ending1
stringlengths 4
149
| ending2
stringlengths 5
156
| startphrase
stringlengths 7
179
| labels
int64 0
1
| split
stringclasses 7
values |
---|---|---|---|---|
Àbíkẹ́ mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí dáadáa | Àbíkẹ́ ò mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí rárá | Àbíkẹ́ ní òye tó dájú nípa iṣẹ́ agbẹ̀bí bí i àwọn dọ́kítà ilẹ̀ òkèrè | 0 | yo |
Àbíkẹ́ mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí dáadáa | Àbíkẹ́ ò mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí rárá | Àbíkẹ́ ní òye kukurú nípa iṣẹ́ agbẹ̀bí bí i àwọn dọ́kítà ilẹ̀ òkèrè | 1 | yo |
Aṣọ funfun tí ó wọ̀ ti dọ̀tí | Aṣọ funfun tí ó wọ̀ mọ́ gan | Aṣọ àlà tí ó wọ̀ ti pọ́n bí i ẹni tó kó sínú ẹrọ̀fọ̀ | 1 | yo |
Aṣọ funfun tí ó wọ̀ ti dọ̀tí | Aṣọ funfun tí ó wọ̀ mọ́ gan | Aṣọ àlà tí ó wọ̀ mọ́ ju ẹyín tí mo ṣẹ̀ṣẹl fọ̀ láàárọ̀ yìí lọ | 0 | yo |
Wèré ni Òjó | Òjó kì í ṣe wèrè | Oní gángàngán ni Òjó gbogbo wa la mọ̀ bẹ́ẹ̀ | 1 | yo |
Wèré ni Òjó | Òjó kì í ṣe wèrè | Apẹja ni Òjó gbogbo wa la mọ̀ bẹ́ẹ̀ | 0 | yo |
Kò sí ariwo nínu yàrá ìdánwò náà | Ariwo ti pọ̀jù nínu yàrá ìdánwò nàá | Inú yàrá ìdánwò nàá palọ́lọ́ bí i itẹ́ òkú | 0 | yo |
Kò sí ariwo nínu yàrá ìdánwò náà | Ariwo ti pọ̀jù nínu yàrá ìdánwò nàá | Inú yàrá ìdánwò nàá rí bí i ọjà Oṣòdì | 1 | yo |
Òtútù mú ìyá àgbà | Orú mú ìyá àgbà | Gbogbo ara ìyá àgbà ti gan sínú ilé bí i òkú tó wà nínu yìnyín | 0 | yo |
Òtútù mú ìyá àgbà | Orú mú ìyá àgbà | Gbogbo ara ìyá àgbà kò gan sínú ilé | 1 | yo |
Àlàmù rí òkun náà tó ń ru | Àlàmù rí òkun náà tó dákẹ́ | Àlàmú rí òkun náà tó ń kọrin lásìkò tó ń bọ̀ láti ibi iṣẹ́ | 0 | yo |
Àlàmù rí òkun náà tó ń ru | Àlàmù rí òkun náà tó dákẹ́ | Àlàmú rí òkun náà tó ń yọ iná lásìkò tó ń bọ̀ láti ibi iṣẹ́ | 1 | yo |
Àgbẹ̀ náà ti ká gbogbo èso tó wà lóri igi nàá | Àgbẹ̀ náà ò ká èso kankan lóri igi nàá | Àgbẹ̀ náà ti kó gbogbo ọmọ tí igi nàá bí lánàá | 0 | yo |
Àgbẹ̀ náà ti ká gbogbo èso tó wà lóri igi nàá | Àgbẹ̀ náà ò ká èso kankan lóri igi nàá | Àgbẹ̀ náà pa gbogbo ọmọ tí igi nàá bí lánàá | 1 | yo |
Arábìnrin náà ò lójú ara | Arábìnrin lójú ara | Lákíríboto ni arábìnrin tí ọ̀gá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà sí ẹnu iṣẹ́ | 1 | yo |
Arábìnrin náà ò lójú ara | Arábìnrin lójú ara | Ọmọdé ni arábìnrin tí ọ̀gá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà sí ẹnu iṣẹ́ | 0 | yo |
Àṣàbí ò rọ́mọ bí fún ọgbọ̀n ọdún | Àṣàbí bí ọmọ tó pọ̀ fún ọgbọ̀n ọdún | Àgàn ni Àṣàbí fún ọgbọ̀n ọdún | 1 | yo |
Àṣàbí ò rọ́mọ bí fún ọgbọ̀n ọdún | Àṣàbí bí ọmọ tó pọ̀ fún ọgbọ̀n ọdún | Abiyamọ ni Àṣàbí fún ọgbọ̀n ọdún | 0 | yo |
Ìdòwú ti pẹ́ gan nínú iṣẹ́ ọdẹ | Ìdòwú ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọdẹ | Láti kéreké ni Ìdòwú tí ń ṣe iṣẹ́ ọdẹ bí i bàbá rẹ̀ | 0 | yo |
Ìdòwú ti pẹ́ gan nínú iṣẹ́ ọdẹ | Ìdòwú ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọdẹ | Láti kéreké ni Ìdòwú kò ti nífẹ̀ẹ́ si iṣẹ́ ọdẹ ṣíṣe | 1 | yo |
Orí Gbádébọ̀ tóbi gan | Orí Gbádébọ̀ kò tóbi | Orí Gbádébọ̀ rí bí i orí òkè olúmọ | 1 | yo |
Orí Gbádébọ̀ tóbi gan | Orí Gbádébọ̀ kò tóbi | Orí Gbádébọ̀ kò rí bí i orí òkè olúmọ | 0 | yo |
Ẹsẹ Bólájí gùn gan | Ẹsẹ Bólájí kéré gan | Ẹsẹ̀ Bólájí gùn bí i ọ̀pá Ọ̀rànmíyàn | 1 | yo |
Ẹsẹ Bólájí gùn gan | Ẹsẹ Bólájí kéré gan | Ẹsẹ̀ Bólájí rẹwà bí i tọmọ ìkókó | 0 | yo |
Ó gbọ́ èdè Yorùbá dáadáa | Kò gbọ́ èdè Yorùbá rárá | Èdè Yorùbá ẹnu rẹ̀ dánmọ́rán bí i tàwọn ará Ọ̀yọ́ | 0 | yo |
Ó gbọ́ èdè Yorùbá dáadáa | Kò gbọ́ èdè Yorùbá rárá | Èdè Yorùbá ẹnu rẹ̀ kò dánmọ́rán bí i tàwọn Ẹ̀gùn | 1 | yo |
Gàrí náà kan | Gàrí náà ò kan | Gàrì náà kan bí i omi ògì | 0 | yo |
Gàrí náà kan | Gàrí náà ò kan | Gàrì náà korò bí i omi ògì àná | 1 | yo |
Eyin rẹ̀ mọ́ | Eyin rẹ̀ dọ̀tí | Eyín rẹ̀ funfun bí i ẹyẹ àdàbà | 0 | yo |
Eyin rẹ̀ mọ́ | Eyin rẹ̀ dọ̀tí | Eyín rẹ̀ kò funfun bí i ẹyẹ àdàbà | 1 | yo |
Orí Adékúnlé pọ́n | Orí Adékúnlé kò pọ́n | Adékúnlé dárípọ́ bí i orí aláǹgbá | 0 | yo |
Orí Adékúnlé pọ́n | Orí Adékúnlé kò pọ́n | Adékúnlé ti fọ́ lórí níbi tó ti lọ jà | 1 | yo |
Bọ́látitó máa ń dá nìkan wà | Bọ́látitó máa ń wà pẹ̀lú àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn | Àso erin ni Bọ́látitó | 1 | yo |
Bọ́látitó máa ń dá nìkan wà | Bọ́látitó máa ń wà pẹ̀lú àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn | Ọlọ́yàyà ni Bọ́látíto | 0 | yo |
Eégún ni Àjàní | Àjàní kì í ṣe Eégún | Ará ọ̀run ni Àjàní | 0 | yo |
Eégún ni Àjàní | Àjàní kì í ṣe Eégún | Àjàní kì i ṣe Ará ọ̀run | 1 | yo |
Kò sí ẹni tó mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́ | Gbogbo wa la mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́ | Paramọ́lẹ̀ ni Àbẹ̀kẹ́ | 1 | yo |
Kò sí ẹni tó mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́ | Gbogbo wa la mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́ | Àbẹ̀kẹ́ kì i ṣe Paramọ́lẹ̀ | 0 | yo |
Àgbékẹ́ máa ń fẹnu ba èèyàn jẹ́ | Àgbékẹ́ máa ń fẹnu kọrin | Ẹlẹ́nu ẹyẹ ni Àgbékẹ́ | 1 | yo |
Àgbékẹ́ máa ń fẹnu ba èèyàn jẹ́ | Àgbékẹ́ máa ń fẹnu yin ènìyàn | Aládúrà ni Àgbékẹ́ | 0 | yo |
Ọmọ náà mọ Ifá dáadáa | Wọ́n ti kọ Ifá fún ọmọ náà sínú ìwè | Ọmọ náà gbọ́ Ifá, ó mọ nú ìgbín nínú ìkàrahun bí í abọrẹ̀ agboolé wa | 0 | yo |
Ọmọ náà mọ Ifá dáadáa | Wọ́n ti kọ Ifá fún ọmọ náà sínú ìwè | Ọmọ náà kò mọ nǹkankan nípa Ifá | 1 | yo |
Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ ti tú | Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò ti bò | Àkàrà Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ ti tú sépo bí i ti bàbá wọn tó wà lẹ́wọ̀n | 0 | yo |
Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ ti tú | Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò ti bò | Àkàrà Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ kò tú sépo | 1 | yo |
Àbẹ̀ní se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá | Àbẹ̀ní kò se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá | Àbẹ̀ní se onírurú ọbẹ̀ lánàá bí i àwọn tó ń dáná olópò | 0 | yo |
Àbẹ̀ní se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá | Àbẹ̀ní kò se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá | Àbẹ̀ní se onírurú ọbẹ̀ tí kò dùn lánàá. | 1 | yo |
Òjò náà sú lánàá ó tó ago mọ́kànlá kó tó rọ̀ | Òjò náà kò sú lánàá kò sì rọ̀ ní ago mọ́kànlá | Ojú ọ̀run náà lóyún omi nǹkan bí i ago mọ́kànlá ló tó bímọ | 0 | yo |
Òjò náà sú lánàá ó tó ago mọ́kànlá kó tó rọ̀ | Òjò náà kò sú lánàá kò sì rọ̀ ní ago mọ́kànlá | Ojú ọ̀run náà ò lóyún omi | 1 | yo |
Òòrùn àná mú gan | Òòrùn àná kò mú rárá | Òòrun àná ta ènìyàn lára bí i iná àdògán | 1 | yo |
Òòrùn àná mú gan | Òòrùn àná kò mú rárá | Òòrun àná kò ta ènìyàn lára | 0 | yo |
Ojú Yẹmí le gan | Ojú Yẹmí kò le rárá | Ojú Yẹmí le bí i ojú ọ̀daràn kò sí eni tó lè ba sọ̀rọ̀ | 1 | yo |
Ojú Yẹmí le gan | Ojú Yẹmí kò le rárá | Ojú Yẹmí ni àwọn ọmọge fẹ́ rí | 0 | yo |
Aṣọ Títílayọ̀ kò dára rárá | Aṣọ Títílayọ̀ dára gan | Aṣọ Títílayọ̀ rí bí i aṣọ egbéré | 1 | yo |
Aṣọ Títílayọ̀ kò dára rárá | Aṣọ Títílayọ̀ dára gan | Aṣọ Títílayọ̀ rí bí i aṣọ ọba ilé ifẹ̀ | 0 | yo |
Afọlábí ò lè gbé láàárín àwọn ènìyàn | Afọlábí lè gbé láàárín àwọn ènìyàn | Adẹ́tẹ̀ ni Afọlábí | 1 | yo |
Afọlábí ò lè gbé láàárín àwọn ènìyàn | Afọlábí lè gbé láàárín àwọn ènìyàn | Afọlábí kì i ṣe Adẹ́tẹ̀ | 0 | yo |
Adé ń pariwo gan | Adé kò pariwo rárá | Adé ń pariwo bí i eni tí ajá bùjẹ | 1 | yo |
Adé ń pariwo gan | Adé kò pariwo rárá | Adé ń pariwo bí i eni tí ó sù lọ fọnfọn | 0 | yo |
Àdìsá pọn omi púpọ̀ | Omi díẹ̀ ni Àdìsá pọn | Ike omi ọgọ́rùn-ún ni Àdìsá pọn kó tó lọ sí ilé ìwé láàárọ̀ yìí | 0 | yo |
Àdìsá pọn omi púpọ̀ | Omi díẹ̀ ni Àdìsá pọn | Ike omi kan ṣoṣo ni Àdìsá pọn kó tó lọ sí ilé ìwé láàárọ̀ yìí | 1 | yo |
Olùdíje mọ eré sá gan | Olùdíje náà kò sáré ba ṣe fẹ́ | Olùdíje náà sáré bí i atẹ́gùn | 0 | yo |
Olùdíje mọ eré sá gan | Olùdíje náà kò sáré ba ṣe fẹ́ | Olùdíje náà sáré bí i ìgín | 1 | yo |
Àpò náà wúwo gan | Àpò náà fuyẹ́ | Àpò náà wúwo bí i àpo tó kún fún òkúta ńlá | 0 | yo |
Àpò náà wúwo gan | Àpò náà fuyẹ́ | Àpò náà kò wúwo rárá | 1 | yo |
Ètè rẹ̀ ti dúdú jù | Ètè rẹ̀ pupa | Ètè rẹ̀ dúdú bí i ètè ẹni tó ń fa igbó | 1 | yo |
Ètè rẹ̀ ti dúdú jù | Ètè rẹ̀ pupa | Ètè rẹ̀ kò dúdú bí i ètè ẹni tó ń fa igbó | 0 | yo |
Fọlárìn ò jẹun bàṣùbàṣù | Fọlárìn bá ẹlẹ́dẹ̀ ṣeré | Fọlárìn jẹun bí i ẹlẹ́dẹ̀ | 1 | yo |
Fọlárìn ò jẹun bàṣùbàṣù | Fọlárìn bá ẹlẹ́dẹ̀ ṣeré | Fọlárìn ò jẹun bí i ẹlẹ́dẹ̀ | 0 | yo |
Ayọ̀mídé ò lẹ̀ rìn dáadáa lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá | Ayọ̀mídé rìn dáada lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá | Ayọ̀mídé jẹ abọ́ ẹ̀bà méjìlá, ó wá ń gbẹ́sẹ̀ bí i olóyún tó ń rọbí | 1 | yo |
Ayọ̀mídé ò lẹ̀ rìn dáadáa lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá | Ayọ̀mídé rìn dáada lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá | Ayọ̀mídé ò lè jẹ abọ́ ẹ̀bà méjìlá, kò sì rìn bí i olóyún | 0 | yo |
Eléégún ni Dánṣọfúnjó | Oní ìlù ni Dánṣọfúnjó | Ọlọ́jẹ̀ ni Dáṣọfúnjó | 0 | yo |
Eléégún ni Dánṣọfúnjó | Oní ìlù ni Dánṣọfúnjó | Oníjó ni Dáṣọfúnjó | 1 | yo |
Igi náà tóbi gan | Igi náà kò tóbi gan | Igi tí wọ́n fi pa ejó náà rí ràbàtà bí i igi ìrókò | 0 | yo |
Igi náà tóbi gan | Igi náà kò tóbi gan | Igi tí wọ́n fi pa ejó náà rí sọrọ | 1 | yo |
Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti kéré jù | Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti tóbi jù | Ìyá Bọ́lájí sọ pé nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí rí bí i tọmọ ìkókó | 0 | yo |
Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti kéré jù | Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti tóbi jù | Ìyá Bọ́lájí sọ pé nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ṣiṣẹ́ dáadáa | 1 | yo |
Mo fẹ́ ní ìmọ̀ ti ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ní | Ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ò ní ìmọ̀ tí mo ní | Ró mi láṣọ ìmọ̀ bí i ọ̀jọgbọ̀n Wọlé Ṣóyinká | 0 | yo |
Mo fẹ́ ní ìmọ̀ ti ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ní | Ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ò ní ìmọ̀ tí mo ní | Bàbá mi ni ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Ṣóyinká | 1 | yo |
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà mọ ìlú lù dáadáa | Ọmọ ọdún mẹ́fà náà kò mọ ìlú lù rárá | Ọmọ ọdún mẹ́fà náà lu ìlù bí i ẹni tí wọ́n bí sí ìdílé àyàn | 0 | yo |
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà mọ ìlú lù dáadáa | Ọmọ ọdún mẹ́fà náà kò mọ ìlú lù rárá | Ọmọ ọdún mẹ́fà náà gbé ìlù kọ́rùn bí i ẹni tí wọ́n bí sí ìdílé àyàn | 1 | yo |
Mo nífẹ̀ẹ́ Adédoyin gan | Mo ò nífẹ̀ẹ́ Adédoyin rárá | Ìfẹ́ Adédoyin pamí bí i ọtí | 0 | yo |
Mo nífẹ̀ẹ́ Adédoyin gan | Mo ò nífẹ̀ẹ́ Adédoyin rárá | Ìfẹ́ Adédoyin ti yọ́ kúrò lọ́kàn mi | 1 | yo |
Àbẹ̀ún wọ aṣọ púpọ̀ | Àbẹ̀ún wọ aṣọ díẹ̀ | Àbẹ̀ún kó sí aṣọ bí i ẹni tí òtútù ń mú | 0 | yo |
Àbẹ̀ún wọ aṣọ púpọ̀ | Àbẹ̀ún wọ aṣọ díẹ̀ | Àbẹ̀ún kó sí́ aṣọ tuntun tó rà | 1 | yo |
Ayé ò lọ lóju kan | Ọ̀nà kan layé wà | Ayé ò lọ bí i ọ̀pá ìbọn | 0 | yo |
Ayé ò lọ lóju kan | Ọ̀nà kan layé wà | Ayé lọ bí i ọ̀pá òrúnmìlà | 1 | yo |
Àdùnní tí ń ṣe orí ire | Orí burúkú ni Àdùnnní ṣe | Àdùnnị ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní gun àkàbà orí ire rẹ | 0 | yo |
Àdùnní tí ń ṣe orí ire | Orí burúkú ni Àdùnnní ṣe | Àdùnnị ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ ilé ìwé | 1 | yo |
Tímìlẹ́yìn ṣe àṣeyọrí | Tímìlẹ́yìn ṣe òfò | Tìmílẹ́yìn kógo já níbi ìdánwò àṣekágbá | 0 | yo |
Tímìlẹ́yìn ṣe àṣeyọrí | Tímìlẹ́yìn ṣe òfò | Tìmílẹ́yìn fìdí rẹmi níbi ìdánwò àṣekágbá | 1 | yo |
Àmọ̀pé yára mí lọ sókè sílẹ̀ | Àmọ̀pé mí lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo | Àmọ̀pé mí gúlegúle bí i ajá tí ẹbí pa | 0 | yo |
Àmọ̀pé yára mí lọ sókè sílẹ̀ | Àmọ̀pé mí lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo | Àmọ̀pé kò mí mọ. | 1 | yo |
Àsàkẹ́ kò jókòó dáadáa | Àsàkẹ́ jókòó fẹ̀yìntì | Àṣàkẹ́ jókòó sórí àga bí i ẹni ti ìsó gún nídìí | 0 | yo |
Àsàkẹ́ kò jókòó dáadáa | Àsàkẹ́ jókòó fẹ̀yìntì | Àṣàkẹ́ fọ́ àga tó ṣẹ̀ṣẹ̀ rà | 1 | yo |
Ojú Ìgè kò rẹwà | Wọ́n fi ẹ̀rín sí ẹnu Ìgè | Ojú Ìgè rí bí i ojú eye àdán | 1 | yo |
Ojú Ìgè kò rẹwà | Wọ́n fi ẹ̀rín sí ẹnu Ìgè | Ojú Ìgè kún fún ẹ̀rín àti ayọ | 0 | yo |
Ó ń ranjú | Ó ń rẹ́rìn ín | Ó taná ojú bí i iná mọ́to ayọ́kẹ́lẹ́ | 0 | yo |
Ó ń ranjú | Ó ń rẹ́rìn ín | Ó taná ojú kò rí nǹkankan | 1 | yo |
Ojú Fọlárìn ti fọ́ | Fọlárìn ríran kedere | Ojú Fọlárìn ti relé dèé | 0 | yo |
Ojú Fọlárìn ti fọ́ | Fọlárìn ríran kedere | Ojú Fọlárìn ti tóbi jú | 1 | yo |
Subsets and Splits