ending1
stringlengths 4
149
| ending2
stringlengths 5
156
| startphrase
stringlengths 7
179
| labels
int64 0
1
| split
stringclasses 7
values |
---|---|---|---|---|
Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá rìn | Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá ṣeré | Ẹsẹ̀ mẹ́ta ni Bọ́lájókòó fi ń rin bí i àwọn atọrọbáárà | 0 | yo |
Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá rìn | Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá ṣeré | Ẹsẹ̀ tó ti kán ni Bọ́lájókòó fi ń rin | 1 | yo |
Iyán náà rọ̀ | Iyán náà le | Iyán náà fẹ́lẹ́ bí i etí | 0 | yo |
Iyán náà rọ̀ | Iyán náà le | Iyán náà wúwo bí i òkúta | 1 | yo |
Ìdánwò náà gbomi mu | Ìdánwò náà rọrùn | Ìdí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yọ eruku lala bí i omi gbóná nínú yàrá ìdánwò | 0 | yo |
Ìdánwò náà gbomi mu | Ìdánwò náà rọrùn | Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sùn fọnfọn nínú yàrá ìdánwò | 1 | yo |
Adé́gbètẹ̀ bínú nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò | Adé́gbètẹ̀ rẹ́rìn ín nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò | Adégbètẹ́ tu itọ́ sókè fojú gbáà nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ Mákindé sòrò | 0 | yo |
Adé́gbètẹ̀ bínú nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò | Adé́gbètẹ̀ rẹ́rìn ín nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò | Adégbètẹ́ bú sẹ́kún nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ Mákindé sòrò | 1 | yo |
Arákùnrin ná́à ti kú | Arákùnrin ná́à wá ọ̀nà àbáyọ | Arákunrìn náà ta téru nípàá níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ọkọ̀ | 1 | yo |
Arákùnrin ná́à ti kú | Arákùnrin ná́à wá ọ̀nà àbáyọ | Arákunrìn náà ra ọkọ̀ tuntun | 0 | yo |
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá ò ga | Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá sùn lọ | Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá rí bí i Àdìgún tí kò yọ kúrò nílẹ̀ | 1 | yo |
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá ò ga | Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá sùn lọ | Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá ti fẹ́ àbúrò Àdìgún tó rẹwà | 0 | yo |
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ń jà | Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ṣeré kiri | Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ yóò kẹsẹ̀ bọ sòkòtò kan ná-àn, ọlọ́pàá sì kó wọn | 1 | yo |
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ń jà | Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ṣeré kiri | Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ yóò aṣọ tó rẹwà tó sì jọra | 0 | yo |
Ilé awòṣífìnà náà rẹwà | Ilé awòṣífìnà náà ti wó | Ilé awòṣífìlà tó kọ́ rí bí i ààfin Ọba Ọọ̀ni ilé Ifẹ̀ | 0 | yo |
Ilé awòṣífìnà náà rẹwà | Ilé awòṣífìnà náà ti wó | Ilé awòṣífìlà tó kọ́ ti wó lul̀e | 1 | yo |
O tí dàgbà gan | O kéré gan | Ọjọ́ orí rẹ̀ ju ọjọ́ ori ij̀àpá lọ | 0 | yo |
O tí dàgbà gan | O kéré gan | Ọjọ́ orí rẹ̀ kò tó ọjọ́ ori ij̀àpá lọ | 1 | yo |
Àdìsá mu ẹmu púpọ̀ | Àdìsá mu ẹmu kekeré | Àdìsà mu kòkò ẹmu ọgbọ̀n ní ilé ẹmu lánàá | 0 | yo |
Àdìsá mu ẹmu púpọ̀ | Àdìsá mu ẹmu kekeré | Àdìsà kò mu ẹmu rárá ní ilé ẹmu lánàá | 1 | yo |
Ọdẹ́ṣọlá mọ iṣẹ́ ọdẹ náà dáadáa | Ọdẹ́ṣọlá ń fi iṣẹ́ ọdẹ ṣeré | Ọdẹ́ṣọlá ní òye iṣẹ́ ọdẹ náà dójú àmì bí i olúọ́dẹ agboolé wa | 0 | yo |
Ọdẹ́ṣọlá mọ iṣẹ́ ọdẹ náà dáadáa | Ọdẹ́ṣọlá ń fi iṣẹ́ ọdẹ ṣeré | Ọdẹ́ṣọlá ò mọ iṣẹ́ tí wọ́n pè ni iṣẹ́ ọdẹ. | 1 | yo |
Díẹ̀ díẹ̀ ló ń gba owó rẹ̀ padà | Ó ṣe ìtọrẹ àánú pẹ̀lú owó rẹ̀ | Ení tere èji tere ló ń gba owó rẹ̀ padà bí i àwọn alájẹṣẹ́ku | 0 | yo |
Díẹ̀ díẹ̀ ló ń gba owó rẹ̀ padà | Ó ṣe ìtọrẹ àánú pẹ̀lú owó rẹ̀ | Ení tere èji tere kọ́ ló gba owó rẹ̀ padà | 1 | yo |
Agbẹjọ́rò náà ti sọ àṣírí ọ̀rọ̀ náà | Agbẹjọ́rò náà ti sú ìgbẹ́jọ́ náà | Agbẹjọ́rò náà ti ṣíṣọ lójú eégún ọ̀rọ̀ náà nílé ẹjọ́ | 0 | yo |
Agbẹjọ́rò náà ti sọ àṣírí ọ̀rọ̀ náà | Agbẹjọ́rò náà ti sú ìgbẹ́jọ́ náà | Agbẹjọ́rò náà ò sọ ẹni tó jẹ̀bi | 1 | yo |
Àwọn ènìyàn púpọ̀ wà lọ́jà | Àwọn mẹ́ta péré ló wà lọ́jà | Èrò tó wà lọ́jà kún àkúnfàya lánàá | 0 | yo |
Àwọn ènìyàn púpọ̀ wà lọ́jà | Àwọn mẹ́ta péré ló wà lọ́jà | Àwọ́n èrò tó wà lọ́jà tí fi ọlọ́pàá gbé bàbá ọjà lánàá | 1 | yo |
Fadékẹ́ ti padà dárjíì mìí | Fadékẹ́ ti padà bínú sí mi | Inú Fadékẹ́ ti padà yọ́ sí mi bí i òrí lánàá lẹ́yìn gbogbo ìjà wa | 0 | yo |
Fadékẹ́ ti padà dárjíì mìí | Fadékẹ́ ti padà bínú sí mi | Fadékẹ́ ti padà bí ìbejì lẹ́yìn gbogbo ìjà wa | 1 | yo |
Eréepá ni àwọn ọmọ náà ṣe kiri | Àwọn ọmọ náà jókòó sí ibìkan | Ìka kan ò wọ àwọn ọmọ yìí nídìí mọ́ | 0 | yo |
Eréepá ni àwọn ọmọ náà ṣe kiri | Àwọn ọmọ náà jókòó sí ibìkan | À̀wọn ọmọ yìí ti lọ sóko ọ̀gẹ̀dẹ̀ | 1 | yo |
Wọ́n dájọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá fun nílé ẹjọ́ | Ó ń polówó ọjà nílé ẹjọ́ | Ó rí ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá he nílé ẹjọ́ lóri ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn-án | 1 | yo |
Wọ́n dájọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá fun nílé ẹjọ́ | Ó ń polówó ọjà nílé ẹjọ́ | Lẹ́yìn ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá tó rí he ó padà gba ìtúsílẹ̀ | 0 | yo |
Adénúgà pọ́n igi gùn dáadáa | Adénúgà sùn lóri igi | Ẹ wo bí Adénúgà ṣe ń gun igi bí i ọ̀bọ | 1 | yo |
Adénúgà pọ́n igi gùn dáadáa | Adénúgà sùn lóri igi | Adénúgà nífẹ̀ẹ́ sí bí àwọn ọ̀bọ ṣé n gun igi | 0 | yo |
Tifẹ́ladé máa ń sọ àsọdùn ọ̀rọ̀ | Tifẹ́ladé kì í sòrò | Ẹnu ni Tifẹ́ladé ni bí i tajakàrà | 0 | yo |
Tifẹ́ladé máa ń sọ àsọdùn ọ̀rọ̀ | Tifẹ́ladé kì í sòrò | Tifẹ́ladé kò mọ̀ bi wọ́n ṣe dan ẹnu | 1 | yo |
Ìwà ọmọdé ni Adéṣínà máa ń wù | Adéṣínà nífẹ̀ẹ́ sí kó ma tọ̀ sára | Kí ló dé tí Adéṣínà ṣe máa ń hùwà bí i atọ̀ọ́lé? | 1 | yo |
Ìwà ọmọdé ni Adéṣínà máa ń wù | Adéṣínà nífẹ̀ẹ́ sí kó ma tọ̀ sára | Kí ló dé tí Adéṣínà ṣe ra ilé tuntun? | 0 | yo |
Àlàó kò kúrò lójú kan | Àlàó ń rìn kiri | Ẹ wo bí Àlàó ṣe duró bí i omi adágún odò | 1 | yo |
Àlàó kò kúrò lójú kan | Àlàó ń rìn kiri | Ẹ wo bí Àlàó ṣe duró bí i Ọba | 0 | yo |
Àwọn olè náà sálọ | Àwọn olè náà gbé ìbọn wọn jáde | Àwọn olè náà júbà eworo nígbà tí wọ́n gbúròó àwọn ọlọ́pàá | 0 | yo |
Àwọn olè náà sálọ | Àwọn olè náà gbé ìbọn wọn jáde | Àwọn olè náà yin ìbọn nígbà tí wọ́n gbúròó àwọn ̀ọlọ́pàá | 1 | yo |
Ó ti pẹ́ gan tí Wọléọlá ti wà nínú yàrá | Wọléọlá ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ inú yàrá | Ọ̀sẹ̀ kan rèé tí Wọléọlá ti wà nínú yàrá bí i ẹni tọ́ fi s'ẹ́wọ̀n | 1 | yo |
Ó ti pẹ́ gan tí Wọléọlá ti wà nínú yàrá | Wọléọlá ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ inú yàrá | Ọ̀sẹ̀ kan rèé tí Wọléọlá ti lọ sí ìlú ọba | 0 | yo |
Ọdẹ́wùnmí kò kí àwọn àgbà ọdẹ dáadáa | Ọdẹ́wùnmí pariwo mọ́ àwọn àgbà ọdẹ | Ọdẹ́wùnmí júbà gbogbo àwọn àgbà ọdẹ bí i ẹni tí kò kọ́ṣẹ́ ọdẹ | 0 | yo |
Ọdẹ́wùnmí kò kí àwọn àgbà ọdẹ dáadáa | Ọdẹ́wùnmí pariwo mọ́ àwọn àgbà ọdẹ | Ọdẹ́wùnmí bú gbogbo àwọn àgbà ọdẹ tí wọn jókòó | 1 | yo |
Adénifújà kì í ṣe ọmọ ẹgbẹ́ wa | Olórí ẹgbẹ́ wa ni Adénifújà | Ọ̀gbẹ̀rì ni Adénifújà nínú ẹgbẹ́ wa | 0 | yo |
Adénifújà kì í ṣe ọmọ ẹgbẹ́ wa | Olórí ẹgbẹ́ wa ni Adénifújà | Adénifújà kì í ṣe Ọ̀gbẹ̀ri nínú ẹgbẹ́ wa | 1 | yo |
Wọ́n na Bọ́lájí gan | Wọ́n gbé Bọ́lájí lọ jayé | Wọ́n na Bólájí nílù bààrà bí i ẹni tó jalè | 1 | yo |
Wọ́n na Bọ́lájí gan | Wọ́n gbé Bọ́lájí lọ jayé | Wọ́n gbé oúnjẹ tó dùn fún Bólájí | 0 | yo |
Arákùnrin náà fẹ́ ìyàwó púpọ̀ | Ìyàwó kan ṣoṣo ni arákùnrin náà fẹ́ | Arákùnrin náà fẹ́ ìyàwọ̀ lọ bìbà bí i ọba Aláàfin | 0 | yo |
Arákùnrin náà fẹ́ ìyàwó púpọ̀ | Ìyàwó kan ṣoṣo ni arákùnrin náà fẹ́ | Arákùnrin náà fẹ́ burẹ́wà | 1 | yo |
Ènìyàn tó pọ̀ ló wà ní pápá ìṣeré náà | Ènìyàn mẹ́fà páré ló wà ní pápá ìṣeré náà | Ogúnlọ́gọ̀ àwọn ènìyàn ló wà ní pápá ìṣeré tí wọ́n ti fẹ́ gbá bọ́ọ̀lù ikọ̀ Nàìjíríà | 0 | yo |
Ènìyàn tó pọ̀ ló wà ní pápá ìṣeré náà | Ènìyàn mẹ́fà páré ló wà ní pápá ìṣeré náà | Àwọn ènìyàn tó wà ní pápá ìṣeré tí wọ́n ti fẹ́ gbá bọ́ọ̀lù tí ń jà | 1 | yo |
Ikọ̀ Nàìjíríà ṣe dáadáa níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé | Ikọ̀ Nàìjíríà hùwà ìbàjẹ́ níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé | Àwọn ikọ̀ Nàìjíríà ti fakọyọ níbí ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé ju ti àtẹ̀yìn wá lọ | 0 | yo |
Ikọ̀ Nàìjíríà ṣe dáadáa níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé | Ikọ̀ Nàìjíríà hùwà ìbàjẹ́ níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé | Àwọn ikọ̀ Nàìjíríà ti kó igbá wọlé níbí ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé | 1 | yo |
Etí Arínájà tóbi gan | Etí Arínájà kéré gan | Etí Arínájà rí bí i eté eworo | 1 | yo |
Etí Arínájà tóbi gan | Etí Arínájà kéré gan | Etí Arínájà tí gbọ́ ọ̀rọ̀ dáadáa | 0 | yo |
Adérẹ̀mí na Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá | Adérẹ̀mí ṣeré pẹ̀lú Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá | Adérẹ̀mí ṣe Arímọrọ̀ bí ọṣẹ́ ṣé ń ṣojú nígbà tí wọ́n ja ìjà ìjàkadi lánàá | 1 | yo |
Adérẹ̀mí na Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá | Adérẹ̀mí ṣeré pẹ̀lú Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá | Adérẹ̀mí gbé Arímọrọ̀ lọ jayé ọba lánàá | 0 | yo |
Àrẹ̀mú ti ń nífẹ̀ẹ́ Ọmọ́ṣaléwá | Àrẹ̀mú ti lọ pọn omi fún Ọmọ́ṣaléwá lódò | Àrẹ̀mú ti ń lúwẹ̀ẹ́ nínú odò ìfẹ́ Ọmọ́ṣaléwá | 0 | yo |
Àrẹ̀mú ti ń nífẹ̀ẹ́ Ọmọ́ṣaléwá | Àrẹ̀mú ti lọ pọn omi fún Ọmọ́ṣaléwá lódò | Àrẹ̀mú ò fẹ́ràn láti ma fojú ri Ọmọ́ṣaléwá | 1 | yo |
Bàbá Agbájé mọ ọyùn mu | Bàbá Agbájé mọ oúnjẹ sè | Bàbá Agbájé ń fẹnu fa ọyùn ìyàwò rẹ̀ bí i ọmọ ìkókó tí kò tí ì já lẹ́nu ọyùn | 0 | yo |
Bàbá Agbájé mọ ọyùn mu | Bàbá Agbájé mọ oúnjẹ sè | Bàbá Agbájé kò fẹnu fa ọyùn ìyàwò rẹ̀ | 1 | yo |
Iná ọdẹ náà kò mọ́lẹ̀ dáadáa | Iná ọdẹ náà ti kú | Iná ọdẹ náà tàn bí i iná àtùpà tí epo ti fẹ́ tán nínú rẹ̀ | 1 | yo |
Iná ọdẹ náà kò mọ́lẹ̀ dáadáa | Iná ọdẹ náà ti kú | Iná ọdẹ náà tàn, ó sì ríran kedere | 0 | yo |
Adéyẹmí bínú láti àárọ̀ | Adéyẹmí rẹ́rìn ín láti àárọ̀ | Adéyẹmí kanra bí i ajá elégbọn láti àárọ̀ | 1 | yo |
Adéyẹmí bínú láti àárọ̀ | Adéyẹmí rẹ́rìn ín láti àárọ̀ | Adéyẹmí má ń bá àwọn ajá ṣeré | 0 | yo |
Adéṣọlá ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá | Adéṣọlá ní orí kuku | Ọmọ ọ̀dọ̀ àgbà ni Adéṣọlá nínú àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá | 0 | yo |
Adéṣọlá ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá | Adéṣọlá ní orí kuku | Ọmọ Ègùn ni Adéṣọlá kò mọ̀ nípa àṣà ilẹ̀ Yorùbá | 1 | yo |
Adésuà bí ọmọ tuntun lánàá | Adésuà na ọmọ tuntun tó bí | Adésuà fọwọ́ osùn pa ògiri gbígbe lánàá nílé ìwòsàn | 0 | yo |
Adésuà bí ọmọ tuntun lánàá | Adésuà na ọmọ tuntun tó bí | Adésuà ti bẹ̀rẹ̀ sí ni ṣe àìsàn lánàá nílé ìwòsàn | 1 | yo |
Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú ma bàjẹ́ | Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú yìí ma tòrò | Ọjọ́ tí òbò bá jẹ ọba lorílẹ̀ èdè yìí ni ìlú bàjẹ́ | 1 | yo |
Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú ma bàjẹ́ | Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú yìí ma tòrò | Ọba orílẹ̀ èdè yìí ti ṣe ohun mánigbàgbé sí ìlú wa | 0 | yo |
Iyàwò Rọ̀gbà sunkún àìrọ́mọ bí nílé ọkọ rẹ̀ | Iyàwò Rọ̀gbà dunnú sí àwọn ọmọ tó bí | Iyàwò Rọ̀gbà sunkún àìrípọ̀n nílé ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn ìgbéyàwó ọdún mọ́kànlá | 1 | yo |
Iyàwò Rọ̀gbà sunkún àìrọ́mọ bí nílé ọkọ rẹ̀ | Iyàwò Rọ̀gbà dunnú sí àwọn ọmọ tó bí | Iyàwò Rọ̀gbà se oúnjẹ aládùn fún ọkọ rẹ̀ | 0 | yo |
Ajá náà bí ọkùnrin àti obìnirin | Ajá náà jẹ ọmọ tó bí | Ajá náà bí akọ àti abo bí i àgùntàn tó bímọ láàrọ́ yìí | 0 | yo |
Ajá náà bí ọkùnrin àti obìnirin | Ajá náà jẹ ọmọ tó bí | Ajá náà kò bí akọ àti abo | 1 | yo |
Àdìmúlà ti kú | Àdìmúlà lọ jí èkuru jẹ | Àdìmúlà ti gbà èkuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra | 1 | yo |
Àdìmúlà ti kú | Àdìmúlà lọ jí èkuru jẹ | Àdìmúlà se èkuru fún à̀wọn ẹgbẹ́ rẹ̀ | 0 | yo |
Ilé tí bàbá mi kọ́ rẹwà gan | Ilé tí bàbá mi kọ́ ti wó | Ilé àwòdamiẹnu ni ilé tí bàbá mi kọ́ | 0 | yo |
Ilé tí bàbá mi kọ́ rẹwà gan | Ilé tí bàbá mi kọ́ ti wó | Ilé àwòdamiẹnu tí bàbá mi kọ́ ti wó | 1 | yo |
Ìjọba pa arákùnrin náà | Ìjọba gbé arákùnrin náà lọ ilé ẹjọ́ | Ìjọba yẹgi fún arákùnrin náà tó jí owó ìjọba gbé | 1 | yo |
Ìjọba pa arákùnrin náà | Ìjọba gbé arákùnrin náà lọ ilé ẹjọ́ | Ìjọba ti fún arákùnrin náà ní owó tó pọ̀. | 0 | yo |
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ tú àṣírí ohun tí a ṣe lánàá | Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ gbé ohun tí a ṣe lánàá | Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ gbẹ̀yìn bẹbo jẹ́ lóri ohun tí a ṣe lánàá | 1 | yo |
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ tú àṣírí ohun tí a ṣe lánàá | Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ gbé ohun tí a ṣe lánàá | Àwọn ọ̀rẹ́ mi ló ra aṣọ tí mo wọ̀ lánàá | 0 | yo |
Ẹ̀pà tó pọ̀ ni Mojí yan lálẹ́ àná | Ẹ̀pà ni Mojí jẹ lálẹ́ àná | Apo ẹ̀pà ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ni Mojí yan lálẹ́ àná kin tó sùn | 0 | yo |
Ẹ̀pà tó pọ̀ ni Mojí yan lálẹ́ àná | Ẹ̀pà ni Mojí jẹ lálẹ́ àná | Ẹ̀pà hóró mẹ́fà ni Mojí yan lálẹ́ àná kin tó sùn | 1 | yo |
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn tí wọ́n lóyún | Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn ọmọdé | Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn tí wọ́n diwọ́ disẹ̀ sínú | 0 | yo |
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn tí wọ́n lóyún | Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn ọmọdé | Àmọ̀pé ṣépè fún gbogbo àwọn tí wọ́n diwọ́ disẹ̀ sínú | 1 | yo |
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ láì sinmi | Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ ọpọlọ | Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ bí i omi òjò lánàá | 0 | yo |
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ láì sinmi | Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ ọpọlọ | Ọ̀kẹ́ ò ṣiṣẹ́ kankan rárá lánàá | 1 | yo |
Bàbá Àgbà ti kú | Bàbá Àgbà ti wo aṣọ tuntun | Bàbá àgbà tẹ́rígbaṣọ lẹ́yìn ìnáwó tí a ṣe lánàá | 0 | yo |
Bàbá Àgbà ti kú | Bàbá Àgbà ti wo aṣọ tuntun | Bàbá àgbà raṣọ àti bàtà lẹ́yìn ìnáwó tí a ṣe lánàá | 1 | yo |
Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ mìíràn lẹ́yìn iṣẹ́ ìjọba | Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ tó pọ̀ lánàá | Lẹ́yìn iṣẹ́ ìjọba ti Àlàkẹ́ ń ṣe, ó tún wá nǹkan mìíràn fi pawọ́dà | 0 | yo |
Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ mìíràn lẹ́yìn iṣẹ́ ìjọba | Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ tó pọ̀ lánàá | Lẹ́yìn tí ìjọba mú Àlàkẹ́, kò ri iṣẹ́ gbà mọ | 1 | yo |
Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè rí oúnjẹ jẹ | Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè sùn | Bí ọwọ́ Okùnọlá ò bá ṣe, ẹnu rẹ̀ kòlè jẹ | 1 | yo |
Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè rí oúnjẹ jẹ | Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè sùn | Okùnọlá ń fi iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ra oúnjẹ sí ẹnu ara rẹ̀ | 0 | yo |
Subsets and Splits