ko ni niyi , koda won tie le maa wulo .
Àwọn mìíràn ti rí irú àdánù yẹn nígbà táwọn tí wọ́n ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sọ fún wọn láìròtẹ́lẹ̀ pé àwọn ò kẹ́kọ̀ọ́ mọ́ .
Awon miiran ti ri iru adanu yen nigba tawon ti won n ko lekoo Bibeli so fun won lairotele pe awon o kekoo mo .
wọ́-jọ
wo-jo
Ìwé ìhìn rere Gospel of Mary Magdalene , tí wọ́n dọ́gbọ́n sọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan ṣẹ́ kù ìwé àjákù méjì péré , èyí tó gùn jù tó jẹ́ ìkẹta sì ti sọ nù .
Iwe ihin rere Gospel of Mary Magdalene , ti won dogbon soro re leekan se ku iwe ajaku meji pere , eyi to gun ju to je iketa si ti so nu .
sísẹ
sise
Níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀yin jẹ ẹ̀ran pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ ni inú rẹ̀, tí ẹ̀yin sì wó àwọn ère yín, tí ẹ sì ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀, Ẹ̀yin yóò ha gba ilẹ̀ náà
Niwon igba ti eyin je eran pelu eje ni inu re, ti eyin si wo awon ere yin, ti e si ta eje sile, Eyin yoo ha gba ile naa
Àpéjọ yẹn ni mo ti pàdé Maria Pizzato .
Apejo yen ni mo ti pade Maria Pizzato .
Èwo ninu yín ló fetí sí èyí,tabi tí yóo farabalẹ̀ gbọ́ nítorí ẹ̀yìn ọ̀la?
Ewo ninu yin lo feti si eyi,tabi ti yoo farabale gbo nitori eyin ola?
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 5 ]
[ Awon aworan to wa ni oju iwe 5 ]
Ǹjẹ́ ó tiẹ̀ bọ́gbọ́n mu fún un láti ṣe bẹ́ẹ̀ ?
Nje o tie bogbon mu fun un lati se bee ?
Kódà , àwọn ọkùnrin pàtàkì àti àwọn àlùfáà kan tó gbajúmọ̀ lọ gba ìmọ̀ràn lọ́dọ̀ irú àwọn obìnrin yìí . — Àwọn Onídàájọ́ 4 : 4 - 8 ; 2 Àwọn Ọba 22 : 14 - 16 , 20 .
Koda , awon okunrin pataki ati awon alufaa kan to gbajumo lo gba imoran lodo iru awon obinrin yii . -- Awon Onidaajo 4 : 4 - 8 ; 2 Awon Oba 22 : 14 - 16 , 20 .
Ẹni tó fọwọ́ sí bí wọ́n ṣe fòfin de gbogbo ìgbòkègbodò wa nígbà yẹn ni olórí orílẹ̀ - èdè náà , Mobutu Sese Seko , tó ti di olóògbé báyìí .
Eni to fowo si bi won se fofin de gbogbo igbokegbodo wa nigba yen ni olori orile - ede naa , Mobutu Sese Seko , to ti di oloogbe bayii .
Àlòkù bẹ́ẹ̀dì ti lè fa òógùn ara àwọn ẹlòmíràn mu , ìpẹ́pẹ́ ara wọ́n sì ti lè ṣí mọ́ ọn , ó tún lè ní kòkòrò tó lè bá ara rẹ jà , ó lè fa ikọ́ fée , tàbí ifo .
Aloku beedi ti le fa oogun ara awon elomiran mu , ipepe ara won si ti le si mo on , o tun le ni kokoro to le ba ara re ja , o le fa iko fee , tabi ifo .
dájúdájú pé: 'Éyí kò j$ -. nìkan
dajudaju pe: 'Eyi ko j$ -. nikan
Síbẹ̀ , kò sóhun tó ń fún wọn láyọ̀ tó àǹfààní tí wọ́n ní láti máa mú ìhìn rere lọ sáwọn ibi jíjìnnà réré ní Áfíríkà àti bí wọ́n ṣe ń rí i tó ń tún ayé àwọn tó ń gbà á ṣe .
Sibe , ko sohun to n fun won layo to anfaani ti won ni lati maa mu ihin rere lo sawon ibi jijinna rere ni Afirika ati bi won se n ri i to n tun aye awon to n gba a se .
pẹ̀lú ẹnu wọn; ṣùgbọn Allah kò
pelu enu won; sugbon Allah ko
Jẹ́nẹ́sísì tún pèsè ìtọ́sọ́nà lórí ìwà rere .
Jenesisi tun pese itosona lori iwa rere .
Ó ní : “ Àwọn èèyàn tó wà ní orílẹ̀ - èdè Brazil àti gbogbo àwọn tó wà ní Amẹ́ríkà ti Gúúsù ńkọ́ ? . . .
O ni : “ Awon eeyan to wa ni orile - ede Brazil ati gbogbo awon to wa ni Amerika ti Guusu nko ? . . .
ìyapa
iyapa
In Teresópolis , I had the wonderful privilege of helping more than 60 people to dedicate their lives to Jehovah .
In Teresopolis , I had the wonderful privilege of helping more than 60 people to dedicate their lives to Jehovah .
Ọ̀dọ̀ ta ni Ọlọ́run wà nínú àwọn ọmọ ogun tó dojú ìjà kọ́ ara wọn yìí ? ”
Odo ta ni Olorun wa ninu awon omo ogun to doju ija ko ara won yii ? ”
Fún àpẹẹrẹ , nítorí ìṣòro ìṣúnná owó , ọ̀pọ̀ iléèwé ni kò lómi rárá , tó sì jẹ́ pé ilé ìgbẹ́ mélòó kan ni wọ́n ní , tàbí kí wọ́n má tiẹ̀ níkankan rárá .
Fun apeere , nitori isoro isunna owo , opo ileewe ni ko lomi rara , to si je pe ile igbe meloo kan ni won ni , tabi ki won ma tie nikankan rara .
Jọ̀wọ́ má ṣe jẹ́ kí èyí kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọ .
Jowo ma se je ki eyi ko irewesi ba o .
Mo kẹ́kọ̀ọ́ pé ìfẹ́ Ọlọ́run ni láti sọ ayé yìí di Párádísè , kó jí àwọn òkú dìde àti pé ọjọ́ iwájú aláyọ̀ yìí ò yọ èmi náà sílẹ̀ .
Mo kekoo pe ife Olorun ni lati so aye yii di Paradise , ko ji awon oku dide ati pe ojo iwaju alayo yii o yo emi naa sile .
Ìgbàgbọ́ àti ìbẹ̀rù Ọlọ́run nìkan kọ́ ni àwọn ànímọ́ tó ń jẹ́ kéèyàn ní ìgboyà , kódà ìfẹ́ lágbára jù wọ́n lọ .
Igbagbo ati iberu Olorun nikan ko ni awon animo to n je keeyan ni igboya , koda ife lagbara ju won lo .