diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ẹ̀jẹ̀ Jésù ló ṣí ọ̀nà fáwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì tí wọ́n jẹ́ ẹni mímọ́ láti rí àjíǹde sínú ògo lókè ọ̀run .
Eje Jesu lo si ona fawon oke meje o le egbaaji ti won je eni mimo lati ri ajinde sinu ogo loke orun .
Wọ́n ti báṣẹ́ débì kan lórí ẹ̀ .
Won ti base debi kan lori e .
kíyèsi i, mo ní ọmọbìnrin méjì tí kò mọ ọkùnrin rí, ẹ jẹ́ kí n mú wọn tọ̀ yín wá kí ẹ sì ṣe ohun tí ẹ fẹ́ pẹ̀lú wọn. Ṣùgbọ́n ẹ má ṣe ṣe àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ní ibi kan nítorí wọ́n wá wọ̀ lábẹ́ ààbò ní ilé mi.”
kiyesi i, mo ni omobinrin meji ti ko mo okunrin ri, e je ki n mu won to yin wa ki e si se ohun ti e fe pelu won. Sugbon e ma se se awon okunrin wonyi ni ibi kan nitori won wa wo labe aabo ni ile mi.”
Ṣùgbọ́n àwọn ará Siria sálọ kúrò níwájú Israẹli, Dafidi sì pa ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin agun-kẹ̀kẹ́ wọn àti ẹgbàá-mẹ́rin ọmọ-ogun ẹlẹ́ṣẹ̀. Ó pa Ṣofaki alákòóso ọmọ-ogun wọn pẹ̀lú.
Sugbon awon ara Siria salo kuro niwaju Israeli, Dafidi si pa eedegbaarin agun-keke won ati egbaa-merin omo-ogun elese. O pa Sofaki alakooso omo-ogun won pelu.
Nítorí , ní ti tòótọ́ , Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò jẹ́ ìgbọ́kànlé rẹ , dájúdájú , kì yóò jẹ́ kí a gbá ẹsẹ̀ rẹ mú . ” — Òwe 3 : 25 , 26 ; Mátíù 24 : 21 .
Nitori , ni ti tooto , Jehofa funra re yoo je igbokanle re , dajudaju , ki yoo je ki a gba ese re mu . " -- Owe 3 : 25 , 26 ; Matiu 24 : 21 .
Lẹ́yìn ọjọ́ mẹfa, Jesu mú Peteru ati Jakọbu ati Johanu arakunrin Jakọbu, wọ́n lọ sí orí òkè gíga kan; àwọn nìkan wà níbẹ̀.
Leyin ojo mefa, Jesu mu Peteru ati Jakobu ati Johanu arakunrin Jakobu, won lo si ori oke giga kan; awon nikan wa nibe.
72 : 17 - 19 .
72 : 17 - 19 .
Ó fún wa ni ogún ainipẹkun, ogún tí kò lè díbàjẹ́, tí kò lè ṣá, tí a ti fi pamọ́ fun yín ní ọ̀run.
O fun wa ni ogun ainipekun, ogun ti ko le dibaje, ti ko le sa, ti a ti fi pamo fun yin ni orun.
Kí ó ṣẹlẹ̀ sí mi ní ìbámu pẹ̀lú ìpolongo rẹ . ” — Lúùkù 1 : 26 - 38 .
Ki o sele si mi ni ibamu pelu ipolongo re . ” — Luuku 1 : 26 - 38 .
( Àwa la kọ ọ́ lọ́nà tó dúdú yàtọ̀ . )
( Awa la ko o lona to dudu yato . )
▪ Jẹ́ Kí Jèhófà Dáàbò Bo Ìgbéyàwó Rẹ Kó sì Fún Un Lókun
# Je Ki Jehofa Daabo Bo Igbeyawo Re Ko si Fun Un Lokun
Àkókò yìí làwọn Gíríìkì láti àgbègbè Ayóníà lọ tẹ̀dó sí apá ìwọ oòrùn etíkun Éṣíà Kékeré .
Akoko yii lawon Giriiki lati agbegbe Ayonia lo tedo si apa iwo oorun etikun Esia Kekere .
Pọ́ọ̀lù kọ̀wé pé : “ Owó ọ̀yà tí ẹ̀ṣẹ̀ máa ń san ni ikú . ”
Poolu kowe pe : “ Owo oya ti ese maa n san ni iku . ”
Àwọn tó ń kó wọn jọ kì í sábà ka ère náà sí ohun mímọ́ tí wọ́n ń lò fún ìjọsìn , bí kò ṣe iṣẹ́ ọ̀nà tó ń fi àṣà ìbílẹ̀ Byzantium hàn .
Awon to n ko won jo ki i saba ka ere naa si ohun mimo ti won n lo fun ijosin , bi ko se ise ona to n fi asa ibile Byzantium han .
Ní òní èmi ti sọ ọ́ di ìlú alágbára, òpó irin àti odi idẹ sí àwọn ọba Juda, àwọn ìjòyè rẹ̀, sí àwọn àlùfáà àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà.
Ni oni emi ti so o di ilu alagbara, opo irin ati odi ide si awon oba Juda, awon ijoye re, si awon alufaa ati awon eniyan ile naa.
Ǹjẹ́ Ìrètí Kankan Tiẹ̀ Wà Pé A Ó Gbà Wá Là ?
Nje Ireti Kankan Tie Wa Pe A O Gba Wa La ?
Ṣé orílẹ̀ - èdè míì ni bàbá tàbí màmá rẹ ń gbé ?
Se orile - ede mii ni baba tabi mama re n gbe ?
Láti ìgbà ọmọdé jòjòló ni ìyá rẹ̀ Yùníìsì àti ìyá rẹ̀ àgbà Lọ́ìsì ti kọ́ ọ ní “ ìwé mímọ́ . ”
Lati igba omode jojolo ni iya re Yuniisi ati iya re agba Loisi ti ko o ni “ iwe mimo . ”
Ní ìbámu pẹ̀lú ìfẹ́ Jèhófà , ọdún tó tẹ̀ lé e ni àwọn Júù tó pa dà sílé láti ìgbèkùn yìí fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì tuntun lélẹ̀ .
Ni ibamu pelu ife Jehofa , odun to te le e ni awon Juu to pa da sile lati igbekun yii fi ipile tenpili tuntun lele .
ibùgbé tí ô dára jùlọ wà.
ibugbe ti o dara julo wa.
Díẹ̀díẹ̀ , ó bẹ̀rẹ̀ sí í mọyì bí àwọn òtítọ́ Bíbélì ṣe ṣeyebíye tó .
Diedie , o bere si i moyi bi awon otito Bibeli se seyebiye to .
“Nítorí náà, ilé Israẹli, èmi yóò da yín lẹ́jọ́, gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ẹnìkọ̀ọ̀kan yín bá ṣe rí ni Olódùmarè wí. Ẹ yípadà! Kí ẹ si yí kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín, bẹ́ẹ̀ ni ìrékọjá kì yóò jẹ́ ọ̀nà ìṣubú yín.
"Nitori naa, ile Israeli, emi yoo da yin lejo, gege bi ona enikookan yin ba se ri ni Olodumare wi. E yipada! Ki e si yi kuro ninu gbogbo ese yin, bee ni irekoja ki yoo je ona isubu yin.
Ìwádìí kan tí wọ́n ṣe nípa àwọn ọ̀gá iléeṣẹ́ ní orílẹ̀ - èdè Ọsirélíà fi hàn pé àwọn mẹ́sàn - án nínú mẹ́wàá ló gbà pé àbẹ̀tẹ́lẹ̀ àti ìwà ìbàjẹ́ “ kò dára , àmọ́ kò sí bí èèyàn ò ṣe ní lọ́wọ́ sí i . ”
Iwadii kan ti won se nipa awon oga ileese ni orile - ede Osirelia fi han pe awon mesan - an ninu mewaa lo gba pe abetele ati iwa ibaje “ ko dara , amo ko si bi eeyan o se ni lowo si i . ”
Kí nìdí tí jíjí ìwé wò tàbí rírẹ́ àwọn ẹlòmíì jẹ fi wá di ìṣòro tó ń kọni lóminú ?
Ki nidi ti jiji iwe wo tabi rire awon elomii je fi wa di isoro to n koni lominu ?
gbogbo àwọn tí ó wọ inú ilẹ̀ lọ yóò kúnlẹ̀ ní iwájúu Rẹ̀ àti ẹni ti kò le pa ọkàn ara Rẹ̀ mọ́ ni ààyè
gbogbo awon ti o wo inu ile lo yoo kunle ni iwajuu Re ati eni ti ko le pa okan ara Re mo ni aaye
Àmọ́ , wọ́n ṣáà gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà , wọ́n sì múra láti lọ .
Amo , won saa gbeke le Jehofa , won si mura lati lo .
Nígbà tí àwọn eniyan rí i pé Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ kò sí níbẹ̀, àwọn náà bọ́ sinu àwọn ọkọ̀ tí ó wà níbẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí tọpa Jesu lọ sí Kapanaumu.
Nigba ti awon eniyan ri i pe Jesu ati awon omo-eyin re ko si nibe, awon naa bo sinu awon oko ti o wa nibe, won bere si topa Jesu lo si Kapanaumu.
Bákan náà ni Jésù ṣe ké sí gbogbo ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ òdodo , nígbà tó sọ pé : “ Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn , kí ó sẹ́ níní ara rẹ̀ , kí ó sì gbé òpó igi oró rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́ , kí ó sì máa tọ̀ mí lẹ́yìn nígbà gbogbo . ”
Bakan naa ni Jesu se ke si gbogbo eni to ba nifee ododo , nigba to so pe : “ Bi enikeni ba fe to mi leyin , ki o se nini ara re , ki o si gbe opo igi oro re lati ojo de ojo , ki o si maa to mi leyin nigba gbogbo . ”
Jẹ́ Kí Ẹ̀kọ́ Nípa Ìwà Funfun Dé Ọkàn - Àyà Rẹ
Je Ki Eko Nipa Iwa Funfun De Okan - Aya Re
A ô ku àwọn òké dànù, ìwọ yòò
A o ku awon oke danu, iwo yoo
Síbẹ̀ , má ṣe máa dá ara rẹ̀ lẹ́bi pé kí ló dé tó o fi bínú lọ́nà yẹn . ”
Sibe , ma se maa da ara re lebi pe ki lo de to o fi binu lona yen . ”
• Ọ̀nà wo ni Ọlọrun ti gbà lo àwọn áńgẹ́lì láti ràn wá lọ́wọ́ ?
• Ona wo ni Olorun ti gba lo awon angeli lati ran wa lowo ?
Ibujoko ni Akowe Ipinle Eko ati awon ofiisi ti Gomina ati Igbakeji Gomina ipinle Eko.
Ibujoko ni Akowe Ipinle Eko ati awon ofiisi ti Gomina ati Igbakeji Gomina ipinle Eko.
Ilé ẹ̀kọ́ náà dá lórí ṣíṣèwádìí nípa Bíbélì àti sísọ̀rọ̀ níwájú àwùjọ .
Ile eko naa da lori sisewadii nipa Bibeli ati sisoro niwaju awujo .
Bíbú ramúramù kìnnìún àti ohùn òǹrorò kìnnìúnàti eyín àwọn ẹgbọrọ kìnnìún ní a ká.
Bibu ramuramu kinniun ati ohun onroro kinniunati eyin awon egboro kinniun ni a ka.
pé: Ẹ níláti ronúpìwàdà kí ẹ sì kígbe pé ohùn nã, àní títí ẹ̀yin ó fi ní ìgbàgbọ́ nínú Krístì, ẹnití Álmà, àti Ámúlẹ́kì, àti Sísrọ́mù ti kọ́ nyín lẹ́kọ̣́ nípa rẹ̀; àti nígbàtí ẹ̀yin o bá ṣe eleyĩ, a ó ka ìkũkù tí ó ṣókùnkùn nnì kúrò kí ó má lè bò nyín mọ́lẹ̀ mọ́.
pe: E nilati ronupiwada ki e si kigbe pe ohun na, ani titi eyin o fi ni igbagbo ninu Kristi, eniti Alma, ati Amuleki, ati Sisromu ti ko nyin leko nipa re; ati nigbati eyin o ba se eleyi, a o ka ikuku ti o sokunkun nni kuro ki o ma le bo nyin mole mo.
Ìmọ̀ tó péye tí Nóà ní mú kó nígbàgbọ́ àti ọgbọ́n Ọlọ́run . Ìmọ̀ tó ní yìí ni kò jẹ́ kó ṣe ohun tó máa múnú bí Ọlọ́run .
Imo to peye ti Noa ni mu ko nigbagbo ati ogbon Olorun . Imo to ni yii ni ko je ko se ohun to maa munu bi Olorun .
alijannu pé: bí àwọn bá mọ ohun tí
alijannu pe: bi awon ba mo ohun ti
Ní ti àwọn èèyàn tó múra tán láti di ọlọ́kàn tútù , onírẹ̀lẹ̀ , àti ẹni àlàáfíà , onísáàmù náà ṣèlérí pé : “ Ní ìrètí nínú Jèhófà , kí o sì máa pa ọ̀nà rẹ̀ mọ́ , òun yóò sì gbé ọ ga láti gba ilẹ̀ ayé .
Ni ti awon eeyan to mura tan lati di olokan tutu , onirele , ati eni alaafia , onisaamu naa seleri pe : “ Ni ireti ninu Jehofa , ki o si maa pa ona re mo , oun yoo si gbe o ga lati gba ile aye .
Ẹ má ṣe jẹ́ kó rẹ̀ yín !
E ma se je ko re yin !
Mo sì lọ sí Jérúsálẹ́mù, lẹ́yìn ìgbà tí mo dúró níbẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́ta
Mo si lo si Jerusalemu, leyin igba ti mo duro nibe fun ojo meta
Ìṣọ̀kan Ayé , 6 / 1
Isokan Aye , 6 / 1
Ó dájú pé ìrètí wa láti wà láàyè títí láé àti láti máa yin Jèhófà títí ayé yóò mú kí ètò ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Ẹlẹ́gbẹ̀rún ọdún náà gbádùn mọ́ni gan - an .
O daju pe ireti wa lati wa laaye titi lae ati lati maa yin Jehofa titi aye yoo mu ki eto ikonilekoo Elegberun odun naa gbadun moni gan - an .
Wọ́n ń wádìí ìgbà wo tàbí irú sáà wo ni Ẹ̀mí Kírísítì tí ó wà nínú wọn ń tọ́ka sí, nígbà tí ó jẹ́rìí ìyà Kírísítì àti ògo tí yóò tẹ̀lé e
Won n wadii igba wo tabi iru saa wo ni Emi Kirisiti ti o wa ninu won n toka si, nigba ti o jerii iya Kirisiti ati ogo ti yoo tele e
Mo máa ń sọ fún wọn pé ìrètí àrà ọ̀tọ̀ tí mo ní ló fà á .
Mo maa n so fun won pe ireti ara oto ti mo ni lo fa a .
OJÚ ÌWÉ 15 • ORIN : 108 , 117
OJU IWE 15 • ORIN : 108 , 117
Jésù mọ ohun tí gbogbo èyí túmọ̀ sí .
Jesu mo ohun ti gbogbo eyi tumo si .
Bákan náà nígbà tí Lásárù kú , àwọn ọmọ ẹ̀yìn ti ní láti rí bí Baba ṣe ní ẹ̀mí ìbánikẹ́dùn tó nígbà tí Jésù ‘ kérora nínú ẹ̀mí , tó dààmú , tó sì bẹ̀rẹ̀ sí da omijé . ’
Bakan naa nigba ti Lasaru ku , awon omo eyin ti ni lati ri bi Baba se ni emi ibanikedun to nigba ti Jesu ' kerora ninu emi , to daamu , to si bere si da omije . '
Àwọn kan gbà gbọ́ pé ọ̀rọ̀ Gíríìkì táa tú sí “ ẹ̀mí asọ̀ ” ní í ṣe pẹ̀lú ìwà anìkànjọpọ́n , jíjẹ àwọn èèyàn lẹ́sẹ̀ nítorí ipò .
Awon kan gba gbo pe oro Giriiki taa tu si “ emi aso ” ni i se pelu iwa anikanjopon , jije awon eeyan lese nitori ipo .
Àmọ́ , àwọn àgbà òṣìṣẹ́ tó ti hewú lórí , tí wọ́n ti pẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ ilé kíkọ́ , máa ń fi ọwọ́ wọn àti irinṣẹ́ ṣe àwọn iṣẹ́ ọnà ara ilé .
Amo , awon agba osise to ti hewu lori , ti won ti pe lenu ise ile kiko , maa n fi owo won ati irinse se awon ise ona ara ile .
Irúgbìn náà àti ẹ̀gún bẹ̀rẹ̀ sí du oúnjẹ , oòrùn àti àyè mọ́ra wọn lọ́wọ́ , àmọ́ nígbà tó yá ọwọ́ ẹ̀gún le ju ti irúgbìn náà lọ ó sì “ fún un pa . ” — Lúùkù 8 : 7 .
Irugbin naa ati egun bere si du ounje , oorun ati aye mora won lowo , amo nigba to ya owo egun le ju ti irugbin naa lo o si " fun un pa . " -- Luuku 8 : 7 .
24. Ẹnikẹni tô bá ṣe àìgbàgbọ, ma
24. Enikeni to ba se aigbagbo, ma
Ó tiẹ̀ ṣeé ṣe kóun náà ti ṣe lára irú àwọn eré orí kọ̀ǹpútà tó o rò pé kò dáa yẹn .
O tie see se koun naa ti se lara iru awon ere ori konputa to o ro pe ko daa yen .
SI. Àwọn tò (gbìmò pò láti) dúré
SI. Awon to (gbimo po lati) dure
□ Kò kàn mí
# Ko kan mi
‘ Èmi ò dá rúkèrúdò kankan sílẹ̀ .
‘ Emi o da rukerudo kankan sile .
Láìsí ìrì tó máa ń mú kójú ọjọ́ tutù , ṣe ni àwọn ewéko máa gbẹ tí wọ́n á sì rẹ̀ dà nù .
Laisi iri to maa n mu koju ojo tutu , se ni awon eweko maa gbe ti won a si re da nu .
Ọ̀lẹ ènìyàn kò sun ẹran tí ó pa lóko ọdẹ ṣùgbọ́n ẹni tí kì í ṣe ọ̀lẹ máa ń díwọ̀n ohun ìní rẹ̀
Ole eniyan ko sun eran ti o pa loko ode sugbon eni ti ki i se ole maa n diwon ohun ini re
Ẹ gbọdọ̀ ṣe ìwádìí kí ẹ sì jẹ wọ́n ní ìyà tó tọ́ ṣùgbọ́n ẹ kò gbọdọ̀ pa wọ́n, torí pé kò ì tíì di òmìnira
E gbodo se iwadii ki e si je won ni iya to to sugbon e ko gbodo pa won, tori pe ko i tii di ominira
10 , 11 . ( a ) Kí ni kò ní jẹ́ ká máa hùwà ìkùgbù nínú ìdílé ?
10 , 11 . ( a ) Ki ni ko ni je ka maa huwa ikugbu ninu idile ?
Bẹrẹ ni ọdun 1956, NPA tuntun ti a ṣẹda bẹrẹ lati faagun nọmba awọn berths laarin eka naa, ni afikun aaye gbigbe mẹfa.
Bere ni odun 1956, NPA tuntun ti a seda bere lati faagun nomba awon berths laarin eka naa, ni afikun aaye gbigbe mefa.
Ṣùgbọ́n Kaiafa, ọ̀kan nínú wọn, ẹni tí í ṣe olórí àlùfáà ní ọdún náà, ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin kò mọ ohunkóhun rárá!
Sugbon Kaiafa, okan ninu won, eni ti i se olori alufaa ni odun naa, o wi fun won pe, "Eyin ko mo ohunkohun rara!
òfin fún yín, Allah jẹ Onímímẹ,
ofin fun yin, Allah je Onimime,
Pẹ̀lú ìyàlẹ́nu , ó sọ pé , “ Ọkọ mi ló ń jẹ́ bẹ́ẹ̀ . ”
Pelu iyalenu , o so pe , “ Oko mi lo n je bee . ”
Tipẹ́tipẹ́ ni wọ́n ti ń fi òróró ólífì ṣe lọ́fínńdà tí wọ́n ń lò ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì ìgbàanì .
Tipetipe ni won ti n fi ororo olifi se lofinnda ti won n lo ni ile Isireli igbaani .
Jákọ́bù wá fi ìdánilójú náà kún un pé : “ Àdúrà ìgbàgbọ́ yóò sì mú aláàárẹ̀ náà lára dá , Jèhófà yóò sì gbé e dìde .
Jakobu wa fi idaniloju naa kun un pe : “ Adura igbagbo yoo si mu alaaare naa lara da , Jehofa yoo si gbe e dide .
Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ń tan àrùn kálẹ̀ , òfò kékeré sì kọ́ ni wọ́n ń ṣe fún àwọn ohun alààyè àti àyíká . ”
Bee ni won si n tan arun kale , ofo kekere si ko ni won n se fun awon ohun alaaye ati ayika . "
Ẹ̀kọ́ Tá A Rí Kọ́ :
Eko Ta A Ri Ko :
Nígbà tí nǹkan kò rí bí wọ́n ṣe rò , ó ṣeé ṣe kí wọ́n máa ronú pé ńṣe ni Ọkọ Ìyàwó ń fi dídé rẹ̀ falẹ̀ .
Nigba ti nnkan ko ri bi won se ro , o see se ki won maa ronu pe nse ni Oko Iyawo n fi dide re fale .
Bákan náà ni wọ́n tún jẹ́ káwọn èèyàn rí ọ̀rọ̀ ìtùnú tó wà nínú Sáàmù 34 : 18 ; Sáàmù 37 : 29 ; Aísáyà 25 : 8 àti Ìṣípayá 21 : 3 , 4 .
Bakan naa ni won tun je kawon eeyan ri oro itunu to wa ninu Saamu 34 : 18 ; Saamu 37 : 29 ; Aisaya 25 : 8 ati Isipaya 21 : 3 , 4 .
[ Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ]
[ Alaye isale iwe ]
Ní ayé èṣù tá a wà yìí , ju ti ìgbàkígbà rí lọ , àwọn alàgbà ní láti fiyè sí ọ̀rọ̀ yìí : “ Ẹ kíyè sí ohun tí ẹ ń ṣe , nítorí pé kì í ṣe ènìyàn ni ẹ ń ṣe ìdájọ́ fún bí kò ṣe Jèhófà . ” — 2 Kíróníkà 19 : 6 .
Ni aye esu ta a wa yii , ju ti igbakigba ri lo , awon alagba ni lati fiye si oro yii : " E kiye si ohun ti e n se , nitori pe ki i se eniyan ni e n se idajo fun bi ko se Jehofa . " -- 2 Kironika 19 : 6 .
Eto Oro Aje
Eto Oro Aje
Tí inú Náómì kò bá tiẹ̀ dùn sí ohun tí wọ́n ṣe yẹn tàbí pé kò tẹ́ ẹ lọ́rùn , ẹ̀rí fi hàn pé ó fi inú rere àti ìfẹ́ hàn sí Rúùtù àti Ópà , ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì .
Ti inu Naomi ko ba tie dun si ohun ti won se yen tabi pe ko te e lorun , eri fi han pe o fi inu rere ati ife han si Ruutu ati Opa , iyawo awon omo re mejeeji .
Ó wá túbọ̀ ṣe kedere sí mi pé Ìjọba Ọlọ́run nìkan ló lè yanjú ìṣòro aráyé .
O wa tubo se kedere si mi pe Ijoba Olorun nikan lo le yanju isoro araye .
Jèhórámù ․ ․
Jehoramu . .
Ó bẹ Jèhófà pé kó bá òun yan ọmọbìnrin fún Ísákì láti fi ṣaya .
O be Jehofa pe ko ba oun yan omobinrin fun Isaki lati fi saya .
Bó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i tàbí tó o fẹ́ kí ẹnì kan kàn sí ọ nílé láti kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ , jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Jehovah’s Witnesses , P.M.B . 1090 , Benin City 300001 , Edo State , Nigeria , tàbí sí àdírẹ́sì tó bá yẹ lára èyí tí a tò sí ojú ìwé 4 .
Bo o ba fe isofunni siwaju si i tabi to o fe ki eni kan kan si o nile lati ko e lekoo Bibeli lofee , jowo kowe si Jehovah's Witnesses , P.M.B . 1090 , Benin City 300001 , Edo State , Nigeria , tabi si adiresi to ba ye lara eyi ti a to si oju iwe 4 .
Ọlọ́run kan àti Baba gbogbo aráyé, ẹni tí ó ṣe olórí ohun gbogbo àti nípá gbogbo àti nínú ohun gbogbo.
Olorun kan ati Baba gbogbo araye, eni ti o se olori ohun gbogbo ati nipa gbogbo ati ninu ohun gbogbo.
Àwọn èèyàn tó ti rí irú ajá tó tóbi tó bẹ́ẹ̀ yẹn rí kò pọ̀ ní Lomé , nítorí pé àwọn ajá ilẹ̀ Tógò sábà máa ń kéré .
Awon eeyan to ti ri iru aja to tobi to bee yen ri ko po ni Lome , nitori pe awon aja ile Togo saba maa n kere .
ihòòhò
ihooho
Ó mọ̀ pé òun nílò okun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run kí òun tó lè dojú kọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú láìfòyà , kí òun tó lè tọ́jú àwọn ọmọ òun , kí òun sì tó lè mú èrò pé òun kò já mọ́ nǹkan kan kúrò lọ́kàn .
O mo pe oun nilo okun lati odo Olorun ki oun to le doju ko ohun to maa sele lojo iwaju laifoya , ki oun to le toju awon omo oun , ki oun si to le mu ero pe oun ko ja mo nnkan kan kuro lokan .
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 29 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 29 ]
Jésù tilẹ̀ sọ fáwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé : “ Bí nǹkan wọ̀nyí bá ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣẹlẹ̀ , ẹ gbé ara yín nà ró ṣánṣán , kí ẹ sì gbé orí yín sókè , nítorí pé ìdáǹdè yín ń sún mọ́lé . ”
Jesu tile so fawon omo eyin re pe : “ Bi nnkan wonyi ba ti bere si sele , e gbe ara yin na ro sansan , ki e si gbe ori yin soke , nitori pe idande yin n sun mole . ”
Ṣùgbọ́n , ọdún Kérésìmesì ò jẹ́ ká mọ irú ẹni tí Kristi jẹ́ mọ́ nítorí ìtàn àtẹnudẹ́nu nípa ìbí rẹ̀ .
Sugbon , odun Keresimesi o je ka mo iru eni ti Kristi je mo nitori itan atenudenu nipa ibi re .
Ojúlówó Ìrànwọ́ fún Àwọn Òtòṣì
Ojulowo Iranwo fun Awon Otosi
Ọlọ́run fẹ́ di Ọ̀rẹ́ wa . ​ — Jákọ́bù 4 : 8 .
Olorun fe di Ore wa . ​ — Jakobu 4 : 8 .
Nítorí náà , ìwọ ni kó o kọ́kọ́ fìfẹ́ hàn sáwọn èèyàn , tó fi mọ́ àwọn ọ̀rẹ́ tó o ti ní tẹ́lẹ̀ .
Nitori naa , iwo ni ko o koko fife han sawon eeyan , to fi mo awon ore to o ti ni tele .
Ó ní : “ Nǹkan kan tó mú ki n yí pa dà ni ìwàásù tí Jésù ṣe lórí òkè , mo kà á , mo sì lóye ẹ̀ dáadáa .
O ni : " Nnkan kan to mu ki n yi pa da ni iwaasu ti Jesu se lori oke , mo ka a , mo si loye e daadaa .
Nígbà tí wọ́n sì ṣe ìparí ẹbọ rírú, ọba àti gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ tẹ ara wọn ba, wọ́n sì sìn.
Nigba ti won si se ipari ebo riru, oba ati gbogbo awon ti o wa pelu re te ara won ba, won si sin.
Àwòrán - ilẹ̀ àgbáyé tí wọ́n yà sára bọ́ọ̀lù àtèyí tó wà lórí ìwé fẹ̀rẹ̀gẹ̀dẹ̀ wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kan nínú kíláàsì náà .
Aworan - ile agbaye ti won ya sara boolu ateyi to wa lori iwe feregede wa legbee kan ninu kilaasi naa .
ìhúnra
ihunra
Ohun tí Phyllis àti Paul tí wọ́n ti tọ́ ọmọ márùn - ún ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní àtọ́yanjú ṣe nìyẹn .
Ohun ti Phyllis ati Paul ti won ti to omo marun - un otooto ni atoyanju se niyen .
Ó wá sọ fún olùtọ́jú ọgbà pé, ‘Ṣé o rí i! Ó di ọdún mẹta tí mo ti ń wá èso lórí igi ọ̀pọ̀tọ́ yìí tí n kò rí. Gé e lulẹ̀. Kí ló dé tí yóo kàn máa gbilẹ̀ lásán?’
O wa so fun olutoju ogba pe, ‘Se o ri i! O di odun meta ti mo ti n wa eso lori igi opoto yii ti n ko ri. Ge e lule. Ki lo de ti yoo kan maa gbile lasan?’
Ṣé ó lo ẹ̀bùn náà lọ́nà rere ?
Se o lo ebun naa lona rere ?
Omi sì bẹ̀rẹ̀ sí ní gbẹ kúrò lórí ilẹ̀, lẹ́yín àádọ́jọ ọjọ́, ó sì ti ń fà
Omi si bere si ni gbe kuro lori ile, leyin aadojo ojo, o si ti n fa
Àwọn ilé alájà púpọ̀ tí wọ́n fi òkúta kọ́ wà lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ojú pópó tí wọ́n fi òkúta tẹ́ , àwọn ọmọ onílẹ̀ àtàwọn tó rí já jẹ ló ni wọ́n .
Awon ile alaja pupo ti won fi okuta ko wa lo legbee oju popo ti won fi okuta te , awon omo onile atawon to ri ja je lo ni won .
Ìwé Oníwàásù 4 : 6 tiẹ̀ sọ pé : “ Ẹ̀kúnwọ́ kan ìsinmi sàn ju ẹ̀kúnwọ́ méjì iṣẹ́ àṣekára àti lílépa ẹ̀fúùfù . ”
Iwe Oniwaasu 4 : 6 tie so pe : " Ekunwo kan isinmi san ju ekunwo meji ise asekara ati lilepa efuufu . "
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé abala àkájọ ìwé máa ń gùn tó ìwé àjákọ , síbẹ̀ àwọn abala kan wà tí kì í gùn tó o , bákan náà sì lọ̀rọ̀ rí ní ti fífẹ̀ àkájọ ìwé .
Bo tile je pe abala akajo iwe maa n gun to iwe ajako , sibe awon abala kan wa ti ki i gun to o , bakan naa si loro ri ni ti fife akajo iwe .
Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì , táwọn àlùfáà ti kó sí lórí ló jagun láti gbèjà ẹ̀sìn wọn .
Egbeegberun awon omo soosi Katoliiki , tawon alufaa ti ko si lori lo jagun lati gbeja esin won .